File name: | appwiz.cpl.mui |
Size: | 30720 byte |
MD5: | dcec005e34a0e9d9e2c60ea36e15a085 |
SHA1: | c59f6f9cd7e00a44bc8fbd0ccfb35b3500fbfddf |
SHA256: | 282406c43277cc8d96c9d51b0935e9ee9b54a7c1b747f0a316793feb3ef2248f |
Operating systems: | Windows 10 |
Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id | Yoruba | English |
---|---|---|
21 | Ìwọ̀n | Size |
43 | Orúkọ | Name |
68 | %1 fún %2 (%3) | %1 for %2 (%3) |
69 | Microsoft Windows | Microsoft Windows |
70 | Àfikún Pàtàkì | Critical Update |
71 | Họtifix | Hotfix |
72 | Àfikún Ààbò | Security Update |
73 | Àkójọpọ̀ Ohun èlò isẹ́ | Service Pack |
74 | Àfikún Sọ́fítìwià | Software Update |
75 | Ṣàfikún | Update |
76 | Àkópọ̀ Àfikún | Update Rollup |
77 | Adarí aláìrídìmú | Driver |
83 | Ìrànwọ́ | Help |
89 | Jọ̀wọ́ dúró... | Please wait... |
95 | Ìlànà àtojọ-ètò kan ń tọ́ka sí àwọn àtòjọ-ètò àkọ́yàn fún àwọn iṣẹ́ kan, bíi wíwá Wẹ́ẹ̀bù tàbí fífí ímeèlì ráńsẹ́, àwọn ètò yíí ni a lè ráyèsí láti mẹ́nù Ìbẹ̀rẹ̀, àtẹ iṣẹ́, àti àwọn ibi mìíràn.
Yan ìlànà kan: |
A program configuration specifies default programs for certain activities, such as Web browsing or sending e-mail, and which programs are accessible from the Start menu, desktop, and other locations.
Choose a configuration: |
96 | Ó DÁA | OK |
97 | Paá rẹ́ | Cancel |
98 | Ń fi àwọn Ìyípadà sìí | Applying Changes |
99 | Ń fi ìgbàláyè síi: | Enabling access: |
100 | Ń yọ ìgbàláyè síi: | Removing access: |
101 | Ń se ààtò bíi ètò àìlèyípadà: | Setting as default application: |
102 | Olùse Kọ̀ǹpútà | Computer Manufacturer |
103 | Se àtúntò àwọn ètò tí olùro ẹ̀rọ kọ̀ǹpútà ti tọka sí gẹ́gẹ́ bí àkùnàyàn, àti fi àwọn àyè sílẹ̀ tàbí yọ àwọn ètò ìsàlè yìí. | Sets programs specified by your computer manufacturer as defaults, and enables or removes access to the programs shown below. |
104 | %MICROSOFT_COMPANYNAME% %WINDOWS_GENERIC% | %MICROSOFT_COMPANYNAME% %WINDOWS_GENERIC% |
105 | Se àtúntò àwọn ètò tí a fi kún %MICROSOFT_COMPANYNAME% %WINDOWS_GENERIC% agẹgẹ bí àkùnàyàn, àti fi àwọn àyè sílè tàbí yọ ànfàní àti lè rí àwọn ètò ìsàlè yìí. | Sets programs included in %MICROSOFT_COMPANYNAME% %WINDOWS_GENERIC% as defaults, and enables or removes access to the programs shown below. |
106 | Kò sí-%MICROSOFT_COMPANYNAME% | Non-%MICROSOFT_COMPANYNAME% |
107 | Ṣètò àwọn tí kìí se-%MICROSOFT_COMPANYNAME% (tí wọn bá wà ní àrọwọtó) sí àkùnàyàn, yóò sì gbàláyè tàbí yọ ànfàní àti lè rí àwọn ètò ìsàlè yìí. | Sets non-%MICROSOFT_COMPANYNAME% programs (when available) as defaults, and enables or removes access to the programs shown below. |
108 | Ìbáffẹ̀ẹ́-ara-ẹni-mu | Custom |
109 | Àkíyèsí: Bí ètò kan kò bá dáhùn bí o ti fẹ láti sé tàbí yọ ànfàní láti lè rí ètò náà, jọwọ kànsí olùtà ètò náà. | Note: If a program does not respond to your choice to enable or remove access to it, please contact the vendor of that program. |
110 | Aṣàwárí wẹ́ẹ̀bù : | Web browser : |
111 | Lo aṣàwárí wẹ́ẹ̀bù mi tí mò ń lò lọwọ | Use my current Web browser |
112 | Yan Aṣàwárí wẹ́ẹ̀bù àkùnàyàn kan | Choose a default Web browser |
113 | Ètò í-meèlì : | E-mail program : |
114 | Lo ìlànà í-meèlì mi tí mò ń lò lọ́wọ́ | Use my current e-mail program |
115 | Yan ètò í-meèlì àkùnàyàn | Choose a default e-mail program |
116 | Òṣèrè Mídíà : | Media player : |
117 | Lo òṣèrè mídíà mi tí mò ń lò lọ́wọ́ | Use my current media player |
