File name: | MusUpdateHandlers.dll.mui |
Size: | 39936 byte |
MD5: | f6ea1623dcdc8b7c26e52b554f097ad4 |
SHA1: | 097cb6889e86fbd03d4fa4964ef8931fd4ed88f2 |
SHA256: | 464bd7e6eb0fbaa04483e8414759864e087704052eb17eab71535c65ef038a0a |
Operating systems: | Windows 10 |
Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id | Yoruba | English |
---|---|---|
50 | Ń ṣàyẹwò fún àwọn àfikún... | Checking for updates... |
51 | Ńgba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún %1!u!%% | Downloading updates %1!u!%% |
52 | Ńgbáradì láti ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún %1!u!%% | Preparing to install updates %1!u!%% |
53 | Jọ̀wọ́ dúró... | Please wait... |
54 | Ohun èlò rẹ kójú òṣùwọ̀n. Ti ṣàyẹ̀wò gbẹ̀yìn %1, %2 | Your device is up to date. Last checked: %1, %2 |
55 | Kò sì ìṣàfikún kankan. Ojoójúmọ́ la ó máa ṣàyẹ̀wò fún ìṣàfikún tuntun. | No updates are available. We'll continue to check daily for newer updates. |
56 | Àwọn àfikún ti ṣetán láti ṣàgbékalẹ̀ | Updates are ready to install |
57 | A ó ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún ni aládàáṣe nígbàtí o kò lo ohun èlò rẹ, tàbí o le ṣàgbékalẹ̀ wọn báyìí tí o bá fẹ́. | We'll automatically install updates when you aren't using your device, or you can install them now if you want. |
58 | Àwọn àfikún ti ṣetán láti gbàsílẹ̀ | Updates are ready to download |
59 | Ń ṣe ìfisípò àwọn àfikún... | Installing updates... |
60 | A ó ní láti bẹ̀rẹ̀ àgbékalẹ̀ ọ̀tọ̀ kan láti parí àfikún yìí. Yan Ṣàgbékalẹ̀ láti bẹ̀rẹ̀ rẹ̀. Tí o kò bá rí wínńdò tí a ṣàgbékalẹ̀, dín wínńdò yìí kù, tàbí ṣàyẹ̀wò pẹpẹ iṣẹ́. | We need to start a separate installation to complete this update. Select Install to start it. If you don't see the install window, minimize this window, or check the taskbar. |
61 | Ohun èlò rẹ kójú ìwọ̀n. Ti ṣàyẹ̀wò gbẹ̀yìn: Lónìí, %1 | Your device is up to date. Last checked: Today, %1 |
62 | Ohun èlò rẹ kójú ìwọ̀n. Ti ṣàyẹ̀wò gbẹ̀yìn: Àná, %1 | Your device is up to date. Last checked: Yesterday, %1 |
63 | Initializing updates... | Initializing updates... |
64 | Preparing to download updates %1!u!%% | Preparing to download updates %1!u!%% |
100 | Ṣàyẹ̀wò fún àwọn àfikún | Check for updates |
101 | Àwọn àfikún tó wà nílẹ̀ ni a ó gbàsílẹ̀ tí a ó sì ṣàgbékalẹ̀ ní aládàáṣe, àyàfi lórí ìsopọ̀ àlòsanwó (níbití a ti le ṣàmúlò ìdíyelé). | Available updates will be downloaded and installed automatically, except over metered connections (where charges may apply). |
102 | Ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ nísìnyí | Restart now |
103 | Ṣàgbékalẹ̀ báyìí | Install now |
104 | Gbàsílẹ̀ | Download |
105 | Tún gbìyànjú síi | Retry |
106 | Yanjú àwọn ìṣòro | Fix issues |
107 | Lọ sí Ibi ìpamọ́ láti ṣèmúkúrò àwọn ohun tí o kò nílò | Go to Storage to remove things you don't need |
108 | Tókàn | Next |
109 | A ń dojúkọ wàhálà ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ láti parí àgbékalẹ̀ náà. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi nígbà díẹ̀. Tí o bá sì ń rí èyí, gbìyànjú àyẹ̀wò wẹ́ẹ̀bù tàbí kíkàn sí àtìlẹ́yìn fún ìrànwọ́. Kóòdù àfìkùnànhàn yìí le ṣèrànwọ́: (%1) | We're having trouble restarting to finish the install. Try again in a little while. If you keep seeing this, try searching the web or contacting support for help. This error code might help: (%1) |
110 | Láti ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kí o sì parí àfikún, a nílò: | To restart and finish updating, we need: |
111 | • Bátìrì rẹ ti gbaná sára sí 40%. |
• Your battery charged to 40%. |
112 | • Ìpè fóònù rẹ láti parí. |
• Your phone call to be finished. |
113 | This option is managed by your organization. | This option is managed by your organization. |
114 | Resume updates | Resume updates |
130 | Fún mi ní àfikún fún ìgbéjáde Microsoft mìíràn nígbàtí mo bá ṣàfikún Windows | Give me updates for other Microsoft products when I update Windows. |
131 | Ṣàyẹ̀wò lóníforíkorí fún àwọn àfikún láti Àfikún Microsoft. | Check online for updates from Microsoft Update. |
133 | Kọ́ síwájú síi | Learn more |
134 | Lo ìwífún ìwọlé mi láti parí àgbékalẹ̀ ohun èlò mi ní aládàáṣe lẹ́yìn àfikún kan. | Use my sign in info to automatically finish setting up my device after an update. |
136 | Gbólóhùn ìpamọ́ | Privacy statement |
137 | Include driver updates when I update Windows | Include driver updates when I update Windows |
