10000 | Phone Service |
Phone Service |
10001 | Ń ṣàkóso ipò Ìfifóònùperaẹni lòri ohun elò |
Manages the telephony state on the device |
10002 | Ọ̀rọ̀ aṣínà tí o tẹ̀ kò báramu. |
The passwords you typed don't match. |
10003 | Ọ̀rọ̀ aṣínà ti yípadà |
Password changed |
10004 | Ọ̀rọ̀ aṣínà kòfẹṣẹ̀múlẹ̀. Ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀ aṣínà tótọ́ kí o sì gbìyànjú síi. |
The password isn't valid. Enter the correct password and try again. |
10005 | Kò le ráyè sí ayélujára. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
Can't access the network. Try again. |
10007 | Kò faramọ́ kóòdù yíi. |
This code isn't supported. |
10008 | Òdiwọ̀n náà kò fẹsẹ̀múlẹ̀. |
The parameters are invalid. |
10010 | Ìṣòro wà pẹ̀lú kóòdù yíi |
There was a problem with this code. |
10012 | Sáà ti padé |
Session closed |
10014 | Káàdì SIM náà sọnù. |
The SIM card is missing. |
10015 | Nílò PUK |
PUK required |
10017 | Káàdì SIM náà kò fẹsẹ̀múlẹ̀. |
The SIM card is invalid. |
10018 | Kòle parí ipè nítorí móòdù Nọ́ḿbà Ìpè Máyẹ̀ ti tàn lórí SIM káàdì rẹ. |
The call can't be completed because Fixed Dialing Number mode is enabled on your SIM card. |
10019 | Ti fi kóòdù ránṣẹ́ |
Code sent |
10020 | Tí Sàseyọrí |
Succeeded |
10021 | Ṣàìdí fóònù |
Phone unblocked |
10022 | Ìpèsè ti tàn |
Service enabled |
10023 | Ìpèsè ti tàn fún %1 |
Service enabled for %1 |
10024 | Ìpèsè wà nípò àìseélò |
Service disabled |
10025 | Ìpèsè wà nípò àìseélò fún %1 |
Service disabled for %1 |
10026 | Ìpò ìpèsè àìmọ̀ |
Service state unknown |
10027 | Síwájú %1 ni %2 sí %3 fún %4 |
Forward %1 is %2 to %3 for %4 |
10028 | Síwájú %1 ni %2 fún %4 |
Forward %1 is %2 for %4 |
10029 | Síwájú %1 ni %2 sí %3 fún %4 lẹ́hìn %5 ìṣẹjú àayá |
Forward %1 is %2 to %3 for %4 after %5 seconds |
10030 | Síwájú %1 ni %2 fún %4 lẹ́hìn %5 ìṣẹjú àayá |
Forward %1 is %2 for %4 after %5 seconds |
10031 | Síwájú %1 ni %2 sí %3 |
Forward %1 is %2 to %3 |
10032 | Síwájú %1 ni %2 |
Forward %1 is %2 |
10033 | Síwájú %1 ni %2 sí %3 lẹ́hìn ìṣẹjú àayá %5 |
Forward %1 is %2 to %3 after %5 seconds |
10034 | Síwájú %1 ni %2 lẹ́hìn ìṣẹjú àayá %5 |
Forward %1 is %2 after %5 seconds |
10035 | Ti mu ṣiṣẹ̀ |
Enabled |
10036 | A ti gbé Sípò Àìṣeélò |
Disabled |
10037 | Ní ipò ìdájú |
Unconditionally |
10038 | Àwọn ipè ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́ |
Busy calls |
10039 | Bí kòbásí èsì |
If no reply |
10040 | Bí akò bále pe fóònù |
If phone isn't reachable |
10041 | Gbogbo ìpè |
All calls |
10042 | Gbogbo ipé ní ipò àìdájú |
All calls conditionally |
10043 | %1 |
%1 |
10044 | %1 àti %2 |
%1 and %2 |
10045 | %1, %2 àti %3 |
%1, %2, and %3 |
10046 | %1, %2, %3 àti %4 |
%1, %2, %3, and %4 |
10047 | %1, %2, %3, %4, àti %5 |
%1, %2, %3, %4, and %5 |
10048 | %1, %2, %3, %4, %5, àti %6 |
%1, %2, %3, %4, %5, and %6 |
10049 | %1, %2, %3, %4, %5, %6, àti %7 |
%1, %2, %3, %4, %5, %6, and %7 |
10050 | %1, %2, %3, %4, %5, %6, %7, àti %8 |
