| 1 | Àwọn Ẹ̀yàn Agbára |
Power Options |
| 2 | Tọ́jú agbára tàbí mú ìṣesí gbòòrò nípa yíyan bí kọ̀ǹpútà rẹ ṣe ń lo agbára. |
Conserve energy or maximize performance by choosing how your computer manages power. |
| 3 | Lórí Bátìrì |
On battery |
| 4 | Ètò kẹ́kẹ̀kẹ́ tí ó ń ṣáfikún ètò |
Plugged in |
| 5 | Ṣàfipamọ́ àwọn àyípadà |
Save changes |
| 6 | Paá rẹ́ |
Cancel |
| 9 | kò tó ìṣẹ́jú kan |
Less than 1 minute |
| 10 | ìṣẹ́jú 1 |
1 minute |
| 11 | %2!u! àwọn ìṣẹ́jú |
%2!u! minutes |
| 12 | 1 wákàtí |
1 hour |
| 13 | %1!u! àwọn wákàtí |
%1!u! hours |
| 14 | %1!u! àwọn wákàtí %2!u! àwọn ìṣẹ́jú |
%1!u! hours %2!u! minutes |
| 15 | Láíláí |
Never |
| 16 | %1!u! %2 |
%1!u! %2 |
| 17 | 1 wákàtí 1 ìṣẹ́jú |
1 hour 1 minute |
| 18 | %1!u! àwọn wákàtí 1 àwọn ìṣẹ́jú |
%1!u! hours 1 minute |
| 19 | 1 wákàtí %2!u! àwọn ìṣẹ́jú |
1 hour %2!u! minutes |
| 20 | Àwọn àgbékalẹ̀ kan tí a sàbojútó rẹ̀ láti ọwọ́ alábòójútó ẹ̀rọ rẹ. Kí ló dé tí mi ò le ṣàyípadà àwọn àgbékalẹ̀ kan? |
Some settings are managed by your system administrator. Why can't I change some settings? |
| 21 | Alábòójútó ẹ̀rọ rẹ ni ó ń bójútó lára àwọn àgbékalẹ̀. Kí ló dé tí mí kò le ṣàyípadà lára àwọn àgbékalẹ̀? |
Some settings are managed by your system administrator. Why can't I change some settings? |
| 25 | Windows kò le ṣàfipamọ́ ọ̀pọ̀ nínú àwọn àyípadà rẹ sí àwọn àgbékalẹ̀ ètò agbára yìí. |
Windows can't save some of your changes to this plan's power settings. |
| 26 | Windows kò le ta ètò agbára tí o yàn jí. Yan ètò mìíràn. |
Windows can't make the power plan that you selected active. Choose a different plan. |
| 27 | Windows kò le bẹ̀rẹ̀ ètò wọnyí: %1!s! %2!s! |
Windows can't start the following program: %1!s! %2!s! |
| 28 | %s (%s) |
%s (%s) |
| 30 | Ṣàyípadà àwọn àgbékalẹ̀ tí kò sí fún lílò lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Change settings that are currently unavailable |
| 31 | A kò lè yí àwọn àgbékalẹ̀ yí padà |
These settings can't be changed |
| 35 | Sùn |
Sleep |
| 50 | Darí àwọn Ètò Agbára |
Manage Power Plans |
| 51 | Ṣẹ̀dá Ètò Agbára |
Create a Power Plan |
| 52 | Ṣàtúnṣe ìṣètò Ètò-àgbékalẹ̀ |
Edit Plan Settings |
| 54 | Ààtò Ẹ̀rọ |
System Settings |
| 70 | Pánẹ́ẹ̀lì Ìdarí Àwọn Ẹ̀yàn Agbára |
Power Options Control Panel |
| 100 | Yan ètò tàbí ṣe àdání ètò agbára kan |
Choose or customize a power plan |
| 101 | Àwọn ètò agbára jẹ́ àkójọpọ̀ ohun-èlò alárídìmú àti àwọn ìlànà àgbékalẹ̀ (gẹ́gẹ́bí ìṣàfihàn ìmọ̀lẹ̀, sísùn, abbl.) tí ó ń ṣàkóso bí kọ̀ǹpútà rẹ ṣe ń lo agbára. Sọ ọ̀pọ̀ fún mi nípa àwọn ètò àgbara |
A power plan is a collection of hardware and system settings (like display brightness, sleep, etc.) that manages how your computer uses power. Tell me more about power plans |
| 102 | Àwọn ètò agbára jẹ́ àkójọpọ̀ ohun-èlò alárídìmú àti àwọn ìlànà àgbékalẹ̀ (gẹ́gẹ́bí ìṣàfihàn ìmọ̀lẹ̀, sísùn, abbl.) tí ó ń ṣàkóso bí kọ̀ǹpútà rẹ ṣe ń lo agbára. Sọ ọ̀pọ̀ fún mi nípa àwọn ètò àgbara |
A power plan is a collection of hardware and system settings (like display brightness, sleep, etc.) that manages how your computer uses power. Tell me more about power plans |
| 103 | Yan ètò tàbí ṣe àdání èròńgbà agbára kan |
