2 | Ìsẹ́jú àáyà %d%s%d |
%d%s%d seconds |
3 | Kọ́ nípa àfikún ìrànwọ́ àwọn ìmọ̀ ẹ̀rọ lóníforíkorí |
Learn about additional assistive technologies online |
4 | Àwọn ìdàhùn rẹ ni a lò fi pinu àwọn ààtò tì a gbàníyànjú nìkan. Tí àtòjọ-ètò míràn tàbí ojúlé Wéébù bá fé lo ìròyìn tí o bá ìnìlò rẹ mu, needs,a ma gba ìgbàláyè taratara lówó ẹ nípa àtòjọ-ètò. Gbólóhùn ìpamó |
Your answers are used to determine recommended settings only. If another program or Web site wants to use this information to better suit your needs, you will be explicitly asked for permission by that program. Privacy Statement |
5 | àwọn ìṣẹ́jú %d |
%d minutes |
6 | ìṣẹ́jú 1 |
1 minute |
7 | Ìṣẹ́jú ààyá %d |
%d seconds |
10 | Ibi Ìrọ̀rùn ìgbàwọlé |
Ease of Access Center |
45 | Jẹ́ kí kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò. |
Make your computer easier to use. |
46 | Gba àwọn ìfọwọ́sí láti leè mú kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò (àfojúrí) |
Get recommendations to make your computer easier to use (eyesight) |
47 | Gba àwọn ìfọwọ́sí láti leè mú kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò (aápọn) |
Get recommendations to make your computer easier to use (dexterity) |
48 | Gba àwọn ìfọwọ́sí láti leè mú kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò (gbígbọ́) |
Get recommendations to make your computer easier to use (hearing) |
49 | Gba àwọn ìfọwọ́sí láti leè mú kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò (sísọ̀rọ̀) |
Get recommendations to make your computer easier to use (speech) |
50 | Gba àwọn ìfọwọ́sí láti leè mú kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò (ríronú) |
Get recommendations to make your computer easier to use (cognitive) |
56 | Lo kọ̀ǹpútà náà láìsí àfihàn |
Use the computer without a display |
57 | Jẹ́ kí kọ̀ǹpútà rọrùn láti lò |
Make the computer easier to see |
58 | Jẹ́ kí atọ́ka rọrùn láti lò |
Make the mouse easier to use |
59 | Jẹ́ kí àtẹ bọ́tìnnì rọrùn láti lò |
Make the keyboard easier to use |
60 | Lo kọ̀ǹpútà náà láìsí atọ́ka tàbí àtẹ bọ́tìnnì |
Use the computer without a mouse or keyboard |
61 | Lo ọ̀rọ̀ tàbí àwọn ọ̀nà mìíràn ti ìfihàn fún àwọn ohùn |
Use text or visual alternatives for sounds |
62 | Jẹ́ kí o rọrùn láti dojúkọ àwọn iṣẹ́ |
Make it easier to focus on tasks |
63 | Ṣe Àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Atọ́ka |
Set up Mouse Keys |
64 | Ṣe Àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Aṣẹ́ |
Set up Filter Keys |
65 | Se àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Àtúnse àti Ìlọ́ra |
Set up Repeat and Slow Keys |
66 | Àwọn àgbékalẹ̀ tí a gbàníyànjú |
Recommended settings |
67 | Ṣàyípadà ìṣètò ìfọwọ́sí-wọlé |
Change sign-in settings |
68 | Ṣe àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlẹ̀mọ́ |
Set up Sticky Keys |
70 | Yàn Ìyàtọ̀ &Gíga kókó |
Choose a High Cont&rast theme |
72 | %s Lẹ̀yìn ìfọwọ́sí-wọlé |
%s after sign-in |
73 | %s ní ìfọwọ́sí-wọlé |
%s at sign-in |
74 | Gbọ́ ọ̀rọ̀ orí aṣàfihàn kà sókè (olùṣàlàyé) |
Hear text on screen read aloud (Narrator) |
75 | Mú kí àwọn ohun ojú aṣàfihàn tóbi (Amóhuntóbi) |
Make items on the screen larger (Magnifier) |
76 | Tẹ̀ lá lo àtẹ bọ́tìnnì (Àtẹ bọ́tìnnì Orí-aṣàfihàn) |
Type without the keyboard (On-Screen Keyboard) |
78 | Tẹ àwọn àbùjá àtẹ bọ́tìnnì kọ́kọ́rọ́ kan lẹ́ẹ̀kan (àwọn Kọ́kọ́rọ́ ìsisẹ́) |
Press keyboard shortcuts one key at a time (Sticky Keys) |
79 | Tí mo bá tẹ àwọn kọ́kọ́rọ́ léraléra, pa àfikún àwọn títẹ̀ tì (àwọn Kọ́kọ́rọ́ asẹ́) |
If I press keys repeatedly, ignore extra presses (Filter Keys) |
80 | Lo àtẹ bọ́tìnnì onínọ́nbà látí máa sún àtọ́ka káàkiri àṣàfihàn (Bọ́tìnnì Àtọ́ka) |
Use the numeric keypad to move the mouse around the screen (Mouse Keys) |
81 | Gbọ́ ohùn dídùn nígbàtí o bá tẹ CAPS LOCK, NUM LOCK, or SCROLL LOCK (Àwọn Bọ́tìnnì Ìṣípòpadà) |
Hear a tone when you press CAPS LOCK, NUM LOCK, or SCROLL LOCK (Toggle Keys) |
82 | Mú kí àfọwọ́kàn àti àwọn tábúlẹ̀ẹ̀tì rọrùn láti lò |
Make touch and tablets easier to use |
83 | Olùṣàlàyé |
Narrator |
84 | Amútóbi |
Magnifier |
