File name: | SyncRes.dll.mui |
Size: | 29696 byte |
MD5: | 1c1e7cfe21ac616208ab1345bc6f98ac |
SHA1: | 1a73e0cd1f12007201999e4364d49b892f909933 |
SHA256: | 4a96bc40d1bfb6d6a06309da6e26d324c6e9ffc2c8131bcc328a129144a4b000 |
Operating systems: | Windows 10 |
Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id | Yoruba | English |
---|---|---|
1020 | Apèsè | server |
1024 | Ó dàbí pé a kò le gba ẹ̀dà fáìlì gbogbo àwọn àkíyèsí wọ̀nyí láti apèsè náà. O sì le ṣàtúnṣe àwọn àkíyèsí wọ̀nyí lórí PC kan nínú Outlook tàbí aṣàwákiri kan, ṣùgbọ́n tí o bá ṣàtúnṣe wọn lórí ohun èlò rẹ àwọn àyípadà rẹ yóò pa àwọn àkíyèsí orí apèsè náà rẹ́. | We can't seem to download all these notes from the server. You can still edit these notes on a PC in Outlook or a browser, but if you edit them on your device your changes will overwrite the notes on the server. |
1026 | Ọ̀pọ̀ àwọn olùgbà kò gba ìfiránṣẹ́ yìí.
Àkórí: %2!s! A kò le dí ibi àwọn olùgbà wọ̀nyí: %1!s! on %3!s! %4!s! Àpótí méèlì fún àwọn olùgbà wọ̀nyí le ti kún tàbí àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì le má tọ̀nà. |
Some of the recipients didn't get this message.
Subject: %2!s! We couldn't reach these recipients: %1!s! on %3!s! %4!s! The mailbox for these recipients may be full or the email mail address may be incorrect. |
1027 | Ìfiránṣẹ́ rẹ
Sí: %1!s! Àkórí: %2!s! ni a kà ní %3!s! %4!s! |
Your message
To: %1!s! Subject: %2!s! was read on %3!s! %4!s! |
1028 | Ìfiránṣẹ́ rẹ
Sí: %1!s! Àkórí: %2!s! ni a fi jíṣẹ́ sí (àwọn) olùgbà wọ̀nyí: %1!s! ní %3!s! %4!s! |
Your message
To: %1!s! Subject: %2!s! was delivered to these recipients(s): %1!s! on %3!s! %4!s! |
1029 | We can’t sync right now. But you may be able to find more information about this error code at https://answers.microsoft.com. | We can’t sync right now. But you may be able to find more information about this error code at https://answers.microsoft.com. |
1034 | àìmọ̀ | unknown |
1045 | Ìfiránṣẹ́ rẹ
Sí: %1!s! Àkórí: %2!s! ni a ṣèparẹ́ láì kà ní %3!s! %4!s! |
Your message
To: %1!s! Subject: %2!s! was deleted without being read on %3!s! %4!s! |
1088 | A kò le fi ọ̀kan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn ìfiránṣẹ́ í-meèlì rẹ ránṣẹ́. A ó gbìyànjú láti fi wọ́n ránṣẹ́ nígbà míràn tí a bá múdọ́gba. Tí èyí bá jẹ́ pàjáwìrì, ṣàrídájú pé o ní ìsopọ̀ kan, lẹ́yìn náà fọwọ́ba Múdọ́gba. | We couldn't send one or more of your email messages. We'll try sending them the next time we sync. If this is urgent, make sure you have a connection, then tap Sync. |
1089 | A kò le ṣàmúdọ́gba ọ̀kan tàbí ọ̀pọ̀ àwọn àsomọ́ sí ohun èlò rẹ. Láti gbìyànjú èyí lẹ́ẹ̀kan síi, ṣàmìsí àsomọ́ kọ̀ọ̀kan fún gbígba ẹ̀dà fáìlì nínú í-meèlì rẹ kí o sì tún múdọ́gba lẹ́ẹ̀kan síi. | We couldn't sync one or more attachments to your device. To try this again, mark each attachment for download in your email and sync again. |
1090 | ohun èlò rẹ | your device |
1104 | Àkórí: %1!.200s! | Subject: %1!.200s! |
1105 | Bẹ̀rẹ̀: %1!s! %2!.200s! | Start: %1!s! %2!.200s! |
1106 | Òpin: %1!s! %2!.200s! | End: %1!s! %2!.200s! |
1107 | Ti kópọ̀ bíi: %1!.200s! | Filed as: %1!.200s! |
1109 | Láti: %1!.200s! | From: %1!.200s! |
1111 | Àkókò: %1!.200s! | Time: %1!.200s! |
