| 1 | Ohun èlò tí a kò Mọ̀ |
Unknown Device |
| 2 | Tí a kò mọ̀ |
Unknown |
| 5 | Mìíràn |
Other |
| 8 | ohun èlò |
device |
| 10 | Àwọn Ohun Èlò Ohùn |
Audio Devices |
| 11 | Ohun èlò ohùn |
Audio device |
| 12 | Àwọn ohun èlò ohùn |
Audio devices |
| 15 | Ẹ̀rọ Àdágbórinsétí |
Headphone |
| 17 | Ẹ̀rọ gbohùngbohùn |
Microphone |
| 18 | Àwọn ẹ̀rọ gbohùngbohùn |
Microphones |
| 19 | Àwọn Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ |
Speakers |
| 21 | Àwọn Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ aláìlókùn |
Wireless speakers |
| 23 | Àwọn Agbóhùnsáfẹ́fẹ́ USB |
USB speakers |
| 25 | Fóònù agbóhùnsáfẹ́fẹ́ |
Speaker phone |
| 26 | Àwọn Fóònù agbóhùnsáfẹ́fẹ́ |
Speaker phones |
| 27 | ohun èlò ohùn àfetígbọ́ |
audio device |
| 29 | ẹ́rọ Àdágbórinsétí |
headphone |
| 30 | ẹ̀rọ gbohùngbohùn |
microphone |
| 31 | fóònù agbóhùnsáfẹ́fẹ́ |
speaker phone |
| 60 | Àwọn Ohun Èlò Ìbánisọ̀rọ |
Communications Devices |
| 61 | Ohun Èlò Ìbánisọ̀rọ |
Communications device |
| 62 | Àwọn Ohun Èlò ìbánisọ̀rọ |
Communications devices |
| 63 | Àgbékọ́rí |
Headset |
| 64 | Àwọn Àgbékọ́rí |
Headsets |
| 65 | Bluetooth Àgbékọ́rí |
Bluetooth headset |
| 66 | Àwọn Bluetooth Àgbékọ́rí |
Bluetooth headsets |
| 67 | Fóònù |
Phone |
| 68 | Àwọn Fóònù |
Phones |
| 69 | Fóònù alágbèéká |
Cell phone |
| 70 | Àwọn Fóònù alágbèéká |
Cell phones |
| 71 | Fóònù IP |
IP phone |
| 72 | Àwọn Fóònù IP |
IP phones |
| 120 | Àwọn kọ̀ǹpútà Àdáni |
PCs |
| 121 | Kọ̀ǹpútà |
PC |
| 123 | Kọ̀ǹpútà Àdáni gbogboǹṣe |
All-in-one PC |
| 125 | Kọ̀ǹpútà Àgbékatábìlì |
Desktop PC |
| 126 | Àwọn Kọ̀ǹpútà Àgbékatábìlì |
Desktop PCs |
| 131 | Kọ̀ǹpútà ìgbékọ́wọ́ |
Handheld PC |
| 132 | Kọ̀ǹpútà àdáni ìgbékọ́wọ́ |
Handheld PCs |
| 133 | Kọ̀ǹpútà ìgbékọ́wọ́ Windows |
Windows handheld PC |
| 134 | Àwọn kọ̀ǹpútà ìgbékọ́wọ́ Windows |
Windows handheld PCs |
| 135 | Kọ̀ǹpútà àgbélétan |
Laptop |
| 136 | Àwọn Kọ̀ǹpútà àgbélétan |
Laptops |
| 137 | Kọ̀ǹpútà Lunchbox |
Lunchbox PC |
| 138 | Àwọn kọ̀ǹpútà Lunchbox |
Lunchbox PCs |
| 139 | Kọ̀ǹpútà Nẹtibúùkù |
Netbook |
| 140 | Àwọn nẹtibúùkù |
Netbooks |
| 141 | Kọ̀ǹpútà Alábọ́dé |
Notebook PC |
| 142 | Àwọn Kọ̀ǹpútà Alábọ́dé |
Notebook PCs |
| 143 | Kọ̀ǹpútà Notebook kékèké |
Subnotebook PC |
| 145 | kọ̀ǹpútà Rack mount |
Rack mount PC |
| 146 | Kọ̀ǹpútà alágbèéká |
Portable PC |
| 147 | Àwọn Kọ̀ǹpútà alágbèéká |
Portable PCs |
| 148 | Kọ̀ọǹpútà Rack mount |
Rack mount PCs |
| 149 | Kọ̀ǹpútà Àṣepamọ́ke |
Sealed-case PC |
| 150 | Àwọn kọ̀ǹpútà Àṣépamọ́ke |
Sealed-case PCs |
| 151 | Apèsè |
Server |
| 152 | Àwọn Apèsè |
Servers |
| 153 | Kọ̀ǹpútà Afààyèpamọ́ |
Space saving PC |
| 154 | Àwọn Kọ̀ǹpútà Afààyèpamọ́ |
Space saving PCs |
| 155 | Kọ̀ǹpútà Àdáni Alogègé |
Tablet PC |
| 156 | Àwọn Kọ̀ǹpútà Àdáni Alogègé |
Tablet PCs |
| 157 | Kọ̀ǹpútà oníbàárà |
Thin client PC |
| 158 | Àwọn kọ̀ǹpútà oníbàárà |
Thin client PCs |
| 159 | Kọ̀ǹpútà Tòwà |
Tower PC |
| 160 | Àwọn Kọ̀ǹpútà Tòwà |
Tower PCs |
| 161 | Kọ̀ǹpútà Tòwà kékeré |
Mini-tower PC |
| 162 | Àwọn kọ̀ǹpútà Tòwà kékèké |
Mini-tower PCs |
| 163 | PC |
PC |
| 164 | Kọ̀ǹpútà Gbogboǹṣe |
all-in-one PC |
| 165 | Kọ̀ǹpútà Àtẹ iṣẹ́ |
desktop PC |
| 168 | Kọ̀ǹpútà Àgbéléwọ́ |
handheld PC |
| 169 | Kọ̀ǹpútà Windows àgbélọ́wọ́ |
Windows handheld PC |
| 170 | àgbélétan |
laptop |
| 171 | Kọ̀ǹpútà lunchbox |
lunchbox PC |
| 172 | nẹ́tìbuùkù |
netbook |
| 173 | kọ̀ǹpútà alábọ̀dé |
notebook PC |
