200 | Controlpanel not found |
Controlpanel not found |
201 | Àwọn kọ́kọ́rọ́ Ìsisẹ́ |
Sticky Keys |
202 | Àwọn bọ́tìnnì Asẹ́ |
Filter Keys |
203 | Àwọn kọ́kọ́rọ́ Tọ́gùlù |
Toggle Keys |
204 | Àwọn bọ́tìnnì Atọ́ka |
Mouse Keys |
205 | Ìṣèdáyàtọ̀ àwọ̀ gíga |
High Contrast |
1117 | Àwọn kọ́kọ́rọ́ ìsisẹ́ ń jẹ́ kí o lo SHIFT, CTRL, ALT, tàbí àwọn kọ́kọ́rọ́ lógò Windows nípa títẹ kọ́kọ́rọ́ kan lẹ́ẹ̀kan. Àbùjá àtẹ bọ́tìnnì láti tan àwọn kọ́kọ́rọ́ ìsisẹ́ ni láti tẹ kọ́kọ́rọ́ SHIFT nígbà 5. |
Sticky Keys lets you use the SHIFT, CTRL, ALT, or Windows Logo keys by pressing one key at a time. The keyboard shortcut to turn on Sticky Keys is to press the SHIFT key 5 times. |
1118 | Filter Keys lets you ignore brief or repeated keystrokes and slows down the keyboard repeat rate. The keyboard shortcut to turn on Filter Keys is to hold down the right SHIFT key for 8 seconds. |
Filter Keys lets you ignore brief or repeated keystrokes and slows down the keyboard repeat rate. The keyboard shortcut to turn on Filter Keys is to hold down the right SHIFT key for 8 seconds. |
1122 | Mouse Keys lets you control the mouse pointer by using the numeric keypad on your keyboard. The keyboard shortcut to turn on Mouse Keys is to press the ALT, left SHIFT, and NUM LOCK keys. |
Mouse Keys lets you control the mouse pointer by using the numeric keypad on your keyboard. The keyboard shortcut to turn on Mouse Keys is to press the ALT, left SHIFT, and NUM LOCK keys. |
1124 | Ìtànmọ́lẹ̀ ńlá máa ń mú kí àfihàn kíkà gbòòrò nípa lílo ìlànà àwọ̀ ẹ̀rọ pàtàkì. Àbùjá àtẹ bọ́tìnnì láti tan Ìtànmọ́lẹ̀ ńlá ni láti tẹ àwọn kọ́kọ́rọ́ SHIFT òsì, ALT òsì, àti PRINT SCREEN. |
High Contrast improves readability of the display by applying a special system color scheme. The keyboard shortcut to turn on High Contrast is to press the left SHIFT, left ALT, and PRINT SCREEN keys. |
1128 | Àwọn kọ́kọ́rọ́ tọ́gùlù ń fa kí ohùn kan jáde nígbàtí o bá tẹ CAPS LOCK, NUM LOCK, tàbí àwọn kọ́kọ́rọ́ SCROLL LOCK. Àbùjá àtẹ bọ́tìnnì láti tan àwọn kọ́kọ́rọ́ tọ́gùlù ni láti tẹ kọ́kọ́rọ́ NUM LOCK mọ́lẹ̀ fún àwọn ìsẹ́jú àáyá 5. |
Toggle Keys causes a tone to sound when you press the CAPS LOCK, NUM LOCK, or SCROLL LOCK keys. The keyboard shortcut to turn on Toggle Keys is to hold down the NUM LOCK key for 5 seconds. |
1134 | Bẹ́ẹ̀&kọ́ |
&No |
1135 | &Bẹ́ẹ̀ni |
&Yes |
1137 | Lọ sí Ibi Ìrọ̀rùn ìgbàwọlé láti pa àbùjá àtẹ bọ́tìnnì |
Go to the Ease of Access Center to disable the keyboard shortcut |
1138 | Ṣé o fẹ́ tan àwọn Kọ́kọ́rọ́ Ìsisẹ́? |
Do you want to turn on Sticky Keys? |
1139 | Do you want to turn on Filter Keys? |
Do you want to turn on Filter Keys? |
1140 | Do you want to turn on Mouse Keys? |
Do you want to turn on Mouse Keys? |
1141 | Ṣé o fẹ́ tan Ìtànná ńlá ? |
Do you want to turn on High Contrast? |
1142 | Ṣé o fẹ́ tan àwọn Kọ́kọ́rọ́ Tọ́gùlù? |
Do you want to turn on Toggle Keys? |