118 | Yan òṣèrè mídíà akùnàyàn | Choose a default media player |
119 | Ètò àkọránṣẹ́ ojú ẹsẹ̀ : | Instant messaging program : |
120 | Lo ètò àkọránṣẹ́ mi tí mò ń lò lọ́wọ́ | Use my current instant messaging program |
121 | Yan ètò àkọránṣẹ́ àkùnàyàn | Choose a default instant messaging program |
122 | Ẹ̀rọ ìfarajọ fún Java : | Virtual machine for Java : |
123 | Lo maṣíìnì àfojúinúṣe fún Java mi tí mò ń lò lọ́wọ́ | Use my current virtual machine for Java |
124 | Yan ẹ̀rọ ìfarahàn àkùnàyàn kan fún Java | Choose a default virtual machine for Java |
125 | Fi àyè làti dé ètò yìí sílẹ | Enable access to this program |
126 | Mú ìráyè wọlé sí ṣiṣẹ́: | Enable access: |
127 | Yọ ààyè kúrò: | Remove access: |
128 | %1, %2 | %1, %2 |
129 | O kò ní àsẹ láti se àgbékalẹ̀ ìgbàláàyè ètò àti àwọn akùnàyàn. | You do not have permission to set program access and defaults. |
130 | Ṣàgbékalẹ̀ Ìlànà Ìgbàwọlé àti ti àkùnàyàn orí Kọ̀ǹpútà | Set Program Access and Computer Defaults |
131 | Ń se ààtò àawọn Aláìlèyípadà... | Setting Defaults... |
132 | Yan Aṣàwárí wẹ́ẹ̀bù àkùnàyàn kan : | Choose a default web browser : |
133 | Yan ìlànà í-meèlì àkùnàyàn kan : | Choose a default e-mail program : |
134 | Yan òṣèrè mídíà àkùnàyàn kan : | Choose a default media player : |
135 | Yan ètò àkọránṣẹ́ àkùnàyàn : | Choose a default instant messaging program : |
136 | Yan ẹ̀rọ ìfarahàn àkùnàyàn kan fún Jáfà : | Choose a default virtual machine for Java : |
137 | Lo ètò Microsoft í-meèlì tí mò ńlò báàyí | Use my current Microsoft e-mail program |
138 | Fi àyè àgbékalẹ̀ ètò yìí sílẹ (%1) | Enable access to this program (%1) |
139 | Parser Error | Parser Error |
143 | Ti fisípò Lóríi | Installed On |
144 | Àṣìṣe kan wáyé nínú ìgbìyànjú àti yọ %1. Ó ti wà ní yíyọ. |
An error occurred while trying to uninstall %1. It has already been uninstalled. |
152 | Ńjẹ́ ó dá ẹ lójú pé o fẹ́ yọ àfikún yìí? | Are you sure you want to uninstall this update? |
155 | Gba àwọn ètò tuntun láti alásopọ̀ tàbí lóníforíkorí íntánẹ́ẹ̀tì. | Get new programs from the network or online. |
156 | Gba Àwọn Àtòjọ-ètò | Get Programs |
157 | Àwọn Àfikún tí a fi sórí ẹ̀rọ | Installed Updates |
158 | Yọ ètò kan kúrò | Uninstall a program |
159 | Àwọn Àtòjọ-ẹtò àti àbùdá | Programs and Features |
160 | Yọ tàbí yí àwọn ètò oríi kọ̀ǹpútà rẹ padà. | Uninstall or change programs on your computer. |
162 | Yọ tàbí yí àwọn ìbèrè yìí padà | Uninstall or change an application |
165 | Yọ́ nípò | Uninstall |
166 | Yọ ètò yìí kúrò. | Uninstall this program. |
167 | Yípadà | Change |
168 | Yí ìfisí ètò yìí padà. | Change the installation of this program. |
169 | Ṣàtúnse | Repair |
170 | Ṣàtúnse ìfisí ètò yìí. | Repair the installation of this program. |
171 | Yọ/Ṣàyípadà | Uninstall/Change |
172 | Yọ tàbí yí ètò yìí padà. | Uninstall or change this program. |
173 | &Yọ́ nípò | &Uninstall |
174 | &Yípadà | &Change |
175 | Ṣàtú&nse | R&epair |
176 | &Yọ/Ṣàyípadà | &Uninstall/Change |
177 | &Ṣàgbékalẹ̀ | &Install |
178 | Ṣàgbékalẹ̀ | Install |
179 | Máa ń fi ètò sípò | Installs a program |
180 | Yọ nípò tàbí ṣàyípadà ètò kan | Uninstall or change a program |
182 | Fi ètò kan láti alásopọ̀ sórí ẹ̀rọ | Install a program from the network |
183 | Your system administrator has disabled Programs and Features. | Your system administrator has disabled Programs and Features. |
