| File name: | prnntfy.dll.mui |
| Size: | 14336 byte |
| MD5: | fe5ee82402d672ba8da21a4805130280 |
| SHA1: | cf06c2312d523e56ffef23d586df920bb7d769c1 |
| SHA256: | 853537a0a8594b768356da6dc06569da4ab69f754436534df757a6765622d854 |
| Operating systems: | Windows 10 |
| Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
| id | Yoruba | English |
|---|---|---|
| 100 | … | … |
| 101 | A fi àkọsílẹ̀ yìí ránṣẹ́ sí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé | This document was sent to the printer |
| 102 | Àkọsílẹ̀: %1 Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé: %2 Àkókò: %3 Àpapọ̀ àwọn ojú ìwé: %4 |
Document: %1 Printer: %2 Time: %3 Total pages: %4 |
| 103 | Ìwé ti tán nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé | Printer out of paper |
| 104 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ‘%1’ kò ní ìwé nínú mọ́. | Printer ‘%1’ is out of paper. |
| 105 | Àkọsílẹ̀ ìwé ti kùnà làti tẹ̀wé | This document failed to print |
| 107 | Ilẹ̀kùn ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ti ṣí | Printer door open |
| 108 | Ilẹ̀kùn lórí ‘%1’ ti ṣí. | The door on ‘%1’ is open. |
| 109 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ní ipò àṣìṣe | Printer in an error state |
| 110 | ‘%1’ wà nípò àṣìṣe kan. | ‘%1’ is in an error state. |
| 111 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kò ní ohun ìtẹ̀wé/ọ̀dà mọ́ | Printer out of toner/ink |
| 112 | ‘%1’ kò ní ohun ìtẹ̀wé/ọ̀dà mọ́. | ‘%1’ is out of toner/ink. |
| 113 | Kò sí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé nílẹ̀ | Printer not available |
| 114 | ‘%1’ kò sí nílẹ̀ fún títẹ̀wé. | ‘%1’ is not available for printing. |
| 115 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé àìsílóníforíkorí | Printer offline |
| 116 | ‘%1’ wà ní àìsílóníforíkorí. | ‘%1’ is offline. |
| 117 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kò ní ibi ìpamọ́ mọ́ | Printer out of memory |
| 118 | ‘%1’ kò ní ibi ìpamọ́ mọ́. | ‘%1’ has run out of memory. |
| 119 | Ààtàn ìgbéjáde ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ti kún | Printer output bin full |
| 120 | Ààtàn ìgbéjáde lórí ‘%1’ ti kún. | The output bin on ‘%1’ is full. |
| 121 | Pépà ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ti há | Printer paper jam |
| 122 | Pépà ti há nínú ‘%1’. | Paper is jammed in ‘%1’. |
| 124 | ‘%1’ kò ní pépà mọ́. | ‘%1’ is out of paper. |
| 125 | Ìṣòrò pépà ẹ̀rọ ìtẹ̀wé | Printer paper problem |
| 126 | ‘%1’ ní ìṣòro pépà kan.. | ‘%1’ has a paper problem. |
| 127 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ti dúró díẹ̀ | Printer paused |
| 128 | ‘%1’ ti dúró díẹ̀. | ‘%1’ is paused. |
| 129 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé nílò ìdásí aṣàmúlò | Printer needs user intervention |
| 130 | ‘%1’ ní ìṣòro kan tó nílò ìdásí rẹ. | ‘%1’ has a problem that requires your intervention. |
| 131 | Ohun ìtẹ̀wé/ọ̀dà ti kéré nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé | Printer is low on toner/ink |
| 132 | ‘%1’ kéré lórí ohun ìtẹ̀wé/ọ̀dà. | ‘%1’ is low on toner/ink. |
| 133 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ni a ń ṣèparẹ́ | Printer is being deleted |
| 134 | %1 ni a ń ṣèparẹ́. | %1 is being deleted. |
| 135 | %1 lórí %2 | %1 on %2 |
| 136 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kò le tẹ̀wé %1 | The printer couldn’t print %1 |
| 137 | Ti tẹ̀wé | Printed |
| 138 | Kò sí pépà | Paper out |
| 139 | Àṣìṣe títẹ̀wé | Error printing |
| 140 | Ìfitónilétí Ìtẹ̀wé | Print Notification |
| 141 | Ti ṣàfipamọ́ fáìlì sí Fódà àwọn àkọsílẹ̀ | File saved to the Documents folder |
| 142 | Wo %1. | View %1. |
| 600 | Ó DÁA | OK |
| 601 | Paárẹ́ | Cancel |
| 1000 | Àkọsílẹ̀: %1 |
Document: %1 |