| 174 | kọ̀ǹpútà kélébé |
subnotebook PC |
| 175 | kọ̀ǹpútà àlágbèéká |
portable PC |
| 176 | Kọ̀ǹpútà oníráàkì |
rack mount PC |
| 177 | kọ̀ǹpútà àṣepamọ́ke |
sealed-case PC |
| 181 | Kọ̀ǹpútà oníbàárá |
thin client PC |
| 184 | Convertible PC |
Convertible PC |
| 185 | Convertible PCs |
Convertible PCs |
| 186 | Detachable PC |
Detachable PC |
| 187 | Detachable PCs |
Detachable PCs |
| 188 | convertible PC |
convertible PC |
| 189 | detachable PC |
detachable PC |
| 200 | Àwọn Àfihàn àti Pòjẹ́tọ̀ |
Displays and Projectors |
| 201 | Ṣàfihàn |
Display |
| 202 | Àwọn Àfihàn |
Displays |
| 203 | Díígí Kọ̀ǹpútà |
Monitor |
| 204 | Àwọn díígí Kọ̀ǹpútà |
Monitors |
| 205 | Díígí Kọ̀ǹpútà CRT |
CRT monitor |
| 206 | Àwọn díígí Kọ̀ǹpútà CRT |
CRT monitors |
| 207 | Díígí Kọ̀ǹpútà LCD |
LCD monitor |
| 208 | Àwọn díígí Kọ̀ǹpútà LCD |
LCD monitors |
| 209 | Aṣàfihàn pẹrẹsẹ |
Plasma display |
| 210 | Àwọn Aṣàfihàn pẹrẹsẹ |
Plasma displays |
| 211 | Férémù àwòrán |
Picture frame |
| 212 | Àwọn férémù àwòrán |
Picture frames |
| 213 | Pòjẹ́tọ̀ |
Projector |
| 214 | Àwọn Pòjẹ́tọ̀ |
Projectors |
| 215 | Ohun èlò fún SideShow-tí o báramu pẹ̀lú Windows |
Windows SideShow-compatible device |
| 216 | Àwọn ohun èlò fún SideShow-tí o báramu pẹ̀lú Windows |
Windows SideShow-compatible devices |
| 217 | Àmóhùnmáwòrán |
Television |
| 218 | Àwọn Amóhùnmáwòrán |
Televisions |
| 228 | díígí kọ̀ǹpútà |
monitor |
| 229 | Díígí kọ̀ǹpútà CRT |
CRT monitor |
| 230 | Díígí kọ̀ǹpútà LCD |
LCD monitor |
| 231 | aṣàfihàn pẹrẹsẹ |
plasma display |
| 232 | férémù àwòrán |
picture frame |
| 234 | Ohun èlò tí o bá Windows SideShow mu |
Windows SideShow-compatible device |
| 240 | Head-mounted display |
Head-mounted display |
| 241 | Head-mounted displays |
Head-mounted displays |
| 242 | head-mounted display |
head-mounted display |
| 270 | Àwọn amúbádọ́gba ìta àti àwọn ẹ̀yà hádiwià |
External Adapters and Hardware Components |
| 271 | Amúbádọ́gba |
Adapter |
| 273 | Amúbádọ́gba ohùn |
Audio adapter |
| 274 | Àwọn amúbádọ́gba ohùn |
Audio adapters |
| 275 | Bátìrì |
Battery |
| 276 | Àwọn Bátìrì àti ìpèsè agbára tí kò ní ìdínlọ́wọ (UPS) |
Batteries and uninterruptable power supplies (UPS) |
| 277 | Ohun èlò afárá |
Bridge device |
| 278 | Àwọn ohun èlò afárá |
Bridge devices |
| 279 | Afárá alásopọ̀ |
Network bridge |
| 280 | Àwọn Afárá alásopọ̀ |
Network bridges |
| 281 | Afárá àpamọ́ |
Storage bridge |
| 282 | Àwọn Afárá àpamọ́ |
Storage bridges |
| 283 | Kébù |
Cable |
| 284 | Àwọn Kébù |
Cables |
| 285 | Kébù Ìfiránṣẹ́ |
Transfer cable |
| 286 | Àwọn Kébù Ìfiránṣẹ́ |
Transfer cables |
| 287 | Kébù Ìfiránṣẹ́ USB |
USB transfer cable |
| 288 | Àwọn Kébù Ìfiránṣẹ́ USB |
USB transfer cables |
| 289 | Ohun èlò ìgbámú |
Capture device |
| 290 | Àwọn Ohun èlò ìgbámú |
Capture devices |
| 291 | Ohun èlò ìgbámú fídíò |
Video capture device |
| 292 | Àwọn Ohun èlò ìgbámú fídíò |
Video capture devices |
| 293 | Olùdarí |
Controller |
| 294 | Àwọn Olùdari |
Controllers |
| 295 | Olùdari 1394 |
1394 controller |
| 296 | Àwọn Olùdari 1394 |
1394 controllers |
| 297 | Bluetooth amúbádọ́gba |
Bluetooth adapter |
| 298 | Àwọn Bluetooth Amúbádọ́gba |
Bluetooth adapters |
| 299 | Olùdari KáàdìAjọlọ |
CardBus controller |
| 300 | Àwọn Olùdari KáàdìAjọlọ |
CardBus controllers |
| 301 | Olùgba infrared |
Infrared receiver |
| 302 | Àwọn Olùgba infrared |
Infrared receivers |
| 303 | Olùgba infrared MCE |