184 | Yọ àfikún kan | Uninstall an update |
185 | Your system administrator has disabled Get Programs. | Your system administrator has disabled Get Programs. |
186 | Àwọn Àbùdá Windows | Windows Features |
187 | Tan àwọn àbùdá Windows tàbí kí o pa á. | Turn Windows features on or off. |
188 | Tan àwọn àbùdá Windows tàbí kí o pa á | Turn Windows features on or off |
189 | Láti tan àbùdá kan, tan iná sí àpótí ìyẹ̀wò rẹ. Láti pa àbùdá kan, palẹ̀ àpótí àyẹ̀wò rẹ mọ́. Bí àpótí àyẹ̀wò bá kún, ó túmọ̀ sí pé díẹ̀ nínú àbùdá rẹ ni ó wà ní títàn. | To turn a feature on, select its check box. To turn a feature off, clear its check box. A filled box means that only part of the feature is turned on. |
190 | System Restore | System Restore |
191 | Restores system to chosen restore point. | Restores system to chosen restore point. |
193 | Jọ̀wọ́ dúró Windows ńse àtúntò àwọn àbùdá lọ́wọ́. Èyí leè gba ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìsẹ́jú. | Please wait while Windows makes changes to features. This might take several minutes. |
194 | Àṣìṣe kan ti wáyé. Kìí se gbogbo àbùdá ni a ńrí pàrọ̀. | An error has occurred. Not all of the features were successfully changed. |
196 | Ń wá alásopọ̀ fún àwọn ètò tí ó wà... | Searching the network for available programs... |
197 | Kò sí àwọn ètò tí a lè fisi láti orí alásopọ̀. | There are no programs available to install from the network. |
200 | Ń fi àwọn ètò sípò lọ́wọ́lọ́wọ́ | Currently installed programs |
201 | %d àwọn ètò tí a ti fi sípò | %d programs installed |
202 | Ń fi àwọn àfikún sípò lọ́wọ́lọ́wọ́ | Currently installed updates |
203 | %d àwọn àfikún tí a ti fi sípò | %d updates installed |
204 | Àwọn ètò tí a lè rí lò | Available programs |
205 | %d àwọn ètò tí a lè lò | %d programs available |
206 | Kò sí àwọn ètò tí a lè fisípò láti alásopọ̀. Fi dísìkì sí láti fi ètò tuntun si | There are no programs available to install from the network. Insert a disc to install a new program |
210 | Kò sí àwọn ètò tí a fi sórí kọ̀ǹpútà yìí. | No programs are installed on this computer. |
211 | Ń wá àwọn ètò tí a fi si... | Searching for installed programs... |
212 | A kò fi àfikún kankan sí orí kọ̀ǹpútà yìí. | No updates are installed on this computer. |
213 | Ń wá àwọn àfikún tí a fi si... | Searching for installed updates... |
214 | Àwọn Iṣẹ́ | Tasks |
215 | Tún wo | See also |
216 | Your system administrator has disabled Installed Updates. | Your system administrator has disabled Installed Updates. |
217 | Wo àwọn àfikún tí a fisíi | View installed updates |
222 | Láti yọ ètò kan, yàn án láti inúu àkọsílẹ̀ kí o si ṣíra tẹ Yọ́ nípò, Yípadà, tàbí Ṣàtúnse. | To uninstall a program, select it from the list and then click Uninstall, Change, or Repair. |
223 | Láti fi ètò kan sí, yàn án láti inúu àkọsílẹ̀ kí o si ṣíra tẹ Ṣàgbékalẹ̀. | To install a program, select it from the list and then click Install. |
224 | Láti yọ àfikún kan, yàn án láti inúu àkọsílẹ̀ kí o si ṣíra tẹ Yọ́ nípò tàbí Yípadà. | To uninstall an update, select it from the list and then click Uninstall or Change. |
231 | Hyper-V kò ṣeé fisípò: Àgbéṣẹ́ kò ní ìleṣe àwòmọ́ pàtàkì. | Hyper-V cannot be installed: The processor does not have required virtualization capabilities. |