Choose or customize a power plan |
| 104 | Èròńgbà tí a yàn |
Selected plan |
| 105 | Ìrànwọ́ |
Help |
| 106 | %s |
%s |
| 110 | Yan ohun tí àwọn bọ́tìnnì agbára ń ṣe |
Choose what the power buttons do |
| 111 | Yan ohun tí bọ́tìnnì agbára ń ṣe |
Choose what the power button does |
| 112 | Yan ohun tí pípa ìdérí dé ń ṣe |
Choose what closing the lid does |
| 114 | Ṣẹ̀dá ètò agbára |
Create a power plan |
| 120 | Yan ìgbàtí a le pa àfihàn náà |
Choose when to turn off the display |
| 121 | Ṣàyípadà ìgbà tí kọ̀ǹpútà ń rẹjú |
Change when the computer sleeps |
| 123 | Ìmọ́lẹ̀sí aṣàfihàn: |
Screen brightness: |
| 124 | Change screen brightness |
Change screen brightness |
| 131 | Ibi ìṣààtò Alágbèéka Windows |
Windows Mobility Center |
| 132 | Ṣàdáni |
Personalization |
| 133 | Àwọn Ààyè Aṣàmúlò |
User Accounts |
| 150 | Àwọn ètò tí a fẹ́ |
Preferred plans |
| 151 | Àwọn ètò tí a fíhàn lórí ìwọn mítà bátìrì |
Plans shown on the battery meter |
| 152 | Ṣàfihàn àfikún àwọn ètò |
Show additional plans |
| 153 | Fi àfikún àwọn ètò pamọ́ |
Hide additional plans |
| 155 | Agbára bátìrì: |
Battery life: |
| 156 | Àwọn títọ́jú agbára: |
Energy savings: |
| 157 | Ìṣesì: |
Performance: |
| 160 | Ìṣesí dáradára lórí ìgbà bátìrì |
Favors performance over battery life |
| 161 | Battery life and performance are on par |
Battery life and performance are on par |
| 162 | Favors battery life over performance |
Favors battery life over performance |
| 165 | Ṣàyípadà àwọn àgbékalẹ̀ ètò |
Change plan settings |
| 166 | Ṣàyípadà àwọn àgbékalẹ̀ ètò fún %s èto náà |
Change plan settings for the %s plan |
| 170 | %s (tí a gbà nímọ̀ràn) |
%s (recommended) |
| 180 | Your power plan information isn't available. %s Why can't Windows retrieve this information? |
Your power plan information isn't available. %s Why can't Windows retrieve this information? |
| 181 | Ìwífún ètò agbára rẹ kò wà fún lílò. %s Kí ni ìdí tí Windows kò fi le gba ìwífún yìí padà? |
Your power plan information isn't available. %s Why can't Windows retrieve this information? |
| 200 | Ṣàyípadà àwọn àgbékalẹ̀ fún ètò náà: %s |
Change settings for the plan: %s |
| 201 | Yan àwọn àgbékalẹ̀ àfihàn àti oorun tí o fẹ́ kí kọ̀ǹpútà rẹ́ lò. |
Choose the sleep and display settings that you want your computer to use. |
| 210 | Pa àfihàn náà: |
Turn off the display: |
| 211 | Jẹ́ kí kọ̀ǹpútà náà sùn: |
Put the computer to sleep: |
| 212 | Hibernate the computer: |
Hibernate the computer: |
| 213 | Ṣàtúnṣe ètò ìmọ́lẹ̀sí: |
Adjust plan brightness: |
| 220 | Ṣà&yípadà àwọn àgbékalẹ̀ Gbèdéke agbára |
&Change advanced power settings |
| 221 | &Yọ ètò yìí kúrò |
De&lete this plan |
| 222 | Njẹ́ ó dá ọ lójú wí pé o fẹ́ pa ètò yìí rẹ́? |
Are you sure you want to delete this plan? |
| 223 | O kò le dá ètò yìí padà lẹ́yìn tí o bá ti paá rẹ́. |
This plan can't be restored after you delete it. |
| 224 | &Dá àwọn àgbékalẹ̀ àkùnàyàn padà fún ètò yìí |
&Restore default settings for this plan |
| 225 | Ṣé o dá ọ lójú pé o fẹ́ dá ìlànà àwọn ètò àgbékalẹ̀ àkùnàyàn yìí padà? |
Are you sure you want to restore this plan's default settings? |