MCE Infrared receiver |
| 304 | Àwọn Olùgba infrared MCE |
MCE Infrared receivers |
| 305 | Olùdari olùpèsè Aláàbò Olónkà |
Secure Digital host controller |
| 306 | Àwọn Olùdari olùpèsè Aláàbò Olónkà |
Secure Digital host controllers |
| 307 | Ojú ìkànpọ̀ atẹ̀léra amúbádọ́gba |
Serial port adapter |
| 308 | Àwọn Ojú atẹ̀léra amúbádọ́gba |
Serial port adapters |
| 309 | Olùdari àpamọ́ |
Storage controller |
| 310 | Àwọn Olùdari àpamọ́ |
Storage controllers |
| 311 | Olùdari IDE |
IDE controller |
| 312 | Àwọn Olùdari IDE |
IDE controllers |
| 313 | Olùdari iSCSI |
iSCSI controller |
| 314 | Àwọn Olùdari iSCSI |
iSCSI controllers |
| 315 | Olùdari SATA |
SATA controller |
| 316 | Àwọn Olùdari SATA |
SATA controllers |
| 317 | Olùdari SCSI |
SCSI controller |
| 318 | Àwọn Olùdari SCSI |
SCSI controllers |
| 319 | Olùdari RAID |
RAID controller |
| 320 | Àwọn Olùdari RAID |
RAID controllers |
| 321 | Olùdari USB |
USB controller |
| 322 | Àwọn Olùdari USB |
USB controllers |
| 323 | Amúbádọ́gba aláìlókùn USB |
Wireless USB adapter |
| 324 | Àwọn Amúbádọ́gba aláìlókùn USB |
Wireless USB adapters |
| 325 | Káàdì aláwòrán |
Graphics card |
| 326 | Àwọn Káàdì aláwòrán |
Graphics cards |
| 327 | Aṣàkójọ |
Hub |
| 328 | Àwọn Ibi ìpàdè |
Hubs |
| 329 | Ibi ìpàdè 1394 |
1394 hub |
| 330 | Àwọn Ibi ìpàdè 1394 |
1394 hubs |
| 331 | Ibi ìpàdè USB |
USB hub |
| 332 | Àwọn Ibi ìpàdè USB |
USB hubs |
| 333 | Ṣèpapòdà KVM |
KVM switch |
| 334 | Àwọn ṣèpapòdà KVM |
KVM switches |
| 337 | Àfikà káàdì ìsanwó |
Smart card reader |
| 338 | Àwọn Olùkà káàdì ìsanwó |
Smart card readers |
| 339 | Ẹ̀̀yà ẹ̀rọ |
System component |
| 340 | Àwọn Ẹ̀̀yà ẹ̀rọ |
System components |
| 341 | Ẹ̀rọ Àtẹ |
System board |
| 342 | Àwọn Ẹ̀rọ Àtẹ |
System boards |
| 343 | Ẹ̀rọ ààyè ìrántí |
System memory |
| 345 | Ẹ̀rọ agbésẹ |
System processor |
| 346 | Ẹ̀rọ àwọn agbésẹ́ |
System processors |
| 347 | Ayíun |
Tuner |
| 348 | Àwọn Ayíun |
Tuners |
| 349 | Ayíun TV |
TV tuner |
| 350 | Àwọn Ayíun TV |
TV tuners |
| 375 | Ayíun rẹ́díò |
Radio tuner |
| 376 | Àwọn Ayíun rẹ́díò |
Radio tuners |
| 377 | Àdápútà |
adapter |
| 378 | Amúbádọ́gba ohùn àfetígbọ́ |
audio adapter |
| 379 | bátìrì |
battery |
| 380 | ohun èlò afárá |
bridge device |
| 381 | afárá Alásopọ̀ |
network bridge |
| 382 | afárá àpamọ́ |
storage bridge |
| 383 | kébù |
cable |
| 384 | kébù ìfiránṣẹ́ |
transfer cable |
| 385 | kébù ìfiránṣẹ́ USB |
USB transfer cable |
| 386 | ohun èlò yíyà |
capture device |
| 387 | ohun èlò yìya fídíò |
video capture device |
| 389 | olùdari 1394 |
1394 controller |
| 396 | olùdari àpamọ́ |
storage controller |
| 405 | aṣàkójọ |
hub |
| 406 | họ́ọ̀bù 1394 |
1394 hub |
| 407 | họ́ọ̀bù USB |
USB hub |
| 411 | ẹ́yà ẹ̀rọ |
system component |
| 412 | ẹ́rọ Àtẹ |
system board |
| 413 | ẹ́rọ ààyè ìrántí |
system memory |
| 414 | ẹ̀rọ agbésẹ |
system processor |
| 415 | ayíun |
tuner |
| 429 | ayíun rẹ́díò |
radio tuner |
| 500 | Àwọn Àtẹ bọ́tìnnì, Àwọn Ẹ̀rọ atọ́ka àti Àwọn Ohun èlò ìgbéwọlé mìíràn |
Keyboards, Mice and Other Input Devices |
| 501 | Àwọn Ohun èlò ìgbéwọlé |
Input device |
| 502 | Àwọn Àtẹ bọ́tìnnì, àwọn ẹ̀̀rọ atọ́ka àti àwọn ohun èlò ìgbéwọlé mìíràn |
Keyboards, mice and other input devices |
| 503 | Onídíjítà |
Digitizer |
| 504 | Àwọn Àdáni Alogègé áti Àwọn Onídíjítà |
Tablets and digitizers |
| 505 | Ohun èlò ìgbéwọlé ọlọpọ̀-ìfọwọ́kàn |
Multi-touch input device |