232 | Hyper-V kò ṣeé fisípò: Agbéṣẹ́ kò ní ìleṣe títúmọ̀ àdírẹ́ẹ̀sì onípele kejì (SLAT). | Hyper-V cannot be installed: The processor does not have second level address translation (SLAT) capabilities. |
233 | Hyper-V cannot be installed: Virtualization support is disabled in the firmware. | Hyper-V cannot be installed: Virtualization support is disabled in the firmware. |
234 | Hyper-V cannot be installed: Data Execution Prevention is not enabled. | Hyper-V cannot be installed: Data Execution Prevention is not enabled. |
500 | Windows Update | Windows Update |
501 | Àṣìṣe kan ti wáyé. Kì ń se gbogbo àfikún ni a rí yọ kúrò. | An error has occurred. Not all of the updates were successfully uninstalled. |
504 | Jọ̀wọ́ dúró kí á fi yọ àwọn àfikún kúro. Èyí lè gba ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ìsẹ́jú. | Please wait while the updates are being uninstalled. This might take several minutes. |
505 | A óò pa àwọn àbùdá Windows wọnyí bákan náà nítorí wọ́n gbáralé %1. Njẹ́ ìwọ́ fẹ́ tẹ̀síwájú? | The following Windows features will also be turned off because they are dependent on %1. Do you want to continue? |
506 | Pípa %1 lè dojúkọ àwọn àbùdá mìíràn tí Windows áti àgbékalẹ̀ àwọn ètò lóri kọ̀ǹpútà rẹ, pẹ̀lú àwọn Ìṣètò àkùnàyàn. Se o fẹ́ tẹ̀síwájú? | Turning off %1 might affect other Windows features and programs installed on your computer, including default settings. Do you want to continue? |
507 | Lọ lóníforíkorí láti kọ́ ọ̀pọ̀ | Go online to learn more |
508 | Àwọn àbùdá mìíràn tí Windows áti àgbékalẹ̀ àwọn ètò lóri kọ̀ǹpútà rẹ lè ní ìdojúkọ, pẹ̀lú àwọn Ìṣètò aláìyípadà. Lọ lóníforíkorí láti kọ́ ọ̀pọ̀ |
Other Windows features and programs installed on your computer might also be affected, including default settings. Go online to learn more |
1000 | Àwọn ètò àti Àwọn àbùdá | Programs and Features |
1001 | Jọwọ dúró títí ètò tó ń lọ lọ́wọ́ yíò parí yíyọ tán tàbí yípadà. | Please wait until the current program is finished uninstalling or being changed. |
2003 | A kò sàwárí fáìlì %1 náà. | The file %1 cannot be found. |
2012 | Ọnà àbùjá kan tí à ń pè ní %1 ti ń bẹ nínu fódà yìí. Sé o fẹ́ pàrọ rẹ? | A shortcut named %1 already exists in this folder. Do you want to replace it? |
2013 | Yan àkòrí kan | Choose a Title |
2014 | exe | exe |
2016 | Ṣàwárí | Browse |
2020 | Setup Programs@*Instal*.exe;*Setup*.exe;Felrak.exe;Imposta.exe;KUR.exe;Yükle*.exe;Ayarla.exe;*.msi@Programs@*.exe;*.com;*.bat;*.cmd@All Files@*.* | Setup Programs@*Instal*.exe;*Setup*.exe;Felrak.exe;Imposta.exe;KUR.exe;Yükle*.exe;Ayarla.exe;*.msi@Programs@*.exe;*.com;*.bat;*.cmd@All Files@*.* |
2027 | Kò leè dá ọ̀nà àbùjá. | Unable to create shortcut. |
2028 | install@setup@uninst@unwise@felrak@imposta@kur@Yükle@Ayarla | install@setup@uninst@unwise@felrak@imposta@kur@Yükle@Ayarla |
2031 | An error occurred while trying to uninstall %1. It may have already been uninstalled. Would you like to remove %1 from the Programs and Features list? |
An error occurred while trying to uninstall %1. It may have already been uninstalled. Would you like to remove %1 from the Programs and Features list? |
2032 | An error occurred while trying to uninstall %1. It may have already been uninstalled. Would you like to remove %1 from the Installed Updates list? |
An error occurred while trying to uninstall %1. It may have already been uninstalled. Would you like to remove %1 from the Installed Updates list? |
