If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id |
Yoruba |
English |
101 | Àgbékalẹ̀-ètò kò parí. Ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ PC rẹ. |
Setup incomplete. Restart your PC. |
103 | Adárí aláríìdímú kò sí nílẹ̀ |
Driver is unavailable |
104 | @DeviceDisplayStatusManager.dll,-102 |
@DeviceDisplayStatusManager.dll,-102 |
105 | Ìlànà ẹgbẹ́ ti dènà àgbékalẹ̀-ètò |
Setup blocked by group policy |
106 | Kò baramu pẹ̀lú ẹ̀yà Windows yìí |
Not compatible with this version of Windows |
110 | Ń ṣàyọkúrò ohun èlò |
Removing device |
111 | Ìṣàyọkúrò ti kùnà |
Remove failed |
112 | Kò le ṣàyọkúrò ohun èlò yìí lákóòkò lílo rẹ̀. |
Can’t remove this device while it’s in use. |
114 | Àgbékalẹ̀-ètò kò parí. Somọ́ íntánẹ̀ẹ̀tì. |
Setup incomplete. Connect to the Internet. |
115 | Wọlé sí Ìtàjà oníforíkorí Windows láti ṣàgbékalẹ̀ ìṣàfilọ́lẹ̀ ohun èlò. |
Sign-in to Windows Store to install the device app. |
118 | ìṣàgbékalẹ̀ ìṣàfilọ́lẹ̀ ohun èlò kò parí. Lọ sí Ìtàjà oníforíkorí Windows fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ àlàyé. |
Device app install incomplete. Go to Windows Store for details. |
119 | Kò somọ́ |
Not connected |
120 | Àgbékalẹ̀-ètò kò parí. Somọ́ Íntánẹ̀ẹ̀tì. |
Setup incomplete. Connect to the Internet. |
121 | Àgbékalẹ̀-ètò kò parí nítorí ìsomọ́ onímítà. |
Setup incomplete because of a metered connection. |
128 | Ti ṣàsopọ̀ |
Paired |