1112 | Ti gbàá: %1!.200s! | Received: %1!.200s! |
1113 | Ti firánṣẹ́: %1!.200s! | Sent: %1!.200s! |
1115 | Dópin: %1!.200s! | Due: %1!.200s! |
1117 | Àwọn Wúnrẹ̀n Tó Sọnù: | Missed Items: |
1118 | Named as: %1!.200s! | Named as: %1!.200s! |
1119 | ID: %1!.200s! | ID: %1!.200s! |
1200 | Èyí le jẹ́ nítorí ohun èlò sẹ́lúlà rẹ wà ní pípa tàbí ipò òfurufú. | This may be because your cellular device is turned off or in airplane mode. |
1201 | O kò ní sẹ́lúlà kan, WLAN, tàbí ìsopọ̀ dátà Wi-Fi tí a ṣàgbékalẹ̀. Láti mú ìwífún dọ́gba, ṣàfikún ìsopọ̀ kan. | You don't have a cellular, WLAN, or Wi-Fi data connection set up. To sync information, add a connection. |
1202 | Ohun èlò rẹ wà ní ipò òfurufú. | Your device is in airplane mode. |
1203 | Èyí le jẹ́ nítorí àwọn ìsopọ̀ dátà sẹ́lúlà rẹ wà ní pípa. | This may be because your cellular data connections are turned off. |
1204 | Èyí le jẹ́ nítorí ìsopọ̀ ìrìnkiri dátà sẹ́lúlà rẹ wà ní pípa. | This may be because your cellular data roaming connection is turned off. |
1205 | Kò le mú ìṣẹ̀lẹ̀ yìí dọ́gba sí %1!s!. | This event couldn't be synced to %1!s!. |
1206 | Kò le ṣàfikún ìṣẹ̀lẹ̀ yìí lórí %1!s!. | This event couldn't be updated on %1!s!. |
1207 | Kò le mú olùbásọ̀rọ̀ yìí dọ́gba sí %1!s!. | This contact couldn't be synced to %1!s!. |
1208 | Kò le ṣàfikún olùbásọ̀rọ̀ yìí ní %1!s!. | This contact couldn't be updated on %1!s!. |
1209 | Kò le mú iṣẹ́ yìí dọ́gba sí %1!s!. | This task couldn't be synced to %1!s!. |
1210 | Kò le ṣàfikún iṣẹ́ yìí ní %1!s!. | This task couldn't be updated on %1!s!. |
1213 | Kò le mú í-mèlì yìí dọ́gba sí %1!s!. | This email couldn't be synced to %1!s!. |
1214 | Kò le ṣàfikún í-meèlì yìí ní %1!s!. | This email couldn't be updated on %1!s!. |
1215 | This folder couldn't be updated. | This folder couldn't be updated. |
2063 | Ńmúdọ́gba... | Syncing... |
2064 | Àkọọ́lẹ̀ %s rẹ nílò àyẹ̀wò. | Your %s account requires attention. |
3012 | Ohun èlò rẹ kò ṣàtìlẹ́yìn fún ẹ̀yà apèsè yìí. Kàn sí ẹni àtìlẹ́yìn rẹ tàbí olùpèsè ìpèsè rẹ. | Your device doesn't support this server version. Contact your support person or service provider. |
3013 | Ohun èlò rẹ kò ní ọ̀pọ̀ ibi ìpamọ́ láti mú ìwífún dọ́gba ní àkókò yìí. | Your device doesn't have enough memory to sync information at the moment. |
3014 | Kò sí ọ̀pọ̀ ààyè lórí ohun èlò rẹ láti mu gbogbo ìwífún rẹ dọ́gba. O le pèsè ààyè díẹ̀ nípa ṣíṣèparẹ́ àwọn àwòrán díẹ̀, fídíò, tàbí orin láti ohun èlò rẹ, kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | There isn't enough space on your device to sync all your information. You can free up some space by deleting some pictures, videos, or music from your device, and try again. |
3016 | Ó dàbí pé a kò rí ìwífún apèsè rẹ. Ṣàfikún rẹ̀ kí o sì gbìyànjú sísopọ̀ lẹ́ẹ̀kan síi. | We can't seem to find your server information. Update it and try connecting again. |
3017 | Ṣàfikún ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ kí o le mú ìwífún rẹ dọ́gba. | Update your password so you can sync your information. |
3026 | Apèsè náà tí o ń gbìyànjú láti sopọ̀ mọ́ kò ṣàtìlẹ́yìn fún Microsoft Exchange ActiveSync. | The server you are trying to connect to doesn't support Microsoft Exchange ActiveSync. |
