17500 | Lákọ̀ọ́kọ́, ṣàrídájú ìwífún àkọọ́lẹ̀ rẹ. |
First, verify your account info. |
17501 | Ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán kan |
Create a picture password |
17503 | Káàbọ̀ sí ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòrán |
Welcome to picture password |
17504 | Yan àwòrán |
Choose picture |
17512 | Ṣetò ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán rẹ |
Set up your picture password |
17513 | Wọ́ àwòrán rẹ sí ipò tí o bá wù ọ́. |
Drag your picture to position it the way you want. |
17514 | Lo àwòrán yìí |
Use this picture |
17515 | Yan àwòrán tuntun |
Choose new picture |
17516 | Yan ìfarajúwe mẹ́ta sórí àwòrán rẹ. O le lo àkópọ̀ èyíkéyìí róbótó, ìlà tótọ́, àti àfọwọ́bà. |
Draw three gestures on your picture. You can use any combination of circles, straight lines, and taps. |
17517 | Rántí, ìwọ̀n, ipò, àti ìdòríkọ àwọn ìfarajúwe rẹ — àti àtẹ̀léra bí o ṣe ṣe wọ́n — máa jẹ́ ẹ̀yà ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán rẹ. |
Remember, the size, position, and direction of your gestures — and the order in which you make them — become part of your picture password. |
17518 | Ṣàtẹ̀wọlé e ìfarajúwe àkọ́kọ́ rẹ |
Enter your first gesture |
17519 | Ti ṣàtẹ̀wọlé ìfarajúwe àkọ́kọ́ |
First gesture entered |
17520 | Ṣàtẹ̀wọlé ìfarajúwe rẹ kejì |
Enter your second gesture |
17521 | Ti ṣàtẹ̀wọlé ìfarajúwe kejì |
Second gesture entered |
17522 | Ṣàtẹ̀wọlé ìfarajúwe rẹ kẹta |
Enter your third gesture |
17523 | Ti ṣàtẹ̀wọlé ìfarajúwe kẹtà |
Third gesture entered |
17524 | Láti parí ṣíṣe se ààtò ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòrán rẹ, tun ìfarajúwe rẹ mẹ́ta ṣe. (O le máa bẹ̀rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ nípa fífọwọ́bà bọ́tìnnì ìbẹ̀rẹ̀.) |
To finish setting up your picture password, just repeat your three gestures. (You can always start over by tapping the Start over button.) |
17526 | Bẹ̀rẹ̀ látibẹ̀rẹ̀ |
Start over |
17527 | Ṣe-àtúntẹ̀wọlé ìfarajúwe rẹ àkọ́kọ́ |
Re-enter your first gesture |
17528 | Ṣe-àtúntẹ̀wọlé ìfarajúwe rẹ kejì |
Re-enter your second gesture |
17529 | Ṣe-àtúntẹ̀wọlé ìfarajúwe rẹ kẹta |
Re-enter your third gesture |
17530 | Paá rẹ́ |
Cancel |
17531 | O ti ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòrán láṣeyọrí . Lo ó nígbà mìíràn láti wọlé sí Windows. |
You’ve successfully created your picture password. Use it the next time you sign in to Windows. |
17533 | Ṣàtúntò ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòráan |
Reset picture password |
17535 | 0 |
0 |
17536 | Lo àwọn àwòrán tó ní ìbádọ́gba |
Use synced picture |
17538 | Ṣàtúnṣeré |
Replay |
17539 | Ó DÁA |
OK |
17540 | Láti ṣàrídájú ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòrán lọ́wọ́lọ́wọ́, kàn wo ìṣàtúnṣeré kí o tọ́ àpẹẹrẹ ìfarajúwe tí ó hàn lórí àwòrán rẹ. |
To confirm your current picture password, just watch the replay and trace the example gestures shown on your picture. |
17541 | Gbíyanjú ṣíṣe ìfarajúwe rẹ lẹ́ẹ̀kansíi. |
Try making your gestures again. |
17543 | 20;light;none;segoe ui |
20;light;none;segoe ui |
17544 | 11;light;none;segoe ui |
11;light;none;segoe ui |
17545 | 56;normal;none;segoe ui |
56;normal;none;segoe ui |
17546 | Ọ̀rọ̀ aṣínà Aláwòrán |
Picture password |
17547 | Ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán rẹ ní ọ̀rọ̀ aṣínà àtijọ́ nínú. Jọ̀wọ́ wọlé pẹ́lú ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ tuntun. |
Your picture password enrollment contains an old password. Please sign in with your new password. |
17548 | Ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòrán kò péye. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
The picture password is incorrect. Try again. |
17550 | Ìkọrúkọsílẹ̀ kùnà |
