credprovslegacy.dll.mui Àwọn Olùpèsè Ohun Ẹ̀rí Tàtijọ́ b7f4a36b8dfb7c9796e85261d52d4a74

File info

File name: credprovslegacy.dll.mui
Size: 9728 byte
MD5: b7f4a36b8dfb7c9796e85261d52d4a74
SHA1: 3119baed6bacafc0514b10f0c404bde39f78acb5
SHA256: ef8facf013b65b94b3c6dd73f94a6a5ac61714b9e5eb8212c5eb9e3d3558a564
Operating systems: Windows 10
Extension: MUI

Translations messages and strings

If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.

id Yoruba English
101Ọ̀rọ̀ aṣínà kò péye. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. The password is incorrect. Try again.
102Àkọọ́lẹ̀ rẹ ní àwọn ìdíwọ́ àkókò tí kò jẹ́kí o lè wọlé nísìnyí. Jọ̀wọ́ gbìyànjú síi láìpẹ́. Your account has time restrictions that prevent you from signing in at this time. Please try again later.
103Àkọọ́lẹ̀ rẹ wà ní àtòpọ̀ tí ó ńdènà rẹ láti lo kọ̀ǹpútà yìí. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lóríi kọ̀ǹpútà mìíràn. Your account is configured to prevent you from using this PC. Please try another PC.
104Ati pa àyè rẹ. Jọ̀wọ́ kàn sí alábòójútó ẹrọ rẹ. Your account has been disabled. Please see your system administrator.
105Àyè rẹ ti parí. Jọ̀wọ́ kàn sí alábòójútó ẹrọ rẹ. Your account has expired. Please see your system administrator.
106Láti wọlé sí ọ̀nà jínjìn, o nílò ẹ̀tọ́ láti wọlé nípa ní láti Gbà ẹ́ láyè ìwọlé nípa òfin Isẹ́ Ìdádúró. Nípa àkùnàyàn, àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Àwọn Àkójọpọ̀ Aṣàmúlò Àtẹ iṣẹ́ Ìjìnnà ní àyè yìí. Tí o bá kìń se ọmọ ẹgbẹ́ Àwọn ìpèsè Àtẹ iṣẹ́ tàbí ẹgbẹ́ mìíràn tó ní àyè yìí, tàbí tí ẹgbẹ́ Àwọn Àkójọpọ̀ Aṣàmúlò Àtẹ iṣẹ́ Ọ̀nàjínjìn kò bá ní àyè yìí, a ní láti gbà ẹ́ láàyè yìí pẹ̀lú ọwọ́. To sign in remotely, you need the right to sign in through Remote Desktop Services. By default, members of the Administrators group have this right. If the group you're in doesn't have this right, or if the right has been removed from the Administrators group, you need to be granted this right manually.
107Láti ṣe ìwọlésí ọ̀lọ́nà jínjìn, o nílò ẹ̀tọ́ láti wọlé nípa Ìpèsè Àtẹ iṣẹ́ Ọlọ́nàjínjìn. Nípa àkùnàyàn, ọmọ ẹgbẹ́ Aṣàmúlò Àtẹ iṣẹ́ ọ́nàjínjìn ní ẹ̀tọ́ yìí. Tí ọ̀wọ́ tí o wà kò bá ní ẹ̀tọ́ yìí, tàbí tí ẹ̀tọ́ yìí bá ti di yíyọkúrò láti Ọ̀wọ́ Aṣàmúlò Àtẹ iṣẹ́ ọ́nàjínjìn, o nílò láti gba ẹ̀tọ́ yìí ní aláfọwọ́ṣe. To sign in remotely, you need the right to sign in through Remote Desktop Services. By default, members of the Remote Desktop Users group have this right. If the group you're in doesn't have this right, or if the right has been removed from the Remote Desktop Users group, you need to be granted this right manually.
