| File name: | UserLanguagesCpl.dll.mui |
| Size: | 15360 byte |
| MD5: | 5068530e40cb795ce1a7af26ef099792 |
| SHA1: | e409cb2b7f57547400ea9415fb477910849c022b |
| SHA256: | 01fb75d23faf7f6e355db5b6631cbe8a21da770d14037feb63228927e5155795 |
| Operating systems: | Windows 10 |
| Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
| id | Yoruba | English |
|---|---|---|
| 1 | Èdè | Language |
| 2 | Ṣàdáni àwọn ìnífẹ̀ẹ́sí rẹ àti àwọn ìṣètò àgbàyé | Customize your language preferences and international settings |
| 3 | Ètò yìí ní a ti dènà nípasẹ̀ ìlànà ẹgbẹ́. Fún ọ̀pọ̀ ìwífún, kànsí alábòójútó ẹrọ rẹ. | This program is blocked by group policy. For more information, contact your system administrator. |
| 4 | Ìrànlọ́wọ́ | Help |
| 5 | Ṣàfikún àwọn èdè | Add languages |
| 6 | Ìyàtọ̀ ẹlẹ́kùnjẹkùn | Regional variants |
| 7 | Àwọn ìṣètò aládàńlá | Advanced settings |
| 8 | Àwọn ẹ̀yàn èdè | Language options |
| 9 | Ìlànà ìgbàwọlé | Input method |
| 10 | Àwọn Ẹ̀yàn | Options |
| 11 | Yọkúrò | Remove |
| 12 | Sún Sókè | Move up |
| 13 | Sún Sísàlẹ̀ | Move down |
| 14 | Orúkọ èdè | Language name |
| 16 | Ìlànà ìkọwé | Writing system |
| 17 | Àwọn ìṣètò èdè tówọ́pọ̀ | Common language settings |
| 18 | Ṣàfikún | Add |
| 19 | Ṣí | Open |
| 20 | Ìye àwọn èdè: | Number of languages: |
| 21 | Ṣàyípadà déètì, àkókò, tàbí ìgúnrégé nọ́ńbà | Change date, time, or number formats |
| 22 | Ìbójútó | Administrative |
| 23 | Àwọn Ìrísí-lẹ́tà | Fonts |
| 24 | Tọ̀ èdè lọ́wọ̀wọ́ nípa | Group languages by |
| 25 | Ṣàfikún èdè kan | Add a language |
| 26 | Àwọn ìṣètò tówọ́pọ̀ | Common settings |
| 28 | Paá rẹ́ | Cancel |
| 29 | Expand input methods | Expand input methods |
| 30 | Collapse input methods | Collapse input methods |
| 31 | Ṣàfikún ìlànà ìgbàwọlé kan | Add an input method |
| 32 | Ṣàfipamọ́ | Save |
| 33 | Expand text services | Expand text services |
| 34 | Collapse text servives | Collapse text servives |
| 35 | Àwọn ìnífẹ̀sí ìṣàyẹ̀wòsípẹ́lì: | Spellchecking preferences: |
| 36 | Ti ṣàgbékalẹ̀ | Installed |
| 38 | Àtòkọ ìṣàfihàn èdè | Display language list |
| 39 | Àtòkọ ìgbéwọlé àyọkà | Text Input List |
| 40 | Ṣíra tẹ̀ láti ṣí àwọn ẹ̀yàn pẹpẹ èdè | Click to open language bar options |
| 41 | Jáde nísìnyí | Log off now |
| 42 | Ṣàyípadà ìṣàfihàn èdè | Change display language |
| 43 | O gbọ́dọ̀ jáde nísìnyí fún ìṣàfihàn èdè láti le sisẹ́ | You must log off for display language changes to take effect |
| 44 | Ríi dájú pé o ṣàfipamọ́ iṣẹ́ rẹ̀ẹ àti pé kí o sì pa gbogbo àwọn ètò tí o ṣí sílẹ̀ dé kí o tó pa ẹ̀rọ rẹ. | Make sure you save your work and close all open programs before you log off. |
