1100 | Sample header 1 |
Sample header 1 |
1101 | Ìmúsí àwòrán (%d x %d) rẹ ti kéré jù láti mú àtòjọ-ètò ìgbàlódé ṣiṣẹ́ |
Your screen resolution (%d x %d) is too low to run modern application |
1110 | Sample header 2 |
Sample header 2 |
1111 | Ohun èlò aláfọwọ́bà kò ní àtìlẹyìn fún ọlọ́pọ̀ ìfọwọ́kàn |
Your touch device does not support multi-touch |
1120 | Ìmúsí aṣàfihàn rẹ kò ní ohun tí a nílò láti ṣàgbékalẹ̀ àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ láti Ìtàjà oníforíkorí Windows |
Your screen resolution doesn't meet the requirement to install apps from the Windows Store |
1121 | O nílò ìmúsí àwòrán aṣàfihàn, ó kéré jù, 1024 x 768 láti ṣàgbékalẹ̀ àti láti lo àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ láti Ìtàjà Windows Oníforíkorí (èyí jẹ́ gẹ́gẹ́bíi àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ tí ó ti wà ní ìṣàgbékalẹ̀ tẹ́lẹ̀ lórí i PC rẹ). O le ṣàyípadà ìmúsí àwòrán rẹ ní Ṣàfihàn Pánẹ́ẹ̀lì Ìdarí. |
You need a screen resolution of at least 1024 x 768 to install and use apps from the Windows Store (this includes apps that might be pre-installed on your PC). You might be able to change your resolution in the Display Control Panel. |
1130 | Aṣàfihàn-aláfọwọ́bà lórí i PC yìí kò wà fún Windows 10 |
The touchscreen on this PC wasn't designed for Windows 10 |
1131 | O le lo aṣàfihàn-aláfọwọ́bà pẹ̀lú Windows 10 ṣùgbọ́n ó le má ṣe dáadáa tó àtipé àwọn ìfarajúwe kò ní ṣe wẹ́kú bí èyí tí a ṣe fún Windows 10. |
You can use this touchscreen with Windows 10 but it won't be as responsive and gestures won't be as precise as a touchscreen designed for Windows 10. |
1140 | Windows Media Center kò tí ì sí ní ìṣàgbékalẹ̀ tẹ́lẹ̀ |
Windows Media Center isn't preinstalled |
1141 | kẹ́ẹ̀kọ̀ọ́ díẹ̀ síi nípa ṣíṣàgbékalẹ̀ rẹ ní Windows 10. |
Learn more about installing it in Windows 10. |
1150 | Ṣàgbékalẹ̀ ìṣàfilọ́lẹ̀ kan láti mú DVD ṣiṣẹ́ |
Install an app to play DVDs |
1151 | O le nílò láti ṣàgbékalẹ̀ ìṣàfilọ́lẹ̀ kan láti mú àwọn DVD ṣiṣẹ́ ní Windows 10. |
You may need to install an app to play DVDs in Windows 10. |
1160 | Ìmúsí aṣàfihàn rẹ kò báramu pẹ̀lú snap |
Your screen resolution isn't compatible with snap |
1161 | Tí ó bá ṣeéṣe, ṣàyípadà ìmúsí aṣàfihàn rẹ sí , ó kéré jù, 1366 x 768 sí àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ snap. |
If it's possible, change your screen resolution to at least 1366 x 768 to snap apps. |
1170 | Àwọn gájẹ́ẹ̀tì òpó-ẹ̀gbẹ́ kò ni àtìlẹyìn ní Windows 10 |
Sidebar gadgets aren't supported in Windows 10 |
1171 | O kò ní le lo àwọn gájẹ́ẹ̀tì òpó-ẹ̀gbẹ́ tí ó ti wà ní ìṣàgbékalẹ̀ lórí i PC rẹ ní Windows 10. |
You won’t be able to use the sidebar gadgets that are installed on your PC in Windows 10. |
1180 | NX kò sí ní títàn fún agbéṣẹ́ rẹ tàbí kí ó má ní àtìlẹyìn fún NX |
Your processor doesn't have NX turned on or might not support NX |
1181 | Aṣàgbékalẹ̀ máa gbé ìgbéṣẹ̀ láti tan NX lákòókò ìṣàgbékalẹ̀. Tí agbéṣẹ́ rẹ kò bá ṣàtìlẹyìn fún NX, ìṣàgbékalẹ̀ máa di píparẹ́ àtí pé PC rẹ máa padàṣẹ́yìn sí OS ti lọ́wọ́lọ́wọ́. |
Setup will attempt to turn on NX during installation. If your processor doesn't support NX, the installation will be cancelled and your PC will roll back to the current OS. |
1190 | Loss of music and video content with update |
Loss of music and video content with update |
1191 | We recommend you do not proceed with this update as your device may have some music or video content that is protected by an older rights management technology, which is not supported. If you install this update, you may no longer be able to play these music or video files. Close this dialog box to cancel, or you can choose to confirm to install the update. For more info, go to https://support.microsoft.com/windows10wmdrm |
We recommend you do not proceed with this update as your device may have some music or video content that is protected by an older rights management technology, which is not supported. If you install this update, you may no longer be able to play these music or video files. Close this dialog box to cancel, or you can choose to confirm to install the update. For more info, go to https://support.microsoft.com/windows10wmdrm |
1204 | Búùtù tóláàbò kò báramu pẹ̀lú PC rẹ |
Secure Boot isn't compatible with your PC |
1205 | Fámúwíà PC rẹ kò ní àtìlẹyìn fún Búùtù Tóláàbò kí o má báà le lo ò ní Windows 10. |
Your PC's firmware doesn't support Secure Boot so you won't be able to use it in Windows 10. |
1216 | Windows Media Center wà ní àgbékalẹ̀ lórí i PC yìí |
Windows Media Center is installed on this PC |
1217 | Windows Media Center ni a ó ṣàyọkúrò ní àkókò àfikún náà. Kò sí nílẹ̀ ní nú Windows 10. |
Windows Media Center will be uninstalled during the upgrade. It isn't available in Windows 10. |
1220 | Wàá ní àwọn ìṣòro pẹ̀lú aṣàfihàn rẹ ní Windows 10. |
You'll have problems with your display in Windows 10. |