| 1001 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé: %1 |
Printer: %1 |
| 1002 | Ìwọ̀n pépà: %1 |
Paper size: %1 |
| 1003 | Ọ̀dà: %1 |
Ink: %1 |
| 1004 | Ike ọ̀dà: %1 |
Cartridge: %1 |
| 1005 | Agbègbè tí pépà ti há: %1 |
Paper jam area: %1 |
| 1006 | Ìṣòro ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kan ti wáyé | A printer problem occurred |
| 1007 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé fún èyíkéyìí àwọn ìṣòro. | Please check the printer for any problems. |
| 1008 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ipò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé àti àwọn ààtò. | Please check the printer status and settings. |
| 1009 | Ṣàyẹ̀wò bóyá ẹ̀rọ ìtẹ̀wé wá lóníforíkorí ó sì ṣetán láti tẹ̀wé. | Check if the printer is online and ready to print. |
| 1100 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà ti ṣetán láti tẹ̀wé sí ẹ̀gbẹ́ kejì pépà náà. | The printer is ready to print on the other side of the paper. |
| 1101 | Láti parí ìtẹ̀wé ẹlẹ́gbẹ̀ẹ́-méjì, yọ pépà náà kúrò láti pẹpẹ ìgbéjáde. Tún fi pépà náà sínú pépé àgbéwọlé náà, kò dojúkọ òkè. | To finish double-sided printing, remove the paper from the output tray. Re-insert the paper in the input tray, facing up. |
| 1102 | Láti parí ìtẹ̀wé ẹlẹ́gbẹ̀ẹ́-méjì, yọ pépà náà kúrò láti pẹpẹ ìgbéjáde. Tún fi pépà náà sínú pépé àgbéwọlé náà, kò dojúkọ ìsàlẹ̀. | To finish double-sided printing, remove the paper from the output tray. Re-insert the paper in the input tray, facing down. |
| 1200 | Tẹ Bọ́tìnnì túnbẹ̀rẹ̀ lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé nígbàtí o bá parí. | Press the Resume button on the printer when done. |
| 1201 | Tẹ Bọ́tìnnì paárẹ́ lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé nígbàtí o bá parí. | Press the Cancel button on the printer when done. |
| 1202 | Tẹ Bọ́tìnnì Ó DÁA lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé nígbàtí o bá parí. | Press the OK button on the printer when done. |
| 1203 | Tẹ Bọ́tìnnì oníforíkorí lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé nígbàtí o bá parí. | Press the Online button on the printer when done. |
| 1204 | Tẹ Bọ́tìnnì ṣàtúntò lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé nígbàtí o bá parí. | Press the Reset button on the printer when done. |
| 1300 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kò sí lóníforíkorí. | The printer is offline. |
| 1301 | Windows kò le sopọ̀ mọ́ ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ. Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ìsopọ̀ náà láàrín kọ̀npútà àti ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà. | Windows could not connect to your printer. Please check the connection between the computer and the printer. |
| 1302 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kò dáhùn. Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ìsopọ̀ náà láàrín kọ̀npútà àti ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà. | The printer is not responding. Please check the connection between your computer and the printer. |
| 1400 | Ìhámọ́ Pépà | Paper Jam |
| 1401 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ ìhámọ́ pépà. | Your printer has a paper jam. |
| 1402 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kí o sò ká ìhámọ́ pépà kúrò. Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kò le tẹ̀wé àyàfi tí o bá mú ìhámọ́ pépà kúrò. | Please check the printer and clear the paper jam. The printer cannot print until the paper jam is cleared. |
| 1403 | Jọ̀wọ́ ká ìhámọ́ pépà kúrò lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé. | Please clear the paper jam on the printer. |
| 1500 | Pépà ti tán nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ. | Your printer is out of paper. |
