systemreset.exe Ìṣàtúntò ẹ̀rọ fún Windows 6d47c81bca6fefeeafa90e8675acd531

File info

File name: systemreset.exe.mui
Size: 20992 byte
MD5: 6d47c81bca6fefeeafa90e8675acd531
SHA1: 154b31de4522bd011ba37468bd072f86546da525
SHA256: 9d7c0132f10c7f8add975fe56ce3d68d4d7247407d166492df4572e459cf19fd
Operating systems: Windows 10
Extension: MUI
In x64: systemreset.exe Ìṣàtúntò ẹ̀rọ fún Windows (bíìtì-32)

Translations messages and strings

If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.

id Yoruba English
136Tókàn Next
137Paá rẹ́ Cancel
138Ṣàtúntò Reset
139Pa dé Close
140Start Start
142Àwo àká-ọ̀rọ̀ Windows níbi tí a ṣe ìfisípò Windows sí nìkan Only the drive where Windows is installed
143Gbogbo Ìtukọ All drives
144Ṣàfihàn àwọn àtòkọ ìtukọ̀ tí ó máa kàn Show me the list of drives that will be affected
145Ǹjẹ́ o fẹ́ ṣàyọkúrò gbogbo fáìlì láti gbogbo ìtukọ̀? Do you want to remove all files from all drives?
147Nílò àfikún ààyè dísìkì Additional disk space needed
148Láti fààyè dísìkì díẹ̀ sílẹ̀ síi ààyè, o le: To free up disk space, you can:
149Rọ́ọ̀nù Aṣàfọ̀dọ̀tí Dísìkì Run Disk Cleanup
150Ṣẹ̀dà àwọn fáìlì rẹ sí ohun èlò àtìtawá kí o wá Ṣèparẹ́ wọn kúrò láti kọ̀ǹpútà rẹ Copy your files to an external device and delete them from this PC
151Ṣàyọnípò àwọn ètò Uninstall programs
153Èyí kò ní pẹ́ This won’t take long
155Yan ẹ̀yàn kan Choose an option
156Tọ́jú àgbékalẹ̀ PC yìí fún ibi-iṣẹ́ rẹ Keep this PC set up for your workplace
157Bẹ́ẹ̀ni Yes
158Ńṣàfipamọ́ àwọn àkópọ̀ pípèsè èyítí ń jẹ́ kí PC rẹ lo àwọn ohun àmúlò ibi-iṣẹ́. Saves provisioning packages that let your PC use workplace resources.
159Bẹ́ẹ̀kọ́ No
160Ńṣèmúkúrò àwọn àkópọ̀ pípèsè èyítí ń jẹ́ kí PC rẹ lo àwọn ohun àmúlò ibi-iṣẹ́. Removes provisioning packages that let your PC use workplace resources.
161Ìkìlọ̀! Warning!
162PC yìí ni a ṣàfikún láìpẹ́ sí Windows 10. Tí o bá Ṣàtúntò PC yìí, o kò ní le dá àfikún náà padà kí o sì padà sí ẹ̀yà Windows àtijọ́. This PC was recently upgraded to Windows 10. If you Reset this PC, you won’t be able to undo the upgrade and go back to the previous version of Windows.
163Ti ṣetán láti ṣàtúntò PC yìí Ready to reset this PC
165Ti ṣetán láti múpadà sípò Ready to restore
166Fresh start Fresh start
167Let's get started Let's get started
169Ńpèsè àwọn nkan sílẹ̀ Getting things ready
171Èyí yóò pẹ́ díẹ̀ àti pé PC rẹ yóò ṣàtúnbẹ̀rẹ̀. This will take a while and your PC will restart.
173Àlékún %1!ws! ààye tó sófo ní a nílò lórí i (%2!ws!). An additional %1!ws! of free disk space is needed on (%2!ws!).