109A kò lè ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà lórí àyè aṣàmúlò ní àkókò yìí. The password on this account cannot be changed at this time.
110Ọ̀rọ̀ asínà rẹ ti dópin. Láti ṣètò ọ̀rọ̀ aṣínà titun, yan Ó DÁA, yan Yí aṣàmúlò po, tún ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ ìsinsìnyí tẹ̀wọlé, lẹ́yìn náà tẹ̀lé àwọn ìfitónilétí lórí asàfihàn náà. Your password has expired. To set a new password, select OK, select Switch user, reenter your current password, and then follow the prompts on the screen.
111Ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ ti dópin o sì nílò ìyípadà. Your password has expired and must be changed.
112Ìlànà ìwọlé tí o ń gbìyànjú láti lò ni a kò gbàláyè. Fún ìwífún síwájú síi, kàn sí alábòójútó alásopọ̀ rẹ. The sign-in method you're trying to use isn't allowed. For more info, contact your network administrator.
113A ti ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ. Your password has been changed.
114O ní láti sàmúlò káàdì amúṣẹ́yá láti wọlé. You must use a smart card to sign in.
116Kóòdù ìwọlé tí o lò kò báa mu. The passwords you entered did not match.
117Jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé orúkọ aṣàmúlò àti ọ̀rọ̀ aṣínà. Please enter a user name and password.
121Orúkọ aṣàmúlò tàbí ọ̀rọ̀ aṣínà kòpéye. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansíi. The user name or password is incorrect. Try again.
125Ọ̀rọ̀ aṣínà Tuntun New password
126Fídí ọ̀rọ̀ aṣínà Múlẹ̀ Confirm password
127Fàkalẹ̀ Submit
13000Orúkọ aṣàmúlò User name
13001Ọ̀rọ̀ aṣínà Password
13002Ọ̀rọ̀ aṣínà tẹ́lẹ̀ Old password
13005Orúkọ tó fanimọ́ra Friendly name
13006Ipò aṣàmúlò User status
13009Aṣàmúlò mìíràn Other user
13010Sí Kọ̀ǹpútà náà Unlock the PC
13011Ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà kan Change a password
13012Lo àkọọ́lẹ̀ míràn Use a different account
13013Àwòrán àkọọ́lẹ̀ Account picture
13015Báwo ni mo ṣe lè wọlé sí agbègbè ìkápá mìíràn? How do I sign in to another domain?
13016Tẹ orúkọ agbègbè ìkápá \orúkọ aṣàmúlò agbègbè ìkápá láti wọlé sí agbègbè ìkápá mìíràn

