| File name: | ConsentUX.dll.mui |
| Size: | 7680 byte |
| MD5: | 2352bede45f2f2952c87a6cd6d333558 |
| SHA1: | 3337efba9299bf48bee529f6709dd52d1d595fe1 |
| SHA256: | 4e308a52654962b427ec3aaf3ec2f10014b914669059d6028d0e7ed45e65ea9f |
| Operating systems: | Windows 10 |
| Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
| id | Yoruba | English |
|---|---|---|
| 100 | Ǹjẹ́ o fẹ́ kí %1 ráyèsí %2 rẹ bí? | Let %1 access your %2? |
| 101 | Láti ṣàyípadà èyí tóbáyá, lọ sí Ìfilọ́lẹ̀ Àwọn ààtò. | To change this later, go to the Settings app. |
| 102 | Ǹjẹ́ %1 le gba %2 tàbí firánṣẹ́ bí? | Can %1 send and receive %2? |
| 103 | A nílò ìyọ̀nda rẹ | We need your permission |
| 104 | Bẹ́ẹ̀ni | Yes |
| 105 | Bẹ́ẹ̀kọ́ | No |
| 106 | Iṣẹ́ àyọkà | text messages |
| 107 | 1 | 1 |
| 108 | Ǹjẹ́ o fẹ́ fààyè gba %1 láti máa wà ní ìbádọ́gba ní àgbétẹ́lẹ̀ nígbà tí o bá ń ṣe nǹkan mìíràn bí? | Do you want to allow %1 to keep syncing in the background while you do something else? |
| 109 | Ìṣàfilọ́lẹ̀ %1 ti ṣetán láti ṣàfikún “%2”. Tí PC rẹ bá ń lo àmúbádọ́gba alágbára, kì í bọ iná láti dèná àlòjù bátírì náà. Jẹ́ kí “%3” sì wà ní sísomọ́ sí PC rẹ títí tí àfikún fi máa parí. Èyí le gbà tó ìṣẹ́jú %4!d!. Bẹ̀rẹ̀ ìṣàfikún náà? |
The %1 app is ready to update "%2". If your PC uses a power adapter, plug it in to avoid draining the battery. Keep "%3" connected to your PC until the update is finished. This can take up to %4!d! minutes. Start the update? |
| 110 | Ìṣàfilọ́lẹ̀ %1 ti ṣetán láti ṣàfikún “%2”. Tí PC rẹ bá ń lo àmúbádọ́gba alágbára, kì í bọ iná láti dèná àlòjù bátírì náà. Jẹ́ kí “%3” sì wà ní sísomọ́ sí PC rẹ títí tí àfikún fi máa parí. Èyí le gbà tó ìṣẹ́jú kan. Bẹ̀rẹ̀ ìṣàfikún náà? |
The %1 app is ready to update "%2". If your PC uses a power adapter, plug it in to avoid draining the battery. Keep "%3" connected to your PC until the update is finished. This can take a while. Start the update? |
| 111 | Ìṣàfilọ́lẹ̀ %1 ti gbaradì tàn láti ṣàfikún “%2”. Mú kí “%3” sì somọ́ PC rẹ títí tí ìṣàfikún fi máa parí. Èyí le gbà tó ìṣẹ́jú %4!d!. Bẹ̀rẹ̀ ìṣàfikún náà? |
The %1 app is ready to update "%2". Keep "%3" connected to your PC until the update is finished. This can take up to %4!d! minutes. Start the update? |
| 112 | Ìṣàfilọ́lẹ̀ %1 to gbaradì láti ṣàfikún “%2”. Mú kí “%3” somọ́ PC rẹ títí tí àfikún yóò fi parí. Èyí le gba àkókò díẹ̀. Bẹ̀rẹ̀ àfikún náà? |
The %1 app is ready to update "%2". Keep "%3" connected to your PC until the update is finished. This can take a while. Start the update? |
| 113 | Ṣàfikún ohun èlò rẹ | Update your device |
| 117 | Ìṣàfilọ́lẹ̀ %1 to ṣetán láti ṣàfikún “%2”. Mú kí “%3” somọ́ PC rẹ títí tí àfikún yóò fi parí. Èyí le gba tó ìṣẹ́jú kan. Bẹ̀rẹ̀ àfikún náà? |