140 | Tí o bá fẹ́, o le ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ báyìí. Tàbí, o le tún ètò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ ṣe sí àkókò tó rọrùn jùlọ. Ṣàrídájú pé ohun èlo rẹ wà nínú iná ní àkókò tí a ṣètò. Èyí dá lórí ìwọ̀n àfikún náà, àgbékalẹ̀ náà le pẹ́ díẹ̀. | If you want, you can restart now. Or, you can reschedule the restart to a more convenient time. Be sure your device is plugged in at the scheduled time. Depending on the size of the update, the install might take a while. |
141 | A ó tún ètò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ ṣe ní àkókò tí o kò kí ń lo ohun èlò rẹ (báyìí %1 òní dára). | We'll schedule a restart during a time you usually don't use your device (right now %1 today looks good). |
142 | A ó tún ètò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ ṣe ní àkókò tí o kò kí ń lo ohun èlò rẹ (báyìí %1 ọ̀la dára). | We'll schedule a restart during a time you usually don't use your device (right now %1 tomorrow looks good). |
143 | A ó tún ètò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ ṣe ní àkókò tí o kò kí ń lo ohun èlò rẹ (báyìí %1 ní %2 dára). | We'll schedule a restart during a time you usually don't use your device (right now %1 on %2 looks good). |
144 | Yan àkókò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kan | Select a restart time |
145 | Òní | Today |
146 | Ọ̀la | Tomorrow |
147 | Àkókò náà ti kọjá. Yan àkókò míràn. | That time is in the past. Choose another time. |
148 | We’ll finish installing updates when you tell us to: | We’ll finish installing updates when you tell us to: |
149 | We’ll show a reminder when we’re going to restart. If you want to see more notifications about restarting, turn this on. | We’ll show a reminder when we’re going to restart. If you want to see more notifications about restarting, turn this on. |
150 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. | Updates are available. |
151 | O nílò àtúnbẹ̀rẹ̀ kan láti parí ṣíṣe àgbékalẹ̀ àwọn àfikún wọ̀nyí: | A restart is required to finish installing the following updates: |
152 | Additional language support | Additional language support |
160 | • Ṣàmúgbòrò ìṣàwákiri wẹ́ẹ̀bù àti ìdọ́gba ìfilọ́lẹ̀. | • Improve web browsing and app compatibility. |
161 | • Ṣàmúgbòrò ọ̀nà ti ohun èlò rẹ fi ń ṣiṣẹ́. | • Improve the way your devices work. |
162 | • Ṣèrànwọ́ láti jẹ́ kí ohun èlò rẹ ní ọ̀pọ̀ ààbò. | • Help make your device more secure. |
163 | • %1 | • %1 |
164 | Ìtàn àfikún | Update history |
165 | Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé | Details |
166 | Àwọn Ààtò ìpamọ́ | Privacy settings |
167 | Àkíyèsí: Windows Update le ṣàfikún araarẹ̀ láládàáṣe lákọ̀ọ́kọ́ nígbàtí ó bá ń ṣàyẹ̀wò fún àwọn àfikún mìíràn. | Note: Windows Update might update itself automatically first when checking for other updates. |
168 | Àwọn ẹ̀yàn ìjìnlẹ̀ | Advanced options |
169 | Àwọn ẹ̀yàn ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ | Restart options |
170 | Schedule the restart | Schedule the restart |
180 | Aládàáṣe (ni a gbàníyànjú) | Automatic (recommended) |
181 | Jẹ́ kí ohun gbogbo máa ṣiṣẹ́ ní mẹ̀lọmẹ̀lọ. A ó ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ ohun èlò rẹ ní aládàáṣe nígbàtí o kò lòó. Àwọn àfikún kò ní gbàsílẹ̀ lórí ìsopọ̀ àlòsanwó kan (níbití a ti le ṣàmúlò ìdíyelé). | Keep everything running smoothly. We'll restart your device automatically when you're not using it. Updates won't download over a metered connection (where charges may apply). |
182 | Fitónilétí láti gba ẹ̀dà fáìlì | Notify to download |
183 | Yan ìgbà tí o fẹ́ gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún, a ó sì fitó ọ létí tí o bá nílò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kan. | Choose when to download updates, and you'll be notified if a restart is needed. |
184 | Fitónilétí láti ṣètò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ | Notify to schedule restart |
185 | A ó bèrè lọ́wọ́ rẹ láti ṣètò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kan láti parí ìṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún. Àwọn àfikún kò ní gbàsílẹ̀ lórí ìsopọ̀ àlòsanwó kan (níbití a le díyelé ọ). | You'll be asked to schedule a restart to finish installing updates. Updates won't download over a metered connection (where charges may apply). |
186 | Nígbà gbogbo máa ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ ohun èlò mi ní àkókò yìí nígbà kúgbà tí a bá fẹ́ ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún. | Always restart my device at this time whenever updates need to be installed. |
