2078 | Í-meèlì, nọ́mbà fóònù, tàbí PIN káàdì amúṣẹ́yá kò péye. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. Tí o kò bá tíì ṣàfikún káàdì amúṣẹ́yá sí àkọọ́lẹ̀ rẹ, o le ṣàfikún èyí. |
The email, phone number, or smart card PIN is incorrect. Please try again. If you haven’t added a smart card to your account, you can add one. |
3039 | Fórúkọsílẹ̀ fún àkọọ́lẹ̀ Microsoft |
Sign up for a Microsoft account |
3225 | Wọlé pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ mìíràn |
Sign in with a different account |
3463 | Káàdì amúṣẹ́yá |
Smart Card |
4421 | Tẹ̀ṣíwájú gbígbà Mí wọlé |
Continue Signing Me In |
4720 | Ọ̀rọ̀ aṣínà |
Password |
4775 | Àkọọ̀lẹ̀ Microsoft |
Microsoft account |
5324 | Láti wọlé, jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ. |
To sign in, please enter your password. |
5672 | Ìrànwọ́ |
Help |
6022 | LocVer:0 |
LocVer:0 |
6566 | A fẹ́ rí i dájú pé àdírẹ̀ẹ̀sì í-meèlì rẹ nìyí. Ṣàyẹ̀wò í-meèlì rẹ kí o tẹ̀lé àwọn ìgbéṣẹ̀ nínú iṣẹ́ tí a bá firánṣẹ́ sí ọ. |
We want to make sure this is your email address. Check your email and follow the steps in the message we sent you. |
6619 | Àdírẹ̀ẹ̀sì í-meèlì tàbí nọ́mbà fóònù |
Email address or phone number |
6927 | Rántí ọ̀rọ̀ aṣínà mi |
Remember my password |
7040 | Wọlé pẹ̀lú |
Sign in with |
7236 | Má bìínú, a kò le somọ́ sí agbègbè ìkápá yìí nísìnyí láti jẹ́rìísí ìdanimọ̀ rẹ. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
Sorry, we can’t connect to this domain right now to verify your ID. Please try again. |
7358 | Orúkọ aṣàmúlò tàbí ọ̀rọ̀ aṣínà tí o ṣàtẹ̀wọlé kò péye. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
The user name or password you entered is incorrect. Try again. |
7875 | Ọ̀rọ̀ asínà tẹ ti sọwúlònù. Àkókò tó láti yan tuntun kan. |
Your password has expired. It’s time to choose a new one. |
8433 | Má bìínú, ìṣòro kan wà pẹ̀lú àpèsè náà, fún ìdí èyí a kò le gbé ọ wọlé nísìnyì. A ń ṣiṣẹ́ láti yanjú ìṣòro yìí láìpẹ́. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi láìpẹ́. |
Sorry, there’s a problem with the server, so we can’t sign you in right now. We’re working to fix it as soon as we can. Please try again in a few minutes. |
10466 | Má bìínú, ìṣòro wíwọlé pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ Microsoft yìí wà. |
Sorry, there’s an issue signing in with this Microsoft account. |
10695 | A kò le gbé ọ wọlé nítorípé alásopọ̀ kò sí nílẹ̀. Rí i dájú pé ohun èlò rẹ wà ní ìsopọ̀ sí Íntánẹ́ẹ̀tì kí o wá gbìyànjún lẹ́ẹ̀kan síi. |
We can’t sign you in because the network isn’t available. Make sure your device is connected to the Internet and try again. |
11940 | Ọ̀rọ̀ aṣínà náà kò péye. Ríi dájú pé o ń lo ọ̀rọ̀ aṣínà fún àkọọ́lẹ̀ Microsoft rẹ. |
That password is incorrect. Make sure you’re using the password for your Microsoft account. |
12221 | A ti ṣàkíyèsí àwọn iṣẹ́ tí kò yẹ ní àkọọ́lẹ̀ rẹ. A nílò Ìgbéṣẹ̀ rẹ láti rí i dájú pé kò sí ẹnikẹ́ni tí ó ń lo àkọọ́lẹ̀ rẹ. |
We have noticed some unusual activity in your account. Your action is needed to make sure no one else is using your account. |
12222 | O gbọ́dọ̀ wà lóníforíkorí fún ìgbà àkọ́kọ́ láti parí ìṣàgbékalẹ̀ àkọọ́lẹ̀ rẹ. |