85 | Àtẹ bọ́tìnnì Orí-Aṣàfihàn |
On-Screen Keyboard |
86 | Kò sí |
None |
1102 | Àwọn olùtọ̀nà atọ́ka |
Mouse pointers |
1103 | Darí atọ́ka náà pẹ̀lú àbùjá àtẹ bọ́tìnnì |
Control the mouse with the keyboard |
1105 | Other programs installed |
Other programs installed |
1106 | Dédé F&unfun |
&Regular White |
1107 | &Dédé Dúdú |
Reg&ular Black |
1108 | Dédé Ìdorí&kodò |
Re&gular Inverting |
1109 | Fu&nfun Ńlá |
&Large White |
1110 | Dúdú Ńl&á |
Large &Black |
1111 | Ìd&oríkodò Ńlá |
Large &Inverting |
1112 | Ọ̀pọ̀ &Funfun Ńlá |
E&xtra Large White |
1113 | Ọ̀&pọ̀ Dúdú Ńlá |
Extra Large Blac&k |
1114 | Ọ̀pọ̀ Ìdo&ríkodò Ńlá |
Extra Large I&nverting |
1115 | &Bẹ̀rẹ̀ fèrèsé kan nípa lílọ́ sí orí rẹ̀ pẹ̀lú atọ́ka |
Activate a &window by hovering over it with the mouse |
1117 | Gbọ́ ọ̀rọ̀ àti àwọn àpèjúwe kàá sókè |
Hear text and descriptions read aloud |
1118 | Jẹ́ kí àwọn ohun tówà lórí aṣàfihàn tóbi jù |
Make things on the screen larger |
1119 | Jẹ́ kí àwọn ohun tówà lórí aṣàfihàn rọrùn láti rí |
Make things on the screen easier to see |
1121 | Tan Olù&mútóbi |
Turn on Mag&nifier |
1124 | Lo àwọn ohun rírí dípò àwọn ohùn |
Use visual cues instead of sounds |
1127 | Jẹ́ kí o rọrùn láti dojúkọ àwọn isẹ́ |
Make it easier to focus on tasks |
1129 | Jẹ́ kí o rọrùn láti tẹ̀ |
Make it easier to type |
1131 | Ṣàyípadà àwọn ìṣètò fífọwọ́sí wọlé |
Change sign-in settings |
1138 | Jẹ́ kí kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò |
Make your computer easier to use |
1139 | Ìgbàláyè kíákíá sí àwọn irinṣẹ́ tí o wọ́pọ̀ |
Quick access to common tools |
1141 | Máa &ka apá yìí sókè ní gbogbo ìgbà |
Al&ways read this section aloud |
1142 | Máa ṣe àyẹ̀wò apá yìí nígbà gbogb&o |
Always scan this secti&on |
1143 | &Bẹ̀rẹ̀ Olùmútóbi |
Start Ma&gnifier |
1144 | Bẹ̀rẹ̀ O&níròyìn |
Start &Narrator |
1145 | Bẹ̀rẹ̀ Àbùjá-orí-àtẹ &Lórí-Aṣàfihàn |
Start On-Screen &Keyboard |
1148 | Ṣàgbékalẹ̀ Ìfi&hàn Àwọ̀ Kedere |
Set &up High Contrast |
1153 | Ṣàyẹwò gbogbo àwọn àgbékalẹ̀ |
Explore all settings |
1155 | Lo fún ìfọ́jú dáradára |
Optimize for blindness |
1157 | Lo àfihàn àfojúrí dáradára |
Optimize visual display |
1158 | Lo kọ̀ǹpútà náà láìsí atọ́ka tàbí àbùjá àtẹ bọ́tìnnì |
Use the computer without a mouse or keyboard |
1159 | Ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ohun èlò ìtẹ̀wọlé mìíràn |
Set up alternative input devices |
1161 | Ṣàtúnṣe àwọn àgbékalẹ̀ fún àtọ́ka náà tàbí àwọn ohun èlò ìtọ́ka mìíràn |
Adjust settings for the mouse or other pointing devices |
1162 | Jẹ́ kí àbùjá àtẹ bọ́tìnnì rọrùn láti lò |
Make the keyboard easier to use |
1163 | Ṣàtúnṣe àwọn àgbékalẹ̀ fún àbùjá àtẹ bọ́tìnnì náà |
Adjust settings for the keyboard |
1165 | Ṣe àgbékalẹ̀ àwọn ọ̀nà mìíràn fún ohùn |
Set up alternatives for sounds |
1167 | Ṣàtúnṣe àwọn àgbékalẹ̀ fún kíkà àti títẹ̀ |
Adjust settings for reading and typing |
1168 | Ṣàtúnṣe àwọn ìwọ̀n àkókò àti àwọn ìwò ìtànán |
Adjust time limits and flashing visuals |
1169 | Lo bọ́tìnì òùnkà láti gbé atọ́ka kiiri ojú aṣàfihàn. |
Use the numeric keypad to move the mouse around the screen. |
1171 | S&e Àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Atọ́ka |
Set up Mouse Ke&ys |
1172 | Tẹ àwọn àbùjá àtẹ bọ́tìnnì (bíi CTRL+ALT+DEL) kọ́kọ́rọ́ kan ní ìgbà kan. |
Press keyboard shortcuts (such as CTRL+ALT+DEL) one key at a time. |
1174 | &Se àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlẹ̀mọ́ |
Set up Sti&cky Keys |
1175 | Gbọ́ ohùn kan nígbàtí o bá tẹ CAPS LOCK, NUM LOCK, or SCROLL LOCK. |
Hear a tone when you press CAPS LOCK, NUM LOCK, or SCROLL LOCK. |
1176 | Tan àwọn Kọ́kọ́&rọ́ tẹ̀síwá-tẹ̀sẹ́yìn |
Turn on Toggle &Keys |
1177 | Tan àwọn Kọ́kọ́rọ́ Tọ́gù nípa títẹ kọ́kọ́rọ́ N&UM LOCK fún ìsẹ́jú àáyá 5 |
Turn on Toggle Keys by holding down the NUM LOCK key for &5 seconds |
1178 | Patì tàbí dúró díẹ̀ fún àwọn kọ́kọ́rọ́ tí àbùjá àtẹ bọ́tìnnì kí osì ṣàtúnṣe ìyárasí títẹ̀ léra wòn. |
Ignore or slow down brief or repeated keystrokes and adjust keyboard repeat rates. |
1179 | Tan àwọn Kọ́kọ́rọ́ As&ẹ́ |
Turn on F&ilter Keys |
1180 | Se Àgbékalẹ̀ àwọn &Kọ́kọ́rọ́ Asẹ́ |