187 | Ṣàtúnlò àwọn àfikún tí a gbàsílẹ̀ lórí ohun èlò yìí láti ṣàfikún àwọn ohun èlò míràn lórí alásopọ̀ abẹ́lé mi. | Reuse updates downloaded on this device to update other devices on my local network. |
188 | Máṣe ṣàyẹ̀wò fún àwọn àfikún (akògbà níyànjú) | Never check for updates (not recommended) |
189 | Ibi-iṣẹ́ rẹ ti pa àwọn àfikún aládàáṣe | Your organization has turned off automatic updates |
190 | Fitónilétí láti ṣàgbékalẹ̀ | Notify to install |
191 | Àwọn àfikún kò ní gbàsílẹ̀ lórí ìsopọ̀ àlòsanwó kan. A ó bèrè lọ́wọ́ rẹ láti ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún nígbàtí a bá ti gbà wọ́n sílẹ̀. | Updates won't download over a metered connection. You'll be asked to install updates when they've been downloaded. |
192 | We'll automatically download and install updates, except on metered connections (where charges may apply). In that case, we’ll automatically download only those updates required to keep Windows running smoothly. | We'll automatically download and install updates, except on metered connections (where charges may apply). In that case, we’ll automatically download only those updates required to keep Windows running smoothly. |
193 | We'll ask you to download updates, except when updates are required to keep Windows running smoothly. In that case, we’ll automatically download those updates. | We'll ask you to download updates, except when updates are required to keep Windows running smoothly. In that case, we’ll automatically download those updates. |
194 | We'll automatically download updates, except on metered connections (where charges may apply). In that case, we’ll automatically download only those updates required to keep Windows running smoothly. We'll ask you to install updates after they've been downloaded. | We'll automatically download updates, except on metered connections (where charges may apply). In that case, we’ll automatically download only those updates required to keep Windows running smoothly. We'll ask you to install updates after they've been downloaded. |
200 | A kò tíì ṣàgbékalẹ̀ ìṣàfikún kankan síbẹ̀. | No updates have been installed yet. |
201 | Àṣeyọrí ìsàgbékalẹ̀ lórí %1 | Successfully installed on %1 |
202 | Ti kùnà láti ṣàgbékalẹ̀ sórí %1 | Failed to install on %1 |
203 | Nílò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kan láti parí ìṣàgbékalẹ̀ | Requires a restart to finish installing |
204 | Quality Updates (%1!u!) | Quality Updates (%1!u!) |
205 | Feature Updates (%1!u!) | Feature Updates (%1!u!) |
206 | Driver Updates (%1!u!) | Driver Updates (%1!u!) |
207 | Definition Updates (%1!u!) | Definition Updates (%1!u!) |
208 | Other Updates (%1!u!) | Other Updates (%1!u!) |
209 | Collapsed | Collapsed |
210 | Not Collapsed | Not Collapsed |
240 | Àwọn ẹ̀yàn ìràpadà | Recovery options |
241 | Ṣàyọkúrò àwọn àfikún | Uninstall updates |
300 | Àwọn Ìfẹnukò Ìgbaniláyè Ẹ̀yà Àìrídìmú | Software License Terms |
301 | Láti ṣàgbékalẹ̀ àfikún yìí, faramọ́ Àwọn Ìfẹnukò Ìgbaniláyè Ẹ̀yà Àìrídìmú titun. Pa wínńdò yìí dé tàbí yan Ìtọ́ka ẹ̀yìn lókè tí o kò bá fẹ́ ṣàgbékalẹ̀ àfikún náà báyìí. | To install this update, accept the new Software License Terms. Close this window or select the Back arrow above if you don't want to install the update now. |
302 | Láti ṣàgbékalẹ̀ àfikún yìí, faramọ́ Àwọn Ìfẹnukò Ìgbaniláyè Ẹ̀yà Àìrídìmú titun. Yan Ìtọ́ka ẹ̀yìn lókè tí o kò bá fẹ́ ṣàgbékalẹ̀ àfikún náà báyìí. | To install this update, accept the new Software License Terms. Select the Back button if you don't want to install the update now. |
400 | Padé | Close |
401 | Faramọ́ kí o sì ṣàgbékalẹ̀ | Accept and install |
500 | Ńdúró fún gbígba ẹ̀dà fáìlì | Waiting for download |
501 | Ńgba ẹ̀dà fáìlì | Downloading |
502 | Ńdúró fún àgbékalẹ̀ | Waiting for install |
503 | Ńṣàgbékalẹ̀ | Installing |
504 | Nílò ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ | Requires restart |
505 | Àṣìṣe | Error |
506 | Ńtẹ̀síwájú | In progress |
550 | Choose the branch readiness level to determine when feature updates are installed. Current Branch means the update is ready for most people, and Current Branch for Business means it’s ready for widespread use in organizations. | Choose the branch readiness level to determine when feature updates are installed. Current Branch means the update is ready for most people, and Current Branch for Business means it’s ready for widespread use in organizations. |