3027 | Ohun èlò rẹ ń dojúkọ ìṣòro kan láti múdọ́gba pẹ̀lú %1!s!. Tí èyí bá tẹ̀síwájú, kàn sí ẹni àtìlẹ́yìn kan tàbí olùpèsè ìpèsè rẹ. | Your device is having a problem syncing with %1!s!. If this continues, contact a support person or your service provider. |
3028 | A ń dojúkọ ìṣòro kan pẹ̀lú apèsè náà tàbí ìsopọ̀ rẹ. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. | We're having a problem with the server or your connection. Try again later. |
3029 | A kò le mú %1!s! dọ́gba ní àkókò yìí. A ó máa gbìyànjú síi, ṣùgbọ́n tí èyí kò bá jẹ́ àkọọ́lẹ̀ Microsoft rẹ àkọ́kọ́ tí o sì ń gba àṣìṣe yìí síwájú síi o le ṣèrànwọ́ kí o ṣèparẹ́ àkọọ́lẹ̀ rẹ lẹ́yìn náà kí o tún ṣàfikún rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan síi. Bí bẹ́ẹ̀kọ́, dúró fún ìgbà díẹ̀, lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We can't sync %1!s! at the moment. We'll keep trying, but if this isn’t your primary Microsoft account and you keep getting this error it might help to delete your account and then add it again. Otherwise, wait a little while, then try again. |
3031 | A kò le sopọ̀ ní àkókò yìí. Dúró fún ìgbà díẹ̀m lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. Tí o bá sì ń gba àṣìṣe yìí, ṣàrídájú pé àwọn ààtò apèsè rẹ tọ̀nà. | We can't connect at the moment. Wait a little while, then try again. If you keep getting this error, make sure your server settings are correct. |
3032 | Ṣàfikún ìwífún apèsè rẹ kí o sì gbìyànjú sísopọ̀ lẹ́ẹ̀kan síi. | Update your server information and try connecting again. |
3033 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti sopọ̀ mọ́ %1!s!. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. | We're having a problem connecting to %1!s!. Try again later. |
3035 | Ìṣòro kan wà pẹ̀lú bí a ti ṣagbékalẹ̀ %1!s!. Kàn sí ẹni àtìlẹ́yìn kan tàbí olùpèsè ìpèsè rẹ. | There is a problem with the way %1!s! is set up. Contact a support person or your service provider. |
3037 | Àpótí méèlì rẹ ti kún. Ṣófo àwọn wúnrẹ̀n rẹ tí o ṣèparẹ́ láti ṣẹ̀dá ọ̀pọ̀ ààyè. | Your mailbox is full. Empty your deleted items to create more space. |
3038 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti mú %1!s! dọ́gba ní àkókò yìí. Dúró díẹ̀, lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're having a problem syncing %1!s! at the moment. Wait a little while, then try again. |
3039 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti sopọ̀ mọ́ %1!s!. Kàn sí ẹni àtìlẹ́yìn kan tàbí olùpèsè ìpèsè rẹ. | We're having a problem connecting to %1!s!. Contact a support person or your service provider. |
3040 | Àpótí méèli rẹ ti fẹ́rẹ̀ kún. Ṣófo àwọn wúnrẹ̀n rẹ tí o ṣèparẹ́ láti ṣẹ̀dá ọ̀pọ̀ ààyè síi. | Your mailbox is almost full. Empty your deleted items to create more space. |
3041 | Ohun èlò rẹ kò ṣàtìlẹ́yìn fún àwọn ààtò ààbò èyítí apèsè náà nílò. Kàn sí ẹni àtìlẹ́yìn kan tàbí olùpèsè ìpèsè rẹ. | Your device does not support the security settings that the server requires. Contact a support person or your service provider. |
3042 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti mú ìwífún rẹ dọ́gba. Apèsè náà le nílò rẹ láti yan ìsopọ̀ (SSL) tí a pàrokò nínú àwọn ààtò àkọọ́lẹ̀ yìí. | We're having a problem syncing your information. The server may require you to select an encrypted (SSL) connection in this account's settings. |