| 506 | Àwọn Ohun èlò ìgbéwọlé ọlọpọ̀-ìfọwọ́kàn |
Multi-touch input devices |
| 507 | Kálámù |
Pen |
| 508 | Àwọn Kálámù |
Pens |
| 509 | Páàdì ìfọwọ́kàn |
Touch pad |
| 510 | Àwọn Páàdì ìfọwọ́kàn |
Touch pads |
| 511 | Aṣàfihàn ìfọwọ́kàn |
Touch screen |
| 512 | Àwọn Agbàwòrán ìfọwọ́kàn |
Touch screens |
| 513 | Olùdarí eré |
Game controller |
| 514 | Àwọn Olùdarí eré |
Game controllers |
| 519 | Àtẹ bọ́tìnnì |
Keyboard |
| 520 | Àwọn Àtẹ bọ́tìnnì |
Keyboards |
| 523 | Atọ́ka |
Mouse |
| 524 | Àwọn Ẹ̀rọ atọ́ka |
Mice |
| 525 | Bọ́tìnnì aṣàwárí |
Trackball |
| 526 | Àwọn Bọ́tìnnì aṣàwárí |
Trackballs |
| 527 | Ìdarí ọnàjíjìn |
Remote control |
| 528 | Àwọn Ìdarí ọnàjíjìn |
Remote controls |
| 533 | Páàdì eré |
Gamepad |
| 534 | Àwọn Páàdì eré |
Gamepads |
| 535 | Kẹ̀kẹ́ atọ́ka |
Steering wheel |
| 536 | Àwọn Kẹ̀kẹ́ atọ́ka |
Steering wheels |
| 537 | ohun èlò ìgbéwọlé |
input device |
| 538 | onídíjítà |
digitizer |
| 539 | ohun èlò ìgbéwọlé ọlọpọ̀-ìfọwọ́kàn |
multi-touch input device |
| 540 | kálámù |
pen |
| 541 | káàdì ìfọwọ́kàn |
touch pad |
| 542 | Aṣàfihàn aláfọwọ́kàn |
touch screen |
| 543 | olùdarí eré |
game controller |
| 546 | páàdì eré |
gamepad |
| 548 | Ayíbírí ìdárí |
steering wheel |
| 551 | atọ́ka |
mouse |
| 552 | Bọ́tìnnì ìṣàwárí |
trackball |
| 553 | ìdarí ọlọ́nàjíjìn |
remote control |
| 570 | Àwọn Ohun èlò Ìtọ́júìlẹra |
Healthcare Devices |
| 571 | Ohun èlò Ìtọ́júìlẹra |
Healthcare device |
| 573 | Òdiwọ̀n glúkosí ẹ̀jẹ̀ |
Blood glucose meter |
| 574 | Àwọn Òdiwọ̀n glúkosí ẹ̀jẹ |
Blood glucose meters |
| 575 | Òdiwọ̀n ẹ̀jẹ̀ rúrú |
Blood pressure meter |
| 576 | Àwọn Òdiwọ̀n ẹ̀jẹ̀ rúrú |
Blood pressure meters |
| 577 | Àṣàyẹ̀wò ìgbà Ọkàn |
Heart rate monitor |
| 578 | Àwọn àṣàyẹ̀wò ìgbà Ọkàn |
Heart rate monitors |
| 579 | Òdiwọ̀n ìlà ẹsẹ̀ẹ |
Pedometer |
| 580 | Àwọn òdiwọ̀n ìlà ẹsẹ̀ẹ |
Pedometers |
| 581 | ohun èlò ìtọ́júìlẹra |
healthcare device |
| 582 | òdiwọ̀n glúkosí ẹ̀jẹ̀ |
blood glucose meter |
| 583 | òdiwọ̀n ẹ̀jẹ̀ rúrú |
blood pressure meter |
| 584 | àṣàyẹ̀wò iṣẹ́ Ọkàn |
heart rate monitor |
| 585 | mítà akàgbéṣẹ̀ |
pedometer |
| 700 | Mídíà |
Media |
| 703 | Káàdì ìsanwó |
Smart card |
| 704 | Àwọn Káàdì ìsanwó |
Smart cards |
| 705 | Mídíà àpamọ́ |
Storage media |
| 707 | Ààyè ìrántí ìṣẹ́jú |
Flash memory |
| 709 | Káàdì Àkójọpọ̀ Ìṣẹ́jú |
Compact Flash card |
| 710 | Àwọn Káàdì Àkójọpọ̀ Ìṣẹ́jú |
Compact Flash cards |
| 711 | Ọ̀̀wọ́n Ààyè ìrántí |
Memory Stick |
| 712 | Àwọn Ọ̀̀wọ́n Ààyè ìrántí |
Memory Sticks |
| 713 | Káàdì SD |
SD card |
| 714 | Àwọn Káàdì SD |
SD cards |
| 715 | Dísìkì ojúináa |
Optical disc |
| 716 | Àwọn dísìkì ojúináa |
Optical discs |
| 717 | CD |
CD |
| 718 | Àwọn CD |
CDs |
| 719 | DVD |
DVD |
| 720 | Àwọn DVD |
DVDs |
| 721 | Dísìkì Blu-ray |
Blu-ray disc |
| 723 | mídíà |
media |
| 724 | káàdì ìwífún |
smart card |
| 725 | mídíà apamọ́ |
storage media |
| 726 | ìrántí àká-ọ̀rọ̀ |
flash memory |
| 727 | Káàdì Àkà-ọ̀rọ̀ pélébé |
Compact Flash card |
| 730 | dísìkì ojúináa |
optical disc |
| 734 | Káàdì amúṣẹ́yá àfojúinúṣe |
Virtual smart card |
| 735 | Káàdì Amúṣẹ́yá Àfojúinúṣe |
Virtual smart cards |
| 736 | káàdì amúṣẹ́yá àfojúinúṣe |
virtual smart card |
| 800 | Mídíà àti Àwọn Ohun Èlò Ìdárayá |
Media and Entertainment Devices |
| 801 | Ohun Èlò Ìdárayá |
Entertainment device |
| 802 | Mídíà àti àwọn ohun èlò ìdárayá |
Media and entertainment devices |
| 803 | Olùdari mídíà olónkà |
Digital media controller |
