File name: | ncryptprov.dll.mui |
Size: | 4096 byte |
MD5: | a3652517dd17e70e39954dbb7bef482c |
SHA1: | 44f9d04c0ea27c8f9ea7f561cbbc3c42c931e8b8 |
SHA256: | a37d3a446b523f9b321c6f5841c1319fa660ba2977bfbc78bea6b3ad3f946620 |
Operating systems: | Windows 10 |
Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id | Yoruba | English |
---|---|---|
1200 | Ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí nílò láti ṣẹ̀dá bọ́tìnnì ìkọlẹ́nà kan | This app needs to create a cryptographic key |
1201 | Nílò ohun ẹ̀rí | Credential Required |
1202 | Àtòjọ ètò yìí máa bèèrè ìyànda rẹ nígbàtí ó bá ṣí kọ́kọ́rọ́ yìí. Èyí máa ṣèrànwọ́ láti dènà lílò àtòjọ ètò àti dátà tí kò bófinmu. | The application will request your permission when it opens this key. This helps prevent unauthorized use of the application and data. |
1203 | Ǹjẹ́ o fẹ́ fààyègba ìṣàfilọ́lẹ̀ náà láti ráyèsí kọ́kọ́rọ́ ìpamọ́ rẹ bí? | Do you want to allow the app to access your private key? |
1204 | Láti fààyègba ìṣàfilọ́lẹ̀ náà láti ráyèsí kọ́kọ́rọ́ ìpamọ́ rẹ, ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀ aṣínà náà: | To allow the app to access your private key, enter the password: |
1205 | Láti fààyègba ìṣàfilọ́lẹ̀ náà láti ráyè sí ìpamọ́ rẹ, ṣẹ̀dà àwòrán ìkà tí a ti ṣèforúkọsílẹ̀ rẹ̀ lórí i òǹkà ìlà-ìka-ọwọ́. | To allow the app to access your private key, scan an enrolled finger on the fingerprint reader. |
1206 | Orúkọ bọ́tìnnì : %ls |
Key name : %ls |
1207 | Bọ́tìnnì ìṣàpèjúwe : %ls |
Key description : %ls |
1208 | Fààyègbà | Allow |
1209 | Máṣe fààyègbà | Don't allow |
4000 | Kọ́kọ́rọ́ Ìpamọ́ CryptoAPI | CryptoAPI Private Key |
File Description: | Microsoft KSP |
File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
Company Name: | Microsoft Corporation |
Internal Name: | ncryptprov.dll |
Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́. |
Original Filename: | ncryptprov.dll.mui |
Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
Product Version: | 10.0.15063.0 |
Translation: | 0x46A, 1200 |