500 | Jọ̀wọ́ Dúró |
Please Wait |
501 | Àyẹ̀wò Ààbò |
Security Check |
1000 | Gbìyànjú ìyẹn lẹ́ẹ̀kan síi |
Try that again |
1001 | Ohunkan ṣẹlẹ̀ ní ọ̀dọ̀ wa. Dídúró díẹ̀ le ṣèrànwọ́. Kóòdù afìkùnàn náà jẹ́ %1, tí ó bá ṣẹlẹ̀ pé o nílò rẹ̀. |
Something happened on our end. Waiting a bit might help. The error code is %1, in case you need it. |
1002 | O nílò òbí tàbí alágbàtọ́ rẹ láti ra ǹkan |
You need your parent or guardian to buy stuff |
1003 | O le lo gbogbo àwọn ìfilọ́lẹ̀ àti eré lórí Aṣàfihàn Ìbẹ̀rẹ̀ Igun Ọmọdé. |
You can use all the apps and games on the Kid’s Corner Start Screen. |
1004 | Ra Ìfilọ́lẹ̀ míràn |
Shop for another App |
1005 | %1 kò sí nílẹ̀ mọ́ láti Ìtajà Oníforíkorí. |
%1 is no longer available from Store. |
1006 | Yan wúnrẹ̀n míràn |
Choose another item |
1007 | Wúnrẹ̀n ìrajà inú-ìfilọ́lẹ̀ yìí kò sí nílẹ̀ mọ́ nínú %1. |
This in-app purchase item is no longer available in %1. |
1008 | Ra ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ẹ̀yà |
Buy the full version |
1009 | O ní láti ra ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ẹ̀yà ti %1 láti Ìtajà Oníforíkorí láti rajà inú-ìfilọ́lẹ̀ kan. |
You need to buy the full version of %1 from Store to make an in-app purchase. |
1010 | Ṣàyẹ̀wò Ìsopọ̀ íntánẹ́ẹ̀tì rẹ |
Check your Internet connection |
1011 | Ṣàrídájú pé o sopọ̀ lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
Make sure you're connected, then try again. |
1012 | Kàn sí alábòójútó ìlànà-ètò rẹ |
Contact your system administrator |
1013 | Ìtajà Oníforíkorí kò sí nílẹ̀ lọ́wọ́lọ́wọ́ lórí ohun èlò yìí. |
Store isn't currently available on this device. |
1014 | Ìrajà rẹ kò le parí |
Your purchase can't be completed |
1015 | O wà ní agbègbè tí kò ṣàtìlẹ́yìn fún àwọn ìrajà nínú Ìtajà Oníforíkorí. |
You're in a region that doesn't support purchases in Store. |
1016 | Ìtajà Oníforíkorí kò sí nílẹ̀ |
Store isn't available |
1017 | O wà ní agbègbè kan níbití Ìtajà Oníforíkorí kò sí nílẹ̀. |
You're in a region where Store isn't available. |
1018 | Ṣàyẹ̀wò àwọn ààtò agbègbè rẹ |
Check your region settings |
1019 | O kò le ra àgbéjáde yìí nítorí o farahàn bíi wípé o wà ní agbègbè tó yàtọ̀ sí àwọn ààtò Ìtajà Oníforíkorí. |
You can't buy this product because you appear to be in a different region than Store settings. |
1020 | Wọlé sínú Ìtajà Oníforíkorí |
Sign in to Store |
1021 | Láti parí ìrajà rẹ, wọlé pẹ̀lú àkọọ́lẹ̀ Microsoft rẹ, lẹ́yìn náà gbìyànjú ìrajà rẹ lẹ́ẹ̀kan síi. |
To complete your purchase, sign in with your Microsoft account, then try your purchase again. |
1022 | Padé |
Close |
1023 | Ṣé o fẹ́ dín ìrírí ìrajà rẹ kù bí? |
Streamline your purchase experience? |
