If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
| id |
Yoruba |
English |
| 9320 | Sàfihàn |
Project |
| 9322 | Dárí sí aṣàfihàn tí o somọ́ |
Project to a connected screen |
| 9323 | Aṣàfihàn kọ̀ǹpútà nìkan |
PC screen only |
| 9324 | Ṣẹ̀dà |
Duplicate |
| 9325 | Fà gùn |
Extend |
| 9326 | Aṣàfihàn kejì nìkan |
Second screen only |
| 9328 | Ṣèpínyà |
Disconnect |
| 9329 | Somọ́ aṣàfihàn tóyàtọ̀ |
Connect to a different display |
| 9330 | Bẹ́ẹ̀ni |
Yes |
| 9331 | Bẹ́ẹ̀kọ́ |
No |
| 9332 | Ǹjẹ́ ó dá ọ lójú pé o fẹ́ lo aṣàfihàn kejì nìkan? |
Are you sure you want to use only the second screen? |
| 9333 | Ṣíṣípòpadà àwọn ìṣètò tẹ́lẹ̀ rẹ ní ìṣẹ́jú ààyá 1. |
Switching to your previous settings in 1 second. |
| 9334 | Ṣíṣípòpadà àwọn ìṣètò tẹ́lẹ̀ rẹ ní ìṣẹ́jú ààyá %d. |
Switching to your previous settings in %d seconds. |
| 9340 | Kọ̀ǹpútà rẹ kò lè ṣàgbéjáde àwòrán sí aṣàfihàn mìíràn. Gbìyànjú ṣíṣe àtúnfisípò atukọ̀ tàbí nípa lílo Káàdì fídíò tó yàtọ̀. |
Your PC can’t project to another screen. Try reinstalling the driver or using a different video card. |
| 9341 | A kò rí aṣàfihàn mìíràn láti somọ́. Ṣàyẹ̀wò àwọn ìsopọ̀ rẹ kí o gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansíi. |
We couldn’t find another screen to connect to. Check your connections and try again. |
| 9351 | 11;semilight;none;segoe ui |
11;semilight;none;segoe ui |
| 9352 | 11;Semilight;None;Segoe UI |
11;Semilight;None;Segoe UI |
| 0x10000031 | Response Time |
Response Time |
| 0x30000001 | Start |
Start |
| 0x30000002 | Stop |
Stop |
| 0x50000004 | Information |
Information |
| 0x90000001 | Microsoft-Windows-DisplaySwitch |
Microsoft-Windows-DisplaySwitch |