Set up Fi<er Keys |
1181 | Fàlà sá&bẹ́ ọ̀nà àbùjá àtẹ bọ́tìnnì àti àwọn kọ́kọ́rọ́ ìgbàláyè |
U&nderline keyboard shortcuts and access keys |
1182 | Mú kí àbùjá àtẹ bọ́tìnnì rọrùn láti lò |
Make the keyboard easier to use |
1184 | Jẹ́ kí ó rọrùn láti lo ọ̀nà àbùjá àtẹ bọ́tìnnì |
Make it easier to use keyboard shortcuts |
1185 | Se Àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Asẹ́ |
Set up Filter Keys |
1187 | Tan àwọn Kọ́kọ́rọ́ Asẹ́ níg&bàtí a bá tẹ SHIFT ọ̀tún fún ìsẹ́jú-àáyá 8 |
Turn on Filter &Keys when right SHIFT is pressed for 8 seconds |
1188 | Àwọn ẹ̀yàn asẹ́ |
Filter options |
1189 | Tan àwọn &Kọ́kọ́rọ́ Ìdápadà |
Turn on &Bounce Keys |
1190 | Tí o bá fi àwọn ìka ọwọ́ rẹ sí orí kọ́kọ́rọ́ ní àìrò tẹ́lẹ̀, Kọ́kọ́rọ́ Ìdápadà yíò pa àwọn isẹ́kọ́kọ́rọ́ àtúnse tì títí àwọn ìgbà kan yíò fi kọjá l. |
If you unintentionally bounce your fingers on a key, Bounce Keys will ignore repeated keystrokes for a specific amount of time. |
1191 | Fún ìgbà wo ni kí kọ̀ǹpútà fi dúró kí ó tó gba àwọn isẹ́kọ́kọ́kọ́? |
How long should the computer wait before accepting keystrokes? |
1193 | &Tan àwọn Kọ́kọ́rọ́ Àtúnse àti àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlọ́ra |
Turn on &Repeat Keys and Slow Keys |
1194 | Kọ̀ǹpútà náà yíò pa àwọn ìsẹ́kọ́kọ́rọ́ díẹ̀ kan tì gẹ́gẹ́ bíi ìwọ̀nba àkókò tí o yàn. |
The computer will ignore brief keystrokes according to the time limits you set. |
1195 | &Se àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Àtúnse àti àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlọ́ra |
Set &up Repeat Keys and Slow Keys |
1196 | Tẹ̀ ọ̀rọ̀ síbí láti dán à&wọn àgbékalẹ̀ wò: |
Type text here to test setti&ngs: |
1197 | Àwọn àgbékalẹ̀ mìíràn |
Other settings |
1198 | &Dún nígbàtí a bá tẹẹ tàbí gba àwọn kọ́kọ́rọ́ kan |
Beep &when keys are pressed or accepted |
1200 | Olùṣàlàyé máa ń ka èyíkéyìí àyọkà tí o farahàn lórí aṣàfihàn sókè. O nílò àwọn gbohùngbohùn. |
Narrator reads aloud any text on the screen. You will need speakers. |
1201 | Tan &Olùṣàlàyé |
T&urn on Narrator |
1203 | Ṣàgbékalẹ̀ ìnípọn ti atọ́ka tí ń &sẹ́jú: |
Set the thickness of the &blinking cursor: |
1204 | Àkọ́gbéyẹ̀wò: |
Preview: |
1205 | Pa gbogbo àwọn ìdárayá tí kò wúlò (nígbàtí ó bá s&eése) |
Turn off all unnecessary animations (&when possible) |
1206 | &Yọ àwọn àwòrán abẹ̀lẹ̀ kúrò (níbi tí ó bá wà) |
Remove back&ground images (where available) |
1207 | Gbọ́ àwọn àpèjúwe ohun tí o ń sẹlẹ̀ nínú àwọn fídíò (nígbàtí ó bá wà). |
Hear descriptions of what's happening in videos (when available). |
1208 | Tan Àpèjúwe O&hùn |
Turn on Aud&io Description |
1209 | &Fún ìgbà wo ni àwọn àpótí ìjíròrò ìfitónilétí Windows fi máà wà ní ṣíṣí? |
How long should Windows notification dialog bo&xes stay open? |
1214 | Yẹra fún lílo atọ́ka àti àbùjá àtẹ bọ́tìnnì náà |
Avoid using the mouse and keyboard |
1215 | Sọ̀rọ̀ sí inú ẹ̀rọ ìsọ̀rọ̀ kan láti darí kọ̀ǹpútà náà, ṣí àwọn ètò, kí o sì pe ọ̀rọ̀. |
Speak into a microphone to control the computer, open programs, and dictate text. |
1216 | Lo Ì&dámọ̀ Ọ̀rọ̀ |
&Use Speech Recognition |
1217 | Tẹ̀ nípa lílo atọ́ka tàbí ohun èlò ìtọ́ka mìíràn bíi eré ìdárayá nípa yíyan àwọn kọ́kọ́rọ́ láti àwòrán kan ti àbùjá àtẹ bọ́tìnnì. |
Type using the mouse or another pointing device such as a joystick by selecting keys from a picture of a keyboard. |
1218 | L&o Àbùjá-orí-àtẹ Lórí-aṣàfihàn |
Use On-Screen &Keyboard |
1219 | Se Àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Atọ́ka |
Set up Mouse Keys |
1221 | Tan àwọn kọ́kọ́rọ́ Atọ́ka pẹ̀lú ALT òsì + SHIFT òsì + N&UM LOCK |
Turn on Mouse &Keys with left ALT + left SHIFT + NUM LOCK |
1222 | Ìyára atọ́ka |
Pointer speed |
1223 | Ìyára tí o pọ̀jù: |
Top speed: |
1224 | Kéré |
Low |
1225 | Ga |
High |
1226 | Ìyára: |
Acceleration: |
1227 | Lọ́ra |
Slow |
1228 | Yára |
Fast |
1229 | Tẹ CTRL mọ́lẹ̀ láti se ìyára àti SHI&FT láti se ìlọ́ra |
Hold do&wn CTRL to speed up and SHIFT to slow down |
1231 | Lo Kọ́kọ́rọ́ Atọ́ka nígbàtí NUM LOCK bá: |
Use Mouse Keys when NUM LOCK is: |
1232 | Tà&n án |
O&n |
1233 | Pípa |
Off |
