If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id |
Yoruba |
English |
1591 | Bèèrè fún ìyọ̀nda |
Ask for permission |
1592 | Wàá ní láti bèrè lọ́wọ́ àgbàlagbà kan nínú ẹbí rẹ tí o bá le lo {0}. |
You'll need to ask an adult in your family if you can use {0}. |
1593 | A kò le sopọ̀ báyìí láti bèrè ìyọ̀nda. Jọ̀wọ́ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan síi nígbà díẹ̀. |
We can't connect right now to request permission. Please try again in a little bit. |
1594 | Microsoft Corporation |
Microsoft Corporation |
1595 | Bèrè nípasẹ̀ í-meèlì |
Ask by email |
1596 | Paá rẹ́ |
Cancel |
1598 | Àwọn àgbàlagbà nínú ẹbí rẹ le lo ohun èlò yìí láti wá ọ lórí àwòrán ìtọ́ni kan. |
Adults in your family can use this device to find you on a map. |
1599 | Ẹbí rẹ ń lo àwọn àfidámọ̀ ẹbí Microsoft. Kọ́ síwájú síi nípa èyí, kí o sì ṣàyẹ̀wò ẹlòmíràn tó wà nínú ẹbí rẹ. |
Your family is using Microsoft family features. Learn more about this, and check who else is in your family. |
1600 | Pa dé |
Close |
1601 | Ti fi ìbéèrè ránṣẹ́ |
Request sent |
1602 | A ti fi ìbéèrè rẹ ránṣẹ́ sí àwọn àgbàlagbà nínú ẹbí rẹ |
Your request has been sent to adults in your family |
1603 | Nǹkankan ti kùnà |
Something went wrong |
1604 | A kò le fi ìbéèrè rẹ ránṣẹ́. Ṣé o sopọ̀ mọ́ Íntánẹ́ẹ̀tì bí? |
We were unable to send your request. Are you connected to the Internet? |
1700 | O ní láti jẹ́rìísí àkọọ́lẹ̀ rẹ nínú Ìṣàfilọ́lẹ̀ àwọn ààtò kí o tó le fi àwọn ìbéèrè ìgbàláyè ránṣẹ́. |
You need to verify your account in the Settings app before you can send permission requests. |
32000 | Àwọn àfidámọ̀ ẹbí Microsoft |
Microsoft family features |
32012 | Máa mú àwọn ààtò titun jùlọ ṣiṣẹ́pọ̀ pẹ̀lú ìpèsè àwọn àfidámọ̀ ẹbí Microsoft náà. |
Synchronizes the latest settings with the Microsoft family features service. |