File name: | authui.dll.mui |
Size: | 14336 byte |
MD5: | 7a755f30956f4924a0c5389a617f2322 |
SHA1: | e48f7a60b4dcd22d7b00a9d2bc01c0c3af2fea97 |
SHA256: | fb5c5b3396a594635ecdbe0334a726752b1bf25991db28faa94823b901f9e72e |
Operating systems: | Windows 10 |
Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id | Yoruba | English |
---|---|---|
3000 | Àwọn Ẹ̀yàn agbára | Power Options |
3002 | Kò sàn agbára kankan nílẹ̀. | There are currently no power options available. |
3003 | Yan ìdí tí ó ṣàpèjúwé bí o ṣe fẹ́ pa kọ̀ǹpútà yìí kú jùlọ | Choose a reason that best describes why you want to shut down this PC |
3004 | Ẹnìkan ńlo kọ̀ǹpútà yìí. Tí o bá paá nísisìnyí, wọn le sọ àwọn dátà tí kò sí láfipamọ́ nù. | Someone else is still using this PC. If you shut down now, they could lose unsaved work. |
3005 | Tí o bá paá kú nísisìnyí, ìwọ àti ènìyàn tí o bá ńlo kọ̀ǹpútà yìí le sọ àwọn iṣẹ́ tí wọn kò bá fipamọ́ nù. | If you shut down now, you and any other people using this PC could lose unsaved work. |
3006 | Ẹnìkan ńlo kọ̀ǹpútà yìí lọ́wọ́. Tí o bá ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ nísisìnyí, wọn le sọ iṣẹ́ tí kò bá wà lápamọ́ nù. | Someone else is still using this PC. If you restart now, they could lose unsaved work. |
3007 | Tí o bá ṣàtúnbẹ́rẹ̀ nísínyí, ìwọ àti àwọn ènìyàn mìíràn tó ńlo kọ̀ǹpútà yìí le sọ iṣẹ́ tí kò bá sí ní ìpamọ́ nù. | If you restart now, you and any other people using this PC could lose unsaved work. |
3008 | Tẹ̀síwájú | Continue |
3009 | Pákú bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ | Shut down anyway |
3010 | Ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ | Restart anyway |
3011 | 11;semibold;none;segoe ui | 11;semibold;none;segoe ui |
3012 | 11;semilight;none;segoe ui | 11;semilight;none;segoe ui |
3013 | Pákú | Shut down |
3014 | Pá&kú | Sh&ut down |
3015 | Máa pa gbogbo ìṣàfilọ́lẹ̀ kí o pa kọ̀ǹpútà. | Closes all apps and turns off the PC. |
3016 | Ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ | Restart |
3017 | T&unbẹ̀rẹ̀ | &Restart |
3018 | Máa pa gbogbo ìṣàfilọ́lẹ̀ dé, pa kọ̀ǹpútà,o sì máa ń tàn án padà. | Closes all apps, turns off the PC, and then turns it on again. |
3019 | Sùn | Sleep |
3020 | &Sùn | &Sleep |
3021 | PC máa wà ní títàn ṣùgbọ́n o máa lo agbára tó mọ níwọ̀n. Àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ máa wà ní ṣíṣí nígbàtí PC bá tají, kíá lo máa padà sí ibi tí o ti kúrò. | The PC stays on but uses low power. Apps stay open so when the PC wakes up, you’re instantly back to where you left off. |
3022 | Pa díẹ̀ | Hibernate |
3023 | Pa &díẹ̀ | &Hibernate |
3025 | Pa PC ṣùgbọ́n àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ máa wà ní ṣíṣí. Nígbàtí PC bá wà ní títàn, ó máa padà sí ibi tí ó wà tẹ́lẹ̀. | Turns off the PC but apps stay open. When the PC is turned on, you’re back to where you left off. |
3026 | Ṣàfikún kí o sì pakú | Update and shut down |
3027 | Ṣàfikún kí o sì &pakú | Update and sh&ut down |
3029 | Máa ń pa gbogbo ìṣàfilọ́lẹ̀ dé, ṣàfikún Kọ̀ǹpútà àti pípa. | Closes all apps, updates the PC, and then turns it off. |
3030 | Ṣàfikún kí o ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ | Update and restart |
3031 | Ṣàfikún &kí o ṣàtúnbẹ̀rẹ̀a | Update and &restart |
3033 | Máa ń pa gbogbo ìṣàfilọ́lẹ̀, ṣàfikún Kọ̀ǹpútà, àti títàn padà. | Closes all apps, updates the PC, turns it off, and then turns it on again. |
3034 | Jáde | Sign out |
3035 | Máa pa gbogbo ìṣàfilọ́lẹ̀ yíò sì gbé ọ jáde. | Closes all apps and signs you out. |
3038 | Ṣèpínyà | Disconnect |
3039 | Máa fopin sí ìsomọ́ rẹ sí Kọ̀ǹpútà ọ́nàjínjìn. | Ends your connection to this remote PC. |
3040 | &Ń já ìsopọ̀ | &Disconnect |
3041 | J&áde | S&ign out |
3042 | Tìpa | Lock |
3043 | &Tìpa | L&ock |
3044 | Ti àkọọ́lẹ̀ rẹ lórí kọ̀ǹpútà yìí. | Locks your account on this PC. |
3045 | Àyípadà Ẹ̀rọ | Undock |
3046 | À&yípadà Ẹ̀rọ | U&ndock |
3047 | Ó ma ń yọ ẹ̀rọ kọ̀ǹpútà rẹ alágbèká láti àyè ìyí ẹ̀rọ rẹ padà. | Removes your laptop or notebook computer from a docking station. |
