1 | Agbègbè Ìfitónilétí Àwòrán aṣàmì |
Notification Area Icons |
2 | Yan àwòrán asàmì àti ìpàkíyèsí tí ó bá hàn ní agbègbè ìfitónilétí. |
Select which icons and notifications appear in the notification area. |
3 | Ẹ̀rọ Àwòrán asàmì |
System Icons |
4 | Yan àwòrán asàmì tí ó bá hàn ní agbègbè ìfitónilétí. |
Select which system icons appear in the notification area. |
266 | Click |
Click |
400 | Ṣàfihàn àwòrán asàmì àti ìpàkíyèsí |
Show icon and notifications |
401 | Ṣàpamọ́ àwòrán asàmì àti ìpàkíyèsí |
Hide icon and notifications |
402 | Ṣàfihàn ìpàkíyèsí nìkan |
Only show notifications |
403 | Aago |
Clock |
404 | Ìtóbi |
Volume |
405 | Alásopọ̀ |
Network |
406 | Agbára |
Power |
407 | Pa tàbí tan ẹ̀rọ awòrán asàmì |
Turn system icons on or off |
408 | Ṣe ìsọdi-àdáni àwòrán asàmì ìfitónilétí |
Customize notification icons |
409 | ṣe ìdápadà ìṣe àwòrán asàmì àkùnàyàn |
Restore default icon behaviors |
410 | &Máa ṣàfihàn àwòrán asàmì àti ìpàkíyèsí lórí pẹpẹ iṣẹ́ |
&Always show all icons and notifications on the taskbar |
411 | Àwòrán asàmì ìfitónilétí kò ṣiṣẹ́ nísin ṣìyí |
This notification icon is not currently active |
412 | A ó fihàn nígbà míràn tó bá ṣiṣẹ́. |
It will be shown the next time it becomes active. |
414 | Títàn |
On |
415 | Pípa |
Off |
416 | Ìrànlọ́wọ́ |
Help |
417 | Atọ́ka Ìgbéwọlé |
Input Indicator |
418 | Ìbi Iṣẹ́ |
Action Center |
419 | Ibi |
Location |
420 | Àtẹ ìtẹ̀wé orí aṣàfihàn |
Touch keyboard |
421 | Àtẹ iṣẹ́ Windows Ink |
Windows Ink Workspace |
422 | Touchpad |
Touchpad |
423 | Windows Update Status |
Windows Update Status |
500 | Yan àwòrán asàmì àti ìpàkíyèsí tí ó bá hàn lórí pẹpẹ iṣẹ́ |
Select which icons and notifications appear on the taskbar |
501 | Bí o bá yàn láti fi àwòrán aṣàmì àti ìfitónilétí pamọ́, a kò ní sọ fún ọ nípa àyípadà tàbí àfikún. Láti wo asàmì tí a fipamọ́ ní ìgbàkúùgbà, ṣira tẹ ọfà tí ó kángun sí agbègbè àkíyèsí lórí pẹpẹ ìdúrópàtó. |
If you choose to hide icons and notifications, you won’t be notified about changes or updates. To view hidden icons at any time, click the arrow next to the notification area on the taskbar. |
502 | Àwòrán asàmì |
Icons |
503 | Ìṣe |
Behaviors |
601 | Pípa ẹ̀rọ àwòrán àpèjúwe máa ṣàyọkúrò àwòrán àpèjúwe tí yó sì pa àkíyèsí. |
Turning off a system icon removes the icon and turns off notifications. |
602 | Ẹ̀rọ àwòrán asàmì |
System Icons |
2048 | Some settings are managed by your system administrator. |
Some settings are managed by your system administrator. |
2050 | È é ṣe tí n ò fi lè ṣàyípadà ààtò díẹ̀ṣ |
Why can't I change some settings? |
2051 | Ó DÁA |
OK |
2052 | Paá rẹ́ |
Cancel |
0x30000001 | Start |
Start |
0x30000002 | Stop |
Stop |
0x50000004 | Information |
Information |
0x90000001 | Microsoft-Windows-TaskbarCPL |
Microsoft-Windows-TaskbarCPL |