2035 | The system folder %1 can not be deleted. | The system folder %1 can not be deleted. |
2036 | NEWGRP | NEWGRP |
2037 | Program Group | Program Group |
2038 | No folder selected. | No folder selected. |
2042 | An error occurred while trying to uninstall %s. You do not have access to %s. You can specify the new uninstall program below. |
An error occurred while trying to uninstall %s. You do not have access to %s. You can specify the new uninstall program below. |
2044 | O kò ní àyè tó láti yọ %1 kúrò nínú àwọn orúkọ àwọn Ètò àti Àbùdá. Jọ̀wọ́ kànsí alábòójútó ẹ̀rọ rẹ. |
You do not have sufficient access to remove %1 from the Programs and Features list. Please contact your system administrator. |
2045 | O kò ní àyè tó láti yọ ìfisípò %1. Jọ̀wọ́ kànsí alábòójútó ẹ̀rọ rẹ. |
You do not have sufficient access to uninstall %1. Please contact your system administrator. |
2060 | Orúkọ àbùjá tí o tẹ wọlé ní àwọn ọ̀rọ̀ tí kò kúnjúwọ̀n orúkọ fáìlì tàbí ó ti gùn jù. | The shortcut name you entered either contained characters that are invalid for file names or was too long. |
2072 | Yan ohun tí àbùjá yìí dálé sí sàlẹ̀: | Select the target of the shortcut below: |
2200 | Ṣẹ̀dá Àbùjá | Create Shortcut |
2201 | Irú wúnrẹ̀n wo lo fẹ́ ṣẹ̀dá àbùjá fún? | What item would you like to create a shortcut for? |
2202 | Ibo ni wàá fẹ́ fi àbùjá náà sí? | Where would you like to place the shortcut? |
2203 | Kí ni wàá fẹ́ pe orúkọ àbùjá náà? | What would you like to name the shortcut? |
3001 | Ìṣàfilọ́lẹ̀ kan lóríi kọ̀ǹpútà rẹ nílò àfidámọ́ Windows wọ̀nyìí: | An app on your PC needs the following Windows feature: |
3002 | Ń ṣàwáríi àwọn fáìlì tí a nílò | Searching for required files |
3003 | Windows nílò àwọ̀n fáìlì láti Windows Update kí o le paríi ìfisípò àwọn àfidámọ̀ kan. | Windows needs files from Windows Update to finish installing some features. |
3004 | Ń ṣe àgbàsílẹ̀ àwọn fáìlì tí a bèèrè fún | Downloading required files |
3005 | Ń fi sípò | Installing |
3006 | A ti ṣe ìfisípò àfidámọ̀ wọ̀nyìí láṣeyọrí: | The following feature was successfully installed: |
3007 | Windows ti parí àwọn ìyípadà tí a bèèrè fún. | Windows completed the requested changes. |
3008 | Windows nílò láti ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ Kọ̀ǹpútà rẹ láti paríi ṣíṣèfisípò àfidámọ̀ wọ̀nyìí: | Windows needs to reboot your PC to finish installing the following feature: |
3009 | Àfidámọ̀ wọ̀nyìí kò ṣeé fisípò: | The following feature couldn't be installed: |
3010 | A ti pa ìfisípò rẹ fún àfidámọ̀ wọ̀nyìí: | The installation was canceled for the following feature: |
3011 | Windows kò leè somọ́ Íntọ́nẹ̀ẹ̀tì láti ṣe àgbàsílẹ̀ àwọn fáìlì tí ó yẹ. Ríi dájú pé o ti somọ́ íntánẹ́ẹ̀tì, kí o wá ṣíra tẹ "Tún Gbìyànjú" láti gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansíi. | Windows couldn't connect to the Internet to download necessary files. Make sure that you're connected to the Internet, and click "Retry" to try again. |
3012 | &Tungbìyànjú | &Retry |
3013 | Ó &DÁA | O&K |
3014 | %1 %2 |
%1 %2 |
3015 | • %1 |
• %1 |
3016 | &Tunbẹ̀rẹ̀ nísìnyí | Restart &now |
3017 | Má ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ | Don't restart |
3019 | Windows requires a reboot to return the system to its original state. | Windows requires a reboot to return the system to its original state. |