3043 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti mú àkọọ́lẹ̀ yìí dọ́gba. Tí èyí bá tẹ̀síwájú, ṣèparẹ́ àkọọ́lẹ̀ yìí lẹ́yìn náà ṣàfikún rẹ̀ lẹ́ẹ̀kan síi. | We're having a problem syncing this account. If this continues, delete this account and then add it again. |
3044 | O le ní láti bẹ̀rẹ̀ sí nílo méèlì, olùbásọ̀rọ̀, àti kàlẹ́ndà rẹ lórí PC rẹ kí o tó le mú ìwífún yìí dọ́gba sórí ohun èlò rẹ. Tí ìṣòro yìí bá tẹ̀síwájú, kàn sí ẹni àtìlẹ́yìn kan tàbí olùpèsè ìpèsè rẹ. | You may need to start using your mail, contacts, and calendar on your PC before you can sync this info to your device. If this issue continues, contact a support person or your service provider. |
3045 | A kò fún aṣàmúlò ní àṣẹ láti múdọ́gba. | The user is not authorized to sync. |
3046 | A kò le ṣàfikún àkọọ́lẹ̀ yìí sí ohun èlò rẹ nítorí o ti ṣàgbékalẹ̀ àpọ̀jù iye ohun èlò.
O le gbìyànjú yíyọ àwọn ohun èlò nínú àkọọ́lẹ̀ rẹ lórí wẹ́ẹ̀bù, tàbí kàn sí àtìlẹ́yìn fún àkọọ́lẹ̀ rẹ. |
We can't add this account to your device because you've already set it up on the maximum number of devices.
You can try removing devices from your account on the web, or contact support for your account. |
3048 | %1!s! kò gbà ọ́ láàyè láti fèsì sí ìfiránṣẹ́ yìí. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá, tàbí fii ránṣẹ́ láti inú PC rẹ. | %1!s! did not allow you to reply to this message. Try again later, or send it from your PC. |
3049 | %1!s! ní ìṣòro kan láti fi ìfiránṣẹ́ yìí ránṣẹ́. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá, tàbí fíi ránṣẹ́ láti PC rẹ. | %1!s! had a problem sending this message. Try again later, or send it from your PC. |
3050 | A ní ìṣòro kan láti fi èsì rẹ ránṣẹ́. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá, tàbí fíi ránṣẹ́ láti inú PC rẹ. | We had a problem sending your reply. Try again later, or send it from your PC. |
3053 | A kò le rí èyí nínú àpótí méèlì rẹ. Mú àkọọ́lẹ̀ rẹ dọ́gba láti ṣàrídájú pé wúnrẹ̀n náà sì wà nílẹ̀. | We couldn't find this item in your mailbox. Sync your account to make sure the item still exists. |
3061 | O kò le fi í-meèlì kan ránṣẹ́ láti àkọọ́lẹ̀ yìí. Ó dàbí pé ìṣòro kan jẹyọ pẹ̀lú apèsè náà. Kàn sí ẹni tí ń ṣe àtìlẹ́yìn fún apèsè rẹ láti kọ́ síwájú síi. | You're not able to send mail from this account. There seems to be a problem with the server. Contact the support person for your server to learn more. |
3063 | Ó dà bí pé àwọn àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì wọ̀nyí kò ṣiṣẹ́. Ṣàrídájú pé àwọn àdírẹ́ẹ̀sì náà tọ̀nà, kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | These email addresses don’t seem to work. Make sure the addresses are correct, and try again. |
3064 | O kò le fi èsì kan ránṣẹ́ láti àkọọ́lẹ̀ yìí. Ó dàbí pé ìṣòro kan jẹyọ pẹ̀lú apèsè náà. Kàn sí ẹni tí ń ṣe àtìlẹ́yìn fún apèsè rẹ láti kọ́ síwájú síi. | You're not able to send a reply from this account. There seems to be a problem with the server. Contact the support person for your server to learn more. |
3067 | O kò ní le fi méèlì yìí ránṣẹ́ nítorí àwọn àsomọ́ náà ti tóbi jù. | You won't be able to send this mail because the attachments are too large. |