| 45 | A máa nílò àwọn àǹfààní alábòójútó | Administrative privileges required |
| 46 | Aṣàwárí elédè aṣiṣẹ́ | Languages enabled explorer |
| 47 | Àṣàwárí ẹ̀yàn àwọn èdè | Languages choices explorer |
| 48 | Aṣàwárí Ìlànà Ìgbéwọlé | Input method explorer |
| 49 | Ṣàwárí àwọn èdè | Search languages |
| 51 | Ti le ṣiṣẹ̀ | Enabled |
| 52 | Ti wà nípò aṣiṣẹ́ (sọṣẹ́sílẹ̀) | Enabled (override) |
| 53 | Ṣàyípadà sọsẹ́sílẹ̀ | Change override |
| 54 | Wa nílẹ̀ | Available |
| 55 | Mu kí %1 jẹ́ ìpìlẹ̀ èdè rẹ (o máa rí i lókè àtòkọ rẹ) | Make %1 your primary language (you’ll see it at the top of your list) |
| 56 | Mú kí èyí jẹ́ ìpìlẹ̀ èdè | Make this the primary language |
| 57 | Máa wà nípo aṣiṣẹ́ ní ìwọlé mìíràn | Will be enabled on next sign-in |
| 60 | Wà nílẹ̀ fún ìgbàsílẹ̀ | Available for download |
| 61 | Àkopọ̀ èdè fún %1 kò sí nílẹ̀ fún ìgbàsílẹ̀ | A language pack for %1 is available for download |
| 62 | Ṣe àgbàsílẹ̀ kí o sì ṣàgbékalẹ̀ àkópọ̀ èdè | Download and install language pack |
| 63 | Tí o bá fẹ́ ṣàyípadà èdè ìṣàfihàn, bá ẹni tí ó ń ṣàkóso àkọọ́lẹ̀ yìí sọ̀rọ̀ | If you want to change the display language, talk to the person who manages this account |
| 66 | Àkópọ̀ èdè kò sí nílẹ̀ | A language pack isn't available |
| 67 | A ti ṣètò èdè ìṣàfihàn sí èdè mìíràn nípa lílo sọṣẹ́sílẹ̀ | The display language has been set to another language using override |
| 69 | Ibi | Location |
| 70 | Èdè Ìṣàfihàn Windows: %1 Ètò ìrís Àtẹ bọ́tìnnì: %2 |
Windows display language: %1 Keyboard layout: %2 |
| 71 | %3. Èdè ìṣàfihàn Windows: %1. Ètò ìrísí àtẹ bọ́tìnnì: %2. Ṣíra tẹ fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yàn. | %3. Windows display language: %1. Keyboard layout: %2. Click for more options. |
| 72 | Ètò ìrísí àtẹ bọ́tìnnì: %1 | Keyboard layout: %1 |
| 73 | %3. Ètò ìrísí àtẹ bọ́tìnnì: %2. Ṣíra tẹ fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yàn. | %3. Keyboard layout: %2. Click for more options. |
| 74 | Èdè ìṣàfihàn Windows: %1 Ìlànà ìgbéwọlé: %2 |
Windows display language: %1 Input method: %2 |
| 75 | %3. Èdè ìṣàfihàn Windows: %1. Ìlànà ìgbéwọlé: %2. Ṣíra tẹ̀ fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yàn. | %3. Windows display language: %1. Input method: %2. Click for more options. |
| 76 | Ìlànà ìgbéwọlé: %1 | Input method: %1 |
| 77 | %3. Ìlànà ìgbéwọlé: %2. Ṣíra tẹ̀ fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yàn. | %3. Input method: %2. Click for more options. |
| 78 | %1 %2 |
%1 %2 |
| 79 | %1. %2. Ṣíra tẹ̀ fún àkọwò. | %1. %2. Click for preview. |
| 80 | Àkọwò | Preview |
| 81 | Ọ̀págun | Standard |
| 82 | Ètò ìrísí Àtẹ Ìtẹ̀wé Orí Aṣàfihàn | Touch keyboard layout |