%1, %2, %3, %4, %5, %6, %7, and %8 |
10051 | Ohùn |
Voice |
10052 | Dátà |
Data |
10053 | Fáàsì |
Fax |
10054 | SMS |
SMS |
10055 | Dátà ìbádọ́gba àtẹ iná |
Data circuit sync |
10056 | Dátà àìbádọ́gba àtẹ iná |
Data circuit async |
10057 | Ìráyè sí àkópọ̀ |
Packet access |
10058 | PAD ìráyè sí |
PAD Access |
10059 | Ìpè pàjáwírì |
Emergency call |
10060 | Méèlì-olóhùn |
Voicemail |
10062 | Láti lo àbùjá naa %1# láti pe %3 ní %2 lóri SIM káàdì rẹ, yan Ipè. Láti pe nọ́ḿbà míìràn, yan Parẹ́ kí o tẹ̀sìwájú láti maa pè. |
To use the shortcut %1# to dial %3 at %2 from your SIM card, select Call. To dial a different number, select Cancel and continue dialing. |
10063 | Láti lo àbùjá naa %1# láti pè %2 lóri SIM káàdì rẹ, yan Ipè. Láti pe nọ́ḿbà míìràn, yan Parẹ́ kí o tẹ̀sìwájú láti maa pè. |
To use the shortcut %1# to dial %2 from your SIM card, select Call. To dial a different number, select Cancel and continue dialing. |
10064 | Fóònù |
Phone |
10067 | Pè |
Call |
10068 | Ààtò ipè ìdadúró rẹ kò fàyègba ipè sórí nọ́ḿbà yíi. Pa ipè ìdadúró rẹ kí o gbìyànjú ipè sii. |
Your call barring settings don't allow a call to this number. Disable call barring and try calling again. |
10069 | Móòdù Nọ́ḿbà Ipè Ìduró (FDN) rẹ kò fàyègba ipè sórí nọ́ḿbà yíi. Pa móòdù FDN rẹ kí o gbìyànjú ipè sii. |
Your Fixed Dialing Number (FDN) mode doesn't allow a call to this number. Disable FDN mode and try calling again. |
10070 | Méèlì-olóhùn kò sí ní ìṣàgbékalẹ̀. Ṣàtẹ̀wọlé nọ́ḿbà méèlì-olóhùn rẹ kí o gbìyànjú sii. |
Voicemail isn't set up. Enter your voicemail number and try again. |
10071 | Ń dúró... |
Waiting... |
10072 | Kòle pè. Jọ̀wọ́ dá ipè rẹ yí dúró náà kí o tó pe òmíìràn. |
Can't place the call. Please end your current call before placing an additional call. |
10073 | Kòle sopọ̀ |
Can't connect |
10074 | O le ní aṣàmì aláìlowáyà kan tí kò ní agbára, tàbí nọ́mbà àìtọ̀nà. |
You may have a weak wireless signal, or the wrong number. |
10076 | Ẹni tí o gbìyànjú àti pè kòle gba ipè tí o ń wọlé bọ̀. |
The person you're trying to call is restricted from receiving incoming calls. |
10077 | Kòle sopọ̀. Rii dájú pé o ní afẹ́fẹ́ alásopọ̀, kí o gbìyànjú sii. |
Can't connect. Make sure you have network coverage, and try again. |
10078 | Kòle parí ipè. |
The call can't be completed. |
10080 | Káàdì SIM ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́, jọ̀wọ́ gbìyànjú sii. |
The SIM card is busy, please try again. |
10081 | Kòsí ìpèsè alásopọ̀ naa. jọ̀wọ́ gbìyànjú sii bóyá. |
The network service is unavailable. Please try again later. |
10082 | O lè lo fóònù yíi fún àwọn ìpè pàjáwírì nìkan. |
You can use this phone for emergency calls only. |
10083 | Kòle pe méèlì-olóhùn nítorí ojú ìlà míìràn kò ṣiṣẹ́. |
Can't call voicemail because another line isn't available. |
10084 | Kòle fi ipè jíṣẹ́. |
Can't transfer call. |
10085 | Ṣàtẹ̀wọlé àwọn kóòdù iṣẹ́ tààrà láti páàdì ìpè fóònù. |
