If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id |
Yoruba |
English |
1024 | Ẹ̀rọ ìyàsọ́tọ̀ |
Separator |
1025 | + |
+ |
1026 | Kò sí |
None |
4160 | Padé |
Close |
4161 | Ó DÁA |
OK |
4162 | %s Àwọn ohun ìní |
%s Properties |
4163 | Òní: |
Today: |
4164 | &Lọ sí òní |
&Go to today |
4165 | /.,-: |
/.,-: |
4166 | MMMM |
MMMM |
4167 | MMMM yyyy |
MMMM yyyy |
4176 | Ṣàtẹ̀wọlé àyọkà síbí |
Enter text here |
4177 | Àwọn Àbùdá |
Properties |
32768 | Ń ṣàtúnse ìwọ̀n fèrèsé. |
Resizes this window. |
32784 | Ma ń gbé fèrèsé yìí. |
Moves this window. |
32800 | Ń wó fèrèsé yìí lulẹ̀ sí àwòrán àpèjúwe. |
Collapses this window to an icon. |
32816 | Ma ń fẹ ojú fèrèsé yìí láti kárí aṣàfihàn tàn náà. |
Expands this window to fill the screen. |
32832 | Ń yí padà sí fèrèsé MDI tókàn. |
Switches to the next MDI window. |
32864 | Ma ń pa fèrèsé. |
Closes this window. |
33056 | Ń dá fèrèsé yìí padà sí ìwọ̀n déédé. |
Restores this window to normal size. |
33072 | Ń yí padà sí isẹ́ mìíràn. |
Switches to another task. |
36848 | Ó ní àwọn òfin fún ìpawọ́dà àwọn fèrèsé nínú. |
Contains commands for manipulating windows. |
36849 | Wọ́ sí apá òsì tàbí ọ̀tún láti sàtúnwọ̀n àwọn ìlà òòró. |
Drag to the left or right to resize columns. |
36850 | Ń ṣàtúnse ìwọ̀n àwọn ìlà òòró nípa lílo àwọn kọ́kọ́rọ́ ọfà àti táàbù. |
Resizes columns using the arrow and tab keys. |
36851 | Ń ṣàfikún, ń sún àti ìsàyọkúròoàwọn Bọ́tìnnì lóríi òpó irinsẹ́ náà. |
Adds, moves, and removes buttons on the toolbar. |