You must be online the first time to complete your account setup. |
12223 | Má bìínú fún ìjálù; a kàn fẹ́ rí i dájú pé ìwọ ni. fọwọ́kàn tàbí ṣíra tẹ̀ Ó DÁA láti ṣàrídájú. |
Sorry for the interruption; we just want to make sure this is you. Tap or click OK to confirm. |
12786 | Má bínú, ìṣòro kan gbígbé ọ wọlé kan ti wà. Jọ̀wọ̀ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
Sorry, there was a problem signing you in. Please try again. |
12838 | Í-meèlì tàbí nọ́mbà fóònù náà kò sí nílẹ̀ mọ́. Jọ̀wọ̀ gbìyànjú òmíràn tàbí ṣẹ̀dá tuntun kan. |
That email or phone number is no longer available. Please try another, or create a new one. |
13331 | O níláti yan ọ̀rọ̀ aṣínà tó lágbára kí o tó le wọlé. |
You need to choose a stronger password before you can sign in. |
15239 | O níláti ṣàyípadà ìbéèrè ààbò àti ìdáhùn kí o tó le wọlé. |
You need to change your security question and answer before you can sign in. |
16868 | Ìṣòro kan wà tí ó fa ẹyà Aṣèrànwọ̀ Wíwọlé Àkóọ́lẹ̀ Microsoft láti wà nípò àìṣeélò: O le má le wọlé sí àwọn ètò tí ó ń lo àkọọ́lẹ̀ Microsoft. Ìṣòro náà le wáyé nípa ètò tí o ṣàgbékalẹ̀ láìpẹ́. Fún ọ̀pọ̀ ìwífún, Jọ̀wọ́ lọ sí {l} |
There was a problem that caused parts of the Microsoft account Sign-in Assistant to be disabled. You might not be able to sign in to programs that use your Microsoft account. The problem may have been caused by a program that was recently installed. For more information, please go to: {l} |
16909 | Láti ṣèrànwọ́ ààbò àkọọ́lẹ̀ ìwífún rẹ, Jọ̀wọ́ wọlé lẹ́ẹ̀kan síi. |
To help protect your account information, please sign in again. |
17112 | A kò le gbé ọ wọlé sí àgbègbè ìkápá yìí. Jọ̀wọ̀ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tàbí kànsí àgbègbè ìkápá alábòójútó. |
We couldn’t sign you in to this domain. Please try again or contact the domain administrator. |
17809 | Ìwífún ìwọlé rẹ kò péye. Ṣàrídájú pé o ṣàtẹ̀wọlé àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì, nọ́mbà fóònù, tàbí ọ̀rọ̀ aṣínà tó péye, lẹ́yìn náà ṣàtẹ̀wọlé àwọn ẹyọ ọ̀rọ̀ tí o rí. |
Your sign-in information is incorrect. Make sure you enter the correct email address, phone number, or password, and then enter the characters you see. |
18108 | Má bìínú, ìṣòro kan wà pẹ̀lú àpèsè náà, àtipé a ń ṣagbára láti yanjú rẹẹ̀ láìpẹ́. Jọ̀wọ́ gbìyànjú wíwọlé lẹ́ẹ̀kan síi láìpẹ́. |
Sorry, there’s a problem with the server, and we’re working to fix it as soon as we can. Please try signing in again in a few minutes. |
18189 | Má bìínú, ìṣòro kan wà nípa wíwọlé lọ́wọ́lọ́wọ́. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
Sorry, there’s a problem signing you in right now. Please try again later. |
18392 | O gbọ́dọ̀ ṣàtẹ̀wọlé PIN |
You must enter a PIN |
18407 | Ó DÁA |
OK |
18408 | Paá rẹ́ |
Cancel |
18409 | Kò rí káàdì àmúṣẹ́yá kankan |
No smart card found |
18416 | Ṣíra tẹ iṣẹ́ yìí láti yanjú ìṣòro náà. |
Click this message to fix the problem. |
18417 | Àṣèrànwọ́ Ìwọle Àkọọ́lẹ̀ Microsoft |
Microsoft account Sign-in Assistant |
18418 | Máa ń mú ìfaṣesí Àkọọ́lẹ̀ Microsoft ṣiṣẹ́. |
Enables Microsoft account authentication. |
18419 | Má bínú, ìṣòro kan wà láti gbé ọ wọlé. |
