| 101 | Ẹ̀dà àbọ̀ábá nípa lílo Ìtàn Fáìlì |
Back up using File History |
| 102 | Ṣẹ̀dà àbọ̀ábá fún àwọn fáìlì ní aládàáṣe |
Automatically back up my files |
| 103 | Ṣẹ̀dà àbọ̀ábá àwọn fáìlì rẹ sí àwo aká-ọ̀rọ̀ míràn kí o sì mú wọn padà tí ojúlówó bá sọnù, díbàjẹ́, tàbí ṣèparẹ́. |
Back up your files to another drive and restore them if the originals are lost, damaged, or deleted. |
| 104 | Ṣàfikún àwo aká-ọ̀rọ̀ kan |
Add a drive |
| 105 | Dá lílo àwo aká-ọ̀rọ̀ dúró |
Stop using drive |
| 106 | Ṣẹ̀dà àbọ̀ábá sí àwo aká-ọ̀rọ̀ míràn |
Back up to a different drive |
| 107 | Wàá ní láti dá lílo àwo aká-ọ̀rọ̀ ẹ̀dà àbọ̀ábá rẹ dúró kí o tó ṣàfikún titun kan. Èyí kò ní ṣèparẹ́ èyíkéyìí àwọn fáìlì nínú àwo aká-ọ̀rọ̀ ẹ̀dá àbọ̀ábá rẹ. |
You'll need to stop using your current backup drive before you add a new one. This won't delete any files from your current backup drive. |
| 108 | Ìpàtẹ ìwò |
Overview |
| 109 | Àwọn ẹ̀yàn àbọ̀ábá |
Backup options |
| 110 | Ọ̀pọ̀ àwọn ẹ̀yàn |
More options |
| 111 | Kínni àwọn ohun tí a ń ṣẹ̀dà àbọ̀ábá fún? |
What gets backed up? |
| 112 | %1 (%2!c!:) |
%1 (%2!c!:) |
| 113 | Dísíkì Tí ó seẹ́ Yọkúrò |
Removable Disk |
| 114 | Dísíkì Ìbílẹ̀ |
Local Disk |
| 115 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ Alásopọ̀ |
Network Drive |
| 116 | Ṣàfihàn gbogbo ibi alásopọ̀ |
Show all network locations |
| 117 | Ṣẹ̀dà àbọ̀ábá fún àwọn fáìlì mi |
Back up my files |
| 118 | Gbogbo ìṣẹ́jú 10 |
Every 10 minutes |
| 119 | Gbogbo ìṣẹ́jú 15 |
Every 15 minutes |
| 120 | Gbogbo ìṣẹ́jú 20 |
Every 20 minutes |
| 121 | Gbogbo ìṣẹ́jú 30 |
Every 30 minutes |
| 122 | Gbogbo wákàtí (àkùnàyàn) |
Every hour (default) |
| 123 | Gbogbo wákàtí 3 |
Every 3 hours |
| 124 | Gbogbo wákàtí 6 |
Every 6 hours |
| 125 | Gbogbo wákàtí 12 |
Every 12 hours |
| 126 | Ojojúmọ́ |
Daily |
| 127 | Títí láíláí (àkùnàyàn) |
Forever (default) |
| 128 | Títí yóò fi nílò ààyè |
Until space is needed |
| 129 | Ọdún 2 |
2 years |
| 130 | Ọdún 1 |
1 year |
| 131 | Oṣù 9 |
9 months |
| 132 | Oṣù 6 |
6 months |
| 133 | Oṣù 3 |
3 months |
| 134 | Oṣù 1 |
1 month |
| 135 | Tọ́jú àwọn ẹ̀dà àbọ̀ábá mi |
Keep my backups |
| 136 | Ṣẹ̀dà àbọ̀ábá fún àwọn fódà wọ̀nyí |
Back up these folders |
| 138 | Ṣàfikún fódà kan |
Add a folder |
| 139 | Yọ àwọn fódà wọ̀nyí kúrò |
Exclude these folders |
| 141 | Àwọn ààtò tójọra |
Related settings |
| 142 | Wo àwọn ààtò ìjìnlẹ̀ |
See advanced settings |
| 143 | Dá àwọn fáìlì padà sípò láti ẹ̀dà àbọ̀ábá ìsinsìnyí |
Restore files from a current backup |
| 144 | Ṣàrídájú pé %1 sopọ̀ kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
Make sure %1 is connected and try again. |
| 145 | A kò le sopọ̀ mọ́ %1 báyìí. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. |
We can't connect to %1 right now. Try again later. |
| 146 | Lọ sí Aṣàwákiri Fáìlì, ṣí %1, ṣàtẹ̀wọlé àwọn ohun ẹ̀rí rẹ, kí o sì gbìyànjú ṣíṣe ẹ̀dà àbọ̀ábá lẹ́ẹ̀kan síi. |
Go to File Explorer, open %1, enter your credentials, and try backing up again. |
| 147 | BitLocker ń dá ààbò bo %1.Ṣí àwo aká-ọ̀rọ̀ náà kí o sì gbìyànjú ṣíṣe ẹ̀dà àbọ̀ábá lẹ́ẹ̀kan síi. |
BitLocker is protecting %1.Unlock the drive and try backing up again. |
| 148 | %1 lórí %2 |
%1 on %2 |
| 149 | Ìpamọ́ Alásopọ̀ lórí %1 |
Network Storage on %1 |