The %1 app is ready to update "%2". Keep "%3" connected to your PC until the update is finished. This can take up to a minute. Start the update? |
| 118 | Jẹ́ kí %1 ráyèsí àwọn olùbásọ̀rọ̀ rẹ bí? | Let %1 access your contacts? |
| 119 | Jẹ́ kí %1 r’yèsí àyọkà àti àwọn ìfiránṣẹ́ MMS rẹ bí? | Let %1 access your text and MMS messages? |
| 120 | ibi gangan àti ìtàn ibi | precise location and location history |
| 121 | Jẹ́ kí %1 ráyèsí orúkọ, àwòrán, àti ìwífún àkọọ́lẹ̀ rẹ míràn bí? | Let %1 access your name, picture, and other account info? |
| 122 | Jẹ́ kí %1 tan tàbí pa %2 rẹ bí? | Let %1 turn your %2 on or off? |
| 123 | Bluetooth àti WLAN | Bluetooth and WLAN |
| 124 | ibi gangan | precise location |
| 125 | Jẹ́ kí %1 ṣàsopọ̀ ohun èlò rẹ pẹ̀lú %2 | Let %1 pair your device with %2 |
| 126 | Jẹ́ kí %1 má ṣàsopọ̀ ohun èlò rẹ láti %2 | Let %1 unpair your device from %2 |
| 127 | Jẹ́ kí %1 ráyèsí ìtàn ìpè rẹ bí? | Let %1 access your call history? |
| 128 | Jẹ́ kí %1 ráyèsí kó sì fi í-meèlì ránṣẹ́ bí? | Let %1 access and send email? |
| 129 | ẹ̀rọ gbohùngbohùn | microphone |
| 130 | kámẹ́rà | camera |
| 131 | Yan ìfitónilétí yìí tàbí Bẹ́ẹ̀ni láti gba èyí láàyè. | Select this notification or Yes to allow this. |
| 132 | Ṣé o fẹ́ kí %1 pe ìpè fóònù bí? | Let %1 make phone calls? |
| 133 | Jẹ́ kí %1 ráyèsí àwọn ìfitónilétí rẹ bí? | Let %1 access your notifications? |
| 134 | Jẹ́ kí %1 ráyèsí èyí: %2 | Let %1 access this: %2 |
| 135 | %1: %2 | %1: %2 |
| 136 | Let %1 access your tasks? | Let %1 access your tasks? |
| 137 | Let %1 access diagnostic information about your apps? | Let %1 access diagnostic information about your apps? |
| 138 | Let %1 access your calendar? | Let %1 access your calendar? |
| 0x10000031 | Response Time | Response Time |
| 0x30000001 | Start | Start |
| 0x30000002 | Stop | Stop |
| 0x50000002 | Error | Error |
| 0x50000004 | Information | Information |
| 0x90000001 | Microsoft-Windows-DeviceConfidence | Microsoft-Windows-DeviceConfidence |
| 0xB00007D0 | Failed getting active window for app package %1 and capability name %2 | Failed getting active window for app package %1 and capability name %2 |
| 0xB00007D1 | Failed to show consent prompt for app package %1 with error %2 | Failed to show consent prompt for app package %1 with error %2 |
| 0xB00007D2 | Failed to create consent window for app package %1 with error %2 | Failed to create consent window for app package %1 with error %2 |
| File Description: | Ohun Èlò Ìtanijí búrókà |
| File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
| Company Name: | Microsoft Corporation |
| Internal Name: | Consent UX |
| Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ ni tiwa. |
| Original Filename: | ConsentUX.dll.mui |
| Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
| Product Version: | 10.0.15063.0 |
| Translation: | 0x46A, 1200 |