| File name: | DevicePairing.dll.mui |
| Size: | 10240 byte |
| MD5: | 3a142b31d0c8b9224a63bb097df3fad1 |
| SHA1: | 8e59b4ffa53e5058085a1359e32cc96ea207629f |
| SHA256: | 657b48d8253b1d68a5b9ed2e831766e3b6a04f8353a95419c862935f266c9f64 |
| Operating systems: | Windows 10 |
| Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
| id | Yoruba | English |
|---|---|---|
| 101 | kóòdù ìgbaniwọlé | passcode |
| 102 | WPS PIN | WPS PIN |
| 103 | Ohun èlò | device |
| 104 | %1!s!, %2!s! | %1!s!, %2!s! |
| 105 | Àwọn kóòdù ìgbaníwọlé | passcodes |
| 106 | Àwọn PIN WPS | WPS PINs |
| 107 | %1!s! %2!s! |
%1!s! %2!s! |
| 1601 | Ṣàfikún ohun èlò | Add a device |
| 1602 | Ń so pọ̀mọ́ | Connecting |
| 1604 | O kò rí ohun tí ò ń wá bí? | Not finding what you’re looking for? |
| 1607 | Wo Àlàyé | View Details |
| 3999 | ko rí ohun èlò kankan | No devices found |
| 4000 | Ń ṣàwárí àwọn ohun èlò | Searching for devices |
| 4001 | Yan Ohun èlò kan | Select a device |
| 4004 | Yan ohun èlò tàbí ẹ̀rọ ìtẹ̀wé láti ṣàfikún sí kọ̀ǹpútà yìí | Choose a device or printer to add to this PC |
| 4005 | A kò rí atẹ̀wé | We can’t find that printer |
| 4006 | Ìyẹn kò ṣiṣẹ́ | That didn’t work |
| 4007 | Ohun tó pọ̀ wà láti ṣe | There’s more to do |
| 4008 | Àkòkò ti lọ | Time’s up |
| 4009 | Ṣàfiwé %1!s! náà | Compare the %1!s! |
| 4010 | Ṣàtẹ̀wọlé %1!s! kan sínú %2!s! | Enter a %1!s! into your %2!s! |
| 4011 | Ṣàtẹ̀wọlé %1!s! náà fún %2!s! | Enter the %1!s! for your %2!s! |
| 4012 | Ń somọ́ %2!s! | Connecting to %2!s! |
| 4201 | O le rí %1!s! lórí i %2!s! rẹ tàbí nínú ìwífún tí ó wá pẹ̀lú rẹ̀. | You can find the %1!s! on your %2!s! or in the info that came with it. |
| 4202 | O le nílò láti ṣàtẹ̀wọlé %1!s! kan náà sínú %2!s!. | You might need to enter the same %1!s! into the %2!s!. |
| 4204 | Àti pé %1!s! kò tọ̀nà. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | That %1!s! isn’t right. Try again. |
| 4207 | So %1!s! rẹ mọ́ PC yìí nìkan. | Connect your %1!s! only to this PC. |
| 4208 | O ń so %1!s! rẹ nìkan mọ́ PC yìí. | You’re connecting your %1!s! only to this PC. |
| 4211 | Tẹ %1!s! yìí sínú %2!s! rẹ, kí o wá tẹ Ṣàtẹ̀wọlé tàbí Ó DÁA lórí i %3!s!. | Type this %1!s! into your %2!s!, and then press Enter or OK on the %3!s!. |
| 4212 | Tẹ %1!s! yìí sínú %2!s! rẹ, kí o wá tẹ Ṣàtẹ̀wọlé lórí i %3!s!. | Type this %1!s! into your %2!s!, and then press Enter on the %3!s!. |
| 4213 | Ìyẹn kò ṣiṣẹ́. Ṣàtẹ̀wọlé %1!s! yìí. | That didn’t work. Enter this %1!s!. |
| 4221 | Ǹjẹ́ %1!s! yìí lórí i %2!s! rẹ báramu bí? | Does the %1!s! on %2!s! match this one? |
| 4223 | Bẹ́ẹ̀ni | Yes |
| 4224 | &Bẹ́ẹ̀ni | &Yes |
| 4225 | Bẹ́ẹ̀kọ́ | No |
| 4226 | &Bẹ́ẹ̀kọ́ | &No |