3020 | %2 Kóòdù àṣìṣe: %1 |
%2 Error code: %1 |
3021 | Error code: %1 | Error code: %1 |
3022 | Windows kò leè parí àwọn ìyípadà tí a bèèrè fún. | Windows couldn't complete the requested changes. |
3023 | Ojúṣe Àpèsè Windows àti afidámọ̀ kò ṣeé fisípò tàbí yọnípò láládàáṣe nípaṣẹ̀ Àwọn àfidámọ̀ Windows Pánẹ́ẹ̀lì ìdarí. Láti ṣe ìfisípò Àpèsè Windows àti àwọn àfidámọ̀, bẹ̀rẹ̀ Aṣàkóso Apèsè, tàbí lo Aṣàkóso Apèsè cmdlets fún Windows Powershell. |
Windows Server roles and features cannot be automatically installed or uninstalled via the Windows Features Control Panel. To install Windows Server roles and features, start Server Manager, or use the Server Manager cmdlets for Windows PowerShell. |
3024 | Àwọn ìyípadà kò leè parí. Jọ̀wọ́ ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ kọ̀ǹpútà rẹ kí o gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | The changes couldn't be completed. Please reboot your computer and try again. |
3025 | Mú ṣiṣẹ́:%1 | Enable:%1 |
3026 | Gbé sípò àìṣiṣẹ́:%1 | Disable:%1 |
3027 | Features on Demand User Experience Tool FONDUE.exe /enable-feature: [/caller-name:] [/hide-ux:{all | rebootRequest}] Fondue.exe enables Windows optional features by downloading required files from Windows Update or a source that Group Policy specifies. /enable-feature - Specifies the name of the Windows optional feature that you want to enable. You can enable only one feature per command line. To enable multiple features, use Fondue.exe for each feature. /caller-name - Specifies the program or process name when you call Fondue.exe from a script or a batch file. You can use this option to send a report of the program name to Microsoft. /hide-ux:{all | rebootRequest} - Use "all" to hide all messages to the user, including progress and permission requests to access Windows Update. If permission is required, the operation will fail. Use "rebootRequest" only to hide user messages that ask for permission to reboot the PC. Use this option if you have a script that controls reboot requests. EXAMPLES: FONDUE.exe /enable-feature:NETFX3 FONDUE.exe /enable-feature:NETFX3 /caller-name:Admin.bat /hide-ux:all |
Features on Demand User Experience Tool FONDUE.exe /enable-feature: [/caller-name:] [/hide-ux:{all | rebootRequest}] Fondue.exe enables Windows optional features by downloading required files from Windows Update or a source that Group Policy specifies. /enable-feature - Specifies the name of the Windows optional feature that you want to enable. You can enable only one feature per command line. To enable multiple features, use Fondue.exe for each feature. /caller-name - Specifies the program or process name when you call Fondue.exe from a script or a batch file. You can use this option to send a report of the program name to Microsoft. /hide-ux:{all | rebootRequest} - Use "all" to hide all messages to the user, including progress and permission requests to access Windows Update. If permission is required, the operation will fail. Use "rebootRequest" only to hide user messages that ask for permission to reboot the PC. Use this option if you have a script that controls reboot requests. EXAMPLES: FONDUE.exe /enable-feature:NETFX3 FONDUE.exe /enable-feature:NETFX3 /caller-name:Admin.bat /hide-ux:all |
3028 | Ń gba àlàyé àfidámọ̀ | Collecting feature details |
