If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id |
Yoruba |
English |
1001 | Yọ ohun èlò kúrò |
Remove Device |
1002 | Yọ ohun èlò tí a yàn kúrò ní ìfisípò |
Uninstall the selected Device |
1003 | Ǹjẹ́ ó dá ọ lójú pé o fẹ́ yọ ohun èlò yìí kúrò? |
Are you sure you want to remove this device? |
1004 | Ohun èlò tí a kò mọ̀ |
Unknown device |
1006 | O lè má lè darí kọ̀ǹpútà yìí tí o bá yọ àtẹ bọ́tìnnì tàbí atọ́ka yìí kúrò. |
You may not be able to control this computer if you remove this keyboard or mouse. |
1007 | Yíyọ ohun èlò yìí kúrò máa ṣàyípadà ohun èlò àkùnàyàn rẹ. |
Removing this device will change your default device. |
1008 | Yọ &ohun èlò yìí kúrò |
Remo&ve device |
1009 | Restrictions |
Restrictions |
1010 | A ti pa ìṣètò ìṣiṣẹ́ yìí rẹ́ nítorí àwọn ìdènà tí ó wà lórí kọ̀ǹpútà yìí lọ́wọ́lọ́wọ́. Jọ́wọ́ kánsí alábòójútó ẹ̀rọ rẹ. |
This operation has been cancelled due to restrictions in effect on this computer. Please contact your system administrator. |