3068 | Wàá ní láti ṣèmúkúrò àwọn olùgbà díẹ̀ kí o tó le fi méèlì yìí ránṣẹ́. | You’ll need to remove some recipients before you can send this mail. |
3069 | O kò le fi méèlì ránṣẹ́ sí àtòkọ ìpínkiri tó tóbi báyìí láti àkọọ́lẹ̀ yìí. Ṣèmúkúrò àtòkọ ìpínkiri, kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | You can't send mail to a distribution list this large from this account. Remove the distribution list, and try again. |
3378 | A kò le sopọ̀ mọ́ %1!s! báyìí. Láti ṣàrídájú pé o ní ìsopọ̀, lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We can't connect to %1!s! right now. Make sure you have a connection, then try again. |
3387 | A kò le mú ìwífún titun dọ́gba bí o ti dé. Gbìyànjú ìṣètò míràn fún gbígba ẹ̀dà fáìlì ìwífún. | We're not able to sync new information as it arrives. Try a different schedule for downloading information. |
3396 | Ṣàfikún déètì àti àkókò lórí ohun èlò rẹ kí o sì gbìyànjú sísopọ̀ lẹ́ẹ̀kan síi. | Update the date and time on your device and try connecting again. |
3397 | ó farahàn bíi wípé ìṣòro kan jẹyọ pẹ̀lú ohun ẹ̀rí náà fún %1!s!. Té èyí kìí bá ṣe àkọọ́lẹ̀ Microsoft àkọ́kọ́ rẹ, gbìyànjú láti ṣèparẹ́ àkọọ́lẹ̀ náà, lẹ́yìn náà tún ṣàfikún rẹ̀. Bí bẹ́ẹ̀kọ́, dúró fún ìgbà díẹ̀, lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan sí. | It looks like there's a problem with the certificate for %1!s!. If this isn’t your primary Microsoft account, try deleting the account, then adding it again. Otherwise, wait a little while, then try again. |
3398 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti mú àwọn fódà í-meèlì rẹ dọ́gba. Ṣàyípadà ìṣètò ìmúdọ́gba rẹ, tàbí dín iye àwọn fódà í-meèlì tí o ń múdọ́gba kù. | We're having a problem syncing your email folders. Change your synchronization schedule, or reduce the number of email folders being synced. |
3399 | Ó dà bí wípé o le máa lo àkọọ́lẹ̀ Ìfilọ́lẹ̀ Google kan tí a kò ṣàgbékalẹ̀ láti múdọ́gba pẹ̀lú àwọn ohun èlò alágbèéká. Nínú aṣàwákiri wẹ́ẹ̀bù rẹ lórí PC rẹ, lọ sí Àwọn ààtò alágbèéká fún àkọọ́lẹ̀ Ìfilọ́lẹ̀ Google rẹ, mú Ímúdọ́gba Google ṣiṣẹ́ láti Àwọn ààtò ìpèsè, lẹ́yìn náà gbìyànjú láti múdọ́gba lẹ́ẹ̀kan síi. | It looks like you may be using a Google Apps account that is not set up to sync with mobile devices. In your web browser on your PC, go to Mobile settings for your Google Apps account, enable Google Sync under Service settings, and then try to sync again. |
4053 | Kàlẹ́ńdà | Calendar |
4054 | Àwọn Olùbásọ̀rọ̀ | Contacts |
4055 | Í-meèlì | |
4126 | Àwọn Iṣẹ́ | Tasks |
4130 | Ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ ti dópin. Ní àkọ́kọ́, ṣàyípadà rẹ lórí wẹ́ẹ̀bù náà, lẹ́yìn náà padà wá kí o s[fikún rẹ̀ nínú àkọọ́lẹ̀ rẹ lórí ohun èlò náà. | Your password has expired. First, change it on the web, then come back and update it in your account on the device. |
6009 | Irú ẹyọ ọ̀rọ̀ náà kò fẹsẹ̀múlẹ̀. | The characteristic type is invalid. |
6010 | Iye àmúyẹ náà kò fẹsẹ̀múlẹ̀. | The parameter value is invalid. |
6011 | O gbọ́dọ̀ ṣàfikún àmúyẹ AccountName náà. | You must include the AccountName parameter. |
6012 | O gbọ́dọ̀ ṣàfikún àmúyẹ AccountType náà. | You must include the AccountType parameter. |