| 1501 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kí o sì ṣàfikún ọ̀pọ̀ pépà. | Please check the printer and add more paper. |
| 1502 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kí o sì ṣàfikún pépà síi nínú pẹpẹ %1. | Please check the printer and add more paper in tray %1. |
| 1503 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kí o sì ṣàfikún pépà %1 nínú pẹpẹ %2. | Please check the printer and add more %1 paper in tray %2. |
| 1600 | Pẹpẹ ìgbéjáde nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ ti kún. | The output tray on your printer is full. |
| 1601 | Jọ̀wọ́ ṣófo pẹpẹ àgbéjáde lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé. | Please empty the output tray on the printer. |
| 1700 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ ìṣòro pépà | Your printer has a paper problem |
| 1701 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ fún àwọn ìṣòro pépà. | Please check your printer for paper problems. |
| 1800 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ kò ní ọ̀dà mọ́ | Your printer is out of ink |
| 1801 | Ike ọ̀dà nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ ti ṣófo. | The ink cartridge in your printer is empty. |
| 1802 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ kò ní ohun ìtẹ̀wé mọ́. | Your printer is out of toner. |
| 1803 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kí o sì ṣàfikún ọ̀pọ̀ ọ̀dà. | Please check the printer and add more ink. |
| 1804 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kí o sì rọ́pò ike ọ̀dà. | Please check the printer and replace the ink cartridge. |
| 1805 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kí o sì ṣàfikún ohun ìtẹ̀wé. | Please check the printer and add toner. |
| 1900 | %1 | %1 |
| 1901 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà nílò àyẹ̀wò rẹ. Lọ sí àtẹ iṣẹ́ láti yanjú rẹ̀. | The printer requires your attention. Go to the desktop to take care of it. |
| 1902 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé | Printer |
| 2000 | Siyani | Cyan |
| 2001 | Magẹnta | Magenta |
| 2002 | Yẹ́lò | Yellow |
| 2003 | Dúdú | Black |
| 2004 | Siyani Fẹ́rẹ́fẹ́ | Light Cyan |
| 2005 | Magẹnta Fẹ́rẹ́fẹ́ | Light Magenta |
| 2006 | Pupa | Red |
| 2007 | Àwọ̀ ewé | Green |
| 2008 | Búlúù | Blue |
| 2009 | Olùmúgbòrò gilọsi | Gloss optimizer |
| 2010 | Dúdú Fọ́tò | Photo Black |
| 2011 | Dúdú Matẹ | Matte Black |
| 2012 | Siayni Fọ́tò | Photo Cyan |
| 2013 | Magẹnta Fọ́tò | Photo Magenta |
| 2014 | Dúdú Fẹ́rẹ́fẹ́ | Light Black |
| 2015 | Olùmúdọ́gba ọ̀dà | Ink optimizer |
| 2016 | Fọ́tò búlùù | Blue photo |
| 2017 | Fọ́tò gire | Gray photo |
| 2018 | Fọ́tò aláwọ̀-mẹ́ta | Tricolor photo |
| 2100 | Ike siyani | Cyan cartridge |
| 2101 | Ike magẹnta | Magenta cartridge |
| 2102 | Ike dúdú | Black cartridge |
| 2103 | Ike CMYK | CMYK cartridge |
| 2104 | Ike rẹ́súrẹ́sú | Gray cartridge |
| 2105 | Ike àwọ̀ | Color cartridge |
| 2106 | Ike fọ́tò | Photo cartridge |
| 2200 | Ilẹ̀kùn kan lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ ti ṣí. | A door on your printer is open. |
| 2201 | Àfibò kan lórí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ ti ṣí. | A cover on your printer is open. |
| 2202 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kí o sì pa èyíkéyì ìlẹ̀kùn tó ṣí dé. Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kò le ṣiṣẹ́ nígbàtí ìlẹ̀kùn kan ṣí. | Please check the printer and close any open doors. The printer cannot print while a door is open. |
| 2203 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kí o sì pa èyíkéyìí àfibò tó ṣí dé. Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kò le padé nígbàtí àfibò kan ṣí. | Please check the printer and close any open covers. The printer cannot print while a cover is open. |