Tẹ %1\orúkọ aṣàmúlò ìbílẹ̀ láti wọlé sí Kọ̀ǹpútà yìí nìkan (kìi ṣe agbègbè ìkápá kan).
Type domain name\domain user name to sign in to another domain.

Type %1\local user name to sign in to this PC only (not a domain).
13017Wọlé sí: %s Sign in to: %s
13018Wọlé sí Sign in to
13020Agbègbè: %s Domain: %s
13021Àgbègbè ìkápá Domain
13022Atọ́nà ọ̀rọ̀ aṣínà Password hint
13023Ṣàtúntò Ọ̀rọ̀ Aṣínà Reset password
13024Ṣẹ̀dá dísíkì aṣàtúntò ọ̀rọ̀ aṣínà Create a password reset disk
13025Atọ́nà ọ̀rọ̀ aṣínà: %s Password hint: %s
13026Rántí àwọn ìwé ẹ̀rí mi Remember my credentials
13028Ọ̀rọ̀ aṣínà àkọọ́lẹ̀ àgbègbè ìkápá tàbí abẹ́lé Local or domain account password
13029A kò le sopọ̀ báyìí. Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò alásopọ̀ rẹ kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. We are unable to connect right now. Please check your network and try again later.
13030Àkọọ́lẹ̀ iṣẹ́ tàbí ilé-ìwé rẹ Your work or school account
13031O kò le wọlé pẹ̀lú ID aṣàmúlò kan ní ìgúnrégé yìí. Gbìyànjú láti lo àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì rẹ dípò. You can't sign in with a user ID in this format. Try using your email address instead.
13032Àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì Email address
17004PIN PIN
17005Afikóòdùwọlé rẹ ní ọ̀rọ̀ aṣínà àtijọ́ nínú. Jọ̀wọ́ wọlé pẹ̀lú ọ̀rọ̀ aṣínà tuntun rẹ. Your PIN Sign-in enrollment contains an old password. Please sign in with your new password.
17006PIN kò péye. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. The PIN is incorrect. Try again.
17028Afikóòdùwọlé rẹ àtijọ́ ni a ti ṣàfikún láṣeyọrí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ lọ́wọ́lọ́wọ́. Your PIN Sign-in enrollment has been successfully updated with your current password.
17546Ọ̀rọ̀ aṣínà Aláwòrán Picture password
17547Ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán rẹ ní ọ̀rọ̀ aṣínà àtijọ́ nínú. Jọ̀wọ́ wọlé pẹ́lú ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ tuntun. Your picture password enrollment contains an old password. Please sign in with your new password.
17548Ọ̀rọ̀ aṣínà aláwòrán kò péye. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. The picture password is incorrect. Try again.
17584Ìkọrúkọ̀sílẹ̀ ọ̀rọ̀ aṣínà àwòrán ni a ti ṣàfikún láṣeyọrí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ aṣinà lọ́wọ́lọ́wọ́. Your picture password enrollment has been successfully updated with your current password.

EXIF

File Name:credprovslegacy.dll.mui
Directory:%WINDIR%\WinSxS\amd64_microsoft-windows-c..y-library.resources_31bf3856ad364e35_10.0.15063.0_yo-ng_5a89030d5a8cb815\
File Size:9.5 kB
File Permissions:rw-rw-rw-
File Type:Win32 DLL
File Type Extension:dll
MIME Type:application/octet-stream
Machine Type:Intel 386 or later, and compatibles
Time Stamp:0000:00:00 00:00:00
PE Type:PE32
Linker Version:14.10
Code Size:0
Initialized Data Size:9216
Uninitialized Data Size:0
Entry Point:0x0000
OS Version:10.0
Image Version:10.0
Subsystem Version:6.0
Subsystem:Windows GUI
File Version Number:10.0.15063.0
Product Version Number:10.0.15063.0
File Flags Mask:0x003f
File Flags:(none)
File OS:Windows NT 32-bit
Object File Type:Dynamic link library
File Subtype:0
Language Code:Unknown (046A)
Character Set:Unicode
Company Name:Microsoft Corporation
File Description:Àwọn Olùpèsè Ohun Ẹ̀rí Tàtijọ́
File Version:10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800)
Internal Name:credprovslegacy.dll
Legal Copyright:© Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́.
Original File Name:credprovslegacy.dll.mui
Product Name:Microsoft® Windows® Operating System
Product Version:10.0.15063.0
Directory:%WINDIR%\WinSxS\wow64_microsoft-windows-c..y-library.resources_31bf3856ad364e35_10.0.15063.0_yo-ng_64ddad5f8eed7a10\

What is credprovslegacy.dll.mui?

credprovslegacy.dll.mui is Multilingual User Interface resource file that contain Yoruba language for file credprovslegacy.dll (Àwọn Olùpèsè Ohun Ẹ̀rí Tàtijọ́).

File version info

File Description:Àwọn Olùpèsè Ohun Ẹ̀rí Tàtijọ́
File Version:10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800)
Company Name:Microsoft Corporation
Internal Name:credprovslegacy.dll
Legal Copyright:© Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́.
Original Filename:credprovslegacy.dll.mui
Product Name:Microsoft® Windows® Operating System
Product Version:10.0.15063.0
Translation:0x46A, 1200