| 2002 | Àwọn ààtò ìmúdọ́gba |
Sync settings |
| 2003 | Ṣèbádọ́gba kí o sì ṣe àbọ̀ábá àwọn ìṣètò lórí i àwọn ìsomọ́ onímítà |
Sync and back up settings over metered connections |
| 2004 | Ìráyèsí Ìrọ̀rùn |
Ease of Access |
| 2005 | Àwọn ààtò Windows mìíràn |
Other Windows settings |
| 2006 | Àwọn ọ̀rọ̀ aṣínà |
Passwords |
| 2008 | Àwọn ìnífẹ́ẹ̀sí ède |
Language preferences |
| 2009 | Àwọn ààtò Internet Explorer |
Internet Explorer settings |
| 2010 | Kókó |
Theme |
| 2012 | Alábòójútó ẹ̀rọ rẹ ní ó ńṣàkoso àwọn ìṣètò kan. Kàn sí alábòójútó ẹ̀rọ rẹ láti yanjú ìṣòrò yìí. |
Some settings are managed by your system administrator. Contact your system administrator to resolve this. |
| 2013 | Windows ń ṣiṣẹ́ ní móòdù ààbò. Àwọn ẹ̀yàn arìnkiri kò sí nílẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́. |
Windows is running in safe mode. Roaming options are currently unavailable. |
| 2014 | O ti wọlé pẹ̀lú aṣàpèjúwe onígbàdíẹ̀. Àwọn ìyàn àgbéká kò sí nílẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́. |
You are logged on with a temporary profile. Roaming options are currently unavailable. |
| 2016 | Ìṣòro kan jẹyọ láti sopọ̀ mọ́ àkọọ́lẹ̀ rẹ. Ṣàyẹ̀wò Ìsopọ̀ Íntánẹ́ẹ̀tì rẹ kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
There was a problem connecting to your account. Check your Internet connection and try again. |
| 2017 | Báwo ni mímúdọ́gba ti ń ṣiṣẹ́? |
How does syncing work? |
| 2018 | Mú àwọn ààtò Windows dọ́gba sí àwọn ohun èlò míràn tí ń lo %1!s!. |
Sync Windows settings to other devices using %1!s!. |
| 2019 | Àwọn àfidámọ̀ Windows kan wà nílẹ̀ nìkan tí o bá ń lo àkọọ́lẹ̀ Microsoft tàbí àkọọ́lẹ̀ iṣẹ́. |
Some Windows features are only available if you are using a Microsoft account or work account. |
| 2022 | Àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ tí a gbà nípasẹ̀ tí a sì múdọ́gba pẹ̀lú %1!s! |
Apps acquired by and synced with %1!s! |
| 2023 | Use Windows Anywhere |
Use Windows Anywhere |
| 2024 | How does Windows Anywhere work? |
How does Windows Anywhere work? |
| 2025 | Windows Anywhere powers your device experience with your settings in the cloud using %1!s!. |
Windows Anywhere powers your device experience with your settings in the cloud using %1!s!. |
| 2110 | Ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ kò sí ní ṣe ìbádọ́gba títí tí o fi máa ṣàrídájú ìdánimọ̀ lóríi ohun èlò yìí. |
Your passwords won’t sync until you verify your identity on this device. |
| 2112 | Ṣàrídájú |
Verify |
| 2113 | Àwọn ààtò kò ní múdọ́gba títí wàá fi ṣàfikún àwọn ìwífún kan fún àkọọ́lẹ̀ Microsoft rẹ. |
Settings won’t sync until you update some info for your Microsoft account. |
| 2114 | Ṣàfikún ìwífún |
Update info |
| 2115 | Àwọn ààtò kò ní múdọ́gba títí wàá fi ṣàfikún àwọn ìwífún kan fún àkọọ́lẹ̀ ilé-ìwé tàbí ibi-iṣẹ́ rẹ. |
Settings won’t sync until you update some info for your work or school account. |
| 2117 | Ìbádọ́gba kò sí nílẹ̀ fún àkọọ́lẹ̀ rẹ. Kàn sí alábòójútó ìlànà ètò rẹ láti yanjú èyí. |
Sync is not available for your account. Contact your system administrator to resolve this. |