Sorry, there was a problem signing you in. |
19140 | Alájọṣiṣẹ́pọ̀ |
Partner |
19141 | Aṣèrànwọ́ Wíwọlé Àkọọ́lẹ̀ Microsoft |
Microsoft account Sign-in Helper |
19142 | Ìdarí Ìwọlé Àkọọ́lẹ̀ Microsoft |
Microsoft account Sign-in Control |
19229 | Láti parí ṣíṣe ààtò àkóọ́lẹ̀ Microsoft, o nílò ìyàndà òbí. |
To finish setting up this Microsoft account, you need a parent’s permission. |
19608 | Àkọọ́lẹ̀ yìí ṣeé lò nítorípé tí ilé iṣẹ́ kan ni. Jọ̀wọ́ lo àkọọ́lẹ̀ mìíràn. |
This account cannot be used because it belongs to an organization. Please use a different account. |
20315 | O nílò láti ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ kí o tó le wọlé. |
You need to change your password before you can sign in. |
20591 | A nílò ìjẹ́rìísí aláfikún kí o tó le wọlé. |
We need additional verification before you can sign in. |
20814 | A ti kófìrí àwọn iṣẹ́ afurasí kan pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ rẹ. Láti ṣèránwọ́ fún ọ, a ti dènà àkọọ́lẹ̀ rẹ fúngbàdíẹ̀. |
We detected some suspicious activity with your account. To help protect you, we’ve temporarily blocked your account. |
21035 | Ọ̀ |
Your password has expired. It’s time to choose a new one. |
21266 | Láti wọlé sí ètò yìí, o gbọ́dọ̀ lo káàdì amúṣẹ́yá dípò ọ̀rọ̀ aṣínà. |
To sign in to this program, you must use a smart card instead of a password. |
21674 | Àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì tàbí ọ̀rọ̀ aṣínà kò péye. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
The email address or password is incorrect. Please try again. |
22118 | Jọ̀wọ̀ ṣàtẹ̀wọlé ìwífún ìwọlé kí o gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
Please enter your sign-in information and try again. |
22304 | Jọ̀wọ́ tún àdírẹ̀ẹ̀sì í-meèlì tàbí nọ́mbà fóònù rẹ tẹ̀wọlé. |
Please reenter your email address or phone number. |
22490 | A kò le gbé ọ wọlé nítorípé ìṣòro kan wà pẹ̀lú ọ̀rọ̀ aṣínà tí o fipamọ́. Jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ lẹ́ẹ̀kan síi. |
We can’t sign you in because there’s a problem with the saved password. Please enter your password again. |
22531 | O nílò láti ṣàfikún aṣàpèjúwe àkọọ́lẹ̀ Microsoft rẹ kí o tó le wọlé. |
You need to update your Microsoft account profile before you can sign in. |
23007 | Àkọọ́lẹ̀ rẹ kò tíì di títì pa nítrípé ìgbíyànjú àti wọlé pẹ̀lú ìwífún aṣàmúlò tí kò péyé. |
Your account was locked because there have been too many attempts to sign in with incorrect user information. |
23582 | Láti wọlé, o gbọ́dọ̀ ṣàyípadà yìí sí Ìdánimọ̀ pẹ̀lú ìlé iṣẹ́ rẹ. Tàbí o le ṣàtúnfúnlórúkọ Ìdanimọ̀ rẹ. |
To sign in, you must convert this to an ID with your organization. Or you can rename your ID. |
24863 | Ilé Iṣẹ́ kò le fààyègbà ọ́ láti wọle síbí pẹ̀lúi n àkọọ́lẹ̀ Microsoft. Lati tẹ̀ṣíwájú, wọlé pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ Microsoft mìíràn. |
This organization won’t allow you to sign in here with this Microsoft account. To continue, sign in with a different Microsoft account. |
25352 | O ti wọlé sínú ohun èlò tó pọ̀ jù nípa lílo àkọọ́lẹ̀ Microsoft yìí. |
You have signed in to too many devices using this Microsoft account. |