1234 | Ṣàfihàn àwòrán Kọ́kọ́rọ́ Atọ́ka lórí pẹpẹ-i&sẹ́ |
Display the Mouse Ke&ys icon on the taskbar |
1236 | Gbọ́ ọ̀rọ̀ tí a kà sókè |
Hear text read aloud |
1237 | Se àgbékalẹ̀ Ọ̀rọ̀ láti &Sọ |
&Set up Text to Speech |
1239 | Se àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Àtúnse àti àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlọ́ra |
Set up Repeat Keys and Slow Keys |
1240 | Yẹra fún àwọn ìsekọ́kọ́rọ́ nígbàtí o bá tẹ kọ́kọ́rọ́ kan mọ́lẹ̀ |
Avoid repeated keystrokes when you hold down a key |
1242 | Yẹra fún àtúnse àwọn ìse&kọ́kọ́rọ́ |
Ig&nore all repeated keystrokes |
1244 | Dí&n ìyára iye àtúnse àbùjá àtẹ bọ́tìnnì kù |
Slow down keyboard repeat &rates |
1246 | Fún ìg&bà wo ni kí kọ̀ǹpútà dúró kí o tó gba àtúnse àwọn ìsekọ́kọ́rọ́ tí ó kàn? |
How &long should the computer wait before accepting subsequent repeated keystrokes? |
1247 | Fún ìgbà wo ni kí kọ̀ǹpútà dúró kí o tó gba àtúnse ìsekọ́kọ́rọ́ àkọ́kọ́? |
How long should the computer wait before accepting the first repeated keystroke? |
1248 | Yẹra fún àwọn ìsekọ́kọ́rọ́ àìmọ̀ |
Avoid accidental keystrokes |
1249 | Fún ìgbà w&o ni o fẹ́ tẹ kọ́kọ́rọ́ kan mọ́lẹ̀ kí kọ̀ǹpútà tó gba ìsekọ́kọ́rọ́ náà? |
How long do you want to hold down a &key before your computer accepts the keystroke? |
1250 | Tẹ̀ ọ̀rọ̀ &síbí láti dán àwọn àgbékalẹ̀ wò: |
Type text here to test settin&gs: |
1251 | Gba àwọn ìgbàníyànjú tí ò máa mú kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò |
Get recommendations to make your computer easier to use |
1252 | Dáhùn àwọn ìbéèrè wọ̀nyí láti gba àwọn ìwífún fún àwọn àgbékalẹ̀ tí yíò mú kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti rí, gbọ́, àti lò. |
Answer the following questions to get recommendations for settings that can make your computer easier to see, hear, and use. |
1253 | Fún ìbéèrè kọ̀ọ̀kan, yàn gbogbo àwọn gbólòhùn ọ̀rọ̀ tí ó kàn ọ. Tí o bá parí, o lè yàn àwọn àgbékalẹ̀ tí o fẹ́ tàn. |
For each question, select all statements that apply to you. When you're done, you can decide which settings to turn on. |
1255 | Àfojúrí (1 of 5) |
Eyesight (1 of 5) |
1256 | Àwọn àwòrán àti ọ̀rọ̀ &orí Móhùnmáwòrán kò rọrùn láti rí (kódà tí mo bá wọ àwò ojú). |
Images and te&xt on TV are difficult to see (even when I'm wearing glasses). |
1257 | Àwọn ipò ìtàná kò mún rọrùn láti rí àwọn àwòrán lórí ag&bàwòrántàn mi. |
Lighting conditions make it difficult to &see images on my monitor. |
1258 | &Mi kò ríra. |
I am b&lind. |
1259 | Mo &ní irú àìsàn ojú mìíràn (kódà tí àwò ojú bá túnse). |
I have another type of vision &impairment (even if glasses correct it). |
1263 | Tó&kàn |
&Next |
1264 | P&aá rẹ́ |
&Cancel |
1265 | Aápọn (2 ti 5) |
Dexterity (2 of 5) |
1266 | Àwọn Kálàmù àti Pẹ́n&sù sòro láti lò. |
&Pens and pencils are difficult to use. |
1267 | Ipò àf&ojúrí kan lílo àwọn apá mi, àwọn ọrùn ọwọ́, àwọn ọwọ́, tàbí àwọn ìka. |
A physical condition affects the &use of my arms, wrists, hands, or fingers. |
1268 | Mi kò lo àbùjá àtẹ &bọ́tìnnì. |
I do not use a &keyboard. |
1269 | Gbígbọ́ (3 ti 5) |
Hearing (3 of 5) |
1270 | Àwọn Ìyípadà le sòro láti gbọ́ (kódà pẹ̀lú o&hun èlò gbígbọ́). |
C&onversations can be difficult to hear (even with a hearing aid). |
1271 | Ariwo ìpilẹ̀ kò jẹ́ kí kọ̀ǹpútà rọrù&n láti gbọ́. |
&Background noise makes the computer difficult to hear. |
1272 | Kò rọrùn fún mi láti g&bọ́. |
I a&m hard of hearing. |
1273 | &Mi kò gbọ́ràn. |
&I am deaf. |
1274 | Rírò (5 ti 5) |
Reasoning (5 of 5) |
1275 | &Kò ki ń rọrùn fún mi láti pa ọkàn pọ̀. |
It is often d&ifficult for me to concentrate. |
1276 | &Mo ní àbùkù kíkọ́, bíi àìlè gbọ́ran. |
I have a &learning disability, such as dyslexia. |
1277 | O máa ń sòro fún mi láti rántí àwọn nka&n. |
It is often difficult for me to remember thin&gs. |
1278 | &Ti Ṣe Tán |
D&one |
1281 | &Tan àwọn Kọ́kọ́rọ́ Atọ́ka |
Turn on &Mouse Keys |
1282 | Ta&n àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlẹ̀ |
Tu&rn on Sticky Keys |
1284 | Tẹ̀ nípa lílo ohun èlò ìtọ́ka |
Type using a pointing device |
1286 | Ṣàfi&hàn àwòrán Kọ́kọ́rọ́ Asẹ́ lórí pẹpẹ-isẹ́ |