1024 | Nígbàtí o bá rajà láti Ìtajà Oníforíkorí, a kò ní bèrè ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ. O le ṣàyípadà rẹ̀ nígbàkugbà nínú àwọn ààtò Ìtajà Oníforíkorí. |
When you buy from the Store, we won’t ask for your password. You can change it any time in Store settings. |
1025 | Bẹ́ẹ̀ni |
Yes |
1026 | Rárá |
No |
1027 | Tún ṣàgbékalẹ̀ láti Ìtajà Oníforíkorí |
Reinstall from the Store |
1028 | Yọ ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí kúrò (lọ sí Àwọn Ààtò Ìlànà ètò Àwọn Ìṣàfilọ́lẹ̀ & àfidámọ̀) lẹ́yìn náà ṣàgbékalẹ̀ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan síi láti ojú ìwé àgbéjáde nínú Ìtajà Oníforíkorí Windows. O ni láti sọ ìgbaniláyè rẹ dọ̀tun láti ra àwọn ọjà inú ìṣàfilọ́lẹ̀. |
Uninstall this app (go to Settings System Apps & features) and then install it again from the product page in Windows Store. Your license needs to be refreshed to make in-app purchases. |
2000 | Àwọn àfikún ń dúró láti ṣàgbékalẹ̀ nínú %1.%2 |
Updates are waiting to be installed in %1.%2 |
2001 | Ṣé o fẹ́ gba ẹ̀dà fáìlì àfikún sílẹ̀ báyìí? |
Download updates now? |
2002 | Ó dáa |
Okay |
2003 | Bóyá nígbà míràn |
Maybe later |
2004 | Àwọn àfikún ń dúró láti ṣàgbékalẹ̀. %1 le ní láti ṣàtúnbẹ̀rẹ̀. |
Updates are waiting to be installed. %1 might need to restart. |
2005 | Ṣé o fẹ́ ṣàfikún kí o sì ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ báyìí? |
Update and restart now? |
2008 | Ṣé o fẹ́ gba ẹ̀dà fáìlì sílẹ̀ báyìí bí? |
Download content now? |
2009 | Ṣé kí a gba ẹ̀dà fáìlì sílẹ̀ kí a sì ṣàgbékalẹ̀ àkóónú aláfikún yìí fún %1?%2 |
Should we download and install this extra content for %1?%2 |
2012 | O wà lórí ìsopọ̀ àlòsanwó, fún ìdí èyí a le ṣàmúlò ìdíyelé dátà. |
You're on a metered connection, so data charges might apply. |
0x30000000 | Info |
Info |
0x30D1000C | Error |
Error |
0x30D1000D | Warning |
Warning |
0x30D1000F | Verbose |
Verbose |
0x50000004 | Information |
Information |
0x70000001 | StorefrontClient |
StorefrontClient |
0x700007D0 | Store SDK Module Loaded |
Store SDK Module Loaded |
0x700007D1 | In-App Purchase |
In-App Purchase |
0x70000BB9 | Store Purchase App |
Store Purchase App |
0x90000001 | Windows-ApplicationModel-Store-SDK |
Windows-ApplicationModel-Store-SDK |
0xB0000001 | %1%nError Code: %5%nFunction: %4%nSource: %3 (%2) |
%1%nError Code: %5%nFunction: %4%nSource: %3 (%2) |
0xB0000002 | %1%nException Details: %5%nFunction: %4%nSource: %3 (%2) |
%1%nException Details: %5%nFunction: %4%nSource: %3 (%2) |
0xB0000003 | %1%nFunction: %4%nSource: %3 (%2) |
%1%nFunction: %4%nSource: %3 (%2) |
0xB00007D0 | Process Name: %1%nModule Name: %2%nBuild: %3%n |
Process Name: %1%nModule Name: %2%nBuild: %3%n |
0xB00007D1 | %1%nError: %3%nFunction: %2%nSource: %4 (%5) |
%1%nError: %3%nFunction: %2%nSource: %4 (%5) |