25367 | Jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé PIN rẹ láti wọlé. |
Please enter your PIN to sign in. |
25720 | A fẹ́ rí i dájú pé àdírẹ̀ẹ̀sì í-meèlì rẹ nìyí. Ṣàyẹ̀wò í-meèlì rẹ kí o tẹ̀lé àwọn ìgbéṣẹ̀ nínú iṣẹ́ tí a bá fiiṣẹ́ náà ránṣẹ́ sí ọ. |
We want to make sure this is your email address. Check your email and follow the steps in the message we sent you. |
26553 | Ìdanimọ̀ Alájọṣiṣẹ́pọ̀ |
Partner ID |
27451 | Rántí Mi |
Remember me |
27955 | O ti ṣe ìtọ́kasí àkọọ́lẹ̀ Microsoft àti àkọọ́lẹ̀ aṣàmúlò Windows tó pọ̀ jùlọ lórí i ohun èlò yìí. Ṣàyọkúrò ìtọ́kasí tí ó ti wà ní ìtọ́kasí tẹ́lẹ̀ láti la ṣàfikún òmíìràn. |
You’ve linked the maximum number of Microsoft accounts and Windows user accounts on this device. Remove an existing linked account to add another. |
28306 | Má bínú, o kò le wọlé síì pèsè yìí pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ Microsoft. Láti tẹ̀ṣíwájú, jọ̀wọ́ lo àkọ́ọ̀lẹ̀ tó yàtọ̀. |
Sorry, you can’t sign in to this service with this Microsoft account. To continue, please use a different account. |
29392 | Ìpèsè Àṣèrànwọ́ Wíwọlé Àkọọ́lẹ̀ Microsoft kò ṣiṣẹ́. |
Microsoft account Sign-in Assistant service is not running. |
29600 | ID |
ID |
43000 | Yanjú ìṣòro pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ Microsoft rẹ |
Fix a problem with your Microsoft account |
43001 | Àwọn ohun ẹ̀rí rẹ ti yípadà ní òfurufú ó sì níláti ṣàfikún alábẹ́lé. |
Your credentials have changed in the cloud and need to be updated locally. |
43003 | Ohun èlò rẹ wà ní àìsílóníforíkorí. Jọ̀wọ́ wọlé pẹ̀lú ọ̀rọ̀ aṣínà tó kẹ́hìn lórí i ohun èlò yìí. |
Your device is offline. Please sign in with the last password used on this device. |
43004 | Ǹjẹ́ o kò leè wọ àkọọ̀lẹ̀ rẹ bí? |
Can’t access your account? |
43005 | Yanjú rẹ̀ |
Fix it |
43006 | Ṣàrídájú ìwífún àkọọ̀lẹ̀ Microsoft rẹ |
Verify your Microsoft account info |
43007 | Ṣàfikún àkọọ̀lẹ̀ Microsoft rẹ |
Add your Microsoft account |
43008 | %1 nílò láti jẹ́rìísí ìdánimọ̀ rẹ. |
%1 needs to confirm your identity. |
43009 | A máa ṣàfipamọ́ ìwífúnyìí kí o le lo àkọọ́lẹ̀ rẹ pẹ́lú %1. |
We’ll save this info so you can use your account with %1. |
43010 | Ṣàfipamọ́ |
Save |
43011 | A kò leè gbé ọ wọlé |
We couldn’t sign you in |
43015 | Jọ̀wọ́ dúró |
Please wait |
43016 | Fàkalẹ̀ |
Submit |
43017 | Wọlé lẹ́ẹ̀kan síi |
Sign in again |
43018 | O kò le wọlé sí ohun èlò rẹ nísìnyí. Lọ sí %1 láti yanjú ìṣòro náà, tàbí gbìyànjú ọ̀rọ̀ aṣínà tí o lò kẹ́hìn lórí i ohun èlò yìí. |
You can’t sign in to your device right now. Go to %1 to fix the problem, or try the last password you used on this device. |
43019 | That password is incorrect. Make sure you’re using the password for your Microsoft account. You can always reset it at %1. |
That password is incorrect. Make sure you’re using the password for your Microsoft account. You can always reset it at %1. |
43020 | Láti wọlé láti ọ̀nà jínjìn, o ní ẹ̀tọ́ láti wọlé nípasẹ̀ Àwọn Ìpèsè Àtẹ Iṣẹ́ Ọ̀nà Jínjìn. |
To sign in remotely, you need the right to sign in through Remote Desktop Services. |