Displa&y the Filter Keys icon on the taskbar |
1288 | Dá ibi ìdápadà sílẹ̀ fún ẹ̀dà àbọ̀ábá |
Create a restore point for backup |
1289 | Yan ìkìlọ̀ asàwòrán |
Choose visual warning |
1290 | Kò &sí |
&None |
1291 | Òpó à&korí ìse àwòrán |
Flash active caption &bar |
1292 | Fèrèsé ìse àwòrá&n |
Flash active &window |
1293 | À&tẹ iṣẹ́ àwòrán |
Flash des&ktop |
1294 | Se àgbékalẹ̀ àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlẹ̀mọ́ |
Set up Sticky Keys |
1295 | Tan àwọn &Kọ́kọ́rọ́ Ìlẹ̀mọ́ nígbàtí a bá tẹ SHIFT fún ìgbà máàrún |
Turn on Sticky &Keys when SHIFT is pressed five times |
1296 | Àwọn Ẹ̀yàn |
Options |
1297 | Ti àwọn kọ́kọ́rọ́ olùsọdińlá nígbàtí a bá tẹ̀ẹ́ nígbà méjì nínú ìlà ẹ̀bú ka&n |
&Lock modifier keys when pressed twice in a row |
1298 | &Pa àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlẹ̀ nígbàtí a bá tẹ àwọn kọ́kọ́rọ́ méjì papọ̀ lẹ́ẹ̀kan náà |
T&urn off Sticky Keys when two keys are pressed at once |
1299 | Èsí |
Feedback |
1300 | Gbé &ohùn jáde nígbàtí a bá tẹ aṣàtúntò àwọn kọ́kọ́rọ́ |
Pla&y a sound when modifier keys are pressed |
1301 | Ṣàfi&hàn àwòrán àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlẹ̀mọ́ lórí òpó isẹ́ |
D&isplay the Sticky Keys icon on the task bar |
1302 | Olùmúgbòòrò ń sisẹ́ níbikíbi lórí aṣàfihàn, o sì ń mún gbogbo nkan ní agbègbè náà tóbi. O lè sún Olùmúgbòòrò káàkiri, tìí sí ojú kan, tàbí tún ìwọ̀n rẹ̀ se. |
Magnifier zooms in anywhere on the screen, and makes everything in that area larger. You can move Magnifier around, lock it in one place, or resize it. |
1304 | Ó DÁ&A |
&OK |
1305 | Paá rẹ́ |
Cancel |
1306 | &Lò |
A&pply |
1307 | Àwọn ènìyàn &mìíràn ní ìsòro nípa gbígbọ́ mi ní àsìkò ìbánisọ̀rọ̀ (sùgbọ́n kìíse nítorí ìró ọ̀rọ̀). |
Other &people have difficulty understanding me in a conversation (but not due to an accent). |
1308 | Mo ní ìsòro ọ̀rọ̀ sí&sọ. |
I have a &speech impairment. |
1309 | Nígbàtí o bá ń lo àbùjá àtẹ bọ́tìnnì láti tan àwọn àgbékalẹ̀ Ìráyèsí Ìrọ̀rùn: |
When using keyboard shortcuts to turn Ease of Access settings on: |
1312 | Ọ̀rọ̀ sísọ́ (4 ti 5) |
Speech (4 of 5) |
1314 | Gba àwọn ìgbàníyànjú tí ò &máa mú kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti lò |
Get &recommendations to make your computer easier to use |
1319 | Tún wo |
See also |
1320 | Olùmútóbi mú kí apá kan aṣàfihàn tóbi. |
Magnifier enlarges part of the screen. |
1321 | Olùṣàlàyé máa ń ka èyíkéyìí àyọkà tí o farahàn lórí aṣàfihàn sókè. |
Narrator reads aloud text on the screen. |
1322 | Àtẹ bọ́tìnnì oríi aṣàfihàn ma ń jẹ́ kí ó rọrùn láti fi atọ́ka tàbí ohun èlò ẹlẹ́nu sóńsó tẹ nkan nípa fífi kan àwọn àwòrán kọ́kọ́rọ́ oríi àtẹ bọ́tìnnì. |
On-Screen Keyboard makes it possible to type using the mouse or another pointing device by clicking keys on a picture of a keyboard. |
1325 | Yí ìwọ̀n ọ̀rọ̀ àt&i àwọn àwòrán isẹ́ padà |
Change the si&ze of text and icons |
1326 | Ṣàtúnṣe àw&ọ̀ àti mímọ́ gaara àwọn ààlà fèrèsé náà |
Ad&just the color and transparency of the window borders |
1327 | Jẹ́ kí àwòrán oníg&un mẹ́rin nípọn |
Make the focus rectangle thic&ker |
1328 | À&wọn àgbékalẹ̀ atọ́ka |
Mouse &settings |
1329 | À&wọn àgbékalẹ̀ àbùjá-orí-àtẹ |
Key&board settings |
1330 | À&wọn Ohùn Èlò àfetígbọ́ àti Àwọn Ọ̀rọ̀ Ohùn |
Aud&io Devices and Sound Themes |
1331 | Àwọn àgbékalẹ̀ yìí le ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣàgbékalẹ̀ kọ̀ǹpútà rẹ láti bá àwọn àìní rẹ pàdé. Ṣàyẹwò àwọn àgbékalẹ̀ tí a fọwọ́sí ní ìsàlẹ̀ kí o sì yan àwọn ẹ̀yàn tí o fẹ́. |
These settings can help you set up your computer to meet your needs. Review the recommended settings below and select the options that you want to use. |
1332 | Kò sí àwọn ìwífún tí a fọwọ́sí tí o dá lórí àwọn ìyàn rẹ. |
There are no recommendations based on your selections. |
1333 | O lè gbìyànjú àwọn ohun kan tàbí méjì: |
You can try one of two things: |
1334 | Píparí ìwé ìbéèrè lẹ́ẹ̀kan síi. |
Completing the questionnaire again. |
1335 | Padà sí Ojúlé Ìráyèsí Ìrọ̀rùn. |
Return to the Ease of Access home page. |
