File name: | Windows.UI.CredDialogController.dll.mui |
Size: | 8192 byte |
MD5: | 0a0166ff59ab92eb8917cc4fcab9e04a |
SHA1: | 28a773ba4e3b786f33cdd4ebd096afab4bf825d9 |
SHA256: | 419ce60572e286935cca861803fc0140452db4ac0423cdbe35cd524aff7ccd5b |
Operating systems: | Windows 10 |
Extension: | MUI |
If an error occurred or the following message in Yoruba language and you cannot find a solution, than check answer in English. Table below helps to know how correctly this phrase sounds in English.
id | Yoruba | English |
---|---|---|
100 | Ọ̀rọ̀ aṣínà alásopọ̀ náà kò péye. | The specified network password is not correct. |
101 | Ọ̀rọ̀ aṣínà aṣàmúlò gbọ́dọ̀ yípadà kí o tó le fi wọlé fún ìgbà àkọ́kọ́. | The user’s password must be changed before logging on the first time. |
102 | Ìlànà EAS máa nílò kí aṣàmúlò ṣàyípadà ọ̀rọ̀ aṣínà wọn kí o iṣẹ́ yìí tó le ṣeéṣe. | EAS policy requires that the user change their password before this operation can be performed. |
103 | Ọ̀rọ̀ aṣínà tí kò péye. | Incorrect password. |
104 | A kọ ìgbawọlé. | Access is denied. |
105 | A ti kọ̀ fún Ìràyè sí alásopọ̀. | Network access is denied. |
106 | Orúkọ aṣàmúlò àti ọ̀rọ̀ aṣínà kò péye. | The user name or password is incorrect. |
107 | Ìdánílọ́wọ́kọ́ àkọọ́lẹ̀ ń dènà aṣàmílò láti wọlé. Fún àpẹẹrẹ: a kò fàyègbà ọ̀rọ̀ aṣínà tó sófo, iye ìgbà ìwọle níye, tàbí kí ó jẹ́ pé ìlànà ìdánílọ́wọ́kọ́ tí dí àfipámúṣiṣẹ́. | Account restrictions are preventing this user from signing in. For example: blank passwords aren’t allowed, sign-in times are limited, or a policy restriction has been enforced. |
108 | Àkọọ́lẹ̀ rẹ ní ìdánílọ́wọ́kọ́ àkókò tí ó ń dí ọ lọ́wọ́ láti wọlé nísìnyí. | Your account has time restrictions that keep you from signing in right now. |
109 | A kò gba aṣàmúlò yìí láyè láti wọlé sí kọ̀ǹpútà yìí. | This user isn’t allowed to sign in to this computer. |
110 | Ọ̀rọ̀ aṣíná fún àkọọ́lẹ̀ yìí ti sọwúlònù. | The password for this account has expired. |
111 | Aṣàmúlò yìí kò le wọlé nítorípé àkọọ́lẹ̀ yìí tí wà nípò àìṣeélò. | This user can’t sign in because this account is currently disabled. |
112 | Orúkọ̀ aṣàmúlò kò tọ̀nà. | The specified username is invalid. |
113 | Ń gbìyànjú láti wọlé lákòókò ọjọ́ tí a kò fààyègbà fún àkọọ́lẹ̀ yìí. | Attempting to log in during an unauthorized time of day for this account. |
114 | Ṣé o fẹ́ gba ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí láàyè láti ṣe àwọn àyípadà sí ohun èlò rẹ bí? | Do you want to allow this app to make changes to your device? |
116 | Ṣé o fẹ́ gba ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí láti ṣàgbékalẹ̀ ẹ̀yà àìrídìmú lóri ohun èlò rẹ bí? | Do you want to allow this app to install software on your device? |
117 | Ṣé o fẹ́ gba ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí láàyè láti ṣèmúkúrò ẹ̀yà àirídìmú láti ohun èlò rẹ bí? | Do you want to allow this app to remove software from your device? |
118 | Ṣé o fẹ́ gba ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí láàyè láti ṣàfikún ẹ̀yà àirídìmú lórí ohun èlò rẹ bí? | Do you want to allow this app to update software on your device? |
119 | Ṣé o fẹ́ gba ìṣàfilọ́lẹ̀ yìíí láàyè láti olùtẹ̀jáde kan tí a kò mọ̀ láti se àwọn àyípadà sí ohun èlò rẹ bí? | Do you want to allow this app from an unknown publisher to make changes to your device? |
120 | A ti dí ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí fún ààbò rẹ | This app has been blocked for your protection. |