551 | Current Branch | Current Branch |
552 | Current Branch for Business | Current Branch for Business |
553 | A feature update includes new capabilities and improvements. It can be deferred for this many days: | A feature update includes new capabilities and improvements. It can be deferred for this many days: |
554 | A quality update includes security improvements. It can be deferred for this many days: | A quality update includes security improvements. It can be deferred for this many days: |
555 | Temporarily pause updates from being installed on this device for up to %1!u! days. When updates resume, this device will need to get the latest updates before it can be paused again. | Temporarily pause updates from being installed on this device for up to %1!u! days. When updates resume, this device will need to get the latest updates before it can be paused again. |
556 | You have paused updates for this device. For more info on when updates will resume, select Advanced options. | You have paused updates for this device. For more info on when updates will resume, select Advanced options. |
557 | Your organization paused some updates for this device. For more info on when updates will resume, select Advanced options. | Your organization paused some updates for this device. For more info on when updates will resume, select Advanced options. |
558 | Pausing now will pause updates until %1 | Pausing now will pause updates until %1 |
559 | Updates paused until %1 | Updates paused until %1 |
560 | Quality updates paused by your organization until %1 | Quality updates paused by your organization until %1 |
561 | Feature updates paused by your organization until %1 | Feature updates paused by your organization until %1 |
562 | Some updates were already downloaded and installed and can’t be paused. Restarting this device will finish installing these updates. Any other updates will be paused. | Some updates were already downloaded and installed and can’t be paused. Restarting this device will finish installing these updates. Any other updates will be paused. |
563 | Updates have been resumed so we are checking for updates to keep your machine current with the latest security and quality updates before you can pause updates again. | Updates have been resumed so we are checking for updates to keep your machine current with the latest security and quality updates before you can pause updates again. |
564 | Pause Updates | Pause Updates |
600 | Choose an end time that’s no more than %1!u! hours from the start time. | Choose an end time that’s no more than %1!u! hours from the start time. |
601 | End time (max %1!u! hours) | End time (max %1!u! hours) |
602 | Your organization has chosen your Active hours limits. | Your organization has chosen your Active hours limits. |
700 | A ti ṣètò ohun èlò rẹ láti ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ lóde wákàtí tó ń ṣiṣẹ́. (Wákàtí tó ń ṣiṣẹ́ jẹ́ are %1 sí %2.) | Your device is scheduled to restart outside of active hours. (Active hours are %1 to %2.) |
701 | We’re all set to do the restart you scheduled at %1 on %2, or select Restart now to run more smoothly and securely right away. | We’re all set to do the restart you scheduled at %1 on %2, or select Restart now to run more smoothly and securely right away. |
702 | Your organization will restart your device at %1 to finish updating Windows. Or select Restart now to run more smoothly and securely right away. | Your organization will restart your device at %1 to finish updating Windows. Or select Restart now to run more smoothly and securely right away. |
703 | Ohun èlò rẹ yóò ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ ní %1. Ṣàrídájú pé o ṣàfipamọ́ èyíkéyìí iṣẹ́ kí o tó ṣàtúnbẹ̀rẹ̀. | Your device will restart at %1. Make sure to save any work before the restart. |
704 | Your device will restart at %1 because we tried but were unable to install updates outside of your active hours. Make sure to save any work before the restart. | Your device will restart at %1 because we tried but were unable to install updates outside of your active hours. Make sure to save any work before the restart. |
705 | òní | today |
706 | ọ̀la | tomorrow |
707 | A ti ṣètò ohun èlò rẹ láti ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ lóde wákàtí tó ń ṣiṣẹ́ èyítí ilé-iṣẹ́ rẹ ti ṣètò. (Wákàtí tó ń ṣiṣẹ́ jẹ́ are %1 sí %2.) | Your device is scheduled to restart outside of active hours set by your organization. (Active hours are %1 to %2.) |