1342 | O le jẹ́ kí ìmọ̀ ẹ̀rọ àṣèrànwọ́ bẹ̀rẹ̀ nígbàtí o bá wọlé, lẹ̀yìn tí o bá ti wọlé, tàbí méjèèjì. Yan àpótí adarí yíyàn fún ọ̀kọ̀ọ̀kan ẹ̀yàn tí ó le wù ọ láti lò. |
You can have assistive technologies start automatically when you sign in, after you sign in, or both. Select the check boxes for each option you'd like to use. |
1346 | Yan gbogbo àwọn gbólòhùn tí o kàn ọ́: |
Select all statements that apply to you: |
1347 | Tan àwòrán àwọn ìkìlọ̀ fún àwọn o&hùn (Olùsọ́ Ohùn) |
Tu&rn on visual notifications for sounds (Sound Sentry) |
1348 | Tan ọ̀rọ̀ àwọn àkórí fún ìjíròrò sísọ (tí &o bá wà fún lílò) |
T&urn on text captions for spoken dialog (when available) |
1349 | Tàn tàbí pa Ọ̀pọ̀ Àwọ̀ nígbàtí o bá tẹ ALT òsì + SHIFT òsì + &PRINT SCREEN |
Turn on or off High Contrast when &left ALT + left SHIFT + PRINT SCREEN is pressed |
1357 | Ṣàfihàn isẹ́ rírán ì&kìlọ̀ kan nígbàtí o bá ń sí ààtò kan |
Display &a warning message when turning a setting on |
1358 | Se ohùn níg&bàtí o bá tan tàbí pa ààtò |
&Make a sound when turning a setting on or off |
1359 | Ṣàfihàn isẹ́ rírán ìkìlọ̀ kan nígbàtí &o bá ń sí ààtò kan |
Display &a warning message when turning a setting on |
1360 | Se o&hùn nígbàtí o bá tan tàbí pa ààtò |
Make a sound when t&urning a setting on or off |
1362 | S&e ohùn nígbàtí o bá tan tàbí pa ààtò |
&Make a sound when turning a setting on or off |
1363 | Ṣàfihàn i&sẹ́ rírán ìkìlọ̀ kan nígbàtí o bá ń sí ààtò kan |
Display &a warning message when turning a setting on |
1366 | Tan àwọn &Kọ́kọ́rọ́ Atọ́ka |
Turn on &Mouse Keys |
1367 | Pátì tàbí dúró díẹ̀ tàbí ṣàtúntò àwọn iye kọ́kọ́rọ́ kí o sì ṣàtúnse àwọn iye àtúntò àtẹ bọ́tìnnì. |
Ignore or slow down brief or repeated keystrokes and adjust keyboard repeat rates. |
1368 | Tan àwọn Kọ́kọ́&rọ́ Asẹ́ |
Turn on F&ilter Keys |
1369 | &Tan àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìlẹ̀ |
Tu&rn on Sticky Keys |
1370 | Àwọn Ohùn Èlò àfetíg&bọ́ àti Àwọn Ọ̀rọ̀ Ohùn |
&Audio Devices and Sound Themes |
1371 | Tẹ àwọn àbùjá sí àtẹ bọ́tìnnì (bíi CTRL+ALT+DEL) kọ́kọ́rọ́ kan ní ìgbà kan. |
Press keyboard shortcuts (such as CTRL+ALT+DEL) one key at a time. |
1372 | Ìṣèdáyàtọ̀ àwọ̀ gíga |
High Contrast |
1373 | Magnifier enlarges part of the screen. |
Magnifier enlarges part of the screen. |
1374 | On-Screen Keyboard makes it possible to type using the mouse or another pointing device by clicking keys on a picture of a keyboard. |
On-Screen Keyboard makes it possible to type using the mouse or another pointing device by clicking keys on a picture of a keyboard. |
1376 | Ọ̀pọ̀ Ìfiwéra ń ṣàfikún ìfiwéra ní àwọn àwọ̀ láti dín ìsòro ojú kù kí o sì fi ohun rọrùn láti kà. Láti tàn án, tẹ Shift Òsì+Alt Òsì+Print Screen. |
High contrast increases the contrast in colors to reduce eyestrain and make things easier to read. To turn it on, press Left Shift+Left Alt+ Print Screen. |
1379 | Use the computer without a display |
Use the computer without a display |
1380 | Jẹ́ kí kọ̀ǹpútà rẹ rọrùn láti rí |
Make the computer easier to see |
1381 | Use the computer without a mouse or keyboard |
Use the computer without a mouse or keyboard |
1383 | Make the keyboard easier to use |
Make the keyboard easier to use |
1384 | Use text or visual alternatives for sounds |
Use text or visual alternatives for sounds |
1385 | Make it easier to focus on tasks |
Make it easier to focus on tasks |
1386 | Njẹ́ ibi ìbẹ̀rẹ̀ dá ọ lójú? |
Not sure where to start? |
1387 | Get Help |
Get Help |
1388 | Ìrànwọ́ |
Help |
1389 | Nígbà tí o bá yan àwọn àgbékalẹ̀ yìí, wọn yíò bẹ̀rẹ̀ ní ọ̀nà aládàáṣe ní ìgbàkígbà tí o bá wọlé. |
When you select these settings, they will automatically start each time you sign in. |
1390 | Nígbàtí o bá yan àwọn ìrinṣẹ́ wọ̀nyìí, wọn yíò bẹ̀rẹ̀ ní aládàáṣe ní gbogbo ìgbà tí o bá wọlé. |
When you select these tools, they will automatically start each time you sign in. |
1391 | À&wọn àbájáde ohùn àti ìfihàn ara ẹni |
Pe&rsonalize appearance and sound effects |
1392 | &Ṣe ìgbúnrégé ipa àfihàn |
Fine tune display effe&cts |
1393 | Ṣà&fikún àtẹ bọ́tìnnì Dforaki kí o sì ṣàyípadà àwọn àgbékalẹ̀ ìtẹ̀wọlé àtẹ bọ́tìnnì mìíràn |