3050 | Alábòójútó ẹrọ ti gbé àwọn ipò agbára kan sípò àìṣeélò fún àkọọ́lẹ̀ aṣàmúlò yìí. | The system administrator has disabled some power states for this user account. |
3052 | Pààrọ̀ Aṣàmúlò | Switch user |
3053 | Ṣe ìsípòpadà àwọn aṣàmúlò láìpa ìṣàfilọ́lẹ̀ dé. | Switch users without closing apps. |
3054 | Pààrọ̀ Aṣà&múlò | S&witch user |
3100 | Yan ìdí kan tí ó ṣàpèjúwe ìdí tí o fi fẹ́ pa kọ̀ǹpútà yìí jùlọ | Choose a reason that best describes why you want to shut down this computer |
3101 | Ẹnìkan sì ńlo kọ̀ǹpútà yìí.Tí p bá pa á nísìnyí, ẹni náà le sọ àwọn iṣẹ́ rẹ̀ nù. | Someone else is still using this computer. If you shut down now, they could lose unsaved work. |
3102 | Tí o bá pa á nísìnyí, ìwọ àti àwọn ènìyàn tí ó bá ń lo kọ̀ǹpútà yìí le sọ ìṣẹ́ tí kò tíì sí lápamọ́ nù. | If you shut down now, you and any other people using this computer could lose unsaved work. |
3103 | Ẹnìkan sì ń lo kọ̀ǹpútà yìí. Tí o bá ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ nísìnyí, ó le sọ ìṣẹ́ tí kò sí lápamọ́ nù. | Someone else is still using this computer. If you restart now, they could lose unsaved work. |
3104 | Tí o bá ṣàtúnbẹ̀rẹ̀ nísìnyí, ìwọ àti àwọn ènìyàn mìíràn tí ó ń lo kọ̀ǹpútà yìí le sọ àwọn iṣẹ́ tí kò sí lápamọ́ nù. | If you restart now, you and any other people using this computer could lose unsaved work. |
3105 | Máa pa gbogbo ìṣàfilọ́lẹ̀ dé yíò sí pa kọ̀ǹpútà. | Closes all apps and turns off the computer. |
3106 | Máa pa gbogbo ìṣàfilọ́lẹ̀ dé, pa kọ̀ǹpútà, yíò sì tún tàn padà. | Closes all apps, turns off the computer, and then turns it on again. |
3107 | Kọ̀ǹpútà máa wà ní títàn ṣùgbọ́n ó ńlo àgbára tó mọ níwòn. Ìṣàfilọ́lẹ̀ máa wà ní ṣíṣí nígbàtí kọ̀ǹpútà bá jí, o máa padà sí ibi tí o bá wà tẹ́lẹ̀ lẹ́ṣẹ̀kẹṣẹ̀. | The computer stays on but uses low power. Apps stay open so when the computer wakes up, you’re instantly back to where you left off. |
3108 | Pa kọ̀ǹpútà ṣùgbọ́n ìṣàfilọ́lẹ̀ máa wà ni ṣíṣí. Nígbàtí kọ̀ǹpútà bá tàn, o máa padà sí ibí tí o wà tẹ́lẹ̀. | Turns off the computer but apps stay open. When the computer is turned on, you’re back to where you left off. |
3109 | Máa pa gbogbo ìṣàfilọ́lẹ̀ dé, àwọn àfikún kọ̀ǹpútà, yíò sì pa á. | Closes all apps, updates the computer, and then turns it off. |
3110 | Máa pa gbogbo ìṣàfilọ̀lẹ̀, àwọn àfikún kọ̀ǹpútà, pa wọ́n pátápátá, kí o sì tún tàn wọ́n padà. | Closes all apps, updates the computer, turns it off, and then turns it on again. |
3111 | Máa fòpin sí ìsomọ́ rẹ sí kọ̀ǹpútà ọ̀nàjínjìn yìí. | Ends your connection to this remote computer. |
3112 | Máa ti àkọọ́lẹ̀ rẹ lórí i kọ̀ǹpútà yìí pa. | Locks your account on this computer. |
3120 | Fìkawọ́ láti paá | Slide to shut down |
3121 | Fìkawọ́ láti pa PC rẹ | Slide to shut down your PC |
3122 | Àwọn àfikún tó ti ṣe pàtàkì máa di ṣíṣàgbékalẹ̀. | Critical updates will be installed. |
3123 | Àwọn àfikún tó ti ṣe pàtàkì máa di ṣíṣàgbékalẹ̀. ẹnikẹ́ni tí ó bá ń lo PC yìí máa sọ ìṣẹ́ tí kò bá láfipamọ́ nù. | Critical updates will be installed. Anyone else using this PC will lose unsaved work. |
3124 | Àwọn àfikún tó ti ṣe pàtàkì máa di ṣíṣàgbékalẹ̀. Ìwọ tàbí ẹnikẹ́ni tí ó bá ń lo PC yìí lọ́wọ́ máa sọ | Critical updates will be installed. You or anyone else using this PC will lose unsaved work. |
3125 | Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń lo PC yìí máa sọ iṣẹ́ tí kò bá tíì láfipamọ́ nù. | Anyone else using this PC will lose unsaved work. |
3126 | Ìwọ tàbí ẹnikẹ́ni tí ó bá ń lo PC yìí máa sọ iṣẹ́ tí kò bá tíì láfipamọ́ nù. | You or anyone else using this PC will lose unsaved work. |
3127 | Láti pa PC rẹ, tẹ spacebar. Láti padà síbi ohun tí o ń ṣe, tẹ èyíkéyìí kọ́kọ́rọ́. | To shut down your PC, press the spacebar. To go back to what you were doing, press any other key. |
3128 | Pa pípa rẹ́ | Cancel shutdown |
3129 | ▼ | ▼ |
3130 | 12;semilight;none;Segoe UI | 12;semilight;none;Segoe UI |
3131 | 20;semilight;none;Segoe UI | 20;semilight;none;Segoe UI |
3132 | 20;Light;none;Segoe UI | 20;Light;none;Segoe UI |