6013 | O kò le ṣàyípadà àmúyẹ AccountType náà kété tí a bá ti ṣẹ̀dá àkọọ́lẹ̀ náà. | You can't change the AccountType parameter once the account has been created. |
6014 | Tí o bá ń ṣàgbékalẹ̀ àkọọ́lẹ̀ Microsoft àkọ́kọ́ lórí ohun èlò, o gbọ́dọ̀ ṣètò àmúyẹ AccountType sí WindowsLive. | If you're setting up the primary Microsoft account on the device, you must set the AccountType parameter to WindowsLive. |
6015 | O kò le ṣètò àmúyẹ Domain náà fún àwọn àkọọ́lẹ̀ Microsoft. | You can't set the Domain parameter for Microsoft accounts. |
6016 | O kò le ṣàyípadà àmúyẹ UserName náà láìláí fún àkọọ́lẹ̀ Microsoft àkọ́kọ́ lórí ohun èlò. Fún èyíkéyìí àkọọ́lẹ̀ míràn, o kò le yíi padà kété tí àkọọ́lẹ̀ náà bá ti múdọ́gba. | You can never change the UserName parameter for the primary Microsoft account on the device. For any other account, you can't change it once the account has synced. |
6017 | O gbọ́dọ̀ pèsè àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì náà bíi àmúyẹ UserName náà fún àkọọ́lẹ̀ Microsoft àkọ́kọ́ lórí ohun èlò rẹ. | You must provide the email address as the UserName parameter for the primary Microsoft account on the device. |
6018 | Àdírẹ́ẹ̀sì í-meèlì náà nínú àmúyẹ UserName náà kìíṣe àkọọ́lẹ̀ Microsoft tó fẹsẹ̀múlẹ̀. | That email address in the UserName parameter isn't a valid Microsoft account. |
6019 | O kò le ṣèparẹ́ àkọọ́lẹ̀ Microsoft àkọ́kọ́ láiláí láti inú ohun èlò náà. | You can never delete the primary Microsoft account from the device. |
6020 | O kò le ṣèparẹ́ àwọn irú àkóónú èyítí apèsè náà tìlẹ́yìn, bíi Olùbásọ̀rọ̀, Kàlẹ́ndà, Méèlì, àti SMS. | You can't delete content types that are supported by the server, such as Contacts, Calendar, Mail, Tasks, and SMS. |
6021 | O kò le gbé Àwọn olùbásọ̀rọ̀ àti kàlẹ́ndà sípò àìṣélò láti àkọọ́lẹ̀ Microsoft àkọ́kọ́ lórí ohun èlò náà. | You can't disable Contacts or Calendars from the primary Microsoft account on the device. |
6022 | O kò le mú àwọn ìjábọ̀ ṣiṣẹ́ àyàfi tí o bá ti tún mú àwọn Olùbásọ̀rọ̀ ṣiṣẹ́. | You can't enable feeds unless you've also enabled Contacts. |
6023 | Má bínú, ṣùgbọ́n a kò le ṣàfipamọ́ àwọn àyípadà rẹ. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. | We're sorry, but we weren't able to save your changes. Try again later. |
9781 | Windows | Windows |
9782 | Àṣìṣe ìfiránṣẹ́: %.*s | Send error: %.*s |
9783 | A kò le fi ìfiránṣẹ́ yìí ránṣẹ́, fún ìdí èyí a ti fi dínú Fódà àjùbà rẹ. Kí o tó gbìyànjú fífi ránṣẹ́ lẹ́ẹ̀kan síi, o le ṣàyẹ̀wò láti rí bóyá àdírẹ́ẹ̀sì náà dọ́gba àti pé kò sí àsomọ́ kankan tí ó tóbi jù. | We weren't able to send this message, so we've put it in your Drafts folder. Before you try sending it again, you can check to see if the address is correct and that no attachments are too large. |
9810 | Alábòójútó | Administrator |
9811 | Kò le fi ìfiránṣẹ́ ránṣẹ́ | Couldn't send message |
9812 | "%s" yìí ni a kò le firánṣẹ́ fún ìdí èyí a ń gbée lọ sínú Fódà àjùbà rẹ. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá, tàbí fi ìfiránṣẹ́ yìí ránṣẹ́ láti PC rẹ. | "%s" couldn't be sent so we're moving it to your Drafts folder. Try again later, or send this message from your PC. |
