File name: | notepad.exe.mui |
Size: | 11776 byte |
MD5: | 762bcc1eee2d6cd1083f857704df6b2a |
SHA1: | 11b55015bfbb76bb35a3c0d054ba7ce111c31c6a |
SHA256: | 675ce645e3bcce9375f1469baca3d1f6f34232f2d56f728accb6eab41b8b682c |
Operating systems: | Windows 10 |
Extension: | MUI |
In x64: | notepad.exe Àfikọ̀wéRánpẹ́ (bíìtì-32) |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id | Yoruba | English |
---|---|---|
1 | Kò le ṣí %% fáìlì. Ri dájú pé dísíkì wà nínú àwo àká-ọ̀rọ̀ tí o se pàtó. |
Cannot open the %% file. Make sure a disk is in the drive you specified. |
2 | Kò le rí %% fáìlì. Ṣé o fẹ́ dá fáìlì tuntun sílẹ̀? |
Cannot find the %% file. Do you want to create a new file? |
3 | A ti ṣàyípadà %% ọ̀rọ̀ inú fáìlì. Ṣé o fẹ́ Ṣàfipamọ́ àwọn ìyípadà? |
The text in the %% file has changed. Do you want to save the changes? |
4 | Aláìní àkòrí | Untitled |
5 | %1 - Àfikọ̀wé ránpẹ́ | %1 - Notepad |
6 | Kòle ri "%%" | Cannot find "%%" |
7 | Kò sí ìrántí tí ó tó láti parí isẹ́ yìí. Pa àwọn isẹ́ ọ̀kan tàbí jùbẹ́ẹ̀lọ láti fikún ìrántí tí ó wà, kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan si. | Not enough memory available to complete this operation. Quit one or more applications to increase available memory, and then try again. |
8 | Fáìlì náà %% ti tóbi ju Àfikọ̀wéRánpẹ́ lọ. Lo olùkọ mìíràn láti ṣàtúnṣe fáìlì náà. |
The %% file is too large for Notepad. Use another editor to edit the file. |
9 | Àfikọ̀wéRánpẹ́ | Notepad |
10 | Kùnà láti bẹ̀rẹ̀ àwọn àròyé fáìlì. Ṣàyípadà orúkọ fáìlì náà kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan si. | Failed to initialize file dialogs. Change the file name and try again. |
11 | Kùnà láti bẹ̀rẹ̀ àwọn àròyé ìtẹ̀wé. Ri dájú pé ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ̀ẹ sopọ̀ dáradára kí o sì lo Pánẹ́ẹ̀lì Ìdarí láti ṣàrídájú pé a se ètò àtòpọ̀ ẹ̀rọ ìtẹ̀wé dáradára. | Failed to initialize print dialogs. Make sure that your printer is connected properly and use Control Panel to verify that the printer is configured properly. |
12 | Kòle tẹ fáìlì náà %% jáde. Ri dájú pé ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ̀ẹ sopọ̀ dáradára kí o sì lo Pánẹ́ẹ̀lì Ìdarí láti ṣàrídájú pé a se ètò àtòpọ̀ ẹ̀rọ ìtẹ̀wé dáradára. | Cannot print the %% file. Be sure that your printer is connected properly and use Control Panel to verify that the printer is configured properly. |
13 | Kìíse orúkọ fáìlì tó kúnjúwọ̀n. | Not a valid file name. |
14 | Kòle dá fáìlì %% náà sílẹ̀. Ri dájú pé ọ̀nà àti orúkọ fáìlì náà tọ́. |
Cannot create the %% file. Make sure that the path and file name are correct. |
15 | Kòle se àsẹ Word Wrap nítorí ọ̀rọ̀ ti pọ̀jù nínú fáìlì náà. | Cannot carry out the Word Wrap command because there is too much text in the file. |
16 | %% | %% |
17 | notepad.hlp | notepad.hlp |
18 | &f | &f |
19 | Ojú ìwé &p | Page &p |
20 | Àwọn Àkọsílẹ̀ Àyọkà (*.txt) | Text Documents (*.txt) |
21 | Gbogbo àwọn fáìlì | All Files |
22 | Ṣí | Open |
23 | Ṣàfipamọ́ bíi | Save As |
24 | O kò lè pa Windows tàbí kí o jáde kúrò nínú Windows nítorí àpótí ìsọ̀rọ̀gbèsì Ṣàfipamọ́ Bíi wà ní ṣíṣí nínú àfikọ̀wé ránpẹ́. Sún sí Àfikọ̀wé ránpẹ́, pa àpótí ìsọ̀rọ̀gbèsì dé kí o sì gbìyànjú láti pa Windows tàbí kí o kúrò. |