43021 | Má bínú, ìṣòro kan jẹyọ láti mú ọ wọlé. Jọ̀wọ́ ṣàtúntò PIN rẹ nípa lílọ sí Àwọn ààtò Àwọn Àkọọ́lẹ̀ Àwọn ẹ̀yàn ìwọlé. |
Sorry, there was a problem signing you in. Please reset your PIN by going to Settings Accounts Sign-in options. |
43022 | A ní látí jẹ́rìísí ìdánimọ̀ rẹ fún %1. |
We need to verify your identity for %1. |
43023 | Microsoft account password |
Microsoft account password |
0x10000001 | Telemetry trigger events |
Telemetry trigger events |
0x10000002 | Error |
Error |
0x10000003 | Analytic |
Analytic |
0x10000004 | Function |
Function |
0x10000005 | Operational |
Operational |
0x10000006 | Warning |
Warning |
0x10000007 | Critical |
Critical |
0x10000008 | Request Start |
Request Start |
0x10000009 | livessp |
livessp |
0x1000000A | wlidcredprov |
wlidcredprov |
0x1000000B | wlidnsp |
wlidnsp |
0x1000000C | wlidsvc |
wlidsvc |
0x1000000D | wlidmodern |
wlidmodern |
0x1000000E | wlidcli |
wlidcli |
0x1000000F | wlidprov |
wlidprov |
0x10000010 | wlidbho |
wlidbho |
0x10000011 | TokenProvider |
TokenProvider |
0x10000012 | MSA Extension API |
MSA Extension API |
0x10000013 | Cache |
Cache |
0x10000014 | Credentials |
Credentials |
0x10000015 | StateMachine |
StateMachine |
0x10000016 | SOAP |
SOAP |
0x10000017 | RPC |
RPC |
0x30000000 | Info |
Info |
0x30000001 | Start |
Start |
0x30000002 | Stop |
Stop |
0x50000004 | Information |
Information |
0x50000005 | Verbose |
Verbose |
0x70000065 | WLID Service Operation |
WLID Service Operation |
0x70000066 | LiveSsp Operation |
LiveSsp Operation |
0x70000067 | Identity Provider Operation |
Identity Provider Operation |
0x70000068 | LiveId Modern API Operation |
LiveId Modern API Operation |
0x70000069 | WLIDCredProv Operation |
WLIDCredProv Operation |
0x7000006A | TokenProvider Operation |
TokenProvider Operation |
0x700000C8 | Function Call |
Function Call |
0x90000001 | Microsoft-Windows-LiveId/Analytic |
Microsoft-Windows-LiveId/Analytic |
0x90000002 | Microsoft-Windows-LiveId/Operational |
Microsoft-Windows-LiveId/Operational |
0xB00003ED | ConnectIdentity_Start |
ConnectIdentity_Start |
0xB00003EE | ConnectIdentity_Stop.%nStatus: %1 |
ConnectIdentity_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00003EF | DisconnectIdentity_Start |
DisconnectIdentity_Start |
0xB00003F0 | DisconnectIdentity_Stop.%nStatus: %1 |
DisconnectIdentity_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00003F5 | NetworkCall_Start |
NetworkCall_Start |
0xB00003F6 | NetworkCall_Stop.%nNumber of Targets: %1%nRequestType: %2 |
NetworkCall_Stop.%nNumber of Targets: %1%nRequestType: %2 |
0xB00003F7 | DeviceAuth_Start |
DeviceAuth_Start |
0xB00003F8 | DeviceAuth_Stop.%nStatus: %1 |
DeviceAuth_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00003F9 | UserAuth_Start |
UserAuth_Start |
0xB00003FA | UserAuth_Stop.%nStatus: %1 |
UserAuth_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00003FB | PromptForCredentials_Start |
PromptForCredentials_Start |
0xB00003FC | PromptForCredentials_Stop.%nStatus: %1 |
PromptForCredentials_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00003FD | SignOutUser_RegistryOpenOrReadFailure. %nRegistryLocation: %1. %nStatus: %2 |