708 | We couldn’t find a good time to install updates outside of your active hours and need you to restart your device to finish up. | We couldn’t find a good time to install updates outside of your active hours and need you to restart your device to finish up. |
800 | Your device is at risk because it’s out of date and missing important security and quality updates. Let’s get you back on track so Windows can run more securely. Select this button to get going: | Your device is at risk because it’s out of date and missing important security and quality updates. Let’s get you back on track so Windows can run more securely. Select this button to get going: |
1000 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n a nílò ààyè %1 MB-%2 MB fún ìgbà díẹ̀l áti gba ẹ̀dà fáìlì. Ṣèmúkúrò àwọn nkan díẹ̀ tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Updates are available, but we temporarily need %1 MB-%2 MB of space to download. Remove some things you don't need right now and we'll try again. |
1001 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n a nílò ààyè %1 MB-%2 GB fún ìgbà díẹ̀ láti gba ẹ̀dà fáìlì. Ṣèmúkúrò àwọn nkan díẹ̀ tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Updates are available, but we temporarily need %1 MB-%2 GB of space to download. Remove some things you don't need right now and we'll try again. |
1002 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n a nílò ààyè %1 GB-%2 GB fún ìgbà díẹ̀ láti gba ẹ̀dà fáìlì. Ṣèmúkúrò àwọn nkan díẹ̀ tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Updates are available, but we temporarily need %1 GB-%2 GB of space to download. Remove some things you don't need right now and we'll try again. |
1003 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n a nílò ààyè %1 MB fún ìgbà díẹ̀ láti gba ẹ̀dà fáìlì. Ṣèmúkúrò àwọn nkan díẹ̀ tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Updates are available, but we temporarily need %1 MB of space to download. Remove some things you don't need right now and we'll try again. |
1004 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n a nílò ààyè %1 GB fún ìgbà díẹ̀ láti gba ẹ̀dà fáìlì. Ṣèmúkúrò àwọn nkan díẹ̀ tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Updates are available, but we temporarily need %1 GB of space to download. Remove some things you don't need right now and we'll try again. |
1005 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n a nílò ààyè díẹ̀ fún ìgbà díẹ̀ láti gba ẹ̀dà fáìlì. Ṣèmúkò àwọn nkan tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Updates are available, but we temporarily need some space to download. Remove some things you don't need right now and we'll try again. |
1102 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n a nílò ààyè díẹ̀ fún ìgbà díẹ̀ láti ṣàgbékalẹ̀. Ṣèmúkúrò àwọn nkan tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Updates are available, but we temporarily need some space to install. Remove some things you don't need right now and we'll try again. |
1200 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 MB-%2 MB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ Wi-Fi àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 MB-%2 MB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered Wi-Fi for some updates. |
1201 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 MB-%2 GB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ Wi-Fi àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 MB-%2 GB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered Wi-Fi for some updates. |
1202 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 GB-%2 GB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ Wi-Fi àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 GB-%2 GB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered Wi-Fi for some updates. |
1203 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 MB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ Wi-Fi àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 MB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered Wi-Fi for some updates. |
1204 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 GB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ Wi-Fi àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 GB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered Wi-Fi for some updates. |
