If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id |
Yoruba |
English |
101 | Spot Verifier |
Spot Verifier |
102 | Provides Disk Corruption Spot Verification Capabilities. |
Provides Disk Corruption Spot Verification Capabilities. |
200 | Ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ nísìnyí |
Restart now |
201 | Ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ Láìpẹ́ |
Restart later |
202 | Ààbò àti Ìṣàbójútó |
Security and Maintenance |
205 | Kí o tó tún bẹ̀rẹ̀, ṣàfipamọ́ àwọn fáìlì tó wà ní ṣíṣí, kí o sì pa gbogbo àwọn ìfilọ́lẹ̀ dé. |
Before restarting, save any open files and close all apps. |
206 | O kò ní ìgbaniláàyè láti ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kọ̀ǹpútà yìí. |
You don't have permission to restart this computer. |
207 | Ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kọ̀ǹpútà rẹ sí àwo àká-ọ̀rọ̀ |
Restart your PC to repair drive errors |
208 | O kò ní ìyànda láti ṣètò Chdsk ní ìbẹ̀rẹ̀ tójáfáfá. |
You don't have permission to schedule Chkdsk at startup. |
209 | O kò ní ìyànda láti bẹ́rẹ́ ayẹ́wò. |
You don't have permission to start a scan. |
210 | Àyẹ̀wò náà kò le è ṣiṣẹ́. |
The scan was unable to run. |