179Àkíyèsí: Ìpàrokò Àwo Àká-ọ̀rọ̀ BitLocker máa wà nípò ìdádúró fún ìgbà ráńpẹ́ títí tí a máa fi parí ìṣètò. Note: BitLocker drive encryption will be temporarily suspended until the process is done.
180Pàtàkì: Ki kọ̀ǹpútà rẹ bọná kí o tó bẹ̀rẹ̀ Important: Plug in your PC before you start
181Àwọn ènìyàn mìíràn wà lórí i kọ̀ǹpútà yìí Other people are logged on to this PC
182Ǹjẹ́ o fẹ́ tẹ̀ṣíwájú bí? Èyí máa jẹ́ kí wọ́n sọ détà tí wọn kò bá fipamọ́ nù. Do you want to continue? This will cause them to lose unsaved data.
183Múpadà sípò Restore
189Èyí máa ṣàyọkúrò àwọn fáìlì àdáni àti ìṣàfilọ́lẹ̀ láti kọ̀ǹpútà rẹ, yíò ṣèràpadà gbogbo ìṣètò sí àkùnàyàn wọn. Tí o bá lo Ìtàn Fáìlì, ríi dájú pé Ẹ̀yà àkọ̀tun àwọn fáìlì rẹ ni o ṣẹ̀dá sí àwo àká-ọ̀rọ̀ Ìtàn Fáìlì kí o tó tẹ̀ṣíwájú. Èyí máa gba àwọn ìṣẹ́jú díẹ̀ àtípé kọ̀ǹpútà rẹ máa sàtúnbẹ̀rẹ̀. This will remove your personal files and apps from your PC and restore all settings to their defaults. If you use File History, make sure the latest versions of your files were copied to your File History drive before you proceed. This will take a few minutes and your PC will restart.
190Àkíyèsí: Ìpàrokò Àwo Àká-ọ̀rọ̀ BitLocker máa di pípa. Note: BitLocker drive encryption will be turned off.
191Kọ̀ǹpútà rẹ ní ju àwo àká-ọ̀rọ̀ kan lọ Your PC has more than one drive
192Tí o bá yàn láti ṣàyọkúrò fáìlì láti gbogbo àwo-àká-ọ̀rọ̀, àwọ àwo-àká-ọ̀rọ̀ wọ̀nyìí máa faragbá: If you choose to remove files from all drives, these drives will be affected:
193Àwọn àwo-àká-ọ̀rọ̀ tó máa faragbá Drives that will be affected
194Àwo àká-ọ̀rọ̀ aláìlórúkọ Unnamed drive
195A kò le ṣàtúntò PC rẹ nígbà tí ó bá ń ṣiṣẹ́ lórí agbára bátìrì. We can’t reset your PC while it’s running on battery power.
196ki kọ̀ǹpútà rẹ bọná Plug in your PC
197Kò sí ìyípadà titun. No changes were made.
198Ìṣòro kan wáyé láti ṣàtúntò kọ̀ǹpútà rẹ There was a problem resetting your PC
201Kò le ṣàtúntò PC yìí kí ó sì tọ́jú àwọn fáìlì rẹ Cannot reset this PC and keep your files
202Láti ṣàtúntò PC yìí kí ó sì tọ́jú àwọn fáìlì rẹ, Àwọn aṣàmúlò, Fáìlì Àtòjọ ètò, àti ibi ìpamọ́ fáìlì Windows gbọ́dọ̀ wà nínú àwo aká-ọ̀rọ̀ kannáà. O le yàn láti ṣàtúntò PC yìí kí o sì ṣèmúkúrò ohun gbogbo dípò, ṣùgbọ́n o gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ ṣẹ̀dà àbọ̀ábá fún àwọn fáìlì àdáni rẹ náà. To reset this PC and keep your files, the Users, Program Files, and Windows directories need to be on the same drive. You can choose to reset this PC and remove everything instead, but you should back up your personal files first.