1205 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba wọ́n báyìí nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ Wi-Fi àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can get them now using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered Wi-Fi for some updates. |
1300 | A kò le ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún kan nítori o kò wọlé sínú PC náà. | We couldn't install some updates because you weren't logged on to the PC. |
1301 | A kò le ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún kan nípa lílo àkọọ́lẹ̀ náà tí o fi wọlé. Gbìyànjú wíwọlé pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ míràn. | We couldn't install some updates using the account you're signed in with. Try signing in with another account. |
1302 | A kò fún PC yìí ní àṣẹ láti gba àwọn àfikún kan, ó ṣeéṣe nítorí àfikún kan sí ẹ̀yà Windows míràn ń gbìyànjú láti ṣàgbékalẹ̀. A ó máa gbìyànjú láti ṣàfikún. | This PC isn't authorized to get some updates, possibly because an upgrade to a different edition of Windows is trying to install. We'll keep trying to update. |
8000 | Àwọn ìṣòro kan jẹyọ nígbàtí a ń ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún díẹ̀, ṣùgbọ́n a ó gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. Tí o bá sì ń rí èyí tí o sì sẹ́ ṣàwárí wẹ́ẹ̀bù náà tàbí kàn sí àtìlẹ́yìn fún ìwífún, èyí le ṣèrànwọ́: | There were problems installing some updates, but we'll try again later. If you keep seeing this and want to search the web or contact support for information, this may help: |
8001 | • %1 - Àṣìṣe %2 | • %1 - Error %2 |
8002 | Àwọn ìṣòro kan jẹyọ nígbàtí a ń ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún díẹ̀, ṣùgbọ́n a ó gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. Tí o bá sì ń rí èyí tí o sì sẹ́ ṣàwárí wẹ́ẹ̀bù náà tàbí kàn sí àtìlẹ́yìn fún ìwífún, èyí le ṣèrànwọ́: (%1) | There were some problems installing updates, but we'll try again later. If you keep seeing this and want to search the web or contact support for information, this may help: (%1) |
8003 | A ti rí àwọn ìṣòro díẹ̀. Yan ìfiránṣẹ́ yìí láti yanjú kí o sì parí ìṣàfikún. | We found some issues. Select this message to fix and finish updating. |
8004 | A kò le ṣàyẹ̀wò fún àwọn àfikún, nítorí o kò sopọ̀ mọ́ Íntánẹ́ẹ̀tì náà. Ṣàrídájú pé o ní dátà sẹ́lúlà kan tàbí ìsopọ̀ Wi-Fi kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We couldn't check for updates, because you aren't connected to the Internet. Make sure you have a cellular data or Wi-Fi connection and try again. |
8005 | Ìsopọ̀ rẹ ni ìrìnkiri. A ó gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá ní aládàáṣe. | Your connection is roaming. We'll try again later automatically. |
8006 | A kò le ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún kan nítorí àwọn àfikún míràn ń tẹ̀síwájú. Ìṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kọ̀npútà rẹ le ṣèrànwọ́, a ó sì máa gbìyànjú láti ṣàfikún. | We can't install some updates because other updates are in progress. Restarting your computer may help, and we'll keep trying to update. |
8007 | A kò le parí gbígba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún nítorí ìsopọ̀ Íntánẹ́ẹ̀ti ti sọnù. Ṣàrídájú pé o sopọ̀ a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We couldn't finish downloading updates because the Internet connection was lost. Make sure you're connected and we'll try again later. |
8008 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n wọ́n ti tóbi jù láti gbà lórí ìsopọ̀ ìsinsìnyí. A ó gba ẹ̀dà àwọn àfikún kété tí o bá sopọ̀ mọ́ Wi-Fi. | Updates are available, but they are too big to download over your current connection. We'll download the updates as soon as you connect to Wi-Fi. |
8009 | A kò le gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún kan nítorí o ti jáde nínú àkọọ́lẹ̀ rẹ. Wọlé pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ rẹ, gbìyànjú àfikún lẹ́ẹ̀kan síi, kí o sì wà ní ìwọlé ní àkókò gbígba ẹ̀dà fáìlì. | We couldn't download some updates because you were signed out of your account. Sign in with your account, try the update again, and stay signed in during the download. |
8010 | Battery Saver is on, so we've paused downloads. We'll resume when Battery Saver is off or click the ‘Download’ button to do it now. | Battery Saver is on, so we've paused downloads. We'll resume when Battery Saver is off or click the ‘Download’ button to do it now. |
