If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id |
Yoruba |
English |
1 | Microsoft Passport Container |
Microsoft Passport Container |
2 | Ńṣàkóso àwọn bọ́tìnnì ìdánimọ̀ aṣàmúlò abẹ́lé tí a lò láti ṣàrídájú aṣàmúlò sí àwọn olùpèsè ìdánimọ̀ àti àwọn káàdì amúṣẹ́yá àfojúnuṣe ti TPM. Tí a bá gbé ìpèsè yìí sípò àìṣélò, àwọn bọ́tìnnì ìdánimọ̀ aṣàmúlò abẹ́lé àti àwọn káàdì amúṣẹ́yá àfojúnuṣe ti TPM ni o kò ní ráyèsí. A gbà ọ́ níyànjú pé kí o má ṣe ṣàtúntò ìpèsè yìí. |
Manages local user identity keys used to authenticate user to identity providers as well as TPM virtual smart cards. If this service is disabled, local user identity keys and TPM virtual smart cards will not be accessible. It is recommended that you do not reconfigure this service. |
50 | Ó DÁA |
OK |
100 | Ṣàgbékalẹ̀ PIN kan |
Set up a PIN |
101 | Ṣàgbékalẹ̀ PIN ibi-iṣẹ́ kan |
Set up a work PIN |
102 | Ṣẹ̀dá PIN kan láti lò dípò àwọn ọ̀rọ̀ aṣínà. Níní PIN kan jẹ́ kí ó rọrùn láti wọlé sínú ohun èlò rẹ, ìfilọ́lẹ̀, àti ìpèsè. |
Create a PIN to use in place of passwords. Having a PIN makes it easier to sign in to your device, apps, and services. |
103 | Tókàn |
Next |
104 | Padàsẹ́yìn |
Back |
200 | Nílò PIN |
PIN required |
201 | Nítorí àyípadà ìlànà lórí ohun èlò rẹ, o ní láti ṣẹ̀dá PIN kan. |
Because of a policy change on your device, you need to create a PIN. |
202 | Àyípadà ìlànà PIN |
PIN policy change |
203 | A ní láti ṣàrídájú pé PIN rẹ bá àwọn àmúyẹ titun mu èyítí ilé-iṣẹ́ rẹ ṣètò. Tí kò bá rí bẹ́ẹ̀, a ó ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣàyípadà rẹ̀. |
We need to make sure your PIN meets new requirements set by your organization. If it doesn’t, we’ll help you change it. |