9820 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti mú ìwífún dọ́gba. Apèsè POP3 yìí kò pèsè àwọn ID pàtó fún ìfiránṣẹ́ kọ̀ọ̀kan. | We're having a problem syncing information. This POP3 server does not provide unique IDs for each message. |
9821 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti mú ìwífún dọ́gba. Apèsè POP3 yìí kò ṣàtìlẹ́yìn fún ìgbàpadà ìfiránṣẹ́ díẹ̀. | We're having a problem syncing information. This POP3 server does not support partial message retrieval. |
9845 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti sopọ̀ mọ́ apèsè méèlì tí ń wọlé. Ṣàrídájú pé orúkọ apèsè méèlì tí ń wọlé tọ̀nà kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're having a problem connecting to the incoming mail server. Make sure the incoming mail server name is correct and try again. |
9846 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti sopọ̀ mọ́ apèsè náà. Ṣàrídájú pé orúkọ apèsè méèlì (SMTP) tí ń jáde tọ̀nà kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're having a problem connecting to the server. Make sure the outgoing mail (SMTP) server name is correct and try again. |
9847 | A kò le gba ẹ̀dà fáìlì àwon ìfiránṣẹ́ ní àkókò yìí. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're not able to download messages at the moment. Try again later. |
9848 | A kò le fi àwọn ìfiránṣẹ́ ránṣẹ́ ní àkókò yìí. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're not able to send messages at the moment. Try again later. |
9849 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti sopọ̀ mọ́ apèsè náà. Ṣàrídájú pé ìwífún ìwọlé rẹ tọ̀nà kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're having a problem connecting to the server. Make sure your sign in info is correct and try again. |
9852 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti gba ẹ̀dà fáìlì àwọn ìfiránṣẹ́. Ṣàrídájú pé o ní ìsopọ̀ kan àtí pé ìwífún àkọọ́lẹ̀ rẹ tọ̀nà, lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're having a problem downloading messages. Make sure you have a connection and your account info is correct, and then try again. |
9853 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti fi àwọn ìfiránṣẹ́ ránṣẹ́. Ṣàrídájú pé o ní ìsopọ̀ kan àtí pé ìwífún àkọọ́lẹ̀ rẹ tọ̀nà, lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're having a problem sending messages. Make sure you have a connection and your account info is correct, and then try again. |
9854 | Ohun èlò rẹ kò ní ọ̀pọ̀ ibi-ìpamọ́ tí ó tó láti mú ìwífún dọ́gba ní àkókò yìí. | Your device does not have enough memory to sync information at the moment. |
9855 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti sopọ̀ mọ́ apèsè náà. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. | We're having a problem connecting to the server. Try again later. |
9856 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti sopọ̀ mọ́ apèsè. Té èyí bá tún wáyé, ṣàrídájú pé o sopọ̀ mọ́ Íntánẹ́ẹ̀tì kí o sì ṣàyẹ̀wò àwọn ààtò àkọọ́lẹ̀ í-meèlì rẹ. Tí ìsopọ̀ rẹ bá ń lo ètò ààbò, ṣàrídájú pé kò dènà í-meèlì náà. | We’re having a problem connecting to the server. If this keeps happening, make sure you’re connected to the Internet and check your email account settings. If your connection uses a firewall, make sure email isn’t blocked by it. |