Enter service codes directly from the phone's dial pad. |
10089 | Móòdù ọkọ̀ bàálù wà ní pípa |
Airplane mode is now off |
10091 | Ó DÁA |
OK |
10092 | Paá rẹ́ |
Cancel |
10093 | Kòle ṣàfipamọ́ nọ́ḿbà méèlì-olóhùn. |
Can't save voicemail number. |
10094 | Ó wà ní Móòdù Ipèpadà Pàjáwírì |
In Emergency Callback Mode |
10095 | Paa móòdù yíi rẹ́ láti lo fóònù rẹ bí o ti maá ńṣe. |
Cancel this mode to use your phone as you normally would. |
10096 | Paa móòdù rẹ́ |
Cancel mode |
10097 | Pe ìpè pàjáwìrì |
Dial emergency call |
10108 | Tan ìsopọ̀ alágbekà sẹ́lúlà? |
Turn on cellular connection? |
10109 | Fóònù rẹ wàní móòdù ọkọ̀ bààlú. Láti pè, tan ìsopọ̀ alágbekà rẹ. |
Your phone is in airplane mode. To make a call, turn on your cellular connection. |
10110 | Tàn án |
Turn on |
10115 | Firánṣẹ́ |
Send |
10116 | Padé |
Close |
10117 | Sáà náà ti tán. |
The session timed out. |
10118 | Ohun kan ṣẹlẹ̀ a kòsí lè parí iṣe yìí. |
Something happened and we couldn't complete this action. |
10128 | Tẹ̀siwájú pèlú ipè fídíò? |
Continue with video call? |
10129 | Èyí yóò fòpin sí ipè tí ó dúró. Tẹ̀siwájú? |
This will end the call that's on hold. Continue? |
10130 | Tẹ̀siwájú |
Continue |
10132 | Kòle bẹ̀rẹ̀ ipè fídíò |
Can't start video call |
10133 | %1 kò làfọwọ́sí lọ́wọ́lọ́wọ́ sínu %2. |
%1 is currently not signed into %2. |
10140 | Ṣètò |
Set |
10142 | Ṣé o fẹ́ ṣètò ìṣàfilọ́lẹ̀ àkùnàyàn bí? |
Set default app? |
10143 | Ṣé o fẹ́ ṣètò %1!s! bí ìṣàfilọ́lẹ̀ ID olùpè àkùnàyàn rẹ bí? |
Do you want to set %1!s! as your default caller ID app? |
10144 | Ṣé o fẹ́ ṣètò %1!s! bí ìṣàfilọ́lẹ̀ asẹ́ ìwé àìbèèrèfún bí? |
Do you want to set %1!s! as your default spam filter app? |
50001 | Káàdì SIM/UIM sọnù. |
The SIM/UIM card is missing. |
50002 | Káàdì SIM/UIM kòfẹṣẹ̀múlẹ̀. |
The SIM/UIM card is invalid. |
50003 | Kòle parí ipè nítorí móòdù Nọ́ḿbà Ipè Máyẹ̀ ń ṣiṣẹ́ lóri káàdì SIM/UIM rẹ. |
The call can't be completed because Fixed Dialing Number mode is enabled on your SIM/UIM card. |
50004 | Láti lo àbùjá %1# láti pè %3 ní %2 láti káàdì SIM/UIM rẹ, yan Ipè. Láti pe nọ́ḿbà míìràn, yan Paarẹ́ kí o tẹ̀sìwajú ipè. |
To use the shortcut %1# to dial %3 at %2 from your SIM/UIM card, select Call. To dial a different number, select Cancel and continue dialing. |
50005 | Láti lo àbùjá %1# láti pè %2 láti káàdì SIM/UIM rẹ, yan Ipè. Láti pe nọ́ḿbà míìràn, yan Paarẹ́ kí o tẹ̀sìwajú ipè. |
To use the shortcut %1# to dial %2 from your SIM/UIM card, select Call. To dial a different number, select Cancel and continue dialing. |
50006 | Káàdì SIM/UIM ńṣiṣẹ́ lọ́wọ́, jọ̀wọ́ gbìyànjú sii. |
The SIM/UIM card is busy, please try again. |
50008 | Kòle pè |
Can't call |
50009 | O nílò láti tan ìyikiri ohùn láti pe ẹnìkan nítorí o wà ní agbègbè ìyíkiri. O lè ṣe èyí ní Àwọn Ààtò Alásopọ̀ & aláìlowáyà Alágbèéká & SIM. |
You need to turn on voice roaming to call someone because you're in a roaming area. You can do this in Settings Network & wireless Cellular & SIM. |
