| 202 | Àwọn àkóónú wẹ́ẹ̀bù kan láti {0} ni a ti dènà. Bèèrè láti wo àkóónú náà. | 
                                    Some web content from {0} has been blocked. Ask to view the content. | 
                                                            | 203 | A ti dènà àwọn àkóónú wẹ́ẹ̀bù kan. Bèèrè láti wo àkóónú náà. | 
                                    Some web content has been blocked. Ask to view the content. | 
                                                            | 204 | Àwọn àkóónú wẹ́ẹ̀bù kan láti {0}le má dára pẹ̀lú òbí rẹ. | 
                                    Some web content from {0} might not be OK with your parent. | 
                                                            | 205 | Àwọn àkóónú wẹ́ẹ̀bù kan le má dára pẹ̀lú òbí rẹ. | 
                                    Some web content might not be OK with your parent. | 
                                                            | 310 | {0} lórí i {1} | 
                                    {0} on {1} | 
                                                            | 311 | {0} | 
                                    {0} | 
                                                            | 350 | Ẹbí rẹ ń lo àwọn àfidámọ̀ ẹbí Microsoft | 
                                    Your family is using Microsoft family features | 
                                                            | 351 | A ó tì ọ̀ síta ní {0} lórí i {1}. | 
                                    You'll be locked out at {0} on {1}. | 
                                                            | 352 | Àwọn òdíwọ̀n àkókò aṣàfihàn wà ní pípa. | 
                                    Screen time limits are off. | 
                                                            | 353 | Àwọn òdíwọ̀n àkókò aṣàfihàn wà ní pípa títí {0} lórí {1}. | 
                                    Screen time limits are off until {0} on {1}. | 
                                                            | 400 | Ó kéré sí ìṣẹ́jú 15 tí ó kù | 
                                    Less than 15 minutes left | 
                                                            | 401 | Ó kéré sí ìṣẹ́jú 2 tí ó kù | 
                                    Less than 2 minutes left | 
                                                            | 410 | Ohun èlò yìí yóò tì láìpẹ́ nítorí àwọn ààtò ẹbí rẹ fún àkókò aṣàfihàn. Jọ̀wọ́ parí ohun tí o ń ṣe tàbí bèrè lọ́wọ́ àgbàlagbà kan láti fọwọ́sí àkókò síwájú síi. | 
                                    This device will lock soon because of your family settings for screen time. Please finish what you are doing or ask an adult to approve more time. | 
                                                            | 420 | Pa dé | 
                                    Close | 
                                                            | 421 | Fi ìbéèrè ránṣẹ́ | 
                                    Send a request | 
                                                            | 422 | Òbí mí wà níbí | 
                                    My parent is here | 
                                                            | 423 | Fún láàyè | 
                                    Allow | 
                                                            | 424 | Gba àkókò díẹ̀ síi | 
                                    Get more time | 
                                                            | 425 | Paá rẹ́ | 
                                    Cancel | 
                                                            | 426 | Ṣe ìsípòpadà àwọn aṣàmúlò tàbí pa PC | 
                                    Switch users or turn off PC | 
                                                            | 430 | Ti dènà nípaṣẹ̀ àwọn àfidámọ̀ ẹbí Microsoft | 
                                    Blocked by Microsoft family features | 
                                                            | 440 | ìsẹ́jú 15 | 
                                    15 minutes | 
                                                            | 441 | Ìsẹ́jú 30 | 
                                    30 minutes | 
                                                            | 442 | Wákàtí 1 | 
                                    1 hour | 
                                                            | 443 | Wákàtí 2 | 
                                    2 hours | 
                                                            | 444 | Wákàtíi 4 | 
                                    4 hours | 
                                                            | 445 | Wákàtí 8 | 
                                    8 hours | 
                                                            | 450 | Ìpèsè kò sí nílẹ̀ | 
                                    Service unavailable | 
                                                            | 451 | Má bìínú, ìpèsè náà kò sí nílẹ̀ nísìnyí. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi láìpẹ́. | 
                                    Sorry, the service isn't available right now. Please try again later. | 
                                                            | 452 | Nítorí pé ìwọ ni alábòójútó lórí ohun èlò yìí, wàá ní láti fi ìbéèrè kan ránṣẹ́ fún ọ̀pọ̀ àkókò aṣàfihàn. | 
                                    Since you are an administrator on this device, you'll need to send a request for more screen time. | 
                                                            | 507 | Ǹjẹ́ àwọn òbí rẹ wà níbí nísinyí? | 
                                    Is your parent here right now? | 
                                                            | 510 | A máa fààyègba {0}láti ṣàbẹ̀wò sí ojú-òpó-wẹ́ẹ̀bù yìí: | 
                                    {0} will be allowed to visit this website: | 
                                                            | 511 | O le ṣe ìdádúró aṣàkókò fúngbàdíẹ̀ tí {0} bá nílò àníkún àkókò láti lo kọ̀ǹpútà náà. | 
                                    You can pause the timer temporarily if {0} needs some extra time to use the PC. | 
                                                            | 512 | [{0}] | 
                                    [{0}] | 
                                                            | 513 | Fẹ̀ nípaṣẹ̀: | 
                                    Extend by: | 
                                                            | 516 | A máa fààyègba {0} láti lo: | 
                                    {0} will be allowed to use: | 
                                                            | 517 | Ti ṣòdiwọ̀n fún: {0}+ | 
