File name: | credprovs.dll.mui |
Size: | 8704 byte |
MD5: | 70695532259daf07182094dafe320ca0 |
SHA1: | e1e2af2fcee4c492392240100ac4f66a9b7f5ee7 |
SHA256: | cbbeedf662285ecad6b968be35e9c5a05c86ffc188ef8991f972e905b8da8d40 |
Operating systems: | Windows 10 |
Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id | Yoruba | English |
---|---|---|
101 | Ọ̀rọ̀ aṣínà kò péye. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | The password is incorrect. Try again. |
102 | Àkọọ́lẹ̀ rẹ ní àwọn ìdíwọ́ àkókò tí kò jẹ́kí o lè wọlé nísìnyí. Jọ̀wọ́ gbìyànjú síi láìpẹ́. | Your account has time restrictions that prevent you from signing in at this time. Please try again later. |
103 | Àkọọ́lẹ̀ rẹ wà ní àtòpọ̀ tí ó ńdènà rẹ láti lo kọ̀ǹpútà yìí. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lóríi kọ̀ǹpútà mìíràn. | Your account is configured to prevent you from using this PC. Please try another PC. |
104 | Ati pa àyè rẹ. Jọ̀wọ́ kàn sí alábòójútó ẹrọ rẹ. | Your account has been disabled. Please see your system administrator. |
105 | Àyè rẹ ti parí. Jọ̀wọ́ kàn sí alábòójútó ẹrọ rẹ. | Your account has expired. Please see your system administrator. |
106 | Láti wọlé sí ọ̀nà jínjìn, o nílò ẹ̀tọ́ láti wọlé nípa ní láti Gbà ẹ́ láyè ìwọlé nípa òfin Isẹ́ Ìdádúró. Nípa àkùnàyàn, àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Àwọn Àkójọpọ̀ Aṣàmúlò Àtẹ iṣẹ́ Ìjìnnà ní àyè yìí. Tí o bá kìń se ọmọ ẹgbẹ́ Àwọn ìpèsè Àtẹ iṣẹ́ tàbí ẹgbẹ́ mìíràn tó ní àyè yìí, tàbí tí ẹgbẹ́ Àwọn Àkójọpọ̀ Aṣàmúlò Àtẹ iṣẹ́ Ọ̀nàjínjìn kò bá ní àyè yìí, a ní láti gbà ẹ́ láàyè yìí pẹ̀lú ọwọ́. | To sign in remotely, you need the right to sign in through Remote Desktop Services. By default, members of the Administrators group have this right. If the group you're in doesn't have this right, or if the right has been removed from the Administrators group, you need to be granted this right manually. |
107 | Láti ṣe ìwọlésí ọ̀lọ́nà jínjìn, o nílò ẹ̀tọ́ láti wọlé nípa Ìpèsè Àtẹ iṣẹ́ Ọlọ́nàjínjìn. Nípa àkùnàyàn, ọmọ ẹgbẹ́ Aṣàmúlò Àtẹ iṣẹ́ ọ́nàjínjìn ní ẹ̀tọ́ yìí. Tí ọ̀wọ́ tí o wà kò bá ní ẹ̀tọ́ yìí, tàbí tí ẹ̀tọ́ yìí bá ti di yíyọkúrò láti Ọ̀wọ́ Aṣàmúlò Àtẹ iṣẹ́ ọ́nàjínjìn, o nílò láti gba ẹ̀tọ́ yìí ní aláfọwọ́ṣe. | To sign in remotely, you need the right to sign in through Remote Desktop Services. By default, members of the Remote Desktop Users group have this right. If the group you're in doesn't have this right, or if the right has been removed from the Remote Desktop Users group, you need to be granted this right manually. |
109 | A kò lè ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà lórí àyè aṣàmúlò ní àkókò yìí. | The password on this account cannot be changed at this time. |
110 | Ọ̀rọ̀ asínà rẹ ti dópin. Láti ṣètò ọ̀rọ̀ aṣínà titun, yan Ó DÁA, yan Yí aṣàmúlò po, tún ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ ìsinsìnyí tẹ̀wọlé, lẹ́yìn náà tẹ̀lé àwọn ìfitónilétí lórí asàfihàn náà. | Your password has expired. To set a new password, select OK, select Switch user, reenter your current password, and then follow the prompts on the screen. |
111 | Ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ ti dópin o sì nílò ìyípadà. | Your password has expired and must be changed. |
112 | Ìlànà ìwọlé tí o ń gbìyànjú láti lò ni a kò gbàláyè. Fún ìwífún síwájú síi, kàn sí alábòójútó alásopọ̀ rẹ. | The sign-in method you're trying to use isn't allowed. For more info, contact your network administrator. |