12900 | Input Indicator | Input Indicator |
12901 | 12pt;Bold;;Segoe UI | 12pt;Bold;;Segoe UI |
12902 | 11;semilight;none;Segoe UI | 11;semilight;none;Segoe UI |
25467 | %s %s Láti ṣe ìṣípòpadà ìlànà ìgbàwọlé, tẹ bọ́tìnnì Windows + Òpó àlàfo. |
%s %s To switch input methods, press Windows key+Space. |
0x10000031 | Response Time | Response Time |
0x30000000 | Info | Info |
0x30000001 | Start | Start |
0x30000002 | Stop | Stop |
0x50000002 | Error | Error |
0x50000003 | Warning | Warning |
0x50000004 | Information | Information |
0x90000001 | Microsoft-Windows-Authentication User Interface | Microsoft-Windows-Authentication User Interface |
0x90000002 | Microsoft-Windows-Authentication User Interface/Operational | Microsoft-Windows-Authentication User Interface/Operational |
0x90000003 | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-CredUI/Diagnostic | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-CredUI/Diagnostic |
0x90000004 | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-Logon/Diagnostic | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-Logon/Diagnostic |
0x90000005 | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-Common/Diagnostic | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-Common/Diagnostic |
0x90000006 | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-Shutdown/Diagnostic | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-Shutdown/Diagnostic |
0x90000007 | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-CredentialProviderUser/Diagnostic | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-CredentialProviderUser/Diagnostic |
0x90000008 | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-BootAnim/Diagnostic | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-BootAnim/Diagnostic |
0x90000009 | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-LogonUI/Diagnostic | Microsoft-Windows-Shell-AuthUI-LogonUI/Diagnostic |
0xB0001389 | Logon user interface creation failed. Details: %1 | Logon user interface creation failed. Details: %1 |
0xB000138A | Logon user interface RPC server startup failed. Details: %1 | Logon user interface RPC server startup failed. Details: %1 |
0xB000138B | The username/password credential provider failed to enumerate tiles. | The username/password credential provider failed to enumerate tiles. |
0xB000138C | Autologon failed. Details: %1 | Autologon failed. Details: %1 |
0xB000138D | The autologon password could not be loaded. | The autologon password could not be loaded. |
0xB000138E | The autologon password could not be loaded. Details: %1 | The autologon password could not be loaded. Details: %1 |
0xB000138F | The OEM background could not be loaded for resolution %2 x %3. Details: %1 | The OEM background could not be loaded for resolution %2 x %3. Details: %1 |
0xB0001390 | The OEM background %1 was loaded but its aspect ratio does not match the primary display resolution %2 x %3. | The OEM background %1 was loaded but its aspect ratio does not match the primary display resolution %2 x %3. |
0xB0001391 | The OEM background %1 was not loaded because the file is larger than %2 bytes. | The OEM background %1 was not loaded because the file is larger than %2 bytes. |
0xB0001392 | The credential provider thread creation failed. Details: %1 | The credential provider thread creation failed. Details: %1 |
0xB0001393 | User enumeration failed. Details: %1 | User enumeration failed. Details: %1 |
0xB0001394 | The first run task for package %1 exceeded the maximum runtime alotted and has been cancelled. | The first run task for package %1 exceeded the maximum runtime alotted and has been cancelled. |
File Description: | Síṣàrídájú Windows UI |
File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
Company Name: | Microsoft Corporation |
Internal Name: | AUTHUI |
Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa. |
Original Filename: | AUTHUI.DLL.MUI |
Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
Product Version: | 10.0.15063.0 |
Translation: | 0x46A, 1200 |