8011 | Àwọn ìṣòro kan jẹyọ nígbàtí a ń gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún kan, ṣùgbọ́n a ó tún gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. Tí o bá sì ń rí èyí, gbìyànjú wíwá wẹ́ẹ̀bù tàbí kàb sí àtìlẹ́yìn fún ìrànwọ́. Kóòdù àfìkùnàhàn yìí le ṣèrànwọ́: (%1) | There were problems downloading some updates, but we'll try again later. If you keep seeing this, try searching the web or contacting support for help. This error code might help: (%1) |
8014 | A kò le gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún nítorí àwọn ìṣòro alásopọ̀. A ó máa gbìyànjú láti gba ẹ̀dà fáìlì. | We couldn't download updates because of network problems. We'll keep trying to download. |
8015 | A kò le ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún kan nítorí PC náà wà ní pípa. | We couldn't install some updates because the PC was turned off. |
8016 | Adarí aláìrídìmú ìsinsìnyí kan lórí PC rẹ le dára ju adarí aláìrídìmú tí a ń gbìyànjú láti ṣàgbékalẹ̀ lọ. A ó máa gbìyànjú láti ṣàgbékalẹ̀. | A current driver on your PC may be better than the driver we're trying to install. We'll keep trying to install. |
8017 | Àwọn àfikún kan ni a ti parẹ́. A ó máa gbìyànjú tó bá ṣẹlẹ̀ pé àwọn àfikún míràn bá wà. | Some updates were cancelled. We'll keep trying in case new updates become available. |
8019 | A ní láti ṣe àwọn àyípadà kan sí àfikún rẹ. A ó máa gbìyànjú síi. | We need to make some changes to your update. We'll keep trying. |
8020 | Jọ̀wọ́ ràn wá lọ́wọ́ láti yanjú àwọn nkan díẹ̀ tí ń dènà àfikún rẹ. | Please help us fix some things that are blocking your update. |
8021 | Ibi ìpamọ́ náà tí a ti ń gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún ti yípadà. Ṣàrídájú pé àwo aká-ọ̀rọ̀ kankan tàbí káàdì ààyè ìrántí ni o kò yọkúrò nígbàtí o ń gba ẹ̀dà fáìlì. | The storage location where updates were downloading changed. Make sure any drives or memory cards aren't removed while updates are downloading. |
8022 | Láti ṣàgbékalẹ̀ àfikún yìí, faramọ́ Àwọn Ìfẹnukò Ìgbàláyè Ẹ̀yà Àìrídìmú titun. | To install this update, accept the new Software License Terms. |
8023 | A kò le sopọ̀ mọ́ ìpèsè àfikún náà. A ó gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá, tàbí o le ṣàyẹ̀wò báyìí. Tí kò bá síi ṣiṣẹ́, ṣàrídájú pé o sopọ̀ mọ́ Íntánẹ́ẹ̀tì náà. | We couldn't connect to the update service. We'll try again later, or you can check now. If it still doesn't work, make sure you're connected to the Internet. |
8024 | A nílò ààyè díẹ̀ fún ìgbà díẹ̀ láti gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún rẹ. Jọ̀wọ́ ṣèmúkúrò àwọn nkan díẹ̀ tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We temporarily need more space to download your updates. Please remove some things you don't need right now and we'll try again. |
8025 | A nílò ààyè díẹ̀ fún ìgbà díẹ̀ láti ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún rẹ. Jọ̀wọ́ ṣèmúkúrò àwọn nkan díẹ̀ tí o kò nílò báyìí a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We temporarily need more space to install your updates. Please remove some things you don't need right now and we'll try again. |
8026 | A ń dojúkọ àwọn ìṣòro kan láti gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún. Ṣíṣe àtúnbẹ̀rẹ̀ ohun èlò rẹ le ṣèrànwọ́. | We're having some trouble downloading updates. Restarting your device may help. |
8027 | O le ti ṣèparẹ́ àwọn fáìlì àfikún díẹ̀ kí o tó le ṣàgbékalẹ̀ wọ́n. A ó gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún náà fún ọ tí o bá sì nílò wọn. | You may have deleted some update files before they could be installed. We'll download those files for you if you still need them. |
8028 | Àwọn fáìlì àfikún kan ni a kò buwọ́lù dáradára.
Kóòdù àfikùnànhàn: (%1) |
Some update files aren't signed correctly.
Error code: (%1) |
8029 | Ṣàrídájú pé ìsopọ̀ Íntánẹ́ẹ̀tì rẹ kìíṣe àlòsanwó tàbí rìn kiri, kí o sì gbìyànjú láti gba ẹ̀dà fáìlì àfikún lẹ́ẹ̀kan síi.
Kóòdù àfikùnànhàn: (%1) |
Make sure your Internet connection isn't metered or roaming, and try downloading updates again.
Error code: (%1) |
8030 | Àwọn àfikún kan kò parí gbígba ẹ̀dà fáìlì. A ó máa gbìyànjú.
Kóòdù àfikùnànhàn: (%1) |
Some updates didn't finish downloading. We'll keep trying.
Error code: (%1) |
8031 | A kò le parí àfikún náà. Gbìyànjú títún ohun èlò rẹ bẹ̀rẹ̀ a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi.
Kóòdù àfikùnànhàn: (%1) |
We can't finish the update. Try restarting your device and we'll try again.