| 804 | Àwọn olùdari mídíà olónkà |
Digital media controllers |
| 805 | Olùseré mídíà olónkà |
Digital media player |
| 806 | Àwọn Olùseré mídíà olónkà |
Digital media players |
| 807 | Olùtúmọ̀ mídíà olónkà |
Digital media renderer |
| 808 | Àwọn Olùtúmọ̀ mídíà olónkà |
Digital media renderers |
| 809 | Olùfikún Ojú Eré Mídíà |
Media Center Extender |
| 810 | Àwọn Olùfikún Ojú Eré Mídíà |
Media Center Extenders |
| 811 | Apèsè mídíà olónkà |
Digital media server |
| 812 | Àwọn Apèsè mídíà olónkà |
Digital media servers |
| 813 | Ẹ̀rọ agbá fìdíò olónkà sílẹ̀ |
Digital video recorder |
| 814 | Àwọn Ẹ̀rọ agbá fìdíò olónkà sílẹ̀ |
Digital video recorders |
| 815 | Afàwòrán hàn eré |
Game console |
| 816 | Àwọn Afàwòrán hàn eré |
Game consoles |
| 817 | Olùseré mídíà Alágbèká |
Portable Media Player |
| 819 | Ẹ̀rọ ìgbohùnsílẹ̀ |
Voice recorder |
| 820 | Àwọn Ẹ̀rọ ìgbohùnsílẹ̀ |
Voice recorders |
| 821 | ohun Èlò Ìdárayá |
entertainment device |
| 822 | olùdari mídíà olónkà |
digital media controller |
| 823 | olùseré mídíà olónkà |
digital media player |
| 824 | olùtúmọ̀ mídíà olónkà |
digital media renderer |
| 826 | apèsè mídíà olónkà |
digital media server |
| 827 | ẹ̀rọ agbá fìdíò olónkà sílẹ̀ |
digital video recorder |
| 828 | Àwọn Òṣèré Mídíà Alágèéká |
Portable Media Players |
| 829 | afàwòrán hàn eré |
game console |
| 830 | olùseré mídíà Alágbèká |
portable media player |
| 831 | ẹ̀rọ ìgbohùnsílẹ̀ |
voice recorder |
| 840 | Alásopọ̀ |
Network |
| 841 | Alásopọ̀ ohun èlò àtìlẹ́hìn |
Network infrastructure device |
| 842 | Olùlànà, àwọn ibi ìgbàláàyè àti àwọn ohun èlò alásopọ̀ mìíràn |
Routers, access points and other network devices |
| 843 | Ibi ìgbàláàyè alásopọ̀ |
Network access point |
| 844 | Àwọn ibi ìgbàláàyè alásopọ̀ |
Network access points |
| 845 | Bluetooth rẹ́díò |
Bluetooth radio |
| 846 | A dáàbò bo ohun èlò ààbò Bluetooth ẹ̀yà àìrídìmú áti àwọn káàdì amúbádọ́gba |
Bluetooth dongles and adapter cards |
| 849 | Aláìlókùn sí afárá Étánẹ́tì |
Wireless to Ethernet bridge |
| 850 | Aláìlókùn sí àwọn afárá Étánẹ́tì |
Wireless to Ethernet bridges |
| 851 | Àdarí ètò àdáṣiṣéilé |
Home automation controller |
| 852 | Àwọn Àdarí ètò àdáṣiṣéilé |
Home automation controllers |
| 853 | Amúbádọ́gba ojúnà dátà fífẹ̀ alágbèéká |
Mobile broadband adapter |
| 854 | Àwọn amúbádọ́gba ojúnà dátà fífẹ̀ alágbèéká |
Mobile broadband adapters |
| 855 | Módẹ́ẹ̀mù |
Modem |
| 856 | Àwọn módẹ́ẹ̀mù |
Modems |
| 857 | Amúbádọ́gba alásopọ̀ |
Network adapter |
| 858 | Àwọn Amúbádọ́gba alásopọ̀ |
Network adapters |
| 859 | Amúbádọ́gba étánẹ́tì |
Ethernet adapter |
| 860 | Àwọn amúbádọ́gba étánẹ́tì |
Ethernet adapters |
| 861 | Amúbádọ́gba alásopọ̀ infrared |
Infrared network adapter |
| 862 | Àwọn amúbádọ́gba alásopọ̀ infrared |
Infrared network adapters |
| 863 | Amúbádọ́gba alásopọ̀ aláìlókùn |
Wireless network adapter |
| 864 | Àwọn amúbádọ́gba alásopọ̀ aláìlókùn |
Wireless network adapters |
| 865 | Amúbádọ́gba alásopọ̀ ìlà agbára |
Power line network adapter |
| 866 | Àwọn Amúbádọ́gba alásopọ̀ ìlà agbára |
Power line network adapters |
| 867 | Apèsè ìtẹ̀wé |
Print server |
| 868 | Àwọn Apèsè ìtẹ̀wé |
Print servers |
| 869 | Olùlànà alásopọ̀ |
Network router |
| 870 | Àwọn Olùlànà alásopọ̀ |
Network routers |
| 871 | Olùlànà alásopọ̀ aláìlókùn |
Wireless network router |
| 872 | Àwọn Olùlànà alásopọ̀ aláìlókùn |
Wireless network routers |