| 83 | IME | IME |
| 84 | Ṣàwárí ìdáyàtọ̀ ẹlẹ́kùnjẹkùn | Search regional variants |
| 85 | Ṣàwárí àwọn ìlànà ìgbéwọlé | Search input methods |
| 88 | Ṣàyípadà ẹ̀yọ ọ̀rọ̀ atọ́nà pẹpẹ èdè | Change language bar hot keys |
| 91 | Kósí ọ̀kankan nílẹ̀ | none available |
| 92 | | | | |
| 93 | Èdè ìṣàfihàn Windows: %1 Ètò ìrís Àtẹ bọ́tìnnì: %2... |
Windows display language: %1 Keyboard layout: %2... |
| 94 | Ètò ìrísí àtẹ bọ́tìnnì: %2... | Keyboard layout: %2... |
| 95 | Èdè ìṣàfihàn Windows: %1 Ìlànà ìgbéwọlé: %2... |
Windows display language: %1 Input method: %2... |
| 96 | Ìlànà ìgbéwọlé: %2... | Input method: %2... |
| 97 | Ń ṣàyẹ̀wò ìwàlárọ̀wọ́tó... | Checking availability... |
| 98 | Ti wà nípò aṣiṣẹ́ (máa típadà lẹ́yìn ìwọlé tókàn) | Enabled (will change after next sign-in) |
| 100 | Lo àtòkọ èdè (a gbàá níyànjú) | Use language list (recommended) |
| 101 | _stack | _stack |
| 102 | Ṣàgbékalẹ̀ tàbí ìyọnípò àwọn èdè ìṣàfihàn. A máa nílò àǹfààní alábòójútó | Install or uninstall display languages. Administrative privileges required |
| 103 | Kńni mo le ṣe láti gba ọ̀pọ̀ èdè? | What can I do to get more languages? |
| 105 | %1 - %2 | %1 - %2 |
| 106 | Àtẹ bọ́tìnnì | Keyboard |
| 107 | Ṣàyọkúrò àkópọ̀ èdè | Uninstall language pack |
| 108 | %1 (kò sí nílẹ̀) | %1 (not available) |
| 109 | /u %1 /w | /u %1 /w |
| 110 | Ṣàmúlò àwọn ìṣètò sí aṣàfihàn ìkíni káàbọ̀, àwọn àkọọ́lẹ̀ ẹ̀rọ, àti àkọọ́lẹ̀ aṣànúlò titun | Apply language settings to the welcome screen, system accounts, and new user accounts |
| 111 | Ìlànà ìgbéwọlé tí kò sí nílẹ̀ | Unavailable input method |
| 112 | Ṣèdápadà àkùnàyàn | Restore defaults |
| 113 | Ṣíra tẹ̀ fún àkọwò ìlànà ìgbéwọlé %1 | Click to preview %1 input method |
| 114 | Ṣíra tẹ̀ láti ṣí ẹ̀yàn fún ìlànà ìgbéwọlé %1 | Click to open options for %1 input method |
| 115 | Ṣíra tẹ láti ṣàyọkúrò %1 ìlànà ìgbéwọlé | Click to remove %1 input method |
| 116 | Kò sí àwọn ohun tó bá ohun tí ò ń wá mu | No items match your search |
| 118 | Somọ́ íntánẹ́ẹ̀tì láti ṣàyẹ̀wò fún àkópọ̀ èdè | Connect to the Internet to check for language packs |
| 119 | %1 Orí àtẹ iṣẹ́ nìkan ni ó ti le ṣiṣẹ́ |
%1 Only works on the desktop |
| 122 | Máa ṣiṣẹ́ ní ìwọlé tókàn (sọṣẹ́sílẹ̀) | Will be enabled on next sign-in (override) |
| 123 | %1 | %1 |
| 124 | %1. ṣíra tẹ̀ fún àkọwò. | %1. Click for preview. |
| 125 | Gbálóhùn ìkọ̀kọ̀ | Privacy statement |
| 126 | Tí o bá fẹ́ ṣàyípadà èdè ìṣàfihàn rẹ, bá ẹni tí ó ń ṣàkóso àkọọ́lẹ̀ yìí sọ̀rọ̀ | If you want to change the display language, talk to the person who manages this account |
| 127 | Alábòójútó ẹ̀rọ rẹ ni ó ń ṣàkóso ààtò yìí | This setting is managed by your system administrator |