203Ǹjẹ́ o fẹ́ fọdọ̀tí àwo àká-ọ̀rọ̀, pẹ̀lú? Do you want to clean the drives, too?
204Ṣèmúkúrò àwọn fáìlì kí o sì fọ̀dọ̀tí àwo àká-ọ̀rọ̀ Remove files and clean the drive
205Èyí le gba wákàtí díẹ̀, ṣùgbọ́ a ó jẹ́ kó nira fún ẹnìkan láti mú àwọn fáìlì rẹ tí a ṣèmúkúrò padà. Lo èyí tí o bá ń sọ PC yìí di ọ̀tun. This might take a few hours, but will make it harder for someone to recover your removed files. Use this if you’re recycling the PC.
206Yọ àwọn fáìlì nìkan Just remove my files
207Èyí yá, ṣùgbọ́n kò ní ààbò dáradára. Lo èyí tí o bá ń tọ́jú PC náà. This is quicker, but less secure. Use this if you’re keeping the PC.
211Èyí máa ṣàyọkúrò àwọn fáìlì àdáni rẹ àti ìṣàfilọ́lẹ̀ láti kọ̀ǹpútà rẹ kí ó sì ṣe ìràpadà gbogbo ààtò sí àkùnàyàn wọn. Tí o bá lo Ìtàn Fáìlì, rí i dájú pé ẹ̀yà àkọ̀tun àwọn fáìlì ní o ṣẹ̀dá sí Ìtàn Fáìlì àwo-àká-ọ̀rọ̀ kí o tó tẹ̀ṣíwájú. Kọ̀ǹpútà rẹ máa ṣàtúnbẹ̀rẹ̀. This will remove your personal files and apps from your PC and restore all settings to their defaults. If you use File History, make sure the latest versions of your files were copied to your File History drive before you proceed. Your PC will restart.
214Kọ̀ǹpútà rẹ kò le ṣeé sọdọ̀tun nítorí pé ó ń lo Windows To Go ń ṣiṣẹ́ lórí i rẹ. Your PC can’t be reset because it’s running Windows To Go.
216A kò le ṣàtúntò PC yìí We can’t reset this PC
21811;normal;none;Segoe UI 11;normal;none;Segoe UI
219Nígbà tí o bá ṣàyọkúrò àwọn fáìlì rẹ, o tún le ṣàfọmọ́ àwo àká-ọ̀rọ̀ rẹ kí àwọn fáìlì náà le ṣeé ràpadà nírọ̀rùn. Èyí tún máa ní ọ̀pọ̀ áàbò, ṣùgbọ́n o gbà àkókò díẹ́. When you remove your files, you can also clean the drive so that the files can’t be recovered easily. This is more secure, but it takes much longer.
247Kò rí agbègbè ìgbápadà Could not find the recovery environment
248Fi ìṣàgbékalẹ̀ Windows tàbí médíà ìgbàpadà rẹ sí i, kí wá tún kọ̀ǹpútà rẹ tàn pẹ̀lú mídíà. Insert your Windows installation or recovery media, and restart your PC with the media.
253Ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí yóó nílò kí a tún ṣàgbékalẹ̀ These apps will need to be reinstalled
254Ṣàtúnyẹ̀wò àtòkọ àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀. Wá nílò dísìkì tàbí fáìlì láti ṣàtúngékalẹ̀ wọn tó bá yá. Reveiw the list of apps. You’ll need the discs or files to reinstall them later.
255Padà sẹ́yìn Go back
256Tí o bá parí pẹ̀lú pé o sọ ìṣàwárí ìmúgbòrò nù, ààbò, àti bíbẹ̀rẹ̀, padà wá sí Windows 10 nígbàkugbà. If you end up missing improved search, security, and startup, come back to Windows 10 anytime.
