| 1 | Ààbò àti Ìṣàbójútó |
Security and Maintenance |
| 2 | Ṣe agbéyẹ̀wò àwọn iṣẹ́ tuntun kí o sì ṣe àtúnse si ìsòro pẹ̀lú kọ̀ǹpútà rẹ. |
Review recent messages and resolve problems with your computer. |
| 3 | Ètò yìí ní ìdádúró nípa ètò àlàyé ẹgbẹ́. Fún ọ̀pọ̀ ìwífún, kànsí alábòójútó ẹrọ rẹ. |
This program is blocked by group policy. For more information, contact your system administrator. |
| 4 | Ṣe agbéyẹ̀wò àwọn iṣẹ́ tuntun kí o sì ṣe àtúnse si ìsòro |
Review recent messages and resolve problems |
| 5 | ààyè iṣẹ́ |
Task pane |
| 6 | Ó nílòo àwọn ànfàníi alábòójútó |
Administrator privileges required |
| 7 | Ìrànwọ́ |
Help |
| 8 | Ṣàyípadà Àwọn Ààtò Ààbò àti Ìṣàbójútó |
Change Security and Maintenance settings |
| 9 | Àwọn Ààtò Ààbò àti Ìṣàbójútó |
Security and Maintenance Settings |
| 11 | wà nípò àìseélò |
Disabled |
| 20 | àyẹ̀wò rẹ ko seélò láti ọwọ́ alábòójútó |
Your administrator has disabled this check |
| 21 | Tàn án iṣẹ́ Nípa (iṣẹ́ náà) sílẹ̀ %1 |
Turn on messages about %1 |
| 22 | A kò bójúto lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Currently not monitored |
| 29 | %1!d! Iṣẹ́ nílò o ìfojúsíì rẹ |
%1!d! message needs your attention |
| 31 | %1!d! Àwọn iṣẹ́ nílò o ìfojúsíì rẹ |
%1!d! messages need your attention |
| 33 | ... |
... |
| 34 | Fún ìkọ̀kan wúnrẹ̀n tí o yàn, Windows yóò ṣàyẹ̀wò fún àwọn ìṣòro yóò sì fi ìfiránṣẹ́ kan ránṣẹ́ sí ọ tí o bá rí àwọn ìṣòro náà. Bàwo ní Àwọn Ààtò Ààbò àti Ìṣàbójútó se ṣàyẹ̀wò fún ìsòro? |
For each selected item, Windows will check for problems and send you a message if problems are found. How does Security and Maintenance check for problems? |
| 37 | Bàwo ní èmi yoo se mọ̀ ààbò ti ààtò fún Kọ̀ǹpútà mi? |
How do I know what security settings are right for my computer? |
| 38 | àwọn ìrántí Windows Update |
Windows Update reminders |
| 39 | Ètò ààbò Íntánẹ́ẹ̀tì |
Internet security settings |
| 40 | ètò ààbò alásopọ̀ |
network firewall |
| 41 | Ìdábòbò lórí Sípáìwià àti àwọn ẹ̀yà àìrídìmú kòkòrò mìíràn |
spyware and unwanted software protection |
| 42 | Ìdarí Àkọọ́lẹ̀ Aṣàmúlò |
User Account Control |
| 43 | Ààbò kòkòrò |
virus protection |
| 44 | Ẹ̀dà Àbọ̀ábá Windows |
Windows Backup |
| 45 | Àwọn Ìbójútó iṣẹ́ Windows |
Windows maintenance tasks |
| 47 | Yẹ àyẹ̀wò |
test check |
| 48 | Pá àwọn iṣẹ́ nípa %1 |
Turn off messages about %1 |
| 54 | Windows Update |
Windows Update |
| 59 | Awójúùtú ìṣòro Ìbáramu Àtòjọ-ètò Windows |
Windows Program Compatibility Troubleshooter |
| 60 | (kókó) |
(Important) |
| 61 | Wo àwọn iṣẹ́ ibi-ìpamọ ọlọ́jọ́pípẹ́ |
View archived messages |
| 62 | Ìtàn Fáìlì |