| 128 | Èdè ìṣàfihàn Windows: %1 | Windows display language: %1 |
| 129 | , | , |
| 130 | %3 %1 |
%3 %1 |
| 131 | %2. %3. %1. Ṣíra tẹ̀ fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yàn. | %2. %3. %1. Click for more options. |
| 133 | %2. %1. Ṣíra tẹ̀ fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yàn. | %2. %1. Click for more options. |
| 134 | %3 %1 Déètì, àkókò, àti àti gígúnrégé nọ́ńbà |
%3 %1 Date, time, and number formatting |
| 135 | %2. %3. %1. A máa ńlò fún déètì, àkókò, àti gígúnrégé nọ́ńbà. Ṣíra tẹ̀ fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yàn. | %2. %3. %1. Used for date, time, and number formatting. Click for more options. |
| 136 | %1 Déètì, àkókò, àti àti gígúnrégé nọ́ńbà |
%1 Date, time, and number formatting |
| 137 | %2. %1. A máa ńlò fún déètì, àkókò, àti gígúnrégé nọ́ńbà. Ṣíra tẹ̀ fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yàn. | %2. %1. Used for date, time, and number formatting. Click for more options. |
| 138 | Open overflow menu | Open overflow menu |
| 139 | Kò sí nílẹ̀ nínú ẹ̀yà Windows | Unavailable in this edition of Windows |
| 140 | Pa á tí ó bá yá | Log off later |
| 141 | Àwọn ẹyọ ọ̀rọ̀ Ṣáínà, Kanji tàbí Hanja tí a dámọ̀ ṣùgbọ́n tí a kìí sábà lò nígbàtí a bá ń ṣàyípadà àyọkà àfọwọ́kọ̀ sí títẹ̀. | Recognize rarely used Chinese, Kanji, or Hanja characters when converting handwriting to typed text. |
| 142 | Kò sí àwọn ẹ̀yàn ìfọwọ́kọ fún èdè yìí | There are no handwriting options for this language |
| 594 | Ṣàyípadà àwọn ìnífẹ̀sí èdè rẹ | Change your language preferences |
| 595 | O le tẹ èyíkéyìí èdè tí o ṣàfikún sí àtòkọ náà. Windows, ìṣàfilọ́lẹ̀ àti àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù yóò farahàn nínú èdè àkọ́kọ́ nínú àtòkọ tí wọ́n faramọ́. | You can type in any language you add to the list. Windows, apps and websites will appear in the first language in the list that they support. |
| 611 | Tọ̀ èdè lọ́wọ̀wọ́ nípa: | Group languages by: |
| 612 | Lo àpótí ìṣàwárí láti wá ọ̀pọ̀ èdè. | Use the search box to find more languages. |
| 621 | Àwọn ìpèsè àyọkà | Text services |
| 629 | Sọṣẹ́sílẹ̀ fún Èdè ìṣàfihàn Windows | Override for Windows display language |
| 630 | Sọṣẹ́sílẹ̀ fún ìlànà ìgbéwọlé àkùnàyàn | Override for default input method |
| 631 | Ń ṣí àwọn ìlànà ìgbéwọlé nípò padà | Switching input methods |
| 632 | Détà ìṣoditaraẹni | Personalization data |
| 635 | Tí o bá lo èdè ìṣàfihàn tí ó yàtọ̀ sí èyí tí àtòkọ èdè rẹ ṣe, yàn án níbí. | If you want to use a display language that's different than the one determined by the order of your language list, choose it here. |
