SettingsHandlers_Geolocation.dll.mui Olùmúṣiṣẹ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Ibi Àwọn Ààtò Ìlànà-ètò 282743ef2a6e86efa6f5e37751a8e18c

File info

File name: SettingsHandlers_Geolocation.dll.mui
Size: 5120 byte
MD5: 282743ef2a6e86efa6f5e37751a8e18c
SHA1: f4edbb0d439049e6ceee07ac390ef16768b01983
SHA256: 5dc0917a79580ec45b52a3d48ef33d65664e9347761adf8b6b11ee35a971d2ea
Operating systems: Windows 10
Extension: MUI

Translations messages and strings

If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.

id Yoruba English
200Tí ibi náà bá tàn, ẹni kọ̀ọ̀kan tí ń lo ohun èlò yìí le yan àwọn ààtò ibi tí wọn. If location is on, each person using this device can choose their own location settings.
201Ibi tí ohun èlò yìí wà ti kú Location for this device is off
202Ibi tí ohun èlò yìí wà ti tàn Location for this device is on
203Yípadà Change
210Ìpèsè ibi Location service
212Tí ìpèsè ibi náà bá tàn, Windows, ìṣàfilọ́lẹ̀, àti ìpèsè le lo ibi tí o wà, ṣùgbọ́n o sì le pa ibi fún àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ pàtó. If the location service is on, Windows, apps, and services can use your location, but you can still turn off location for specific apps.
213Ibi gbogbogbò General location
214Àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀ tí kò le lò ibi tí mo wà gangan sì le lo ibi gbogbogbò mi, bíi ìlú, kóòdù ìfìwéránṣẹ́, tàbí agbègbè. Apps that cannot use my precise location can still use my general location, such as city, zip code, or region.
220Tí ìfilọ́lẹ̀ kan bá ń lo ibi rẹ, wàá rí àwòrán aṣàmì yìí: If an app is using your location, you’ll see this icon:
221Ṣàfihàn àwòrán aṣàmì ibi Show location icon
230Tí ibi náà bá tàn, ìtàn ibi tí o wà ni a tọ́jú fún àkókò díẹ̀ lórí ohun èlò náà, àwon ìṣàfilọ́lẹ̀ tí ń lo ibi tí o wà sì le lòó. If location is on, your location history is stored for a limited time on the device, and can be used by apps that use your location.
231Kákúrò Clear
232Ká ìtàn kúrò lórí ohun èlò yìí Clear history on this device
233Lo ìtàn ibi Uses location history
240Ṣètò bíi àkùnàyàn Set default
241Windows, àwọn ìṣàfilọ́lẹ̀, àti àwọn ìpèsè le lo èyí nígbàtí a kò le rí ibi pàtó lórí PC yìí. Windows, apps, and services can use this when we can’t detect a more exact location on this PC.
250Odi kan túmọ̀ sí lílo ibi tí o wà láti rí nígbàtí o bá wọlé tàbí jáde nínú àlà tí a yà kiri ibi tí a fẹ́. Geofencing means using your location to see when you cross in or out of a boundary drawn around a place of interest.
251Ọ̀kan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn ìfilọ́lẹ̀ rẹ ń lo odi lọ́wọ́lọ́wọ́. One or more of your apps are currently using geofencing.
252Kò sí èyíkéyìí nínú àwọn ìfilọ́lẹ̀ rẹ ti ń lo odi lọ́wọ́lọ́wọ́. None of your apps are currently using geofencing.
260Àwọn ojúlé sì nílò ìyọ̀nda Sites still need permission
261Cortana Cortana
262Ìtàn ibi gbọ́dọ̀ wà ní títàn fún Cortana láti ṣiṣẹ́ Location history must be on for Cortana to work
263Ti gbé sípò àìṣiṣẹ́ nípasẹ̀ ìlànà ilé-iṣẹ́ Disabled by company policy

EXIF

File Name:SettingsHandlers_Geolocation.dll.mui
Directory:%WINDIR%\WinSxS\amd64_microsoft-windows-s..olocation.resources_31bf3856ad364e35_10.0.15063.0_yo-ng_8eaed8048b34b149\
File Size:5.0 kB
File Permissions:rw-rw-rw-
File Type:Win32 DLL
File Type Extension:dll
MIME Type:application/octet-stream
Machine Type:Intel 386 or later, and compatibles
Time Stamp:0000:00:00 00:00:00
PE Type:PE32
Linker Version:14.10
Code Size:0
Initialized Data Size:4608
Uninitialized Data Size:0
Entry Point:0x0000
OS Version:10.0
Image Version:10.0
Subsystem Version:6.0
Subsystem:Windows GUI
File Version Number:10.0.15063.0
Product Version Number:10.0.15063.0
File Flags Mask:0x003f
File Flags:(none)
File OS:Windows NT 32-bit
Object File Type:Dynamic link library
File Subtype:0
Language Code:Unknown (046A)
Character Set:Unicode
Company Name:Microsoft Corporation
File Description:Olùmúṣiṣẹ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Ibi Àwọn Ààtò Ìlànà-ètò
File Version:10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800)
Internal Name:SettingsHandlers_Geolocation.dll
Legal Copyright:© Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Original File Name:SettingsHandlers_Geolocation.dll.mui
Product Name:Microsoft® Windows® Operating System
Product Version:10.0.15063.0

What is SettingsHandlers_Geolocation.dll.mui?

SettingsHandlers_Geolocation.dll.mui is Multilingual User Interface resource file that contain Yoruba language for file SettingsHandlers_Geolocation.dll (Olùmúṣiṣẹ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Ibi Àwọn Ààtò Ìlànà-ètò).

File version info

File Description:Olùmúṣiṣẹ́ Àwọn Òṣìṣẹ́ Ibi Àwọn Ààtò Ìlànà-ètò
File Version:10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800)
Company Name:Microsoft Corporation
Internal Name:SettingsHandlers_Geolocation.dll
Legal Copyright:© Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ tiwa.
Original Filename:SettingsHandlers_Geolocation.dll.mui
Product Name:Microsoft® Windows® Operating System
Product Version:10.0.15063.0
Translation:0x46A, 1200