| 1 | Ìlà-ìka-ọwọ́ |
Fingerprint |
| 2 | Láti wọlé, ṣàyẹ̀wò ìka rẹ lórí ònkà ìlà-ìka-ọwọ́. |
To sign in, scan your finger on the fingerprint reader. |
| 3 | Láti ṣí ohun èlò rẹ, ṣàyẹ̀wò ìka rẹ lórí ònkà ìlà-ìka-ọwọ́. |
To unlock your device, scan your finger on the fingerprint reader. |
| 5 | Ṣàyẹ̀wò ìka rẹ lórí ònkà ìlà-ìka-ọwọ́. |
Scan your finger on the fingerprint reader. |
| 6 | Your PIN is required to sign in. |
Your PIN is required to sign in. |
| 10 | Báwo ni %1!s! |
Hello %1!s! |
| 101 | Windows kò le mú ọ wọlé. |
Windows couldn’t sign you in. |
| 110 | Ohun èlò rẹ ń dojúkọ ìṣòro láti dá ọ mọ̀. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
Your device is having trouble recognizing you. Please try again. |
| 111 | Kò le dá ìlà ìka owọ́ náà mọ̀. Ṣàrídájú pé o ti ṣàgbékalẹ̀ ìlà ìka ọwọ́ rẹ nínú Windows Hello. |
Couldn’t recognize that fingerprint. Make sure you’ve set up your fingerprint in Windows Hello. |
| 112 | Kí o tó le bẹ̀rẹ̀ lílo ìlà-ìka-ọwọ́ rẹ láti wọlé, o ní láti ṣàgbékalẹ̀ PIN kan. |
Before you can start using your fingerprint to sign in, you have to set up a PIN. |
| 116 | Ìwọlé ìlà-ìka-ọwọ́ wà nípò àìṣélò lọ́wọ́lọ́wọ́ nípasẹ̀ aládòójútó rẹ. |
Fingerprint sign-in is currently disabled by your administrator. |
| 143 | Rọra gbé ìka rẹ lọ sókè. |
Move your finger slightly higher. |
| 144 | Rọra gbé ìka rẹ lọ sílẹ̀. |
Move your finger slightly lower. |
| 145 | Rọra gbé ìka rẹ lọ sí òsì. |
Move your finger slightly to the left. |
| 146 | Rọra gbé ìka rẹ lọ sí ọ̀tún. |
Move your finger slightly to the right. |
| 147 | Rọra gbé ìka rẹ díẹ̀ sí káàkiri òǹkà. |
Move your finger more slowly across the reader. |
| 148 | Ní kíá gbé ìka rẹ díẹ̀ sí káàkiri òǹkà. |
Move your finger more quickly across the reader. |
| 149 | Gbìyànjú láti di ìka rẹ mú pẹlẹbẹ kí o sì gúnrégé nígbàtí o ń lo òǹkà ìlà ìka owọ́. |
Try holding your finger flat and straight when using the fingerprint reader. |
| 150 | Gbìyànjú lílo sísún gígùn káàkiri òǹkà ìlà ìka ọwọ́. |
Try using a longer stroke across the fingerprint reader. |
| 151 | Ohun èlò rẹ ń dojúkọ ìṣòro kan láti dá ọ mọ̀. Ṣàrídájú pé àmì ayùn rẹ mọ́. |
Your device is having trouble recognizing you. Make sure your sensor is clean. |
| 152 | Ẹlòmíràn ti wọlé lórí ohun èlò yìí. Wọ́n ní láti jáde kí o tó le wọlé. |
Someone is already signed in on this device. They need to sign out before you can sign in. |
| 154 | Má bínú, ohun kan kò lo déédé. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀ka n síi. |
Sorry, something went wrong. Please try again. |
| 155 | Windows kò le lo àwọn ohun ẹ̀rí ìlà ìka owọ́ rẹ nítorí kò le kàn sí agbègbè ìkápá re. Gbìyànjú sísopọ̀ mọ́ alásopọ̀ míràn |
Windows could not use your fingerprint credentials because it could not contact your domain. Try connecting to another network |
| 156 | Aṣàmúlò míràn ti dènà ohun èlò yìí. Láti wọlé, tẹ Esc mọ́lẹ̀, lẹ́yìn náà ṣíra tẹ Yí aṣàmúlò po. |
Another user has locked this device. To sign in, press Esc, and then click Switch user. |
| 159 | Kò ṣàgbékalẹ̀ ìlà-ìka-ọwọ́ náà fún àkọọ́lẹ̀ yìí. |
That fingerprint isn’t set up for this account. |
| 1011 | Ìwọlé ìlà ìka ọwọ́ |
Fingerprint sign-in |
| 1012 | Orúkọ ìṣàfihàn |
Display name |
| 1013 | Ipò aṣàmúlò |
User status |
| 1014 | Ìtalólonbó ìwọlé ìlà ìka ọwọ́ |
Fingerprint sign-in prompt |
| 1015 | Ọ̀rọ̀ aṣínà lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Current password |
| 1016 | Ọ̀rọ̀ aṣínà Tuntun |
New password |
| 1017 | Fídí ọ̀rọ̀ aṣínà Múlẹ̀ |
Confirm password |
| 1018 | Ó DÁA |
OK |