SignOutUser_RegistryOpenOrReadFailure. %nRegistryLocation: %1. %nStatus: %2 |
0xB00003FE | SignOutUser_RegistryWriteFailure. %nRegistryLocation: %1. %nStatus: %2 |
SignOutUser_RegistryWriteFailure. %nRegistryLocation: %1. %nStatus: %2 |
0xB00007D8 | DeviceAuthAsync_Start |
DeviceAuthAsync_Start |
0xB00007D9 | DeviceAuthAsync_Stop |
DeviceAuthAsync_Stop |
0xB00007DA | UserAuthAsync_Start |
UserAuthAsync_Start |
0xB00007DB | UserAuthAsync_Stop |
UserAuthAsync_Stop |
0xB00007DC | SignOutUser_Start |
SignOutUser_Start |
0xB00007DD | SignOutUser_Stop |
SignOutUser_Stop |
0xB00007DE | WLIDSvcReady |
WLIDSvcReady |
0xB00007DF | CommandLinkClicked_Start |
CommandLinkClicked_Start |
0xB00007E0 | CommandLinkClicked_Stop.%nStatus: %1 |
CommandLinkClicked_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00007E1 | UserImageGetBitmapValue_Start |
UserImageGetBitmapValue_Start |
0xB00007E2 | UserImageGetBitmapValue_Stop.%nStatus: %1 |
UserImageGetBitmapValue_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00007E3 | CredProvSetSerialization_Start |
CredProvSetSerialization_Start |
0xB00007E4 | CredProvSetSerialization_Stop.%nStatus: %1 |
CredProvSetSerialization_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00007E5 | CredProvGetSerialization_Start |
CredProvGetSerialization_Start |
0xB00007E6 | CredProvGetSerialization_Stop.%nStatus: %1 |
CredProvGetSerialization_Stop.%nStatus: %1 |
0xB00007E7 | Operation: %1%nDetails: %2%nStatus: %3%n |
Operation: %1%nDetails: %2%nStatus: %3%n |
0xB00007E9 | WLIDSvc service failed to start.%nFunction: %1%nReason: %2%nStatus: %3%n |
WLIDSvc service failed to start.%nFunction: %1%nReason: %2%nStatus: %3%n |
0xB00007EA | Generic telemetry trigger event.%nPointType: %1%nAppName: %2%nModuleName: %3%nModuleVersion: %4%nFileName: %5%nFunctionName: %6%nLineNumber: %7%nErrorCode: %8%n |
Generic telemetry trigger event.%nPointType: %1%nAppName: %2%nModuleName: %3%nModuleVersion: %4%nFileName: %5%nFunctionName: %6%nLineNumber: %7%nErrorCode: %8%n |
0xB00007EB | User specific telemetry trigger event for CID %1. |
User specific telemetry trigger event for CID %1. |
0xB00007EC | ErrorVerifier in function %1 encountered unexpected error code (%2). |
ErrorVerifier in function %1 encountered unexpected error code (%2). |
0xB00007ED | Assertion failure for expression (%4) in function %2 @%1_%3. |
Assertion failure for expression (%4) in function %2 @%1_%3. |
0xB0000BB8 | %3 @%1_%2 |
%3 @%1_%2 |
0xB0000BC0 | +%2@%1_%3 |
+%2@%1_%3 |
0xB0000BC1 | -%1=%2 |
-%1=%2 |
0xB0000BC4 | Process name %1 |
Process name %1 |
0xB0000BC5 | IF_FAILEXIT failure: (%4), hr = %5, in %2 @%1_%3 |
IF_FAILEXIT failure: (%4), hr = %5, in %2 @%1_%3 |
0xB00017D4 | Service Create Context for [%1] |
Service Create Context for [%1] |
0xB00017D5 | Token with target [%1] expired on %2, Deleting it from CredMan. |
Token with target [%1] expired on %2, Deleting it from CredMan. |
0xB00017D6 | Certificate (target = [%1]) has expired. Deleting from CredMan. |
Certificate (target = [%1]) has expired. Deleting from CredMan. |
0xB00017D7 | RemoveCachedAuthInfo Deleting item for target [%1] from CredMan. |