Enrollment Failure |
17551 | Ìkùnà wáyé lákòókò ìkọrúkọsílẹ̀. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi láìpẹ́. |
There was a failure during the enrollment process. Please try again later. |
17552 | Ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòrán jẹ́ ọ̀nà tuntun láti dáàbòbo PC àláfọwọ́bà. O máa yan àwòrán náà — àti ìfarajúwe tí o máa lò pẹ̀lú rẹ̀ — láti ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ aṣínà tí o dáyàtọ̀ rẹ. |
Picture password is a new way to help you protect your touchscreen PC. You choose the picture — and the gestures you use with it — to create a password that’s uniquely yours. |
17553 | Nígbàtí o bá yan àwòrán kan, o máa “yàwòrán” sórí àgbàwòrán aláfọwọ́bà láti ṣẹ̀dá àkópọ̀ róbótó, ìlà tótọ́, àti àfọwọ́bà. Ìwọ̀n, ipò, àti ìdoríkọ ìfarajúwe máa di ẹ̀yà ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòrán. |
When you’ve chosen a picture, you “draw” directly on the touchscreen to create a combination of circles, straight lines, and taps. The size, position, and direction of your gestures become part of your picture password. |
17557 | O le ṣàpamọ́ àwòrán lọ́wọ́lọ́wọ́ rẹ kí o ṣàyípadà ìfarajúwe rẹ, tàbí kí yan àwòrán tuntun kan. |
You can keep your current picture and change your gestures, or choose a new picture. |
17559 | O kú oríre, o ti tún ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán rẹ mọ̀ láṣeyọrí. |
Congratulations, you have successfully relearned your picture password. |
17560 | O kú oríre, o ti ṣáyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán rẹ láṣeyọrí. |
Congratulations, you have successfully changed your picture password. |
17561 | Ṣe àtúnmọ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán rẹ |
Relearn your picture password |
17562 | Ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán rẹ |
Change your picture password |
17564 | 1 |
1 |
17565 | 2 |
2 |
17566 | 3 |
3 |
17567 | Báwo ni o ṣe rí? |
How’s this look? |
17568 | Ṣàgbékalẹ̀ ìfarajúwe rẹ |
Set up your gestures |
17569 | Ṣàrídájú ìfarajúwe rẹ |
Confirm your gestures |
17570 | Nǹkankan kò tọ̀nà … gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi! |
Something’s not right … try again! |
17571 | Ṣàtúntẹ̀wọlé ìfarajúwe lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Reenter your current gestures |
17572 | Nílò àtọ́nà bí? Tọ àwọn àpẹẹrẹ tí ó hàn lórí àwòrán rẹ. |
Need a hint? Just trace the examples shown on your picture. |
17573 | Tí o bá ti gbàgbé àwọn ìfarajúwe rẹ, fọwọkàn Ṣàtúnṣeré láti wò wọ́n. |
If you’ve forgotten your current set of gestures, tap Replay to see them. |
17574 | Kú Oríire! |
Congratulations! |
17579 | Má bínú, ṣùgbọ̀n ìṣàrídájú ìfarajúwe kò bá èyí tí o yà mu. O le gbìyànjú láti rí àwọn ìfarajúwé tí o kọ́kọ́ ṣàtẹ̀wọlé, tàbí bẹ̀rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ láti yan tuntun kan. |
Sorry, but your confirmation gestures didn’t quite match the ones you drew. You can try again to see the gestures you first entered, or start over to choose new ones. |
17580 | Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan si |
Try again |
17581 | Nǹkankan kò tọ̀nà |
Something’s not right |
17582 | Parí |
Finish |
17584 | Ìkọrúkọ̀sílẹ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán ni a ti ṣàfikún láṣeyọrí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ aṣinà lọ́wọ́lọ́wọ́. |
Your picture password enrollment has been successfully updated with your current password. |
17586 | Má bínú, ṣùgbọ́n ìṣàrídájú ìfarajúwe rẹ kò bá èyí tí o yà mu. O le gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi láti wo ìfarajúwe tí o kọ́kọ́ ṣàtẹ̀wọlé. |
Sorry, but your confirmation gestures didn’t quite match the ones you drew. You can try again to see the gestures you first entered. |