| 226 | Títẹ 'Bẹ́ẹ̀ni' ma ń ṣèdápadà gbogbo àwọn ètò àgbékalẹ̀ àkùnàyàn ní lọ́gán. |
Clicking 'Yes' immediately restores all of the plan's default settings. |
| 227 | Ṣàyípadà àwọn àgbékalẹ̀ Gbèdéke agbára |
Change advanced power settings |
| 228 | Delete this plan |
Delete this plan |
| 229 | Dá àwọn àgbékalẹ̀ àkùnàyàn padà fún ètò yìí |
Restore default settings for this plan |
| 230 | Ṣẹ̀dá |
Create |
| 300 | Túmọ̀n àwọn bọ́tìnnì agbára kí o sì tan ààbò ọ̀rọ̀ aṣínà |
Define power buttons and turn on password protection |
| 301 | Yan àwọn àgbékalẹ̀ agbára tí o fẹ́ fún kọ̀ǹpútà rẹ. Àwọn àyípadà tí o ṣe sí àwọn àgbékalẹ̀ ní ojú-ewé yìí kan gbogbo àwọn ètò agbára rẹ. |
Choose the power settings that you want for your computer. The changes you make to the settings on this page apply to all of your power plans. |
| 310 | Àwọn bọ́tìnnì agbára àti oorun àti àwọn àgbékalẹ̀ ìdérí |
Power and sleep buttons and lid settings |
| 311 | Àwọn àgbékalẹ̀ bọ́tìnnì agbára àti oorun |
Power and sleep button settings |
| 312 | Àwọn àgbékalẹ̀ bọ́tìnnì agbára |
Power button settings |
| 313 | Bọ́tìnnì agbára àti àwọn àgbékalẹ̀ ìdérí |
Power button and lid settings |
| 320 | Nígbàtí mó bá tẹ bọ́tìnnì agbára náà: |
When I press the power button: |
| 321 | Nígbàtí mó bá tẹ bọ́tìnnì oorun náà: |
When I press the sleep button: |
| 322 | Nígbàtí mó bá pa ìdérí náà dé: |
When I close the lid: |
| 349 | Ìṣètò pakú |
Shutdown settings |
| 350 | Shutdown settings |
Shutdown settings |
| 351 | Tan ìbẹ̀rẹ̀ tójáfáfá (A gbà ọ níyànjú) |
Turn on fast startup (recommended) |
| 353 | Eléyìí máa ṣèrànwọ́ láti bẹ̀rẹ̀ Kọ̀ǹpútà Àdáni rẹ ní kíákíá lẹ́yìn tí o bá paá. Àtúnbẹ́rẹ́ kò ní ìdíwọ́ ráráKọ́ sí i |
This helps start your PC faster after shutdown. Restart isn’t affected. Learn More |
| 354 | Eléyìí máa ṣèrànwọ́ láti bẹ̀rẹ̀ Kọ̀ǹpútà Àdáni rẹ ní kíákíá lẹ́yìn tí o bá paá. Àtúnbẹ́rẹ́ kò ní ìdíwọ́. Mọ̀ díẹ̀ síi. |
This helps start your PC faster after shutdown. Restart isn’t affected. Learn More. |
| 357 | Ṣàfihàn ní mẹ́nù Àgbára. |
Show in Power menu. |
| 358 | Lúgọ |
Hibernate |
| 360 | Tìpa |
Lock |
| 361 | Ṣàfihàn ní mẹ́nù àwòrán àkọọ́lẹ̀. |
Show in account picture menu. |
| 401 | Bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ètò titẹ́lẹ̀ kí o wá fún un lórúkọ. |
Start with an existing plan and give it a name. |
| 425 | Orúkọ ètò: |
Plan name: |
| 430 | Plan description (optional): |
Plan description (optional): |
| 440 | The name that you entered is used by another power plan. Choose a different name for this plan. |
The name that you entered is used by another power plan. Choose a different name for this plan. |
| 441 | Tí o bá dá ètò agbára kan sílẹ̀, o gbọ́dọ̀ fún ní orúkọ. Tẹ orúkọ kan sí inú àpótí náà. |
When you create a power plan, you must name it. Type a name in the box. |
| 450 | Àkànṣe Ètò Mii %1!u! |
My Custom Plan %1!u! |
| 451 | Àkànṣe Ètò Mi %1!u! |
My Custom Plan %1!u! |
| 460 | Tókàn |
Next |
| 0x10000031 | Response Time |
Response Time |
| 0x30000001 | Start |
Start |
| 0x30000002 | Stop |
Stop |
| 0x50000004 | Information |
Information |
| 0x90000001 | Microsoft-Windows-PowerCpl |
Microsoft-Windows-PowerCpl |