260O ṣeun fún ìgbìyànjú Windows 10 Thanks for trying Windows 10
261Tún ààyè àwo aká-ọ̀rọ̀ gbà Reclaim disk space
262Èyí yóò gba ààyè àwo aká-ọ̀rọ̀ padà tí a lò láti tọ́jú Windows 7. Yóò palẹ̀ ààyè àwo aká-ọ̀rọ̀ náà mọ́, ṣùgbọ́n o kò ní le dá Windows 7 padà lẹ́yìn èyí. This will recover the disk space used to store Windows 7. It will free up that disk space, but you will no longer be able to restore Windows 7 after this.
263Ṣèmúkúrò Windows 7? Remove Windows 7?
264Èyí yóò palẹ̀ ààyè mọ́ lórí PC rẹ, ṣùgbọ́n o kò ní le padà sí Windows 7. This will free up space on your PC, but you won’t be able to go back to Windows 7.
265Ṣèmúkúrò àwọn àkọọ́lẹ̀ titun Remove new accounts
266Kí o tó le lọ sí ẹ̀yà ìṣájú ti Windows, wàá ní láti ṣèmúkúrò èyíkéyìí àwọn àkọọ́lẹ̀ aṣàmúlò tí o ti ṣàfikún lẹ́yìn àfikún rẹ àìpẹ́. Àwọn àkọọ́lẹ̀ náà ni a gbọ́dọ̀ ṣèmúkúrò pátapáta, pẹ̀lú àwọn ìrísí olùlò wọn. Before you can go back to a previous version of Windows, you’ll need to remove any user accounts you added after your most recent upgrade. The accounts need to be completely removed, including their profiles.
267O ti ṣẹ̀dá àkọọ́lẹ̀ kan (%2!ws!) You created one account (%2!ws!)
268O ti ṣẹ̀dá àwọn àkọọ́lẹ̀ %1!ws! náà (%2!ws!) You created %1!ws! accounts (%2!ws!)
269Lọ sí Àwọn Ààtò Àwọn Àkọọ́lẹ̀ Àwọn ènìyàn míràn láti ṣèmúkúrò àwọn àkọọ́lẹ̀ wọ̀nyí, lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. Go to Settings Accounts Other people to remove these accounts, and then try again.
270Gbé àwọn àkọọ́lẹ̀ padà Move accounts back
271Kí o tó le padà sí ẹ̀yà ìṣájú ti Windows, wàá ní láti fi èyíkéyìí àwọn àkọọ́lẹ̀ aṣàmúlò tí o gbé lẹ́yìn àfikún àìpẹ́ rẹ padà sí ojúlówó ibi wọn. Before you can go back to a previous version of Windows, you’ll need to put any user accounts you moved after your most recent upgrade back in their original location.
272O ti gbé àkọọ́lẹ̀ kan (%2!ws!) You moved one account (%2!ws!)
273O ti gbé àwọn àkọọ́lẹ̀ %1!ws! náà (%2!ws!) You moved %1!ws! accounts (%2!ws!)
274A tọrọ gáfárà, ṣùgbọ́n o kò le padà We’re sorry, but you can’t go back
275Àwọn fáìlì tí a nílò láti mú ọ padà sí ẹ̀yà ìṣájú ti Windows ni a ti ṣèmúkúrò nínú PC yìí. The files we need to take you back to a previous version of Windows were removed from this PC.
277A kò le mú ọ padà sínú ẹ̀yà ìṣájú ti Windows nítorí àwo aká-ọ̀rọ̀ USB tàbí àwo aká-ọ̀rọ̀ ìta míràn tí a lò ní àkókò àfikún rẹ àìpẹ́ ti sọnù. Jọ̀wọ́ ṣèfibọ̀ àwo aká-ọ̀rọ̀ náà kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. We can’t take you back to a previous version of Windows because the USB flash drive or other external drive that was used during your most recent upgrade is missing. Please insert the disk and try again.
279A kò le mú ọ padà sí ẹ̀yà ìṣájú ti Windows nítorí ó ti ju oṣù kan lọ tí a ṣàfikún náà. We can’t take you back to the previous version of Windows because it’s been more than a month since the upgrade.
