If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id |
Yoruba |
English |
100 | SKYDRIVE_BRAND_NAME rẹ ti kún |
Your SKYDRIVE_BRAND_NAME is full |
101 | Ra ọ̀pọ̀ ibi ìpamọ́ |
Buy more storage |
102 | Pa tì |
Ignore |
103 | A ṣẹ̀ṣẹ̀ gbìyànjú ṣíṣe àbọ̀ábá àwọn ààtò PC àti dátà ìṣàfilọ́lẹ̀ rẹ sí SKYDRIVE_BRAND_NAME, ṣùgbọ́n kò sí ààyè tó tó. O le ra ọ̀pọ ibi ìpamọ́ tàbí lọ sí àwọn ààtò PC láti ṣàkóso ààyè ibi ìpamọ́ rẹ. |
We just tried backing up your app data and PC settings to SKYDRIVE_BRAND_NAME, but there wasn’t enough space. You can buy more storage or go to PC settings to manage your storage space. |
104 | Ṣàkóso ibi ìpamọ́ |
Manage storage |
105 | Ìṣèràpadà kò leè parí |
Restore could not be completed |
106 | Ó DÁA |
OK |
107 | Kò ṣe é ṣe fún wa láti ṣẹ̀d]a àwọn ààtò rẹ láti SKYDRIVE_BRAND_NAME. Gbìyànjú lílọ sí aabala Àwọn àkọọ́lẹ̀ Microsoft láti PC yìí, kí o wá ṣàfikún rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan síi. í ìyẹn kò bá ṣiṣẹ́, o le gbìyànjú ṣísàtúntò PC rẹ sí àwọn ààtò ilé iṣẹ́, kí o wá gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. |
We weren’t able to copy your settings over from SKYDRIVE_BRAND_NAME. Try going to the Accounts section of PC settings, disconnect your Microsoft account from this PC, and then add it again. If that doesn’t work, you can try resetting your PC to its factory settings, and then adding your account again. |
112 | Ààyè àwó kéré |
Low disk space |
113 | Ààyè ti ń tán lórí i PC yìí. Ṣàkóso ibi ìpamọ́ láti wo ìlò kí o sì pèsè ààyè díẹ̀ síi. |
You’re running out of space on this PC. Manage storage to view usage and free up some space. |
114 | Má rán mi létí mọ́ |
Don’t remind me again |
115 | Padé |
Close |