| 2 | Ìràpadà |
Recovery |
| 4 | Log on using an administrator account and try again. |
Log on using an administrator account and try again. |
| 101 | ìgbàpadà |
Recovery |
| 102 | Irinsẹ́ ìràpadà aládàńlá |
Advanced recovery tools |
| 103 | Yanjú ìsoro lórí kọ̀ǹpútà rẹ nípa dídápadà ìyípadà tí o ti ṣe sí àwọn ètò àti ìṣètò. |
Fix problems on your computer by undoing changes you've made to programs and settings. |
| 104 | Ṣàtúntò |
Reset |
| 105 | Tí o bá fẹ́ ṣàtúnlò kọ̀ǹpútà rẹ tàbí bẹ̀rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀, o le ṣàtúntò rẹ̀ kí o sì ṣàyọkúrò gbogbo wọn. |
If you want to recycle your PC or start over with it, you can reset it and remove everything. |
| 106 | Bíbẹ̀rẹ̀ |
Get Started |
| 107 | Ìrinṣẹ́ Aládàńlá |
Advanced tools |
| 108 | Ṣí Ìrápadà Ẹ̀rọ |
Open System Restore |
| 109 | Ṣàdápadà ìyípadà àìpẹ́ àwọn ẹ̀rọ, ṣùgbọ́n fi àwọn fáìlì sílẹ̀ bíi àwọn àkọsílẹ̀, àwòrán, àti orin. |
Undo recent system changes, but leave files such as documents, pictures, and music unchanged. |
| 110 | Ṣàtòpọ̀ Ìràpadà Ẹ̀rọ |
Configure System Restore |
| 111 | Ṣàyípadà àwọn ìṣètò ìràpadà, ṣàkóso ààyè dísìkì, kí o ṣẹ̀dá tàbí ṣèparẹ́ ọ̀gangan ìràpadà. |
Change restore settings, manage disk space, and create or delete restore points. |
| 112 | Ṣẹ̀dá àwo àká-ọ̀rọ̀ ìràpadà |
Create a recovery drive |
| 113 | Ṣẹ̀dá àwo àká-ọ̀rọ̀ ìràpadà láti wójúùtú àwọn ìsòro, kódà nígbàtí PC rẹ kò bá le bẹ̀rẹ̀. |
Create a recovery drive to troubleshoot problems when your PC can't start. |
| 114 | Sọdọ̀tun |
Refresh |
| 116 | Tí kọ̀ǹpútà rẹ kò bá ṣiṣẹ́ dárádárá, o le ṣe ìsọdọ̀tun rẹ̀ láì sọ àwọn fọ́tò, orin, fídíò àti àwọn fáìlì àdáni rẹ nù. |
If your PC isn’t running well, you can refresh it without losing your photos, music, videos, and other personal files. |
| 117 | Ìrànwọ́ |
Help |
| 118 | System Restore is disabled by your system administrator. |
System Restore is disabled by your system administrator. |
| 119 | Tí o bá ń kójukọ àwọn ìṣòro pẹ̀lú PC rẹ, lọ sí Àwọn ààbò kí o sì gbìyànjú ìṣàtúntò rẹ̀ |
If you're having problems with your PC, go to Settings and try resetting it |
| 460 | Ìtàn Fáìlì |
File History |
| 468 | Recovery |
Recovery |
| 469 | You need to be an administrator to perform this task |
You need to be an administrator to perform this task |
| 470 | System Restore could not start. |
System Restore could not start. |
| 471 | Reset could not start. |
Reset could not start. |
| 472 | RecoveryDrive could not start. |
RecoveryDrive could not start. |
| 473 | Refresh could not start. |
Refresh could not start. |