280Àwọn ìfilọ́lẹ̀ mi tàbí ohun èlò kò ṣiṣẹ́ lórí Windows 10 My apps or devices don’t work on Windows 10
281Àwọn ìkọ àtijọ́ dàbí pé ó rọrùn láti lò Earlier builds seemed easier to use
282Windows 7 dàbí pé ó rọrùn láti lò Windows 7 seemed easier to use
283Windows 8 dàbí pé ó rọrùn láti lò Windows 8 seemed easier to use
284Windows 8.1 dàbí pé ó rọrùn láti lò Windows 8.1 seemed easier to use
285Àwọn ìkọ àtijọ́ dàbí pé ó yá jù Earlier builds seemed faster
286Windows 7 dàbí pé ó yára Windows 7 seemed faster
287Windows 8 dàbí pé ó yára Windows 8 seemed faster
289Àwọn ìkọ àtijọ́ dàbí pé ó ṣeé gbẹ́kẹ̀lé jù Earlier builds seemed more reliable
290Windows 7 dàbí pé o ṣeé gbẹ́kẹ̀lé Windows 7 seemed more reliable
291Windows 8 dàbí pé o ṣeé gbẹ́kẹ̀lé Windows 8 seemed more reliable
293Fún ìdí míràn For another reason
294Kínní dé tí o fi ń padà? Why are you going back?
296Sọ fún wa síwájú síi Tell us more
298Tí o bá ń yanjú ìṣòro, If you’re up for troubleshooting,
299kàn sí àtìlẹ́yìn. contact support.
300Ohun tí o nílò láti mọ̀ What you need to know
301Èyí le pẹ́ díẹ̀ àti pé o kò ní le lo PC rẹ títí yóò fi parí. Ti PC rẹ bọ iná kó sì wà ní títàn. This might take a while and you won’t be able to use your PC until it’s done. Leave your PC plugged in and turned on.
302Lẹ́yìn lílọ padà: After going back:
303• Wàá ní láti tún ṣàgbékalẹ̀ àwọn ìfilọ́lẹ̀ àti àtòjọ-ètò kan. • You’ll have to reinstall some apps and programs.
304• Wàá ní láti tún ṣàgbékalẹ̀ àwọn àtòjọ-ètò kan. • You’ll have to reinstall some programs.
306Máṣe jẹ́ kí a tí ọ pa sí ìta Don’t get locked out
307Tí o bá lo ọ̀rọ̀ aṣínà kan láti wọlé sínú Windows 7, ṣàrídájú pé o mọ̀ ọ́. If you used a password to sign in to Windows 7, make sure you know it.
308Tí o bá lo ọ̀rọ̀ aṣínà láti wọlé sínú Windows 8, ṣàrídájú pé o mọ̀ ọ́. If you used a password to sign in to Windows 8, make sure you know it.
309Tí o bá lo ọ̀rọ̀ aṣínà kan láti wọlé sínú ìkọ ìṣájú rẹ, ṣàrídájú pé o mọ̀ ọ́. If you used a password to sign in to your previous build, make sure you know it.
310Padà sí Windows 7 Go back to Windows 7
311Padà sí Windows 8 Go back to Windows 8
312Padà sí ìkọ ìṣájú Go back to earlier build
315Ti PC rẹ bọná Plug in your PC
316O kò le padà lórí agbára bátìrì nìkan. Ti PC rẹ bọná kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. You can’t go back on battery power alone. Plug in your PC and then try again.
323
324Ṣé o ṣẹ̀dà àbọ̀ábá fún àwọn fáìlì rẹ bí? Èyí kò gbọ́dọ̀ kàn wọ́n, ṣùgbọ́n ó dára láti gbáradì. Are your files backed up? This shouldn’t affect them, but it’s best to be prepared.
