| 1 | Ojú |
Face |
| 2 | Ẹyinjú |
Iris |
| 3 | Bọ́tìnnì ìwọlé |
Sign in button |
| 4 | Ìfiránṣẹ́ ọ̀gàngán ipò |
Context message |
| 5 | Windows Hello |
Windows Hello |
| 50 | Jọ̀wọ́ lo ìlànà míràn láti dá ara rẹ mọ̀. |
Please use a different method to identify yourself. |
| 51 | Báwo ni %1!s!! Yan Ó DÁA láti tẹ̀síwájú. |
Hello %1!s!! Select OK to continue. |
| 52 | Kò le dá ọ mọ̀. Jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé PIN rẹ. |
Couldn't recognize you. Please enter your PIN. |
| 100 | Windows kò le mú ọ wọlé. |
Windows couldn't sign you in. |
| 101 | Báwo ni %1!s! |
Hello %1!s! |
| 104 | Ńwá ọ... |
Looking for you... |
| 105 | Ńgbáradì... |
Getting ready... |
| 106 | Kò le tan kámẹ́rà náà. Jọ̀wọ́ wọlé pẹ̀lú PIN rẹ. |
Couldn't turn on the camera. Please sign in with your PIN. |
| 107 | Your PIN is required to sign in. |
Your PIN is required to sign in. |
| 108 | Ti gbé àkọọ́lẹ̀ rẹ sípò àìṣélò. Jọ̀wọ́ kàn sí ẹni àtìlẹ́yìn rẹ. |
Your account has been disabled. Please contact your support person. |
| 109 | Kí o tó le bẹ̀rẹ̀ lílo Windows Hello, o ní láti ṣàgbékalẹ̀ PIN kan. |
Before you can start using Windows Hello, you have to set up a PIN. |
| 111 | Kí o tó le bẹ̀rẹ̀ lílo Windows Hello, o ní láti ṣàtẹ̀wọlé PIN rẹ. |
Before you can start using Windows Hello, you have to enter your PIN. |
| 113 | Báwo ni, %1!s!! Pa aṣàfihàn alátìpa láti wọlé. |
Hello, %1!s!! Dismiss the lock screen to sign in. |
| 114 | Má bínú ohun kan kò lọ déédé. Jọ̀wọ́ wọlé pẹ̀lú PIN rẹ. |
Sorry something went wrong. Please sign in with your PIN. |
| 120 | Ohun kan kò lọ déédé. Jọ̀wọ́ ṣàtẹ̀wọlé PIN rẹ. |
Sorry something went wrong. Please enter your PIN. |
| 121 | Windows Hello ni alábòójútó rẹ gbé sípò àìṣélò lọ́wọ́lọ́wọ́. |
Windows Hello is currently disabled by your administrator. |
| 123 | Ńṣàrídájú pé ìwọ ni... |
Making sure it's you... |
| 124 | Kò sí kámẹ́rà nílẹ̀. Jọ̀wọ́ wọlé pẹ̀lú PIN rẹ. |
Camera not available. Please sign in with your PIN. |
| 125 | Kò le dá ọ mọ̀. Jọ̀wọ́ wọlé pẹ̀lú PIN rẹ. |
Couldn't recognize you. Please sign in with your PIN. |
| 126 | Kò le dá ọ mọ̀. Fìkawọ́ sókè láti ṣàtẹ̀wọlé PIN. |
Couldn't recognize you. Swipe up to enter PIN. |
| 127 | Fìkawọ́ sókè láti tú aṣàfihàn alátìpa ká. |
Swipe up to dismiss the lock screen. |
| 128 | Abala ọ̀nà jínjìn ń ṣiṣẹ́ lọ́wọ́. Pa aṣàfihàn alátìpa tì láti wọlé. |
Remote session is active. Dismiss the lock screen to sign in. |
| 129 | Dismiss the lock screen to sign in. |
Dismiss the lock screen to sign in. |
| 150 | Kò le dá ọ mọ̀. |
Couldn't recognize you. |
| 152 | Kò le tan kámẹ́rà náà. |
Couldn't turn on the camera. |
| 153 | Kò sí kámẹ́rà nílẹ̀. |
Camera not available. |
| 155 | Má bínú ohun kan kò lọ déédé. |
Sorry something went wrong. |
| 156 | Your password is required to sign in. |
Your password is required to sign in. |