                                    Rated for: {0}+ | 
                                                            | 518 | Fààyègba lílo gbogbo {0} | 
                                    Allow the use of all of {0} | 
                                                            | 1101 | Àkókò ti tó! | 
                                    Time's up! | 
                                                            | 1102 | Ohun èlò yìí ni a tìpa nítorí àwọn ààtò ẹbí rẹ fún àkókò aṣàfihàn. O ní láti bèrè lọ́wọ́ àgbàlagbà kan tí o bá fẹ́ ọ̀pọ̀ àkókò lónìí. | 
                                    This device is locked because of your family settings for screen time. You need to ask an adult if you want more time today. | 
                                                            | 1103 | Ohun èlò yìí ni a tìpa nítorí àwọn ààtò ẹbí rẹ fún àkókò aṣàfihàn. O le lòó lẹ́ẹ̀kan síi ní {0} lórí {1}, tàbí bèrè lọ́wọ́ àgbàlagbà kan fún àkókò síi lónìí. | 
                                    This device is locked because of your family settings for screen time. You can use it again at {0} on {1}, or ask an adult for more time today. | 
                                                            | 1501 | Bèèrè lọ́wọ́ òbí fún ìyànda | 
                                    Ask a parent for permission | 
                                                            | 1521 | Fààyègba àtòjọ ètò {0} | 
                                    Allow an application from {0} | 
                                                            | 1522 | Fààyègba ayò kan láti {0} | 
                                    Allow a game from {0} | 
                                                            | 1523 | Fààyègba ojú-òpó-wẹ́ẹ̀bù | 
                                    Allow a website | 
                                                            | 1524 | Fààyègba fíìmù kan láti {0} | 
                                    Allow a movie from {0} | 
                                                            | 1525 | Fààyègba àkọlé TV kan láti {0} | 
                                    Allow a TV episode from {0} | 
                                                            | 1526 | Fààyègba orin kan láti {0} | 
                                    Allow a song from {0} | 
                                                            | 1527 | Fààyègba àkóónú kan láti {0} | 
                                    Allow content from {0} | 
                                                            | 1528 | Fààyègba àtòjọ ètò | 
                                    Allow an application | 
                                                            | 1529 | Fààyègba ayò kan | 
                                    Allow a game | 
                                                            | 1530 | Àṣìṣe kan ti wáyé | 
                                    An error has occurred | 
                                                            | 1531 | Àṣìṣe tí àìròtẹ́lẹ̀ ti wáyé. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi láìpẹ́. | 
                                    An unexpected error has occurred. Please try again later. | 
                                                            | 1532 | A ti dènà ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí | 
                                    This app is blocked | 
                                                            | 1533 | O gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ ṣàfipamọ́ ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí. Ṣàfipamọ́ rẹ̀ sí ibi tí ó yàtọ̀ sí fódà Temp, lẹ́yìn èyí kí o wá bèèrè ìyàǹda obi láti lòó | 
                                    You must save this app on your PC first. Save it somewhere other than the Temp folder, and then ask for a parent's permission to use it. | 
                                                            | 1540 | Ti fi ìbéèrè ránṣẹ́ | 
                                    Request sent | 
                                                            | 1541 | A ti fi ìbéèrè rẹ ránṣẹ́. Òbí re máa jẹ́ kí o mọ̀ bóyá a ti fún ọ ní ìyàndà. | 
                                    Your request has been sent. Your parent will let you know whether you have been given permission. | 
                                                            | 1560 | Fi ààyè díẹ̀ sílẹ̀? | 
                                    Give more time? | 
                                                            | 1581 | Bèèrè fún ìyànda láti lo {0}. | 
                                    Request permission to use {0}. | 
                                                            | 1591 | Ohun èlò yìí yóò ṣí nígbàtí àgbàlagbà kan bá fọwọ́sí ìbéèrè rẹ. | 
                                    This device will unlock when an adult approves your request. | 
                                                            | 1592 | Ohun èlò yìí yóò ṣí nígbàtí àgbàlagbà kan bá fọwọ́sí ìbéèrè rẹ, tàbí ní {0} lórí {1}, èyíkéyìí tó bá kọ́kọ́ yọjú. | 
                                    This device will unlock when an adult approves your request, or at {0} on {1}, whichever comes first. | 
                                                            | 1593 | Ohun èlò yìí yóò tìpa ní {0} lórí {1} àyàfi tí àgbàlagbà kan bá fọwọ́sí ìbéèrè rẹ. Tí ó bá tìpa, yóò tún ṣí lẹ́ẹ̀kan síi lẹ́yìn tí àgbàlagbà kan bá fọwọ́sí ìbéèrè rẹ. | 
                                    This device will lock at {0} on {1} unless an adult approves your request. If it does lock, it will unlock again after an adult approves your request. | 
                                                            | 1594 | Ohun kan kò lọ déédé | 
                                    Something went wrong | 
                                                            | 1595 | A kò le fi ìbéèrè rẹ ránṣẹ́. Ṣé o sopọ̀ mọ́ Íntánẹ́ẹ̀tì bí? | 
                                    We were unable to send your request. Are you connected to the Internet? | 
                                                            | 32000 | Ẹbí | 
                                    Family | 
                                                            | 32014 | Microsoft Corporation | 
                                    Microsoft Corporation | 
                                                            | 32015 | Ń bẹ̀rẹ̀ ṣíṣàbójútó Ààbò Ẹbí àti ìfipamíṣiṣẹ́. | 
                                    Initializes Family Safety monitoring and enforcement. |