325O kò ní le wọlé láìsí rẹ̀. You won’t be able to sign in without it.
326Àwọn ìfilọ́lẹ̀ tàbí ohun èlò mi kò ṣiṣẹ́ lórí ìkọ yìí My apps or devices don’t work on this build
327• Wàá sọ èyíkéyì àyípadà tí o ṣe sí àwọn ààtò nù lẹ́yìn àfikún sí Windows 10. • You’ll lose any changes made to settings after the upgrade to Windows 10.
328• Wàá sọ èyíkéyì àyípadà tí o ṣe sí àwọn ààtò nù lẹ́yìn tí o ṣàgbékalẹ̀ ìkọ yìí. • You’ll lose any changes made to settings after installing the latest build.
329O ṣe fún gbígbìyànjú ìlò ìkọ yìí Thanks for trying out this build
330A ó ṣàgbékalẹ̀ àkọ́wò tókàn nígbàtí ó bá wà nílẹ̀. We’ll install the next preview build when it’s available.
331Ẹ̀yà àtijọ́ ti Windows dàbí pé ó rọrùn láti lò The old version of Windows seemed easier to use
332Windows 8.1 dàbí pé ó yára jù Windows 8.1 seemed faster
333Ẹ̀yà àtijọ́ ti Windows dàbí pé ó yára jù The old version of Windows seemed faster
334Windows 8.1 dàbí pé ó ṣeé gbẹ́kẹ̀lé jù Windows 8.1 seemed more reliable
335Tí o bá ti lo ọ̀rọ̀ aṣínà kan láti wọlé sínú Windows 8.1, ṣàrídájú pé o mọ̀ ọ́. If you used a password to sign in to Windows 8.1, make sure you know it.
336Tí o bá ti lo ọ̀rọ̀ aṣínà kan láti wọlé sínú ẹ̀yà àtijọ́ ti Windows rẹ, ṣàrídájú pé o mọ̀ ọ́. If you used a password to sign in to your previous version of Windows, make sure you know it.
337Ó dàbí pé ẹ̀yà àtijọ́ ti Windows ṣe gbẹ́kẹ̀lé jù The old version of Windows seemed more reliable
338Padà sí Windows 8.1 Go back to Windows 8.1
339Padà sí Windows ìṣájú Go back to previous Windows
340Palẹ̀ ààyè díẹ̀ mọ́ kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. Free up some space and try again.
341Láti padà sẹ́yìn, o nílò %1!ws! MB ti ààyè ọ̀fẹ́ lórí àwo aká-ọ̀rọ̀ níbití a ti ṣàgbékalẹ̀ Windows. To go back, you’ll need %1!ws! MB of free space on the drive where Windows is installed.
342Láti padà sẹ́yìn, o nílò %1!ws! GB ti ààyè ọ̀fẹ́ lórí àwo aká-ọ̀rọ̀ níbití a ti ṣàgbékalẹ̀ Windows. To go back, you’ll need %1!ws! GB of free space on the drive where Windows is installed.
344Ìlànà ilé-iṣẹ́ rẹ kò gbàá láàyè. Fún ìwífún síwájú síi, bá ẹni àtìlẹ́yìn rẹ sọ̀rọ̀ tàbí ẹ̀ka iṣẹ́ IT. Your organization’s policy doesn’t allow it. For more info, talk to your support person or IT department.
345Kò le gba ìwífún lórí àwọn àfikún Couldn’t get info on updates
346Láti ṣàyẹ̀wò fún àwọn àfikún, lọ sí Àwọn Ààtò Àfikún & Ààbò Windows Update kí o sì yan Ṣàyẹ̀wò àwọn àfikún. To check for updates, go to Settings Update & Security Windows Update and select Check for updates.
347Ṣàyẹ̀wò àwọn àfikún bí? Check for updates?