File History |
| 70 | Ṣàtúnṣe àwọn ètò ààyè aṣàmúlò ètò Ìdarí |
Change User Account Control settings |
| 81 | Ìṣàbójútó Aládàáṣe |
Automatic Maintenance |
| 82 | AlájọṣeLábẹ́le |
HomeGroup |
| 83 | ìsọ di aṣiṣẹ́ Windows |
Windows activation |
| 84 | Ipò àwo àká-ọ̀rọ̀ |
Drive status |
| 85 | Àkọọ́lẹ̀ Microsoft |
Microsoft account |
| 86 | Àwọn ìṣàfilọ̀lẹ̀ ìbẹ̀rẹ̀ |
startup apps |
| 87 | Ohun-èlò àìrídìmú |
Device software |
| 88 | Ààyè Ìfi-nnkan-pamọ́-sí |
Storage Spaces |
| 89 | Àwọn fódà Iṣẹ́ |
Work Folders |
| 500 | ọ̀pọ̀ nínú ìlànà ètò ìṣàyẹ̀wò kò tíì bẹ̀rẹ̀. |
Some of your system checks have not been initialized. |
| 501 | Pá àwọn iṣẹ́ báyìí |
Turn off messages like this |
| 502 | Kò sí àwọn ìṣòro tí a rí nípasẹ̀ Ààbò àti Ìṣàbójútó. |
No issues have been detected by Security and Maintenance. |
| 503 | Ààbò àti Ìṣàbójútó ti rí ṣàwárí ọ̀kan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn ìṣòro fún ọ láti ṣàtúnwò. |
Security and Maintenance has detected one or more issues for you to review. |
| 504 | &Ìbójútó |
&Maintenance |
| 506 | Tọ́gùlù Ìbójútó ìwọ́pọ̀ |
Toggle Maintenance Group |
| 507 | ṣàfihàn tàbí kí o ṣèpamọ́ tí Ìbójútó ìwọ́pọ̀ |
Show or hide the Maintenance group |
| 508 | Ṣàfihàn gbogbo àwọn iṣẹ́ |
Show all messages |
| 509 | &Ààbò |
&Security |
| 511 | Tọ́gùlù ààbò ìwọ́pọ̀ |
Toggle Security Group |
| 512 | Ṣàfihàn tàbí kí o ṣèpamọ́ ààbò ìwọ́pọ̀ |
Show or hide the Security group |
| 514 | Ninu àkọ́sílẹ̀ yí tí o ko bari ìṣòro rẹ,gbìyànjú ìkan nínu àwọn wọ̀nyí: |
If you don't see your problem listed, try one of these: |
| 518 | Wíwá àléé&bù |
Tr&oubleshooting |
| 520 | Tàn án àwọn iṣẹ́ sí tàn àbí pa |
Turn messages on or off |
| 521 | Ìbójútó àwọn iṣẹ́ |
Maintenance messages |
| 523 | Àgbétẹ́lẹ̀ Windows |
Windows Backup |
| 525 | Wíwá àléébù Windows |
Windows Troubleshooting |
| 526 | Ààbò àwọn iṣẹ́ |
Security messages |
| 535 | Ó DÁA |
OK |
| 537 | Paá rẹ́ |
Cancel |
| 539 | | |
| |
| 555 | Ìrànwọ́ àgbékalẹ̀ ààbò |
Security settings help |
| 556 | Wá kí o sì yànjú àwọn ìsòro |
Find and fix problems |
| 557 | Ìdáp&adà |
&Recovery |
| 558 | Ṣe ìdápadà PC rẹ sí àsìkò ìbẹ̀rẹ̀ |
Refresh your PC without affecting your files, or reset it and start over. |
| 561 | Wíwá àléébù |
Troubleshooting |
| 562 | Ìdápadà |
Recovery |
| 564 | Ààbò |
Security |
| 565 | Ìbójútó |
Maintenance |
| 576 | Apps Ìbèèrè |
Startup apps |
| 0x10000031 | Response Time |
Response Time |
| 0x30000001 | Start |
Start |
| 0x30000002 | Stop |
Stop |
| 0x50000004 | Information |
Information |
| 0x90000001 | Microsoft-Windows-HealthCenterCPL |
Microsoft-Windows-HealthCenterCPL |