9890 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti gba ẹ̀dà fáìlì àwọn ìfiránṣẹ́. Gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi tóbáyá. | We're having a problem downloading messages. Try again later. |
9891 | A ń dojúkọ ìṣòro kan láti sopọ̀ mọ́ apèsè méèlì tí ń wọlé. Ṣàrídájú pé ìwífún apèsè rẹ tọ̀nà kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We're having a problem connecting to the incoming mail server. Make sure your server info is correct and try again. |
9896 | Calendar|Contacts|Journal|Notes|Tasks|Drafts | Calendar|Contacts|Journal|Notes|Tasks|Drafts |
9897 | Sent Items | Sent Items |
9898 | Deleted Items | Deleted Items |
9899 | Inbox | Inbox |
23062 | Nílò Ìtẹ́tísílẹ̀ | Attention required |
23082 | Ọ̀rọ̀ aṣínà náà kò tọ̀nà. Ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀ aṣínà tó tọ̀nà láti tẹ̀síwájú mímúdọ́gba. | The password is incorrect. Enter the correct password to continue synchronizing. |
23083 | Your Windows Live account must be enrolled in dogfood. Visit http://livedog to enroll. | Your Windows Live account must be enrolled in dogfood. Visit http://livedog to enroll. |
23084 | Outlook | Outlook |
24501 | A kò le múdọ́gba %1!s! ní àkókò yìí. Dúró fún ìgbà díẹ̀, lẹ́yìn náà gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | We can't sync %1!s! at the moment. Wait a little while, then try again. |
26000 | apèsè náà | the server |
26027 | %1!s! kò ṣàtìlẹ́yìn fún mímú ìwífún titun dọ́gba bí ó ti ń dé. Ṣàyípadà ìṣètò ímúdọ́gba rẹ kí o sì gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi. | %1!s! does not support syncing new information as it arrives. Change your synchronization schedule and try again. |
28000 | Wàá nílò ohun ẹ̀rí àdáni kan láti sopọ̀ mọ́ %1!s!. | You'll need a personal certificate to connect to %1!s!. |
28001 | A kò le so ọ́ pọ̀ mọ́ %1!s!. Ṣàrídájú pé orúkọ aṣàmúlò, ọ̀rọ̀ aṣínà àti ohun ẹ̀rí rẹ tọ̀nà. Láti lo ohun ẹ̀rí míràn, yan Àwọn Ààtò, lẹ́yìn náà yọ àmì kúrò nínú àpótí àyẹ̀wò Yan ohun ẹ̀rí kan fún mi ní aládàáṣe. | We can't connect you to %1!s!. Make sure your user name, password and certificate are correct. To use a different certificate, select Settings, and then clear the Automatically choose a certificate for me check box. |
30000 | Ohun èlò rẹ kò dọ́gba pẹ̀lú àwọn ìlànà ààbò náà èyítí alábòójútó í-meèlì rẹ ti ṣètò. %1!s! |
Your device does not comply with the security policies set by your email administrator. %1!s! |
30007 | Ti firánṣẹ́ láti Ohun èlò Windows mi | Sent from my Windows device |
40000 | A kò le gba kóòdù káàdì àsansílẹ̀ ìfàṣẹsí ìwọlé onígbà kan fún àkọọ́lẹ̀ rẹ. %1!s! |
We're not able to obtain the Single-Sign-on authentication token for your account. %1!s! |
50000 | Ìtàn Àkọránṣẹ́ | Messaging History |
50001 | Àwọn Ènìyàn | People |
50002 | Àwọn Ààtò àti Ọ̀wọ́ | Groups and Settings |
File Description: | Àwọn Ohun Àmúlò ActiveSync |
File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
Company Name: | Microsoft Corporation |
Internal Name: | SyncRes |
Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ ni a fipamọ́. |
Original Filename: | SyncRes.dll.mui |
Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
Product Version: | 10.0.15063.0 |
Translation: | 0x46A, 1200 |