| 2300 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ kò tẹ̀wé | Your printer is not printing |
| 2301 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ | Please check your printer |
| 2302 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ kò ní ibi ìpamọ́ mọ́ | Your printer is out of memory |
| 2303 | Àkọsílẹ̀ rẹ le má tẹ̀wé dáradára. Jọ̀wọ́ wo ìrànwọ́ lóníforíkorí. | Your document might not print correctly. Please see online help. |
| 2400 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ kò ní ọ̀pọ̀ ọ̀dà mọ́ | Your printer is low on ink |
| 2401 | Ike ọ̀dà nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ ti fẹ́rẹ̀ ṣófo. | The ink cartridge in your printer is almost empty. |
| 2402 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ ti kéré lórí ohun ìtẹ̀wé | Your printer is low on toner |
| 2403 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kí o sì ṣàfikún ọ̀pọ̀ ọ̀dà nígbàtí ó bá nílò. | Please check the printer and add more ink when needed. |
| 2404 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kí o sì rọ́pò ike ọ̀dà náà nígbàtí ó bá nílò. | Please check the printer and replace the ink cartridge when needed. |
| 2405 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà kí o sì ṣàfikún ohun ìtẹ̀wé nígbàtí ó bá nílò. | Please check the printer and add toner when needed. |
| 2500 | Ìlànà-ètò ọ̀dà rẹ nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kò ṣiṣẹ́ | The ink system in your printer is not working |
| 2501 | Ike ọ̀dà náà nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kò ṣiṣẹ́ | The ink cartridge in your printer is not working |
| 2502 | Ìlànà-ètò ohun ìtẹ̀wé rẹ nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé kò ṣiṣẹ́ | The toner system in your printer is not working |
| 2503 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ìlànà-ètò ọ̀dà náà nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ. | Please check the ink system in your printer. |
| 2504 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ike ọ̀dà nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ. | Please check the ink cartridge in your printer. |
| 2505 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò ìlànà-ètò ohun ìtẹ̀wé náà nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ. | Please check the toner system in your printer. |
| 2506 | Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò pé ike ọ̀dà náà ni a ṣàgbékalẹ̀ dáradára nínú ẹ̀rọ ìtẹ̀wé. | Please check that the ink cartridge was installed correctly in the printer. |
| 2600 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé náà ti dúró | Printer has been paused |
| 2601 | ‘%1’ kò le tẹ̀wé, nítorí a ti fi sí ipò ìdádúró díẹ̀ ní ohun èlò náà. | ‘%1’ cannot print, because it has been put into a paused state at the device. |
| 2602 | ‘%1’ kò le tẹ̀wé, nítorí a ti fi sí ipò àìsílóníforíkorí ní ohun èlò náà. | ‘%1’ cannot print, because it has been put into an offline state at the device. |
| 2700 | Ti tẹ àkọsílẹ̀ rẹ jáde. | Your document has been printed. |
| 2701 | Àkọsílẹ̀ rẹ wà nínú pẹpẹ àgbéjáde. | Your document is in the output tray. |
| 2702 | %1!d! (àwọn) àkọsílẹ̀ ń dúró fún %2 | %1!d! document(s) pending for %2 |
| 2703 |
| File Description: | prnntfy DLL |
| File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
| Company Name: | Microsoft Corporation |
| Internal Name: | prnntfy.dll |
| Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́. |
| Original Filename: | prnntfy.dll.mui |
| Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
| Product Version: | 10.0.15063.0 |
| Translation: | 0x46A, 1200 |