| 157 | Camera is in use. Please sign in with your PIN. |
Camera is in use. Please sign in with your PIN. |
| 158 | Camera driver is in a bad state. Please sign in with your PIN. |
Camera driver is in a bad state. Please sign in with your PIN. |
| 180 | Hello! Getting things ready... |
Hello! Getting things ready... |
| 200 | Ohun èlò rẹ kò le rí ọ. Ṣàrídájú pé ojú kámẹ́rà rẹ mọ́. |
Your device couldn't detect you. Make sure your camera lens is clean. |
| 201 | Ti mọ́lẹ̀ jù! Pa iná díẹ̀ tàbí lọ inú ilé. |
Too bright! Turn off some lights or go inside. |
| 202 | Ti dúdú jù! Tan iná díẹ̀ tàbí lọ síbi kan tó mọ́lẹ̀ dáradára. |
Too dark! Turn on some lights or move somewhere brighter. |
| 203 | Ṣàrídájú pé o wà ní àárín o sì ń wo kámẹ́rà náà tààrà. |
Make sure you're centered and looking directly at the camera. |
| 204 | Ti súmọ́ jù! Gbìyànjú láti sún sẹ́yìn díẹ̀. |
Too close! Try moving a little farther away. |
| 205 | Ti jìnnà jù! Gbìyànjú láti súmọ́ díẹ̀. |
Too far away! Try moving a bit closer. |
| 206 | Rọra yí orí rẹ sí òsì àti ọ̀tún. |
Turn your head slightly to the left and right. |
| 207 | La ojú rẹ dáradára. |
Open your eyes a little wider. |
| 208 | Rọ́ra gbé láti dènà òjìjí ojú rẹ. |
Move slightly to avoid reflection off your eyes. |
| 209 | Sún síwájú dáradára |
Move farther away |
| 210 | Sún mọ́ra |
Move closer |
| 211 | Gbé ohun èlò rẹ tààrà síwájú ojú rẹ. |
Hold your device straight in front of your eyes. |
| 212 | Ohun èlò rẹ ní ìṣòro láti dá ọ mọ̀. Ṣàrídájú pé ojú kámẹ́rà rẹ mọ́. |
Your device is having trouble detecting you. Make sure your camera lens is clean. |
| 213 | Ohun èlò rẹ kò le rí ojú rẹ. Ṣàrídájú pé ojú kámẹ́rà rẹ mọ́. |
Your device couldn't detect your eyes. Make sure your camera lens is clean. |
| 301 | Ṣé kò le wọlé pẹ̀lú Windows Hello bí? |
Can't sign in with Windows Hello? |
| 302 | Lọ nípa ìṣètò lẹ́ẹ̀kan síi láti ṣàmúgbòrò ìdámọ̀ ní oríṣìí ipò iná, tàbí nígbàtí ìfarahàn rẹ bá yípadà (fún àpẹrẹ, awò titun). |
Go through setup again to improve recognition in different lighting conditions, or when your appearance changes (for example, new glasses). |
| 303 | Ṣàmúgbòrò ìdámọ̀ nínú Windows Hello |
Improve recognition in Windows Hello |
| 304 | Láti ṣàmúlò ànfàní àwọn àfikún titun sí Windows Hello, lọ nípa ìṣètò lẹ́ẹ̀kan síi. |
To take advantage of the latest updates to Windows Hello, go through setup again. |
| 305 | Ǹjẹ́ o mọ̀ pé o le lo ìfàṣẹsí ojú láti wọlé bí? |
Do you know that you can use face authentication to sign in? |
| 306 | Ka ìṣètò ojú Windows Hello náà láti bẹ̀rẹ̀. |
Go through the Windows Hello face setup to get started. |
| 307 | There is a problem with Windows Hello. |
There is a problem with Windows Hello. |
| 308 | Please go through the setup again to fix this issue. |
Please go through the setup again to fix this issue. |