| 636 | Tí ó bá fẹ́ lo ìlànà ìgbéwọlé tí ó yàtọ̀ fún tí àkọ̀kọ̀ nínú àtòkọ̀ èdè, yàn án níbí. | If you want to use an input method that's different than the first one in your language list, choose it here. |
| 637 | Jẹ́ kí ń ṣètò ìlànà ìgbéwọlé mìíràn fún ìṣàfilọ́lẹ̀ wíńdò kọ̀ọ̀kan | Let me set a different input method for each app window |
| 638 | Lo pẹpẹ èdè àtẹ iṣẹ́ nígbàtí ó bá wà nílẹ̀ | Use the desktop language bar when it's available |
| 640 | Lo ìkọ́ni aládàáṣe (a gbàá níyànjú) | Use automatic learning (recommended) |
| 641 | Má ṣe lo ìkóni aládàáṣe kí o sì pa gbogbo détà tí a kó jọ tẹ́lẹ̀ padà rẹ́. | Don't use automatic learning and delete all previously collected data |
| 642 | A kàn ń lo détà yìí láti ṣàmúdàgbà ìdámọ̀ ìfọwọ́kọ àti èsì àsọtẹ́lẹ̀ àyọkà fún àwọn èdè láì sí IME lórí i Kọ̀ǹpútà yìí. Kò sí ìwífún tí a fi ránṣẹ́ sí Microsoft. Gbólóhùn Ìkọ̀kọ̀ | This data is only used to improve handwriting recognition and text prediction results for languages without IMEs on this PC. No info is sent to Microsoft. Privacy statement |
| 646 | click | click |
| 656 | Ìfọwọ́kọ | Handwriting |
| 661 | Èdè ìṣàfihàn Windows | Windows display language |
| 673 | Ṣe àdání ìdámọ̀ ìfọwọ́kọ | Personalize handwriting recognition |
| 674 | Ṣe àdáni ìdámọ̀ ìfọwọ́kọ. | Personalize handwriting recognition. |
| 677 | Ṣàyípadà ẹ̀yọ ọ̀rọ̀ atọ́nà pẹpẹ èdès | Change language bar hot keys |
| 679 | Ẹ̀rọ àfisípẹ́lì lati lò: | Spellchecking engine to use: |
| 680 | Èdè fún àkóónú wẹ́ẹ̀bù | Language for web content |
| 681 | Máṣe jẹ́ kí ojú òpó wẹ́ẹ̀bù ráyè sí àtòkọ èdè mi. Èdè déètì mi, àkókò, àti gígúnrégé nọ́ńbà ní a máa lò dípò. | Don't let websites access my language list. The language of my date, time, and number formatting will be used instead. |
| 0x90000001 | Analytic channel logs minor warnings, major state/configuration change that can help debug admin and operational events. Default enabled state: off. Target audience: PSS/diagnostic tools/component developers | Analytic channel logs minor warnings, major state/configuration change that can help debug admin and operational events. Default enabled state: off. Target audience: PSS/diagnostic tools/component developers |
| File Description: | Pánẹ́ẹ̀lì Ìdarí Àtòpọ̀ Èdè Mi |
| File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
| Company Name: | Microsoft Corporation |
| Internal Name: | USERLANGUAGESCPL |
| Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa. |
| Original Filename: | USERLANGUAGESCPL.DLL.MUI |
| Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
| Product Version: | 10.0.15063.0 |
| Translation: | 0x46A, 1200 |