| 4227 | Ṣàfikún | Add |
| 4228 | Parí | Finish |
| 4231 | Tẹ̀lé èyíkéyìí ìlànà lórí i %1!s! rẹ. | Follow any instructions on your %1!s!. |
| 4241 | Gbìyànjú ṣíṣàfikún %3!s! lẹ́ẹ̀kan síi, tàbí ṣàyẹ̀wò pẹ̀lú olùṣẹ̀dá fún àfikún ìlànà ìṣàgbékalẹ̀. | Try adding your %3!s! again, or check with the manufacturer for additional setup instructions. |
| 4242 | %1!s! rẹ kò dúró mọ́. Gbìyànjú ṣíṣàfikún rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan síi. | Your %1!s! quit waiting. Try adding it again. |
| 4243 | Pé %2!s! kò tọ́. Gbìyànjú ṣíṣàfikún %1!s! rẹ lẹ́ẹ̀kan síi. | That %2!s! isn’t right. Try adding your %1!s! again. |
| 4244 | Gbíyànjú lẹ́ẹ̀kan síi, kí o sì ṣàyẹ̀wò %2!s!. Tàbí, gbìyànjú rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan síi láìsí %2!s! kankan. | Try again, and check the %2!s!. Or, try it again without a %2!s!. |
| 4246 | Window kò ní ìrísí olúlò alásopọ̀ fún ohun èlò yìí. | Windows doesn’t have a network profile for this device. |
| 4247 | O gbọ́dọ̀ ti somọ́ sí alásopọ̀ aláìlókùn kí ṣíṣàfikún ohun èlò yìí tó wáyé. | You must be connected to a wireless network before adding this device. |
| 4248 | Windows kò ní ìrísí olùlò alásopọ̀ tí ó ní àtìlẹyìn fún ohun èlò yìí. | Windows doesn’t have a supported network profile for this device. |
| 4249 | Ṣíṣàfikún %1!s! rẹ kò ṣiṣẹ́. Kọ́kọ́ ṣàyọkúrò rẹ̀ láti PC rẹ, kí o wá gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Adding your %1!s! didn’t work. First remove it from your PC, and then try again. |
| 4250 | Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi, kí o ríi dájú pé %1!s! ṣee ṣàwárí. | Try again, and make sure your %1!s! is still discoverable. |
| 4251 | Kí o tó le ṣàfikún atẹ̀wé yìí, o níláti ṣàgbékalẹ̀ adarí aláìrídìmú rẹ̀. Wá adarí aláìrídìmú lórí i wẹ́ẹ̀bù tàbí lo dísìkì tí ó bá àtẹ̀wé wá, kí o wá gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | Before you can add this printer, you need to install a driver for it. Find the driver on the web or use the disc that came with the printer, and then try again. |
| 4252 | A kò le somọ́ apèsè àtẹ̀wé. Èyí le ṣẹlẹ̀ tí apèsè àtẹ̀wé bá ti parúkọdà, di píparẹ́, tàbí di gbígbé sí alásopọ̀ míìràn. Gbìyànjú ṣíṣàtúngbékalẹ̀ àtẹ̀wé tàbí kànsí alábòójútó alásopọ̀ rẹ fún ìrànlọ́wọ́. | We can’t connect to the print server. This can happen if the print server was renamed, deleted, or moved to a different network. Try reinstalling the printer or contact your network administrator for help. |
| 4253 | A kò rí atẹ̀wé tí o ń gbìyànjú láti ṣàgbékalẹ̀. ṣàyẹ̀wò láti rí i dájú pé àtẹ̀wé náà kò tíì pa oúkọ dà kí o wá gbìyànjú ìṣàgbékalẹ̀ lẹ́ẹ̀kan síi tàbí kànsí alábòójútó alásopọ̀ rẹ fún ìrànlọ́wọ́. | We can’t find the printer you’re trying to install. Check to see if the printer was renamed and try to install it again or contact your network administrator for help. |