Add a Dvorak keyboard and chan&ge other keyboard input settings |
1394 | Kọ̀ǹpútà rẹ le pa àtúnse àwọn ìsekọ́kọ́rọ́ tì tàbí kí o ṣàgbékalẹ̀ ìwọ̀n àkókò kí o tó gba àtúnse àwọn ìsekọ́kọ́rọ́. |
Your computer can ignore all repeated keystrokes or you can set the time interval before it accepts repeated keystrokes. |
1395 | O lè lo àwọn irinsẹ́ ní apá yìí fún ìrànwọ́ láti bẹ̀rẹ̀. |
You can use the tools in this section to help you get started. |
1396 | Windows le kà ó sì le se àyẹ̀wò àkọsílẹ̀ yìí ní ọ̀nà àdáse. Tẹ SPACEBAR náà láti yan irinṣẹ́ tí a tọ́kasí. |
Windows can read and scan this list automatically. Press the SPACEBAR to select the highlighted tool. |
1397 | Ṣàyípadà àwọ̀ àti ìwọ̀n àwọn ẹnu atọ́ka. |
Change the color and size of mouse pointers. |
1399 | Get recommendations to make your computer easier to use. |
Get recommendations to make your computer easier to use. |
1400 | These programs are available on this computer. Running more than one at a time might cause conflicts. |
These programs are available on this computer. Running more than one at a time might cause conflicts. |
1401 | &Yan ètò Ọ̀pọ̀ Àwọ̀ |
Choose a High Cont&rast color scheme |
1402 | Ọ̀nà àbùja àtẹ bọ́tìnnì |
Keyboard shortcut |
1403 | Kíkà |
Reading |
1406 | Ṣàgbékalẹ̀ ìnípọn ti atọ́ka tí ń sẹ́jú |
Set the thickness of the blinking cursor |
1407 | Fún ìgbà wo ni àwọn àpótí ìjíròrò ìfiitónilétíàn Windows fi máà wà ní sísí? |
How long should Windows notification dialog boxes stay open? |
1409 | Fún ìgbà wo ni o fẹ́ tẹ kọ́kọ́rọ́ kan mọ́lẹ̀ kí kọ̀ǹpútà tó gba ìsekọ́kọ́rọ́ náà? |
How long do you want to hold down a key before your computer accepts the keystroke? |
1410 | test |
test |
1412 | Fún ìgbà wo ni kí kọ̀ǹpútà dúró kí o tó gba àtúnse àwọn ìsekọ́kọ́rọ́ tí ó kàn? |
How long should the computer wait before accepting subsequent repeated keystrokes? |
1413 | Ìyára tí o pọ̀jù |
Top speed |
1414 | Ìyára |
Acceleration |
1416 | Lo ìdá&mọ̀ ohùn |
Use Speech Recog&nition |
1417 | Jẹ́ kí ó rọrùn láti bojútó windows |
Make it easier to manage windows |
1419 | Dẹ̀kun windows láti ṣàtúnto aládàáṣe nígbà tí a bá sún un dé igun àfàsòdiwọ̀n aṣàfihàn |
Prevent windows from being automatically arranged when moved to the edge of the screen |
1422 | Ìmọ̀ ẹ̀rọ Àṣèrànlọ́wọ̀ |
Assistive Technology |
1424 | 1429 |
1429 |
1431 | Ṣàtúnṣe ráńpẹ́ sí àwọn ìṣètò fún àfọwọ́kàn àti tábúlẹ̀ẹ̀tì |
Adjust settings for touch and tablets |
1432 | Make touch and tablets easier to use |
Make touch and tablets easier to use |
1433 | Títẹ bọ́tìnnì Windows àti Bọ̀tìnnì ìgbóhùnsókè papọ̀ lárí Kọ̀ǹpútà Alogègé le bẹ̀rẹ̀ ìrnṣẹ̀ ìgbaniwọlé. Ìrúu ìrinṣẹ́ ìgbaniwọlé wo ni o fẹ́ bẹ̀rẹ̀? |
Pressing the Windows button and Volume up button together on your tablet can start an accessibility tool. Which accessibility tool would you like to be launched? |
1435 | Bíbẹ̀rẹ̀ àwọn ìrinṣẹ́ ìwọ́pọ̀ |
Launching common tools |
1436 | Mu kí àfọwọ́kàn rọrùn láti lò |
Make touch easier to use |
1437 | Ìrinṣẹ́ Ìgbaniwọlé |
Accessibility tools |
1438 | Bẹ̀rẹ̀ ìrinṣẹ́ yìí láti aṣàfihàn ìwọlé |
Launch this tool from the sign-in screen |
1439 | Àfọwọ́kàn àti tábúlẹ̀ẹ̀tì |
Touch and tablets |
1440 | Lẹ̀yì ìwọlé |
After sign-in |
1441 | Ní Àtiwọlé |
At sign-in |
1442 | Títẹ Bọ́tìnnì Windows àti Bọ́tìnnì ìgbóhùnsókè pàpọ̀ lórí Kọ̀ǹpútà Alogègéì rẹ le bẹ̀rẹ̀ ìrinṣẹ́ ìgbaniwọlé. Láti ṣàyípadà ìrúu ìrinṣẹ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ tí o bá tẹ àwọn bọ́tìnnì wọ̀nyí lẹ́yìn tí o bá ti wọlé, lọ sí òjú ìwé Mú kí àfọwọ́kàn àti Kọ̀ǹpútà Alogègé rọrùn láti lo. |
Pressing the Windows button and Volume Up button together on your tablet can start an accessibility tool. To change which tool launches when you press these buttons after you've signed in, go to the Make touch and tablets easier to use page. |
5002 | Ọ̀págun Windows (tóbi) |
Windows Standard (large) |
5003 | Windows Standard (extra large) |
Windows Standard (extra large) |
5004 | Windows Black |
Windows Black |
5005 | Windows Black (large) |
Windows Black (large) |