121 | %1 ti dènà ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí láti dábòbò ohun èlò rẹ. | %1 blocked this app to protect your device. |
122 | Láti tẹ̀síwájú, ṣàtẹ̀wọlé ọ̀rọ̀ aṣínà àti orúkọ aṣàmúlò alábòójútó kan wọlé. | To continue, enter an admin user name and password. |
123 | Tí a gbàsílẹ̀ láti ára Íntánẹ́ẹ̀tì | Downloaded from the Internet |
124 | Mídíà tí ó se ń yọ lóri kọ̀ǹpútà yìí | Removable media on this computer |
125 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ lóri kọ̀ǹpútà yìí | Hard drive on this computer |
126 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ Alásopọ̀ | Network drive |
127 | Àwo àká-ọ̀rọ̀ CD/DVD | CD/DVD drive |
128 | Ṣàfihàn ìwífún nípa ohun ẹ̀rí olùtẹ̀jáde | Show information about the publisher’s certificate |
139 | Ṣàyípadà ìgbà tí àwọn ìtọ́ka farahàn | Change when these notifications appear |
140 | Tẹ Control+Alt+Delete mọ́lẹ̀ láti ṣàtẹ̀wọlé àwọn ohun ẹ̀rí rẹ. | Press Ctrl+Alt+Delete to enter your credentials |
141 | Tẹ Control+Alt+End mọ́lẹ̀ láti ṣàtẹ̀wọlé ohun rẹ. | Press Ctrl+Alt+End to enter your credentials |
142 | Tẹ Control+Alt+Delete mọ́lẹ̀ tàbí lo bọ́tìnnì Ààbò Windows láti ṣàtẹ̀wọlé àwọn ohun ẹ̀rí rẹ. | Press Ctrl+Alt+Delete or use the Windows Security button to enter your credentials |
143 | Tẹ̀mọ́lẹ̀ ki o sì di bọ́tìnnì Windows mú, lẹ́yìn náà tẹ bọ́tìnnì àwòrán aṣàmì títàn tàbí pípa mọ́lẹ̀ | Press and hold the Windows button, and then press the power button |
144 | Tẹ Ctrl+Alt+Delete mọ́lẹ̀ tàbí tẹ̀mọ́lẹ̀ kí o sì di bọ́tìnnì Windows mú, lẹ́yìn náà tẹ bọ́tìnnì àwòrán aṣàmì títàn tàbí pípa mọ́lẹ̀ láti ṣàtẹ̀wọlé àwọn ohun ẹ̀rí rẹ | Press Ctrl+Alt+Delete or press and hold the Windows button, and then press the power button to enter your credentials |
145 | Tẹ̀mọ́lẹ̀ kí o sì di bọ́tìnnì agbára mú, lẹ́yìn náà tẹ bọ́tìnnì agbára ìró mọ́lẹ̀ láti ṣàtẹ̀wọlé àwọn ohun ẹ̀rí rẹ | Press and hold the power button, and then press the volume down button to enter your credentials |
146 | Tẹ Ctrl+Alt+Delete mọ́lẹ̀ tàbí tẹ̀mọ́lẹ̀ kí o sì di bọ́tìnnì àwòrán aṣàmì títàn tàbí pípa mú, lẹ́yìn náà tẹ bọ́tìnnì agbára ìró ìsàlẹ̀ mọ́lẹ̀ láti ṣàtẹ̀wọlé ohun ẹ̀rí rẹ | Press Ctrl+Alt+Delete or press and hold the power button, and then press the volume down button to enter your credentials |
147 | Ṣàtẹ̀wọlé àwọn ohun ẹ̀rí mi lórí aṣàfihàn ìwọlé Windows tó dára | Enter my credentials on the authentic Windows sign-in screen |
149 | Alábòójútó kan ti dènà rẹ láti mú ìṣàfilọ́lẹ̀ yìí ṣiṣẹ́. Fún ọ̀pọ̀ ìwífún, kànsí alábòójútó náà. | An administrator has blocked you from running this app. For more information, contact the administrator. |
150 | Fáìlì yìí wá láti ibi tí a kò fọkàn tán. Ǹjẹ́ ó dá ọ lójú pé o fẹ́ múu ṣiṣẹ́ bí? |
This file is from an untrusted location. Are you sure you want to run it? |
151 | Tí a kò mọ̀ | Unknown |
152 | Microsoft Windows | Microsoft Windows |
153 | Àtòjọ-ètò tí a kò mọ̀ | Unknown program |
File Description: | Adarí Ìjíròrò Ohun Ẹ̀rí UX |
File Version: | 10.0.15063.0 (WinBuild.160101.0800) |
Company Name: | Microsoft Corporation |
Internal Name: | Windows.UI.CredDialogController.dll |
Legal Copyright: | © Microsoft Corporation. Gbogbo ẹ̀tọ́ jẹ́ ni a fipamọ́. |
Original Filename: | Windows.UI.CredDialogController.dll.MUI |
Product Name: | Microsoft® Windows® Operating System |
Product Version: | 10.0.15063.0 |
Translation: | 0x46A, 1200 |