| 4254 | Atẹ̀wé náà kò sí nílẹ̀ nítorípé alábòójútó alásopọ̀ ti fúnnàmọ́ ìráyè sí rẹ̀. | The printer isn’t available because your network administrator restricted access to it. |
| 4255 | A kò le ṣàgbékalẹ̀ àtẹ̀wé yìí lọ́wọ́lọ́wọ́. Gbìyànjí lẹ́ẹ̀kan síi láìpẹ́ tàbí kàn sí alábòójútó alásopọ̀ rẹ fún ìrànlọ́wọ́. | We can’t install this printer right now. Try again later or contact your network administrator for help. |
| 4256 | Padé | Close |
| 4257 | &Padé | &Close |
| 4258 | Paá rẹ́ | Cancel |
| 4259 | Tẹ̀ síwájú | Continue |
| 4260 | Atẹ̀wé: %1!s! | Printer: %1!s! |
| 4261 | Ipa: %1!s! | Path: %1!s! |
| 4262 | Àṣìṣe: #%1!d! | Error: #%1!d! |
| 4263 | Ìgúnrégé %2!s! kò tọ́. Gbìyànjú ṣíṣàfikún %1!s! rẹ lẹ́ẹ̀kan síi. | The format of the %2!s! isn’t right. Try adding your %1!s! again. |
| 4300 | Tàbí, gbìyànjú ṣíṣàfikún rẹ̀ pẹ̀lú %1!s! kan. | Or, try adding it with a %1!s!. |
| 4301 | Tàbí, gbìyànjú ṣíṣàtẹ̀wọlé %1!s! kan lórí rẹ̀. | Or, try entering a %1!s! on it. |
| 4302 | Tàbí, gbìyànjú ṣíṣàfikún rẹ̀ pẹ̀lú bọ́tìnnì kan. | Or, try adding it with a button. |
| 4303 | Tàbí, gbìyànjú ṣíṣàfikún rẹ̀ láìsí %1!s! kankan. | Or, try adding it without a %1!s!. |
| 4304 | Tàbí, jẹ́ kí PC rẹ ṣẹ̀dá %1!s! kan fún ọ. | Or, let your PC create a %1!s! for you. |
| 6100 | Ṣàfikún ohun èlò kan | Add a device |
| 6200 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé tí mo fẹ́ kò sí ní àkọsílẹ̀ | The printer that I want isn't listed |
| 7010 | Àwọn ohun èlò | Device |
| 7011 | ohun èlò | device |
| 7100 | 8;Normal;None;Segoe UI | 8;Normal;None;Segoe UI |
| 7101 | 9;Normal;None;Segoe UI | 9;Normal;None;Segoe UI |
| 7102 | 9;Normal;Underline;Segoe UI | 9;Normal;Underline;Segoe UI |
| 7103 | 11;Normal;None;Segoe UI | 11;Normal;None;Segoe UI |
| 7104 | 11;Semilight;None;Segoe UI | 11;Semilight;None;Segoe UI |
| 7105 | 13;Normal;None;Segoe UI | 13;Normal;None;Segoe UI |
| 7106 | 17;Normal;None;Segoe UI | 17;Normal;None;Segoe UI |
| 7107 | 20;Light;None;Segoe UI | 20;Light;None;Segoe UI |
| 7108 | 42;Semibold;None;Segoe UI | 42;Semibold;None;Segoe UI |
| File Description: | Àwọn Ìfàgun Ilé fún ohun èlò pínpín |
| File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
| Company Name: | Microsoft Corporation |
| Internal Name: | DevicePairing |
| Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ ni tiwa. |
| Original Filename: | DevicePairing.dll.mui |
| Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
| Product Version: | 10.0.15063.0 |
| Translation: | 0x46A, 1200 |