5006 | Windows Black (extra large) |
Windows Black (extra large) |
5007 | Windows Inverted |
Windows Inverted |
5008 | Windows Inverted (large) |
Windows Inverted (large) |
5009 | Windows Inverted (extra large) |
Windows Inverted (extra large) |
6000 | Ease of Access Sign-in Settings |
Ease of Access Sign-in Settings |
6001 | The System Restore Wizard failed to start. |
The System Restore Wizard failed to start. |
6002 | You do not have the required privileges to change sign-in settings. |
You do not have the required privileges to change sign-in settings. |
6003 | An unexpected error occured elevating your privileges. (0x%xL) |
An unexpected error occured elevating your privileges. (0x%xL) |
6004 | Ease of Access Center. ,,,,,Make your computer easier to use. ,,,,,You can use the tools in this section to help you get started. Windows can read and scan this list automatically. Press the Spacebar to select the highlighted tool. |
Ease of Access Center. ,,,,,Make your computer easier to use. ,,,,,You can use the tools in this section to help you get started. Windows can read and scan this list automatically. Press the Spacebar to select the highlighted tool. |
6005 | An unexpected error occurred displaying help topic. (0x%xL) |
An unexpected error occurred displaying help topic. (0x%xL) |
6006 | An unexpected error occurred creating help interface. (0x%xL) |
An unexpected error occurred creating help interface. (0x%xL) |
6007 | An unexpected error occurred linking to Color Scheme Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to Color Scheme Control Panel. (0x%xL) |
6008 | An unexpected error occurred linking to the Display (Make fonts larger or smaller) Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to the Display (Make fonts larger or smaller) Control Panel. (0x%xL) |
6009 | An unexpected error occurred linking to the Personalization Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to the Personalization Control Panel. (0x%xL) |
6010 | An unexpected error occurred linking to the Speech Recognition Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to the Speech Recognition Control Panel. (0x%xL) |
6011 | An unexpected error occurred linking to the Mouse Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to the Mouse Control Panel. (0x%xL) |
6012 | An unexpected error occurred linking to the Keyboard Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to the Keyboard Control Panel. (0x%xL) |
6013 | An unexpected error occurred linking to the Sound Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to the Sound Control Panel. (0x%xL) |
6014 | An unexpected error occurred linking to the Text to Speech Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to the Text to Speech Control Panel. (0x%xL) |
6015 | An unexpected error occurred linking to a URL. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to a URL. (0x%xL) |
6016 | Ease of Access Center. ,,,,,Make your computer easier to use. ,,,,,You can use the tools in this section to help you get started. Windows can read and scan this list automatically. Press the Spacebar to select the highlighted tool. ,,,,,You can tab through the options and select them by pressing the Spacebar |
Ease of Access Center. ,,,,,Make your computer easier to use. ,,,,,You can use the tools in this section to help you get started. Windows can read and scan this list automatically. Press the Spacebar to select the highlighted tool. ,,,,,You can tab through the options and select them by pressing the Spacebar |
6019 | An unexpected error occurred linking to the Region and Language Control Panel. (0x%xL) |
An unexpected error occurred linking to the Region and Language Control Panel. (0x%xL) |
6020 | An unexpected error occurred starting or configuring a program to run automatically. (0x%xL) |
An unexpected error occurred starting or configuring a program to run automatically. (0x%xL) |
6021 | An unexpected error occurred configuring program not to run. (0x%xL) |
An unexpected error occurred configuring program not to run. (0x%xL) |