348Kí o tó padà sẹ́yìn, gbìyànjú láti ṣàgbékalẹ̀ àwọn àfikún titun jùlọ. Èyí le yanjú àwọn ìṣòro náà tí o ń ní pẹ̀lú Windows 10. Before you go back, try installing the latest updates. This might fix the problems you’re having with Windows 10.
349Ṣàyẹ̀wò àwọn àfikún Check for updates
350Bẹ́ẹ̀kọ́, o ṣeun No, thanks
351Ńṣàtúntò PC yìí Resetting this PC
352Gbígba àwọn nkan titun díẹ̀ sílẹ̀ %1!d!%% Getting a few things ready %1!d!%%
353This feature is not available in Safe Mode This feature is not available in Safe Mode
354To reset this PC, start Windows normally and try again, or go to Advanced startup and select Troubleshoot. To reset this PC, start Windows normally and try again, or go to Advanced startup and select Troubleshoot.
355This will remove all apps and programs, except those that come standard with Windows. Any store apps installed by your manufacturer will also be kept. Your device will also be updated to the latest version of Windows. Your personal files and some Windows settings will be kept. This will remove all apps and programs, except those that come standard with Windows. Any store apps installed by your manufacturer will also be kept. Your device will also be updated to the latest version of Windows. Your personal files and some Windows settings will be kept.
357Save your work and leave your device plugged in and turned on Save your work and leave your device plugged in and turned on
358This will take a while and your device will restart several times This will take a while and your device will restart several times
359You won't be able to use your device while refreshing Windows, but we will let you know once it's ready You won't be able to use your device while refreshing Windows, but we will let you know once it's ready
360This process could take 20 minutes or longer depending on your device. This process could take 20 minutes or longer depending on your device.
361Refreshing your PC Refreshing your PC
362This will remove all apps and programs you installed. Your device will also be updated to the latest version of Windows. Your personal files and some Windows settings will be kept. This will remove all apps and programs you installed. Your device will also be updated to the latest version of Windows. Your personal files and some Windows settings will be kept.

EXIF

File Name:systemreset.exe.mui
Directory:%WINDIR%\WinSxS\amd64_microsoft-windows-systemreset.resources_31bf3856ad364e35_10.0.15063.0_yo-ng_ac0f66e87a3676c3\
File Size:20 kB
File Permissions:rw-rw-rw-
File Type:Win32 DLL
File Type Extension:dll
MIME Type:application/octet-stream
Machine Type:Intel 386 or later, and compatibles
Time Stamp:0000:00:00 00:00:00
PE Type:PE32
Linker Version:14.10
Code Size:0
Initialized Data Size:20480
Uninitialized Data Size:0
Entry Point:0x0000
OS Version:10.0
Image Version:10.0
Subsystem Version:6.0
Subsystem:Windows GUI
File Version Number:10.0.15063.0
Product Version Number:10.0.15063.0
File Flags Mask:0x003f
File Flags:(none)
File OS:Windows NT 32-bit
Object File Type:Executable application
File Subtype:0
Language Code:Unknown (046A)
Character Set:Unicode
Company Name:Microsoft Corporation
File Description:Ìṣàtúntò ẹ̀rọ fún Windows
File Version:10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800)
Internal Name:systemreset.exe
Legal Copyright:© Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Original File Name:systemreset.exe.mui
Product Name:Microsoft® Windows® Operating System
Product Version:10.0.15063.0

What is systemreset.exe.mui?

systemreset.exe.mui is Multilingual User Interface resource file that contain Yoruba language for file systemreset.exe (Ìṣàtúntò ẹ̀rọ fún Windows).

File version info

File Description:Ìṣàtúntò ẹ̀rọ fún Windows
File Version:10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800)
Company Name:Microsoft Corporation
Internal Name:systemreset.exe
Legal Copyright:© Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Original Filename:systemreset.exe.mui
Product Name:Microsoft® Windows® Operating System
Product Version:10.0.15063.0
Translation:0x46A, 1200