RemoveCachedAuthInfo Deleting item for target [%1] from CredMan. |
0xB00017D8 | RemoveCachedAuthInfo ALL Deleting [%1] items from CredMan. |
RemoveCachedAuthInfo ALL Deleting [%1] items from CredMan. |
0xB00017D9 | RemovePersistedTokens Deleting item for target [%1] from CredMan. |
RemovePersistedTokens Deleting item for target [%1] from CredMan. |
0xB00017E0 | CredMan activity skipped. Credential not changed for [WindowsLive:(token):name=%1;serviceuri=%2 |
CredMan activity skipped. Credential not changed for [WindowsLive:(token):name=%1;serviceuri=%2 |
0xB00017E1 | RPC call to function %1 returned the following error code: %2. |
RPC call to function %1 returned the following error code: %2. |
0xB00017E2 | SOAP Request of type %1 for user CID '%2' in %4 environment received the following error code from the Microsoft Account server: %3. |
SOAP Request of type %1 for user CID '%2' in %4 environment received the following error code from the Microsoft Account server: %3. |
0xB00017E3 | ## SOAP Request: %1 |
## SOAP Request: %1 |
0xB00017E4 | ## SOAP Response: %1 |
## SOAP Response: %1 |
0xB00017E5 | Acquired Service token.%nResourceURI: %1%nCreated: %2%nExpires: %3%nTokenType: %4%nAuthRequired: %5%nRequestStatus: %6%nHasFlowUrl: %7%nHasAuthUrl: %8%nHasEndAuthUrl: %9 |
Acquired Service token.%nResourceURI: %1%nCreated: %2%nExpires: %3%nTokenType: %4%nAuthRequired: %5%nRequestStatus: %6%nHasFlowUrl: %7%nHasAuthUrl: %8%nHasEndAuthUrl: %9 |
0xB0001BBC | Cached ticket for site %1 and policy %2 found which is valid for another %3 seconds. |
Cached ticket for site %1 and policy %2 found which is valid for another %3 seconds. |
0xB0001BBD | ApplicationId Overwritten [%1] becomes [%2] |
ApplicationId Overwritten [%1] becomes [%2] |
0xB0001BBE | ApplicationId [%1] |
ApplicationId [%1] |
0xB0001BBF | Cached ticket for site %1 and policy %2 not found or has expired. |
Cached ticket for site %1 and policy %2 not found or has expired. |
0xB0001BC0 | Attempts = [%1], latestIterationResult = [%2], continueRetry = [%3], isConnected = [%4], flowUrl = [%5], defaultUser = [%6], promptType = [%7], authUrl = [%8], endAuthUrl = [%8] |
Attempts = [%1], latestIterationResult = [%2], continueRetry = [%3], isConnected = [%4], flowUrl = [%5], defaultUser = [%6], promptType = [%7], authUrl = [%8], endAuthUrl = [%8] |
0xB0001BC1 | WLIDCPersistCredential [%1] |
WLIDCPersistCredential [%1] |
0xD0000001 | Auth |
Auth |
0xD0000002 | Service |
Service |
0xD0000003 | DeviceAuth |
DeviceAuth |
0xD0000004 | DeleteDevice |
DeleteDevice |
0xD0000005 | UpdateDevice |
UpdateDevice |
0xD0000006 | AddCredential |
AddCredential |
0xD0000007 | AssociateDevice |
AssociateDevice |
0xD0000008 | DisassociateDevice |
DisassociateDevice |
0xD0000009 | ResolveDevice |
ResolveDevice |
0xD000000A | PublishDevice |
PublishDevice |
0xD000000B | UpdateDeviceReaders |
UpdateDeviceReaders |
0xD000000C | ResolveUser |
ResolveUser |
0xD000000D | OTC |
OTC |
0xD000000E | EnumDevices |
EnumDevices |
0xD000000F | UpdateDeviceProperties |
UpdateDeviceProperties |
0xD0000010 | GetUserKeyData |
GetUserKeyData |
0xD0000011 | Count |
Count |