| 873 | Alásopọ̀ ṣèpapòdà |
Network switch |
| 874 | Àwọn alásopọ̀ ṣèpapòdà |
Network switches |
| 875 | Ojúnà dátà fífẹ̀ rédíò tí wọ́n ti wà |
Ultra wideband radio |
| 876 | Ojúnà dátà fífẹ̀ àwọn rédíò tí wọ́n ti wà |
Ultra wideband radios |
| 877 | USB rẹ́díò aláìlókùn |
Wireless USB radio |
| 878 | USB àwọn rẹ́díò aláìlókùn |
Wireless USB radios |
| 881 | alásopọ̀ ohun èlò àtìlẹ́hìn |
network infrastructure device |
| 882 | ibi ìgbàláàyè alásopọ̀ |
network access point |
| 884 | afárá alásopọ̀ |
network bridge |
| 885 | aláìlókùn sí afárá Étánẹ́tì |
wireless to Ethernet bridge |
| 886 | adarí ètò àdáṣiṣéilé |
home automation controller |
| 887 | amúbádọ́gba ojúnà dátà fífẹ̀ alágbèéká |
mobile broadband adapter |
| 888 | Módẹ́ẹ̀mù |
modem |
| 889 | àdápútà alásopọ̀ |
network adapter |
| 890 | amúbádọ́gba étánẹ́tì |
Ethernet adapter |
| 892 | amúbádọ́gba alásopọ̀ aláìlókùn |
wireless network adapter |
| 893 | amúbádọ́gba alásopọ̀ ìlà agbára |
power line network adapter |
| 894 | apèsè Ìtẹ̀wé |
print server |
| 895 | olùlànà alásopọ̀ |
network router |
| 896 | olùlànà alásopọ̀ aláìlókùn |
wireless network router |
| 897 | alásopọ̀ ṣèpapòdà |
network switch |
| 898 | ojúnà dátà fífẹ̀ rédíò tí wọ́n ti wà |
ultra wideband radio |
| 915 | Cloud printer |
Cloud printer |
| 916 | Cloud printers |
Cloud printers |
| 920 | Àwọn ẹ̀rọ ìtẹ̀wé àti Àwọn Fáàsì |
Printers and Faxes |
| 921 | Atẹ̀wé |
Printer |
| 922 | Àwọn ẹ̀rọ ìtẹ̀wé àti àwọn fáàsì |
Printers and faxes |
| 923 | Fáàsì |
Fax |
| 924 | Àwọn Ẹ̀rọ fáàsì |
Fax machines |
| 925 | Ẹ̀̀rọ ìtẹ̀wé ọlọ́pọ̀ ìse |
Multi Function Printer |
| 926 | Àwọn Ẹ̀̀rọ ìtẹ̀wé ọlọ́pọ̀ ìse |
Multi Function Printers |
| 927 | Ẹ̀rọ ìtẹ-ìwé |
Printer |
| 928 | Àwọn Atẹ̀wé |
Printers |
| 929 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé jẹẹ̀tì tàdáwàá |
Ink-jet printer |
| 930 | Àwọn Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé jẹẹ̀tì tàdáwàá |
Ink-jet printers |
| 931 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé lésà |
Laser printer |
| 932 | Àwọn Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé lésà |
Laser printers |
| 933 | Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé àfojúinúwò |
Virtual Printer |
| 934 | Àwọn Ẹ̀rọ ìtẹ̀wé àfojúinúwò |
Virtual Printers |
| 935 | ìpèsè ẹ́rọ ìtẹ̀wé |
Printer service |
| 936 | Àwọn ìpèsè |
Printer services |
| 937 | ẹ̀rọ ìtẹ̀wé |
printer |
| 938 | fáàsì |
fax |
| 939 | Ẹ̀ẹ̀rọ ìtẹ̀wé ọlọ́pọ̀ ìse |
multi function printer |
| 941 | ẹ̀rọ ìtẹ̀wé jẹẹ̀tì tàdáwàá |
ink-jet printer |
| 942 | ẹ̀rọ ìtẹ̀wé lésà |
laser printer |
| 945 | Ohun èlò àgbéjáde 3D |
3D manufacturing device |
| 947 | Àwọn Ohun èlò Ìṣàgbéjáde 3D |
3D Manufacturing Devices |
| 948 | cloud printer |
cloud printer |
| 950 | Àwọn Afura |
Sensors |
| 951 | Afura |
Sensor |
| 953 | Ohun èlò ìdánimọ̀ àládàáni |
Personal identity device |
| 954 | Àwọn Ohun èlò ìdánimọ̀ àládàáni |
Personal identity devices |
| 955 | Ẹ̀̀rọ ayàwòrán ojú |
Face scanner |
| 956 | Àwọn Ẹ̀̀rọ ayàwòrán ojú |
Face scanners |
| 957 | Ẹ̀̀rọ ayàwòrán ìlà-ìka-ọwọ́ |
Fingerprint scanner |
| 958 | Àwọn Ẹ̀̀rọ ayàwòrán ìlà-ìka-ọwọ́ |
Fingerprint scanners |
| 959 | Ẹ̀̀rọ ayàwòrán ìlà-inú-ojú |
Retinal scanner |
| 960 | Àwọn Ẹ̀̀rọ ayàwòrán ìlà-inú-ojú |
Retinal scanners |
| 961 | Afura alòlẹ́tíríìkì |
Electrical sensor |
| 962 | Àwọn Afura alòlẹ́tíríìkì |
Electrical sensors |
| 963 | Afura sí àyíká |
Environmental sensor |
