100 | Windows Remote Assistance |
Windows Remote Assistance |
103 | àwọn ọjọ́ |
Days |
104 | Àwọn Wákàtí |
Hours |
105 | Àwọn ìṣẹ́jú |
Minutes |
106 | Please enter a value between 1 and 99 |
Please enter a value between 1 and 99 |
107 | The maximum expiry period is 30 days only. Select a value less than 30 days. |
The maximum expiry period is 30 days only. Select a value less than 30 days. |
1604 | Enter the password provided to you by the person you are trying to help. |
Enter the password provided to you by the person you are trying to help. |
1605 | Ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀ aṣínà: |
Enter password: |
1607 | Àtúnṣe Ọ̀rọ̀-aṣínà |
Password Edit |
2000 | Ìsopọ̀ tó lọ %s |
Last connected on %s |
2001 | Ran ènìyàn tuntun lọ́wọ́ |
Help someone new |
2002 | Lo ẹ̀yàn yìí láti sopọ̀ mọ́ ẹni tí kò sí nínú àtòkọ |
Use this option to connect to someone not on the list |
2003 | Pe enìkan láti ran ọ́ lọ́wọ́. |
Invite someone to help you. |
2004 | Lo ẹ̀yàn yìí láti sopọ̀ mọ́ ẹni tí o kò tíì kansí |
Use this option to connect to someone you have not contacted |
2005 | Kọ̀ǹpútà: %s |
Computer: %s |
2020 | Ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀-aṣínà láti sopọ̀ mọ́ kọ̀ǹpútà ìjìnnà |
Enter the password to connect to the remote computer |
2021 | O lè gba ọ̀rọ̀-aṣínà lọ́wọ́ ẹni tó ń bèèrè ìrànlọ́wọ́. Sáà Ìrànlọ́wọ́ Ìjìnnà yóó tí kété tí o bá ti tẹ ọ̀rọ̀-aṣínà kí o wá ṣíra tẹ O DÁRA. |
You can get this password from the person requesting assistance. A Remote Assistance session will start after you type the password and click OK. |
2022 | Ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀-aṣínà Ìsopọ̀ Ìrọ̀rùn |
Enter the Easy Connect password |
2023 | Ṣàtẹ̀wọlé ẹyọ-ọ̀rọ̀ 12 tó jẹ́ tiÌsopọ̀ Ìrọ̀rùn tí o gbà láti ọ̀dọ̀ ẹni tó ń fẹ́ ìrànlọ́wọ́. |
Enter the 12 character Easy Connect password that you got from the person requesting assistance. |
2024 | Ọ̀rọ̀-aṣínà náà kò tọ̀nà. Jọ̀wọ́ ṣàrídájú ọ̀rọ̀-aṣínà pẹ̀lú ẹni tí o fẹ́ rànlọ́wọ́, kí o wá gbìyànjú síi. |
The password is not correct. Please verify the password with the person you are helping, and then try again. |
2025 | Tí o bá gbé ọ̀rọ̀-aṣínà wọlé dáadáa, o lè tó ìṣẹ́jú díẹ̀ kí o tó lè sopọ̀ mọ́ Alásopọ̀ Ìrọ̀rùn. Tí o bá sì tún ń ní ìsòro, ṣíra tẹ Wójútùú láti dá Ìrànlọ́wọ́ Ìjìnnà dúró kí o wá isòro alásopọ̀náà kàn kí o sì yanjú rẹ̀. |
If the password is entered correctly, it might take a few seconds before you can connect using Easy Connect. If you still have problems, click Troubleshoot to stop Remote Assistance and try to identify and resolve network problems. |
2026 | Try Again |
Try Again |
2027 | Ìrànwọ́ Ìjìnnà |
Remote Assistance |
2028 | Ṣàtúnṣe ìṣòro |
Troubleshoot |