50010 | Àwọn ààtò |
Settings |
50020 | Láti lo àbùjá %1# láti pè %3 at %2 láti káàdì UIM rẹ, yan Ipè. Láti pe nọ́ḿbà míìràn, yan Paarẹ́ kí o tẹ̀sìwajú ipè. |
To use the shortcut %1# to dial %3 at %2 from your UIM card, select Call. To dial a different number, select Cancel and continue dialing. |
50021 | Láti lo àbùjá %1# láti pè %2 láti káàdì UIM rẹ, yan Ipè. Láti pe nọ́ḿbà míìràn, yan Paarẹ́ kí o tẹ̀sìwajú ipè. |
To use the shortcut %1# to dial %2 from your UIM card, select Call. To dial a different number, select Cancel and continue dialing. |
50023 | Káàdì UIM ńṣiṣẹ́ lọ́wọ́, jọ̀wọ́ gbìyànjú sii. |
The UIM card is busy, please try again. |
50024 | O nílò láti tan ìyikiri ohùn láti pe ẹnìkan nítorí o wà ní agbègbè ìyíkiri. O lè ṣe èyí ní Àwọn Ààtò Alásopọ̀ & aláìlowáyà Alágbèéká & SIM/UIM. |
You need to turn on voice roaming to call someone because you're in a roaming area. You can do this in Settings Network & wireless Cellular & SIM/UIM. |
50025 | Àwọn ìṣafilọ́lẹ̀ fún àwọn ìpè olóhùn |
Apps for voice calls |
50026 | Wá ìṣafilọ́lẹ̀ nínu ìtàjà oníforíkorí? |
Search for an app in the Store? |
50027 | O nílò láti ṣàgbékalẹ̀ ìṣafilọ́lẹ̀ tí ó fún ọ láyè láti pe ipè olóhùn, asì le bá ọ wá ọ̀kan ní ìtàjà oníforíkorí. |
You need to install an app that lets you make voice calls, and we can help you find one in the Store. |
50028 | Bẹ́ẹ̀ni |
Yes |
50029 | Bẹ́ẹ̀kọ́ |
No |
50030 | Tan ipè fídíò LTE? |
Turn on LTE video calling? |
50031 | A ti pa ipè fídíò LTE. Láti pe ipè olóhùn, tan ipè fídíò LTE. |
LTE video calling is turned off. To make a video call, turn on LTE video calling. |
50034 | Ipè fídíò LTE |
LTE video calling |
50035 | Ojúlówó dátà àti iye ohùn yóò di sísan lákókò àwọn ipè fídíò. Àwọn míìràn lè ṣàwarí pé o lè pè kí o sì gba àwọn ìpè fídíò. |
Standard data and voice rates apply during video calls. Other people may discover that you can make and receive video calls. |
50036 | Má ṣàfihàn iṣẹ́ yíì mọ́ |
Don't show this message again |
50038 | Fídíò |
Video |
50039 | Ṣé o fẹ́ pè lórí Wi-Fi bí? |
Call over Wi-Fi? |
50040 | Kò le parí ìpè náà lórí alásopọ̀ sẹ́lúlà. Tan ìpè Wi-Fi nínú àwọn ààtò SIM, lẹ́yìn náà gbìyànjú láti pè lẹ́ẹ̀kan síi. |
Can't complete the call over a cellular network. Turn on Wi-Fi calling in SIM settings, then try calling again. |
50043 | Má ṣàfihàn ìfiránṣẹ́ yíì mọ́ |
Don't show this message again |
50044 | Ṣé o pè lórí WLAN bí? |
Call over WLAN? |
50045 | Kò le parí ìpè náà lórí alásopọ̀ sẹ́lúlà kan. Tan pípè WLAN nínú àwọn ààtò SIM, lẹ́yìn náà gbìyànjú pípè lẹ́ẹ̀kan síi. |
Can't complete the call over a cellular network. Turn on WLAN calling in SIM settings, then try calling again. |
50100 | %1 %2 |
%1 %2 |
50101 | %1 - ìpè àpéjọ %2 |
%1 - conference %2 |
50102 | Tí a kò mọ̀ |
Unknown |
50200 | End the current call, then try to make the priority call again. |
End the current call, then try to make the priority call again. |