| 964 | Àwọn Afura sí àyíká |
Environmental sensors |
| 965 | Afura ìwọ̀n otútù tàbí ooru |
Temperature sensor |
| 966 | Àwọn Afura ìwọ̀n otútù tàbí ooru |
Temperature sensors |
| 967 | Afura ìmọ̀lẹ̀ |
Light sensor |
| 968 | Àwọn Afura ìmọ̀lẹ̀ |
Light sensors |
| 969 | Afura ibi |
Location sensor |
| 970 | Àwọn Afura ibi |
Location sensors |
| 971 | GPS |
GPS |
| 973 | Afura ẹ̀rọ |
Mechanical sensor |
| 974 | Àwọn Afura ẹ̀rọ |
Mechanical sensors |
| 975 | Afura ìrìn |
Motion sensor |
| 976 | Àwọn Afura ìrìn |
Motion sensors |
| 977 | Afura ìdarísí |
Orientation sensor |
| 978 | Àwọn Afura ìdarísí |
Orientation sensors |
| 979 | Afura ìsúnmọ́sí |
Proximity sensor |
| 980 | Àwọn Afura ìsúnmọ́sí |
Proximity sensors |
| 981 | Afura NFC |
NFC sensor |
| 982 | Àwọn Afura NFC |
NFC sensors |
| 983 | Afura RFID |
RFID sensor |
| 984 | Àwọn Afura RFID |
RFID sensors |
| 985 | afura |
sensor |
| 986 | afura alòlẹ́tíríìkì |
electrical sensor |
| 987 | afura sí àyíká |
environmental sensor |
| 988 | afura ìwọ̀n otútù tàbí ooru |
temperature sensor |
| 989 | afura ìmọ̀lẹ̀ |
light sensor |
| 990 | afura ibi |
location sensor |
| 992 | afura ẹ̀rọ |
mechanical sensor |
| 993 | afura ìrìn |
motion sensor |
| 994 | afura ìdarísí |
orientation sensor |
| 996 | afura NFC |
NFC sensor |
| 997 | afura RFID |
RFID sensor |
| 1100 | Ohun èlò pẹ̀lú Àpamọ |
Devices with Storage |
| 1101 | Ohun èlò àpamọ |
Storage device |
| 1102 | Ohun èlò àwọn àpamọ |
Storage devices |
| 1103 | Àfikà káàdì |
Card reader |
| 1104 | Àwọn Olùkà káàdì |
Card readers |
| 1105 | Àfikà káàdì àkàpọ̀ |
Combination card reader |
| 1106 | Àwọn Olùkà káàdì àkàpọ̀ |
Combination card readers |
| 1107 | Olùyípadà mídíà àpamọ́ |
Storage media changer |
| 1108 | Àwọn Olùyípadà mídíà àpamọ́ |
Storage media changers |
| 1109 | Àyípadà ìpamọ́ mídíà ojúináa |
Optical storage media changer |
| 1110 | Àwọn àyípadà ìpamọ́ mídíà ojúináa |
Optical storage media changers |
| 1111 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ dísìkì fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ |
Floppy disk drive |
| 1112 | Àwọn Atukọ̀ dísìkì fẹ́lẹ́fẹ́lẹ́ |
Floppy disk drives |
| 1113 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ hádisìkì |
Hard disk drive |
| 1114 | Àwọn Ìtukọ̀ àká-ọ̀rọ̀ gbagidi |
Hard disk drives |
| 1115 | Ipò àwo àká-ọ̀rọ̀ tí o nípọn |
Solid state drive |
| 1116 | Ipò àwọn ìtukọ̀ tí o nípọn |
Solid state drives |
| 1117 | Ohun èlò alásopọ̀ àpamọ |
Network storage device |
| 1118 | Àwọn Ohun èlò alásopọ̀ àpamọ |
Network attached storage devices |
| 1119 | Ohun èlò alásopọ̀ aláìlókùn |
Wireless storage device |
| 1120 | Àwọn Ohun èlò alásopọ̀ aláìlókùn |
Wireless storage devices |
| 1121 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ ojúináa |
Optical drive |
| 1122 | Àwọn Ìtukọ̀ ojúináa |
Optical drives |
| 1123 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ Blu-ray |
Blu-ray drive |
| 1124 | Àwọn Atukọ̀ Blu-ray |
Blu-ray drives |
| 1125 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ CD |
CD drive |
| 1126 | Àwọn Atukọ̀ CD |
CD drives |
| 1127 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ DVD |
DVD drive |
| 1128 | Àwọn Atukọ̀ DVD |
DVD drives |
| 1129 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ fánrán |
Tape drive |
| 1130 | Àwọn Atukọ̀ fánrán |
Tape drives |
| 1131 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ USB |
USB flash drive |