You cannot shut down or log off Windows because the Save As dialog box in Notepad is open. Switch to Notepad, close this dialog box, and then try shutting down or logging off Windows again. |
25 | Kòle wọ ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ̀ẹ. Ri dájú pé ẹ̀rọ ìtẹ̀wé rẹ̀ẹ sopọ̀ dáradára kí o sì lo Pánẹ́ẹ̀lì Ìdarí láti ṣàrídájú pé a se ètò àtòpọ̀ ẹ̀rọ ìtẹ̀wé dáradára. |
Cannot access your printer. Be sure that your printer is connected properly and use Control Panel to verify that the printer is configured properly. |
26 | %% O kò sí àṣẹ láti ṣí fáìlì yìí. Rí olóhun fáìlì tàbí alábòójútó ẹ̀rọ kan láti gba àṣẹ. |
%% You do not have permission to open this file. See the owner of the file or an administrator to obtain permission. |
27 | %% Fáìlì yìí ní àwọn ẹyọ ọ̀rọ̀ tí ó wà ní ìṣètò Unicode tí o ma sọnù tí o bá pa fáìlì yí mọ́ bi fáìlì ANSI tí a se ẹnàn ọ̀rọ̀ rẹẹ̀. Láti Ṣàfipamọ́ ìwífún Unicode náà, tẹ Paá rẹ́ nísàlẹ̀ kí o sì yan ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀yàn Unicode láti àkọsílẹ̀ jáwá sílẹ̀ Ìsenàn. Tẹ̀síwájú? |
%% This file contains characters in Unicode format which will be lost if you save this file as an ANSI encoded text file. To keep the Unicode information, click Cancel below and then select one of the Unicode options from the Encoding drop down list. Continue? |
28 | Ojú ìwé kéré jù láti tẹ ìlà kan jáde. Tẹ̀ jáde nípa lílo alárà kékeré. |
Page too small to print one line. Try printing using smaller font. |
29 | Àṣìṣe Àròré tí ó wọ́pọ̀ (0x%04x) | Common Dialog error (0x%04x) |
30 | Àfikọ̀wéRánpẹ́ - Lọsí Ìlà | Notepad - Goto Line |
31 | Nọ́ńbà ìlà ti ju àpapọ̀ nọ́ńbà ìlà lọ | The line number is beyond the total number of lines |
32 | ANSI | ANSI |
33 | Unicode | Unicode |
34 | Unicode big endian | Unicode big endian |
35 | UTF-8 | UTF-8 |
36 | Ojú ìwé %d | Page %d |
37 | Ln %d, Col %d | Ln %d, Col %d |
38 | Tí a Súnpọ̀, | Compressed, |
39 | Ti se ẹnàn, | Encrypted, |
40 | Pamọ́, | Hidden, |
41 | Kò sí ní àìsílóníforíkorí, | Offline, |
42 | KàNìkan, | ReadOnly, |
43 | Ẹ̀rọ, | System, |
44 | Fáìlì | File |
45 | fFpPtTdDcCrRlL | fFpPtTdDcCrRlL |
46 | Ń ṣe&kóòdù: | &Encoding: |
47 | Àfikọ̀wéRánpẹ́ ń sí nínú isẹ́ tí o ti parí. Ṣé o ma níìfẹ́ láti ṣàfipamọ́ %% fáìlì náà láì sísẹ́? |
Notepad was running in a transaction which has completed. Would you like to save the %% file non-transactionally? |
48 | A kò le ṣí fáìlì yìí | We can’t open this file |
49 | Yálà pé ilé-iṣẹ́ rẹ kò gbàá láàyè, tàbí ìṣòro kan jẹyọ pẹ̀lú ìpàrokò fáìlì náà. | Either your organization doesn’t allow it, or there’s a problem with the file’s encryption. |
50 | Text Editor | Text Editor |
469 | Àkọsílẹ̀ Àyọkà | Text Document |
470 | Àkọsílẹ̀ ìwé ọ̀rọ̀ tuntun | New Text Document |
3001 | Ṣé o fẹ́ ṣàfipamọ́ àwọn àyípadà sí %%? | Do you want to save changes to %%? |
3002 | Ṣàfip&amọ́ | &Save |
3003 | &Má ṣàfipamọ́ | Do&n't Save |
File Description: | Àfikọ̀wéRánpẹ́ |
File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
Company Name: | Microsoft Corporation |
Internal Name: | Notepad |
Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa. |
Original Filename: | NOTEPAD.EXE.MUI |
Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
Product Version: | 10.0.15063.0 |
Translation: | 0x46A, 1200 |