113 | A ti ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ. | Your password has been changed. |
114 | O ní láti sàmúlò káàdì amúṣẹ́yá láti wọlé. | You must use a smart card to sign in. |
116 | Kóòdù ìwọlé tí o lò kò báa mu. | The passwords you entered did not match. |
117 | Jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé orúkọ aṣàmúlò àti ọ̀rọ̀ aṣínà. | Please enter a user name and password. |
121 | Orúkọ aṣàmúlò tàbí ọ̀rọ̀ aṣínà kòpéye. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansíi. | The user name or password is incorrect. Try again. |
125 | Ọ̀rọ̀ aṣínà Tuntun | New password |
126 | Fídí ọ̀rọ̀ aṣínà Múlẹ̀ | Confirm password |
127 | Fàkalẹ̀ | Submit |
13000 | Orúkọ aṣàmúlò | User name |
13001 | Ọ̀rọ̀ aṣínà | Password |
13002 | Ọ̀rọ̀ aṣínà tẹ́lẹ̀ | Old password |
13005 | Orúkọ tó fanimọ́ra | Friendly name |
13006 | Ipò aṣàmúlò | User status |
13009 | Aṣàmúlò mìíràn | Other user |
13010 | Sí Kọ̀ǹpútà náà | Unlock the PC |
13011 | Ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà kan | Change a password |
13012 | Lo àkọọ́lẹ̀ míràn | Use a different account |
13013 | Àwòrán àkọọ́lẹ̀ | Account picture |
13015 | Báwo ni mo ṣe lè wọlé sí agbègbè ìkápá mìíràn? | How do I sign in to another domain? |
13016 | Tẹ orúkọ agbègbè ìkápá \orúkọ aṣàmúlò agbègbè ìkápá láti wọlé sí agbègbè ìkápá mìíràn Tẹ %1\orúkọ aṣàmúlò ìbílẹ̀ láti wọlé sí Kọ̀ǹpútà yìí nìkan (kìi ṣe agbègbè ìkápá kan). |
Type domain name\domain user name to sign in to another domain. Type %1\local user name to sign in to this PC only (not a domain). |
13017 | Wọlé sí: %s | Sign in to: %s |
13018 | Wọlé sí | Sign in to |
13020 | Agbègbè: %s | Domain: %s |
13021 | Àgbègbè ìkápá | Domain |
13022 | Atọ́nà ọ̀rọ̀ aṣínà | Password hint |
13023 | Ṣàtúntò Ọ̀rọ̀ Aṣínà | Reset password |
13024 | Ṣẹ̀dá dísíkì aṣàtúntò ọ̀rọ̀ aṣínà | Create a password reset disk |
13025 | Atọ́nà ọ̀rọ̀ aṣínà: %s | Password hint: %s |
13026 | Rántí àwọn ìwé ẹ̀rí mi | Remember my credentials |
13028 | Ọ̀rọ̀ aṣínà àkọọ́lẹ̀ àgbègbè ìkápá tàbí abẹ́lé | Local or domain account password |
13029 | A kò le sopọ̀ báyìí. Jọ̀wọ́ ṣàyẹ̀wò alásopọ̀ rẹ kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. | We are unable to connect right now. Please check your network and try again later. |
13030 | Àkọọ́lẹ̀ iṣẹ́ tàbí ilé-ìwé rẹ | Your work or school account |
13031 | O kò le wọlé pẹ̀lú ID aṣàmúlò kan ní ìgúnrégé yìí. Gbìyànjú láti lo àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì rẹ dípò. | You can't sign in with a user ID in this format. Try using your email address instead. |
13032 | Àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì | Email address |
16000 | Yí ọ̀rọ̀ aṣínà alásopọ̀ kan padà | Change a network password |
16001 | Olùpèsè\Orúkọ aṣàmúlò | Provider\User name |
16003 | Ọ̀rọ̀ aṣínà tuntun | New password |
16005 | Ó DÁA | OK |
File Description: | Àwọn Olùpèsè Ohun Ẹ̀rí |
File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
Company Name: | Microsoft Corporation |
Internal Name: | credprovs.dll |
Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo àwọn ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́. |
Original Filename: | credprovs.dll.mui |
Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
Product Version: | 10.0.15063.0 |
Translation: | 0x46A, 1200 |