| 1132 | Àwọn àwo àká-ọ̀rọ̀ USB |
USB flash drives |
| 1133 | ohun èlò àpamọ |
storage device |
| 1136 | olùyípadà mídíà àpamọ́ |
storage media changer |
| 1137 | Àṣàyípadà ìpamọ́ mídíà ojúináa |
optical storage media changer |
| 1138 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ Fúlọ́ọ̀pì Dísíkì |
floppy disk drive |
| 1139 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ gbagidi |
hard disk drive |
| 1140 | ipò Àwo àká-ọ̀rọ̀tí o nípọn |
solid state drive |
| 1141 | ohun èlò alásopọ̀ àpamọ |
network storage device |
| 1142 | ohun èlò alásopọ̀ aláìlókùn |
wireless storage device |
| 1180 | Àwọn Ohun èlò Fídíò àti Ìṣẹ̀dá |
Video and Imaging Devices |
| 1181 | Ohun èlò ṣíṣe ìrísí |
Imaging device |
| 1182 | Àwọn ohun èlò fídíò àti ìṣẹ̀dá |
Video and imaging devices |
| 1183 | Kámẹ́rà Oníṣẹ́méjì |
Camcorder |
| 1184 | Àwọn Kámẹ́rà Oníṣẹ́méjì |
Camcorders |
| 1185 | Kámẹ́rà |
Camera |
| 1186 | Àwọn Kámẹ́rà |
Cameras |
| 1187 | Ẹ̀rọ ẹ̀dà àwòrán |
Scanner |
| 1188 | Àwọn ẹ̀rọ ẹ̀dà àwòrán |
Scanners |
| 1189 | Kámẹ́rà Wẹ́ẹ́bù |
Webcam |
| 1190 | Àwọn Kámẹ́rà Wẹ́ẹ́bù |
Webcams |
| 1191 | ohun èlò ṣíṣe ìrísí |
imaging device |
| 1192 | Ayàwòrán-ya-fídíò |
camcorder |
| 1193 | kámẹ́rà |
camera |
| 1194 | ẹ̀rọ ẹ̀dà àwòrán |
scanner |
| 1195 | kámẹ́rà wẹ́ẹ́bù |
webcam |
| 1300 | Àwọn Ohun èlò Ìdánimọ̀ Àládàáni |
Personal Identity Devices |
| 1320 | ohun èlò ìdánimọ̀ àládàáni |
personal identity device |
| 1321 | aṣẹ̀dà àwòrán ojú |
face scanner |
| 1322 | aṣẹ̀dà àwòrán ìlà-ìka-ọwọ́ |
fingerprint scanner |
| 1323 | aṣẹ̀dà àwòrán ìlà-inú-ojú |
retinal scanner |
| 1326 | Wearable Devices |
Wearable Devices |
| 1327 | Wearable device |
Wearable device |
| 1328 | Wearable devices |
Wearable devices |
| 1329 | Headset |
Headset |
| 1330 | Headsets |
Headsets |
| 1331 | Holographic headset |
Holographic headset |
| 1332 | Holographic headsets |
Holographic headsets |
| 1333 | Virtual Reality headset |
Virtual Reality headset |
| 1334 | Virtual Reality headsets |
Virtual Reality headsets |
| 1335 | wearable device |
wearable device |
| 1336 | headset |
headset |
| 1337 | holographic headset |
holographic headset |
| 1338 | virtual reality headset |
virtual reality headset |
| 1400 | Àwọn Fáàsì |
Faxes |
| 1401 | Àwọn Òǹkọ̀wé Àkọsílẹ̀ |
Document Writers |
| 1402 | Àwọn ìpèsè ìwé títẹ̀ |
Print Services |
| 1901 | Bluetooth |
Bluetooth |
| 1902 | USB aláìlókùn |
Wireless USB |
| 1903 | Àwọn Isẹ́ Wẹ́ẹ̀bù |
Web Services |
| 1904 | UPnP |
UPnP |
| 1905 | NetBIOS |
NetBIOS |
| 1906 | PnP |
PnP |
| 1907 | Wi-Fi |
Wi-Fi |
| 1908 | Àgbára Bluetooth tó kéré |
Bluetooth Low Energy |
| 1909 | WLAN |
WLAN |
| 3156 | pos line display |
pos line display |
| 3158 | POS Line Display |
POS Line Display |
| 3160 | POS Line Displays |
POS Line Displays |
| 3162 | Aṣẹ̀dá Awòrán Pẹpẹ Kóòdù POS |
POS Barcode Scanner |
| 3164 | Àwọn Àwòrán Aṣẹ̀dá POS |
POS Barcode Scanners |
| 3166 | Olùgba Owó POS |
POS Cash Drawer |
| 3168 | Àwọn Olùgbà Owó POS |
POS Cash Drawers |
| 3170 | Ẹ̀rọ Ìtẹ̀wé POS |
POS Printer |
| 3172 | Àwọn Ẹ̀rọ Ìtẹ̀wé POS |
POS Printers |
| 3174 | Akàwé MagneticStripe POS |
POS MagneticStripe Reader |
| 3175 | Àwọn Akàwé MagneticStripe POS |
POS MagneticStripe Readers |
| 3177 | aṣẹ̀dá awòrán pẹpẹ kóòdù pos |
pos barcode scanner |
| 3178 | olùgba owó pos |
pos cash drawer |
| 3179 | akàwé magneticstripe pos |
pos magneticstripe reader |
| 3180 | ẹ̀rọ ìtẹ̀wé pos |
pos printer |