3029 | Orúkọ̀ àfidámọ̀ Windows tí kò kójú òṣùnwọ̀n ní a lò bíi párámítà. | Invalid Windows feature name has been specified as a parameter. |
3032 | Àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ rẹ le má ṣiṣẹ́ bí ó ṣe yẹ láì lo àfidámọ̀ yìí. | Your apps might not work correctly without this feature. |
3034 | Kò ní sí ìyípadà sí Kọ̀ǹpútà rẹ. | No changes will be made to your PC. |
3036 | Because of network policy settings, Windows couldn't connect to the Internet to download files that are required to complete the requested changes. Contact your network administrator for more information. | Because of network policy settings, Windows couldn't connect to the Internet to download files that are required to complete the requested changes. Contact your network administrator for more information. |
3037 | Windows couldn't find required files to complete the requested changes. Make sure you're connected to Internet, and try again. | Windows couldn't find required files to complete the requested changes. Make sure you're connected to Internet, and try again. |
3038 | Windows máa gba àwọn fáìlì tí ó nílò láti Windows Update yíò sì pari ìfisípò. | Windows will get the files that it needs from Windows Update and complete the installation. |
3040 | Ṣe àgbàsílẹ̀ àti ìfisípò àfidọ́mọ̀ yìí | Download and install this feature |
3041 | Pa dé | Close |
3042 | Windows needs to reboot your PC to finish installing the requested changes. | Windows needs to reboot your PC to finish installing the requested changes. |
3043 | %1 lórí i PC rẹ nílò àfidámọ̀ Windows wọ̀nyìí: | %1 on your PC needs the following Windows feature: |
12309 | Ta lò Kẹ̀yìn Lórí | Last Used On |
12312 | Your system administrator has disabled Set Program Access and Computer Defaults. | Your system administrator has disabled Set Program Access and Computer Defaults. |
12313 | Alábòójútó ẹ̀rọ rẹ ti pa àwọn àbùdá Windows. | Your system administrator has disabled Windows Features. |
12325 | Ṣé ó dá ẹ lójú pé o fẹ́ yọ àìfisípò %s? | Are you sure you want to uninstall %s? |
12800 | Olùtẹ̀jáde | Publisher |
12801 | Ẹ̀yà | Version |
12802 | Olóhun tí a kọ sínú ìwé ìrántí | Registered Owner |
12803 | Ilé isẹ́ tí a kọ sínú ìwé ìrántí | Registered Company |
12805 | Ìsopọ̀ Àtìlẹ́yìn | Support Link |
12806 | Àtìlẹ́yìn Ẹ̀rọ Ìbánisọ̀rọ̀ | Support Telephone |
12807 | Ìsomọ́ Ìrànlọ́wọ́ | Help Link |
12808 | Ibi | Location |
12809 | Orísun | Source |
12816 | Alábàáṣe | Contact |
12817 | Àwọn Àsọyé | Comments |
12818 | Fáìlì kàmí | Readme |
12819 | Ṣàfikún ìwífún ìtọ́kasí | Update Info Link |
12820 | Ètò | Program |
12822 | ID Àbájáde | Product ID |
12823 | Ṣàfikún ID | Update ID |
13056 | Create New Shortcut | Create New Shortcut |
13058 | This program can't run | This program can't run |
0x30000000 | Info | Info |
0x30000001 | Start | Start |
0x30000002 | Stop | Stop |
0x50000004 | Information | Information |
0x90000001 | Microsoft-Windows-Shell-AppWizCpl | Microsoft-Windows-Shell-AppWizCpl |
File Description: | Alákóso Isẹ́ Sẹ́ẹ̀lì |
File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
Company Name: | Microsoft Corporation |
Internal Name: | APPWIZ |
Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa. |
Original Filename: | APPWIZ.CPL.MUI |
Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
Product Version: | 10.0.15063.0 |
Translation: | 0x46A, 1200 |