Error code: (%1) |
8032 | Àwọn fáìlì àfikún kan ti sọnù tàbí ní ìṣòro. A ó gbìyànjú láti gba ẹ̀dà fáìlì àfikún náà lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá.
Kóòdù àfikùnànhàn: (%1) |
Some update files are missing or have problems. We'll try to download the update again later.
Error code: (%1) |
8033 | A kò le gba àwọn àfikún. Ṣàrídájú pé o sopọ̀ mọ́ alásopọ̀ ti ilé-iṣẹ́ rẹ kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We couldn't get updates. Make sure you are connected to your organization's network and try again. |
8034 | Ti tan Olùtọ́jú Bátìrì. Fi ohun èlò rẹ bọ iná kí o tó ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún. | Battery Saver is turned on. Plug in your device before you install updates. |
8035 | Láti ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún, a nílò bátìrì rẹ kó gba iná sára tó 40%. | To install updates, we need your battery charged to 40%. |
8036 | A kò le ṣàyẹ̀wò fún àwọn àfikún, nítorí o kò sopọ̀ mọ́ Íntánẹ́ẹ̀tì náà. Ṣàrídájú pé o ní dátà sẹ́lúlà kan tàbí ìsopọ̀ WLAN kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We couldn't check for updates, because you aren't connected to the Internet. Make sure you have a cellular data or WLAN connection and try again. |
8037 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀, ṣùgbọ́n wọ́n ti tóbi jù láti gbà lórí ìsopọ̀ ìsinsìnyí. A ó gba ẹ̀dà àwọn àfikún kété tí o bá sopọ̀ mọ́ WLAN. | Updates are available, but they are too big to download over your current connection. We'll download the updates as soon as you connect to WLAN. |
8038 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 MB-%2 MB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ WLAN àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 MB-%2 MB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered WLAN for some updates. |
8039 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 MB-%2 GB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ WLAN àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 MB-%2 GB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered WLAN for some updates. |
8040 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 GB-%2 GB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ WLAN àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 GB-%2 GB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered WLAN for some updates. |
8041 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 MB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ WLAN àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 MB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered WLAN for some updates. |
8042 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba ẹ̀dà fáìlì %1 GB nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ WLAN àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can download %1 GB using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered WLAN for some updates. |
8043 | Àwọn àfikún ti wà nílẹ̀. A ó gba ẹ̀dà fáìlì wọn nígbàtí o kò lo ìsopọ̀ àlòsanwó, tàbí o le gba wọ́n báyìí nípa lílo ìsopọ̀ dátà rẹ ìsinsìnyí (a le ṣàmúlò ìdíyelé). O sì le ní láti sopọ̀ mọ́ WLAN àìlòsanwó fún àwọn àfikún kan. | Updates are available. We'll download them when you are not using a metered connection, or you can get them now using your current data connection (charges might apply). You might still need to connect to unmetered WLAN for some updates. |
8044 | A kò le ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún náà nítorí ìṣòro kan jẹyọ pẹ̀lú ìwífún déètì àti àkókò lórí ohun èlò rẹ. Ṣàrídájú pé déètì, àkókò, àti àwọn ààtò agbègbè àkókò tọ̀nà a ó sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. | We couldn't install updates because there's a problem with the date and time information on your device. Make sure your date, time, and time zone settings are correct and we'll try again later. |
8045 | A ó gba ẹ̀dà fáìlì àwọn àfikún, nígbà míràn tí o bá wọ iná tàbí ṣáà ṣíra tẹ bọ́tìnnì 'gba ẹ̀dà fáìlì' láti ṣe bẹ́ẹ̀ báyìí | We'll download updates next time you're plugged in or just click the 'download' button to do it now |
8046 | A ó ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún nígbà míràn tí o bá wọ iná tàbí ṣáà ṣíra tẹ bọ́tìnnì 'ṣàgbékalẹ̀' láti ṣe bẹ́ẹ̀ báyìí | We'll install updates next time you're plugged in or just click the 'install' button to do it now |
8047 | An update is being prepared for your device, but it’s not quite ready yet. We'll keep trying or you can try again now. | An update is being prepared for your device, but it’s not quite ready yet. We'll keep trying or you can try again now. |
File Description: | Ìmúṣiṣẹ́ Olùmú Àwọn Ààtò Àfikún Ìgbàlódé |
File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
Company Name: | Microsoft Corporation |
Internal Name: | MusUpdateHandlers.dll |
Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́. |
Original Filename: | MusUpdateHandlers.dll.mui |
Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
Product Version: | 10.0.15063.0 |
Translation: | 0x46A, 1200 |